Segoye2's Posts
Nairaland Forum › Segoye2's Profile › Segoye2's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 (of 22 pages)
Olo lufe mi, oseun ooo, ku itoju mi, ma dey ma yoju si won tin ba de ni nkan bi ago merin irole oni. Bowo lare e e, se oti ba egbe awon obirin soro lori ti eto na? jowo, je ki a se daadaa, ani mo fe ki baale se eto lati fun iwo pelu ni oye kan, ani oye to si iwo ne. Mo ni ife re tokan tokan, ma se gbagbe oro ajoso wa oo, je ka bara pade ni ori segoye2@itsabove.com. Daddy Baale, Ma yoju siyin loni ni ola edumare. Eseun wa oo, ejowo, ti oba ni nkan ti oye kin se kia kia, ele so fun iyawo mi, yio ba mi se igbese re. Mo nife gbogbo eyin eyan mi lopolopo. |
Iyawo mi owon, mo ti de ooo, bawo ni, Baale, e seun wa ooo, mo sare jade ni, oro lori eto iwuye mi na ni mon ba ka, sugbon, oti see se na, Eku aduro ti wa ooo, ma de ma pada wa, mo fe lo ri iyawo oremi tooto, ani Seun, site admin wa, nitoripe, e mi fe ki won wa ni ojo eto na, sugbon ao wole alagbara gba ara iyawo re, Iyawo re yio bawa bee, lati wa si ori threadi yi, ni ojo eto na. ![]() |
Obo ni e oga Ajayi1, Ire lo de ma n be gala gala. Ki ni o kon iwo pelu babasuwe mi? Tabi ofe ki a be a won agba ni? ehennn ti oba wa nibe yen, ti baale bade bere, o se je kin salaye fun baale wa? Iwo ma n rin agba fin ooo, baale ni ire n pe ni Oya, Ajayi tire, olurun gbo o, dekpe ni. ![]() Baale, emase binu si ore wa yi ooo, olo fofo kan bayi ni lati ojo to ti pe, bo se de, lo de be si ori oro saka saka bi enipe ko e ti jeun lati osu mefa. Omode a ma se bi omode, agba le ti da yi oo, e jowo e fo ri ji, e si fi iye denu, ![]() Well, mo te bobo Suwe ni wire, nigba ti o de dahun, I nu re dun si oye mi, osi seleri wipe owun yio wa ni hin yi, ni ojo oye na, therefore, a o da ojo laipe yi, ani emi pelu Iyawo mi owon. ![]() Mo ni fe yin ooo. |
Hey, Ngini ne me gi people .Wunye gi si n po gi, Ikomi, le, anama nu igbo ofuma ofuma, so be careful, before I send Irun mole and awon Iwin to console U ![]() Kedu maka Ike gi, Odi nu lo or odi na office yi? ![]() |
Mo ba baba suwe soro laaro yi, Ode gba lati bami se MC ni ojo oye mi. Eyi ni awon re! ![]()
|
Si Iyawo mi, Iyawo mi Kaaro oo, ha gbe ran le ki o dide. Bawo ni Jo sare se Indomie fun mi ati wipe ki lo wa ni le, se ounje yi wa ni store house?, Si Omonaija, Ire n wa oko, Hummm, ode ni suru, jeki baale ni pe awon nife ire, mase ti ara re si won mo joo, jo bami fe ore mi Ikomi omo yen ti tryi daadaa ooo. eSi Baale, E seun wa ooo, nipa aworan wa (emi ati iyawo mi ti e bere) a o ma kan si yin pelu re ki a to daa ojo oye. Si Oga Debosky, Eku ojumo ooo, Oluwa yio fun yin ni ife tiyin na oo ati wipe, nigba ni a ba pari ti oye temi ati ti Iyawo mi Desorlah, a o ba baba soro lati consider oye kan fun yin Sir. Si gbogbo Ile, E seun wa ooo, eku ito ju mi ooo, oluwa yio ma wa pelu wa ooooo, Amin. |
Iyawo mi, joo bami soro lori segoye2@itsabove.com Eyin Eyan mi, a de ma soro ti oba ya, Baale e seun wa ooo, Iyawo mi ti soro tan, ti a ba soro wa tan, a o kan si yin, eku ojulona ojo ayeye na, a o fi to yin leti ojo ti a mu, a o ni fi enikeni wa se awati ooo, Ire na a kari wa ooooo, ife ti eni si mi ati iyawo mi ko ni tan oooo, Nigbati baale yio gbesele gbogbo awon obirin ti o wa ni bi, yio se oju emi wa ooo, Amin! ![]() |
Dear brothers, I kept asking myself where is my great friend Diya, I mean the right man of MR. ABACHA ![]() |
Bawo ni se daada lewa, Ikomi o seun ooo, se o wa ni ile abi oti jade? ![]() |
Iyawo mi, o seun ooo, oku ito ju mi ooo, je ka jo soro base ma se se ayeye owun ati wipe, eyin eyan wa, a o fun yin ni abo ipade idile ti a ba se ooo, E seun oooo, Emi ni ore yin ati oloye, Abobajiro Yoruba of Nairaland |
si Desorlah, Kabo, se daada lo de, mo tin reti re ooo, oti e le bere mi tabi ki otile kimi, odaa ooo. Si Baale, E seun fun oye yen ti e bu fun mi ooo (Abobajiro Yoruba of Nairaland), I nu mi dun lopo lopo, ko da, e ni lati se eto fun mi lati se ayeye and ajodun oye owun. Atiwipe, se emi na le ma gbese le awon babes ti o wa ni ihayi. Baalee ooo, eyin na e ranti wipe e ti ba ifa mule o, ma se daba lati da a ifa. So e jo, e ja ewe oye le mi lori o. Bawo ni ese ri iyawo mi tuntun? ![]() |
Si Mushoo, Bawo ni, se iwo na ti ni interest si Aunty Nana ni?, Jo o So fun wa ooo, eje ka ri gbo, emi fe sare lo se road walk, ma pada wa in 1 hours time, Baalee wa, bawo ni, abi e ti rin rin ajo lo si ilu akatapritari tabitabi ni? ![]() |
Ewo lewo, E kwele oo, Anything to Fenu Gbe? ![]() |
Eyin eyan mi, mo fe jade lo si club, I need to do some kekere danciessss ![]() Ama rira ni kutu kutu ni agogo merin owuro ola. Layo ooo aya mi Layo ooo Baale, Layo ooo gbogbo eyin eniyan pataki ori threadi yi, Layo Ikamefa ti on wo Idi onidi, kai, woody woody is dun daa daa ![]() |
Ke le wi na? ati wipe, ololufe mi, ke lo so jare! ![]() |
Olo lufe mi, Eyin Obirin, e man liki lati ma se bi epe e kin se bee, ![]() Joo bere lowo ore re Ikamefa, o ye ki oni alaye si daadaa! ![]() Bere lowo e pe kini Woody woody? abi eti gbo pe segoye2 ti mu burukutu? ![]() |
sowwy oo, I need to learn mallam ko?, I go get ham for goro? If u wanna learn, I guess u go to the North! |
Woody woody is when kinni that is identified as Oko wo inu ibe ti o tutu shennn, Oti ye Ire lowolowo yi abi? ![]() |
Ika mefa sinu Woody Woody! ![]() |
Si Ikamefa, Oda bi eni pe eni ife oko gan oooo |
ki won pe ogede ohun ofo lati eni titi di decemberHa, maso be yen mo ooo, ki baale ma lo gbese le ire ti ka ara re, emi okuku ni ife ee teletele, so cause ija thready ooo! ![]() |
Babi mi Jowo o jeka jo ma gbadun, Emi ti se ti e pee pee! Ani se, nothing dee happen, so aworan tire si ori threadi yi kin wo boya o dun daadaa! ![]() Meanwhile, Emi ti se tire na ooo |
Bobo mi, jo o fi baale sile ooo, je ki oje dodo oni dodo, atleast, the old shall grow, ti eba de bawon dun nn, wo n le bere si ni pegede si yin lori saka saka!, Baby mi, Owo wa, Ile wa, Ogun wa, Oko wa, ki lo kun? |
Ya kuke, Ya jima de na so nan, na yi tapiya nee, na je Swansea, amade na dawo yen su, na giyama muta ni na a yoruba de ibo thread wai nna ni ma n mata de na de giki, ama to, ba n sa mu ko ba. ma Aisha, Ami eleku a salam!. Aisha, ya ki ke, sa mu i ya ha du? na pa tar de lamba wire na, ya ki iya ba ni na ki?, |
nana baby, omo to dara julo bawo niBaby yen ti loko see, iyawo Baale ni ooo, emi a se ofofo ooo, ![]() |
Si desorlah, Omo daadaa ni tire, tie wo bi osen bere lowo mi pe se mo ti jeun, ha o ku itoju ooo, mo de wan ni fe ire lowo lowo yi oooo, se o sa sanra sha? nitori oti mo specificatioring me ooo, se o matchy spec me? abi ofe ki a se bi about borda ati anti se se lori thready yi?, Emi ni ololufe tire lowolowo, Segoye2 ![]() Si gbogbo wa!, Eba mi be won ooo, ki won je kin mu eyi de ile, ![]() Baba Isale (Baale), ti eba gbese le eyi na, ma so jiga si for live. ![]() |
Egbon yin wo sir, se oga Ikomi? Hai, etun gbe omo jeje fun omo Igbo, tabi e gbagbe pe omo Igbo lo ko mi si sasoke at so do yi ni? tabi e ti gbagbe pe Babalawo yin wa etutu fun ise yen ni?, e jo, tani egbon tire ni biyi lowolowo YI. ![]() Ese ooo, mo de ti jeun bayi, iwe lokun ati kin lo ti igi oluwa si ibe. ![]() |
Aworan yi ni awon oni geesi npe ni FIRE!, sugbn nitoto, baba yen hand some bajebaje! ![]()
|
Omoge Desorlah, bawo ni, emi ke wa pa oo, okan jepe mo n wa ounje, nito ri pe ebi n pami lowolowo yi. Baba Revi-t0, ewolewo, ikede yin yen yato, se pe askari mukina2 tin gbese lati fe aya tabi oko?, e se jeje oooo, oju n wo wa ooo. |
Do you think your landlord cares about how you feel? He greets you only when your rent is due He increases his rent every year without consulting you He collects two rent down payment before letting you in He cares only about his property and the money he collects from you He can throw you out whenever he chooses and for whatever reason ![]() Landlord travel and See ![]()
|
Ekasan ni le ooo, se daadaa lewa? ki lon sele, wetin dey eeee! |
People die - which was a bit surprising given we're used to everyone miraculously surviving, but still we have a love interest, some sort fighting, some despair, some history. ![]() I guess I'm kind of hoping that people's interest wanes a little so I can get ahead - that's probably wrong of me isn't it? ![]() |


Jo sare se Indomie fun mi ati wipe ki lo wa ni le, se ounje yi wa ni store house?, 

