.. - Culture (65) - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › .. (1882878 Views)
1 2 3 ... 62 63 64 65 66 67 68 ... 99 Reply (Go Down)
| Re: .. by Zenlife: 4:17am On Mar 14, 2016 |
@healthfirst hopefully it is not this thread you have in mind and made inquiry to the mod in the general section of deleting, ''LILO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN, ITUSILE ATI ASEYORI'' lest it will be insensitive, callous and selfish...considering its many benefits and services to the people. And why do so if it is. that is if the original true 'honest' intent is to help the people as stated in your intro lines and not just to sell your book. I thus implore you, even if you can, despite your displeasure at some recent developments on the thread with some users not to be a spoiler and delete this thread. HONOR AND VIRTUE, If however it is not the above stated thread intended, then do excuse me. |
| Re: .. by ladycomfort(f): 6:19am On Mar 14, 2016 |
Ifankaleluya:. E jowo baba. I sent an email to you but you didn't respond. E se pupo |
| Re: .. by tundeologo: 2:05pm On Mar 14, 2016 |
Ejowo, a won ofin WO lo romo eto lati ko ise jo? |
| Re: .. by odomodeolorire: 2:29pm On Mar 14, 2016 |
@tundeologo, mo mon wipe e beere lati ko a won eniyan leko ni, kii she tori tiyin rara, nitori Momon yin daada |
| Re: .. by Ifankaleluya: 11:19pm On Mar 14, 2016 |
Zenlife:@zenlife With a gaiety,I salute your courage. I think you challenged him(healthfirst) on this thread,but,why he opted to responded on general section? I'l like him to come out here & named those he reffered as ''semi-iliterate, do-no-good,& ill-will chartalans'' that he stated to quoted your post. Before,I see him as a chamelon that do change as its surrounding changes,but,now I can finally resolved that he is jst a gadfly. Let him go ahead to execute his intent. I'l not fold my hands & watch him abusing ifa-verses,& hide under the false pretence that he is ifa-priest to dupe users of this thread. |
| Re: .. by skamo74: 7:32am On Mar 15, 2016 |
Baba pls according to Zenlife teach us any useful things on ewe ati Egbo. since you answered him you've been talking more on Ifa than teaches us ogun and you're more interested in Ifa challenge with Baba health first and most of your useful Ogun is not complete here with the excuse that you don't want people to sell it. I know you want people to know more truth about IFA, i know you're an intelligent and learned man, so I suggest you start maybe ( IMO NIPA IFA ATI IWULO RE ) or any other name you may think of. You may even make your publication here. this is my view thanks Ifankaleluya: |
| Re: .. by sammyjay76(m): 9:29am On Mar 15, 2016 |
skamo74:I think we don't know the truth any more here, pls for the sake of clarity let us have a rebuild of truth in this thread. If something is not right let us address it and keep to the right and genuine. ''Owo ekun won ki fi raja erin '' Eje he ka je ki awon Ogun ati ajo Lori thread yi je ojulowo. Eseun. |
| Re: .. by Ifankaleluya: 10:33am On Mar 15, 2016 |
skamo74: |
| Re: .. by Ifankaleluya: 10:41am On Mar 15, 2016 |
sammyjay76:The truth is that,maybe he(healthfirst) had falls a victim, bought some books sometimes ago & want to re-sale it for you people. You better forget the tag that he is an ifa-priest as he presented himself initially. |
| Re: .. by ONILEIFA: 10:52am On Mar 15, 2016 |
PLEASE MR Ifankaleluya DON'T LET THEM DELETE THIS TREAD I WILL LIKE YOU TO CREATE YOUR OWN TREAD IT FREE AND LEAVE THIS ONE FOR IT OWNER WHY YOU ARE BEHAVING LIKE DONALD TRUMP YOU TOO VOCAL ON IFA MATTER NOBODY KNOW IT ALL EVEN IF HE BUY BOOK AND COPY AND PASTE WE HAVE DO SOME WORKS HE GIVE OUT AND IT WORK PERFECT SO GO AND PULL YOUR OWN TREAD WE WILL COME THERE AND JOIN YOU THERE LEAVE THIS ALONE TO THE OWNER...........Ifankaleluya E DA RI JI MI KE TO RI BA BA JE EKO A UN DA RI JI EWE NI OO. |
| Re: .. by Ifankaleluya: 2:52pm On Mar 15, 2016 |
ONILEIFA:THANK YOU MY FRND,DONALD TRUMP IS A GREAT MAN. BUT, I DO NOT NEED A THREAD. kiise gbogbo ewe-eko ni a ma n darijin. Tori a ma n fi ewe-eko se ifa-abilu o ni osa-lu~ogbe(osa-esu). Sugbon,o ko ti e se(offend) mi rara! |
| Re: .. by Ifankaleluya: 3:08pm On Mar 15, 2016 |
Fun awon ti won bere asiri-bibo lori e-mail. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori. E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada. Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen. Idi-ikoko yen o gbodo kanle mo oo. Ti o ba ti di ni oru,eo bo ara sile ni ihoho,eo se adura si,eo si ko je. E o ti wa iyere-osun sile, iyere-osun yen ni e o fi te eji-ogbe eo wa pe ifa re si. Mo ti fi ifa yen sile lori fanran yi,e lo re wa nibi ti mo ti ki ifa pe''Oro kan n se mi bi kin ma jo,bi kin ma jo''. Ti e ba ti pe ifa yen tan,eo fi owo(money) gba iyere osun yen jo,eo da senu. E le mu schnapps tabi seaman kekere si tori ko dara ki eniyan ma mu omi le aseje lori. Adura yin yio gba ooo. Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. |
| Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 5:18pm On Mar 15, 2016 |
Ifankaleluya:Ejowo Baba Tailor ni mi mo need ogun ti maa fi ni omo ekose(Apprentice)pupo. Eseun baba |
| Re: .. by Ifankaleluya: 9:10pm On Mar 15, 2016 |
Ayomidegbenga1:Se e le ri aloku eni fafa? Ti e ba ti ri ki e kan si mi. |
| Re: .. by zenith329: 8:47am On Mar 16, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43794051]Fun awon ti won bere asiri-bibo lori e-mail. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori. E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada. Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen. Ejo sir, se isu etiponola tabi ewe etiponola? |
| Re: .. by zenith329: 9:33am On Mar 16, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43528328]Boya ki e tun lo bere lowo awon agbalagba, OMI-AGBON NI WON N PE NI OMI - APEGUNRUN. EWE-PEREGUN SI DA WA LOTO. Bayi ni won se ma n lo omi agbon lati fi pa egun, epe, ati ise run. A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san. Ejo sir, kin ni oruko miran ti oguna je tabi ki lo je oguna? |
| Re: .. by Zenlife: 9:48am On Mar 16, 2016 |
@Ifankaleluya Baba ejowo e funwa ni oogun ki iyawo mon se bi oko ba ti fe ni gbogbo igba. E seun. Edumare a to ju yin fun wa o. Ewe a je o. |
| Re: .. by dominicson: 9:49am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya:Ifa, in Iwori meji says: A pa ewure tan, a yan egungun re lodi Beeni ninu eran ni egungun n gbe Won pa esin(horse), won fi esin je, a si yan egungun re lodi... Ehin/eyin erin l'ola, awo ara re ko n'iyi Iwo efon ni ola, eran ara re kii n'iyi A difa fun kiniun, a bu fun ekun, ti oku won yi o d'oku oba Ekun ru eku ago, kiniun ru eku afe Nje a kii fi ago b'ori, a kii f'afe b'orisa Ko si eniti n wipe eran ekun ni ifa oun gba: eewo orisa, a kii fi kiniun b'orisa Ela boru, Ela boye, Ela bosise! I think it's time we resolved this issue behind the scene. Or have we anything to gain disparaging ourselves in the eyes of toddlers/neophytes in mysticism? Ete awo, our elders would say, erin ogberi. But ogbo(do-do)/ogberi too should note, before they sneer, as Ifa rightly pointed out in Iworidi, "Iwori wodu, a difa fun ofidan ti ko gba, ti ko te, ti n lo f'oju wo odu, ti oju re yoo fo..." If we are not very careful, we may end up destroying people whose lives we intend to build by writing/saying things they are not supposed to hear. So, Ifakunle and HealthFirst, I won't ask you to eat 'Ebure', lest you tell me that ebure is 'eran ohun' but mo fi Orunmila, Olofin ati Onile-Ogboduora be yin, let's talk this out as initiates. |
| Re: .. by Zenlife: 9:58am On Mar 16, 2016 |
@Healthfirst Baba ejowo e funwa ni oogun ki iyawo mon see bi oko baa ti fe ni gbogbo igba. E seun. Edumare a to ju yin fun wa o. Ewe a je o. |
| Re: .. by Zenlife: 10:03am On Mar 16, 2016 |
dominicson:Thank you sir for the intervention. |
| Re: .. by zenith329: 10:08am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya:Ejo sir, se a maa jo ata, ikan, ila yen tabi a maa lo ni, bawo ni a maa se pari re ? |
| Re: .. by zenith329: 11:24am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya:Ejo sir, e fun mi ni ise pe nitori mo fe se........08034833675 tabi johnmike329@yahoo.com |
| Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 11:31am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya:Ejowo baba kini won n pe ni aloku eni fafa? Ejowo e tunbo salaye daadaa funmi. |
| Re: .. by zenith329: 11:34am On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya: |
| Re: .. by Ifankaleluya: 3:18pm On Mar 16, 2016*. Modified: 3:38pm On Mar 16, 2016 |
dominicson:@domincson O kare omo-onibabalawo. Ti o ba je wipe o ti te-ifa, ifa o la o si rere. Ti o ko ba si ti te, igbakigba ti o ba te, ifa o ro(do) oo, yio si la o si rere Tori ifa ni; Poro bayii, ala bayii a difa fun Irẹ ti o tẹ meji ti o si la gudugudu. Ero-ipo, Ero-offa igbat ire(do do) te meji lo to la(do) gudugudu. thank you so much. IFA NI; Okiti(do do do) bamba ni pekun opopo a difa fun Alagan a bu fun Esu. Labalaba(re re mi mi) nikan(do do) ni nbe leyin ti n sebo. Labalaba ni, e wo inu(re mi) mi e wehin mi, Labalaba o mo lote(mi do) ninu. E wonu mi e wehin mi,Labalaba o ma lote ninu. I don't keep any grudges with him(healthfirst). Once again, Ifa a gbe oooo. Aboru, Aboye, Abo-sise. |
| Re: .. by Ifankaleluya: 3:21pm On Mar 16, 2016 |
[quote author=zenith329 post=43815028][/quote]Ere(do do) ina. |
| Re: .. by Ifankaleluya: 3:23pm On Mar 16, 2016 |
Zenlife:@Zenlife Pls drop your e-mail. i'l forward it to you. |
| Re: .. by Ifankaleluya: 3:26pm On Mar 16, 2016 |
[quote author=zenith329 post=43813919][/quote]isu etipon-ola ni, kiise ewe-etiponla ooo. |
| Re: .. by Zenlife: 4:13pm On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya: |
| Re: .. by Zenlife: 4:16pm On Mar 16, 2016*. Modified: 5:46pm On Mar 16, 2016 |
Ifankaleluya:ossezx@gmail.com please sir, make it complete. thank you. God bless |
| Re: .. by jbabas: 8:54pm On Mar 16, 2016 |
Baba Ifankaleluya, Ekaale. Eseun lopoplopo. Ejowo, se mo le ni ore ofe lati mo ero ibanisoro yin (cell-phone number) ka le soro lori ibere mi lekun rere. jbabas |
| Re: .. by wale259(m): 11:19pm On Mar 16, 2016 |
Oguna ni edu(chacol)to ti pon ninu ina(esena)[quote author=zenith329 post=43815028][/quote] |
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana • How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? • Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re • 2 • 3 • 4