Segoye2's Posts
Nairaland Forum › Segoye2's Profile › Segoye2's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 22 pages)
Emi ti mo pe eyan pala pala ni awe Obowunmi, and I must confess that, you making yourself an image of bad up bring is a sign that truely, you are not a yoruba, and you must be dame crazy to post such dirty acts in a public forum. Am given you this last chance to amend your ways and posts or you will be standing the chance to lose your username on nairaland.com, don't say you are not warned!. From me, Segoye2 The Abo'ba Jiro of Nairaland.com |
Bawo ni gbogbo yin? se alafia ni mo bayin? Olo lufe mi Desorlah, bawo ni? se daada ni, se o wa pa? |
Eku ikale ooo |
@ Chichi81, yoruba people are tribalist.Expanciate and show proof please, meanwhile, never try nailing people you hardly know. |
Dear Beloved user of nairaland, I nu mi dun gidi gidi fu oye tun tun ti e se fi mi je. ko da, mi o ba ti wa si ori alantako yi lati owuro kutu kutu hai, sugbon mo sare lo si Swansea fun ipade kekere kan ni pa ibi ise mi (board meeting), mo yi wa ni Swansea lowo lowo yi, mi o ni pe fi ibi sile pada si ile mi, ni tori idi eyi, e mase binu pe mi o soro tabi so wipe e seun wa, ko da, ajodun ohun break wa down die nitoripe, ni se ni oni adun, and am pretty glad, I now have a community I call my family online. Ope pataki si Baale wa, Olori Ile wa, Oga gun agba Richy, ati si aya mi, e ku adu ro ti mi, ope pataki si olu ya woran ti baale pe ti won si san wo fun ni apo ara won, Baba e ku ise agba ooo, ope pataki fun awon ore mi ni ile Ibo ati awon ganbari ti a pe, ope pataki si ore mi tooto, ani Tafari, Ikomi, Nana, Mishoo, debosky, Haywhy, Oba Seun Osewa ati be be lo, Ati awon ti a fi we pe ati a won ti o gbo ti won si wa ba wa se ajoyo ohun, esun wa oo, Ilu o ni baje lori wa ooo, ese wa ko de ni ko bata, ara wa ko ni ko aso, ori wa ko ni ko fi la lojo eye awa na oooo (Amin) Kin sare jade, mo n pada bo. Thank you (e seun gan) I love you all! ![]() Si aya mi, Bawo ni ara re ati gbogbo e, se layo lo wa ni naijiria? |
Iyawo mi, mo wa pa, Just wanna get some few jokes in here, lol, I posted See my Ass, naughty someone was expecting to be him/her ass, but furtunately, is still him/her ass. lol, ![]() Desorlah, were u at? I will be in Nigeria soonest! |
Inu mi dun nigbati mo ri ewe oye ohun?, you can't believe it, it was pretty great. ![]() |
Long live aya mi, Desorlah; The Olori of Aboba Jiro of Nairaland.com ![]() |
Eyin eyan mi, Eseun wa ooo, E ku ajodun Iwuye wa oooo, ajoma jumo se ni, ajoma ju mo se rere, ajoma jumo pejo yo ayo ni ojo eye wa ni oooo, e ku aduro ti mi oooo |
Akede oba, e ku ise oooo, ko da, aworan yin ti mo ri ni ha yi fi ye mi wipe e n se ise yen ni ise gidigidi. Baale, e seun fun aworan yen ooo, I nu mi dun gidigidi. |
Igbo Kwenu! With great respect, I invite you all to our Iwuye on yoruba thread on Sat. 7th, July 2007! |
Yes SEE Your Ass (wo assii e) ![]() |
Eyin eyan mi e ku ile ooo, e de ku de de iwoyi, bi e ti se mo wipe ola ni ojo iwuye mi, mo fe fi ye yin wipe gbogbo eto lati fi ti aye re ati pelu wipe gbogbo strategy ti wa in place, paapa julo, Oba ogba, Seun Osewa ma wa ni ahin yi ni asale yi tabi owuro ola lati bawa fi adura bere gbogbo eto ohun. Aya mi, bawo ni, se o wa pa? Mo missi e gan, sugbon ma ronu mo, ma pade e ni nigeria laipe, I mean end of July; end of this month. Haywhy? how ya doing, mo bell e sugbon o da bi enipe ire ti jade , bawo ni ibi ise lo ni? oye kin wa ni ori alantaku ni ojojumo nitori oro oye ti emi ati iyawo fe je yi, sugbon ise aje ati paapa julo, mo fe sare rin rin ajo kekere kan lo si ilu abi nibi mi, ni ile nigeria, iyen lo mu mi fin sa soke so do lati ri wipe eto irin ajo ohun lo dede ati lese lese. A de ma kan si ra wa. |
Heywhy watd up? how ya doing in there? |
Si ogbeni Obowunmi, Oruko ni n ro ni, awe yi, o mo iwon ara re sha, ewo ni ti oro jatijati ni ilu wa yi? ta ni o na? Opo nu Ede ni e, I nu mi dun wipe ole so ara re ni ani iya ni awujo awon ojogbon. |
Baale, Eku ile oo, oro awon awe yi ka ma ma, o de se mi laanu pe oro ti ko ni ila akaye ni won so. OMODE SO Ko SI GBO, WE RE LON YA YEN!. Aya mi Owon, ba wo ni owa, se daada ni oooo, e mi missi re gan ni oooo. |
I curled this out from www.nnpcgroup.com This is to inform the general public to beware of and to ignore the misleading information currently being circulated, particularly on a website "nairaland.com" concerning an on-going recruitment exercise in NNPC. |
Dear Thread Author, I want you to stop speading this news and please apologies to the whole house why you decide to drag the name of this humble house to mud by directing people to a . You yourself knew it was a scam so why spead it? The information about your thread is already on www.nnpcgroup.com and I must confess, you must stop such an criminal act or else, you meet yourself in your rightful place. Meanwhile, to make the name of www.nairaland.com stand out as the no. 1 job seekers website nigeria got, you need to apologies to the house especially the innocent applicants you sent through to that hell link, and also, your apology would enable nnpc group clear the name of www.nairaland.com off their website. @ All Job Seekers, This information is a scam, and mark the lander user name of the author of this thread as a scammer, and if he claims his not 1, is he not aware that his thread has dragged this humble community into mud; hummm? or till he losses access to his membership page before he would realise that this information he supplied was for him, and not for www.nairaland.com?, Please open your eyes, we got breeds of scammers in the house now! @ Tonyblu, I realise you a scam too, why blog too? be sure of what you say to people and never try to scam any innocent soul here, because if you do, you are selling your peace, selling your wealth to the devil! |
Ogbenni MIRACH, Ki ni itumo rada rada yi? se ko n se wipe wo n tele e sha oooo, why are u messing up this thread hummm? Abi o fe ki won begi fun oooo, Ki de ni itumo aworan ti o gbe si ibeyen, Ohun ti a ba awe ti o koja lo so ni yen , ti a si baawi, ode gbo iba wi, sugbon, ire ti fi ye gbogbo ile yi wipe eyan randapri ni o. Ma se be mo oooo, is not good at all. |
WOW, that pix is pretty great!, and funny, u guys are great in here |
Mr Ferlie, Se e le so di e fun wa, bi ese je sir? ati wipe, Ogagun Tafari je eniyan pataki ni awujo wa ni hin yi, ko da Baale wa mo n won daa daa, Oye jije ni Ile yoruba yi ki n se oro awada ra ra oo, ni to ri na, e so fun wa eni ti e je, ati ibi ti eti wa, E seun sir. Si Aya mi, Nibo lo wa? bawo de ni ara re? |
Baba, Ka ra o le oooo, E ku Ilu wa ooo, e de ku oro agba, ko da, inu mi dun lopo lopo pe e n wo gbogbo nkan to n lo ni ilu ilu wa yi, ko da omu omi nu ko mi gan ni. Huummmm, Ojo Satide yi ni iwuye owun? Oda na, a o sare te iwe na jade a o si je ki gbogbo aye mo ojo tuntun ti a se mu na. Oloye Tafari, ba wo ni, se o wa pa, ba wo ni oro iwuye re ni ilu yin lowun? ta bi ire ko lo soro ni pa iwuye bi? bawo de ni gbogbo eto ohun? Desorlah, se o wa ni ori alan taku yi lowo lowo? mo te o ni ago (I bell ya) sugbon ko lo thru, se ki n se pe naija network tun ti bere oooo, Am happy, my baale is online today(Inu mi dun gidi gidi ni). Oloye Mushoo, Mo wa lehin ire pelu, ma gbadun ninu ola eledumare, oga nla ti o ni ola ati ogo ni ikawo re. |
Baby mo wa pa, Ire n ko? se o ba mi ri baale oko Ilu bi? ![]() |
Baale ooo, e wa gba mi oooo, owon omo wonyi fe woju agba oooo, eba mi kolo fun won ooo, ki n to jaale fun won, nitori won ni, kutu kentu, kari ati conga, eji na bo panbo, awon aye ni o ni ti gbogbo, edumare ni oba gbagba, ofele n fe tin so kun bata a mi dio dio, , , (incantation) Huummm Hummmmmm, ema rin agba fin ooooo ![]() |
You guys are not bore with with those naughty pics of naked ladies you got in there, You even got the got to move to Igno thread, representing yoruba there and postin such dirty issues there. I hate what you are doing there, Inu mi o dun si ra ra ra ni, Be de ni, I nu omo yoruba tooto ko gbodo dun si rada rada wonyi ti o pe ni unbored issues, Me no like ham SHIKENA ![]() |
Eyin Ogbeni Tonim ati Ogbeni Olutomiwa, Ki ni itu mo rada rada yi na? Respect is reciprocal ![]() Aya mi, Bawo ni, se daada ni o wa, bawo de ni striki ti mo n polongo ni nigeria, se won ti lift e sha? |
Aya mi, Emi ne kede wa pa oo, bawo ni ara re ati ara baale, ose die ti a ri won laafin, se ki n se wipe o re ra die? Jowo bami lo si Villa mi, fun Ore mi, Emma ni parcel ti mo fun e yen ni Igba ti o wa fun visiting yen, mo fe ki o pe mi tale tale oni, Eyin eyan mi, Eku ise o ni oooooo, se ara le ooo, weekend in advance! |
Mo wa ooo, Nana sebi ore re ni Desorlah, oye ki o so fun e pepe naw ![]() |
Nana mi Owon, Bawo ni, se o wa pa, erin pa ire na? Well, mo ni kin fi to e lati wipe Iyawo mi Desorlah ma come over to the U.K latest by Jan. 08, bo tile je pe, ko i ti gba finally, sugbon arrangement is on lati effect movementi e lati nigeria. Bawo ni oko e? Ki ni oru ko re na? emi o fe se oju isa ju ra ra ra ooo, nitori na ni mo se ni wipe ki ele olori fi enu ara re so oruko oko re Am happy for my WIFE DESORLAH |
wot do u DISAYA wot do u av UNDA,[b] SWEET BANANA,SWEET BANANA[/b] Nje Ire mo wipe arabirin ti ire n bere ohun ti o di saya ni aya mi bi? Nje ire ko mo wipe aya oloye ni bi? Nje ire ko mo wipe ese nla ni ilu ile-ife lati bere ibere basha basha bayi ni owo obirin ti oti ni oko bi? Nje ire ko ni owo fun baale ile wa bi? Nje ire ko mo wipe emi mo wipe eyan daa daa ni ire sugbon aworan ti ire wo ti da agbari Tire run bi? Nje ire ko le ko enu re ni ijanu daadaa mo bi? Nje u no dey fear, fear? ![]() |
Iyawo mi Desorlah, Thank you for your comment. Bawo ni, se o wa pa? Emi tile missi re gan ni oooo, ni bo lowa bayi, se o ti kuro ni nigeria tabi o wa ni afin ni? ope die ti mo ri baale mo, se alafia ni won wa oooo? baba wa ooo, ejowo eba wa be awe oni aworan rada rada yen ki o gbe kuro lori ile wa oooo, ti a ba ti le ba n soro IYAMA, ko to si aworan lati yoju, ati wipe, Oba Seun ko we simi, wo n de fi ye mi pe inu n bi won si awon aworan yen, ejowo, e ba wa ba awe wa Sqanderi soro wipe eyi ti o se to ooo, Inu awon oloye o dun si, inu emi ati aya mi odun si, inu oba seun o dun si, inu awon eyan nlan lan bi Ikomi, Ayefele, Nana, Ikam, , Angeli ale, Mushoo, Al Raheem, Dis_Guy ati be be lo o dun si bi Rada rada yi se wa n tan sii. Desorlah Baby, my PC just came up after some tough time of crashing. Mo ni ife re lopo lopo oooo, Cheers, Segoye2 |
Si olutomiwa, THIS IS FILM TRICK, se aworan ni awon eleyi tabi Egyptian Mummies? |


