₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,580 members, 8,422,641 topics. Date: Monday, 08 June 2026 at 03:16 PM

Toggle theme

Segoye2's Posts

Nairaland ForumSegoye2's ProfileSegoye2's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 22 pages)

CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 3:52pm On Jun 21, 2007
Iyawo mi,

grin Mo wapa daadaa, o de ti to ojometa kan bayi na ooo smiley
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 3:51pm On Jun 21, 2007
Iyawo mi,

Bami Soro, bawo lo se ri? se kin ba baale soro ni?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 2:59pm On Jun 21, 2007
Hummmmm just thinking about it too  huh je ki a pade baba ni afin bo ya o se se. ma de ko we a won loba loba pe ki won gbe solo je for now grin

Awon ore mi omo nna's, se won rinrin ajo ni?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 10:03am On Jun 21, 2007
Mo jeri re aya mi, looto, aya rere ni eyan gidi ni ode oko re.

Meanwhile, mo gbo wipe won striki ni ile, se looto ni? mo ti fi invitationi ranse si ile oo, se embassy ma fun won ni visa lati wa fun ajo yo yi bayi? ko ye mi ooo, tabi bi ere bi ere ni gbogbo oro yen ni, jowo fi to mi leti daadaa si.

Si gbogbo wa,

Eku aduro ti wa ooo.

Si Baale,

Eku ojumo, se daadaa leto n lo nipa Iwuye mi ni afin oooo? se eti gbo nkankan lati odo Oba Seun?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 9:42am On Jun 21, 2007
Desorlah mo wa pa. Bawo ni night e?

Bawo de ni ipalemo iwuye me? ani iwuye wa? cool
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 9:46pm On Jun 20, 2007
heres a yorabra video

Sowwy, Yoruba and not yorabra grin

But I do check it out if really is a yoruba or yorabra grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 8:48pm On Jun 20, 2007
Eyin Eyan mi, Invitation letter ti jade oooo, ejowo e printi e jade ki e si bawa ha. grin
Invitation Letter is now ready for download, you can download it and print out to your friend. Edumare will guide you all till that day.

@ Desorlah,

Bawo ni, bawo de ni ara re? se eto n lo dee dee? Mo se ti ibi ise de na ni.

@ Isrealite,

Bawo ni, se owa pa?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 9:52pm On Jun 19, 2007
Iyawo mi bawo ni, Mo wa pa ooo, mo kan sare rin rin ajo kekere kan ni ooo, jowo, se invitatio yen yi ku? nitori mo fe ki o ba mi fun ore mi Ikomi ni nkan bi mewa lati fun awon ore mi ni odo re. Ma ma pe e to ba ya.

Baale ooo, kara o le ooo, e seun wa oooo

Ma ba yin soro di asale daadaa, mo fe sare lo sun, mo se pada wa lati ibi ise ni, and am pretty tired! grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 9:31pm On Jun 18, 2007
Desorlah, bawo ni, se ounje ti jida, ebi n pa mi ooo, mi o ni pe gbona ibi ise, nitori ise ala ni mo wa ni oni, se ole bami se ko tete jina?,

Eyin wa, eku oro ilu ooo, baale oo, se e wa pa? grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 9:28pm On Jun 18, 2007
Nana, alafia ni a wa ooo, i wo n ko?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 4:35pm On Jun 18, 2007
Baale ooooo grin Inu mi dun wipe e ti pada. Se oko o je epo ooo, bawo deni ipade na? se eba mi sofun won ojoi wuye ti a dana? i nu mi dun wipe oro tiwa lo je ki e rin rin ajo ranpe yi. Ejowo baba wa, e salaye die ninu ohun ti osele ninu ipade ti e lo yi fun wa. Inu mi dun wipe ohun ti Oloye Tafari so, e mo si, ko si n se wipe won fe gbehin da ti nu won se, ejowo, e ba mi ranwo lowo ni ona kona, sugbon, ni ti egbe awo ti won fe daale, inu mi o fi be dun si lo titi ooo. WON LE PE NI (NGO), sugbon, ti o ba je pe egbe awo fun fun bi won se pe, emi oni da si rara oooo,

Iyawo mi owon,
Inu mi dun wipe eba ile ni ayo ati alafia ooo, bawo de ni gbogbo eto se lo ni ile? mo so fun ore re Nana pe ki o pe o, ati wipe ki o fi to o leti wipe ojo satida ton bo yi ni ojo iwuye wa, ati wipe, Oluwaye Nairaland, Oba Seun wa si ori ile yi, sugbon won ko ba o nile, nise ni a fi otin oyinbo, oti ibile, ogoro ati omi sapele se won ni alejo, ama, won se leri lati pada wa ki ojo ayeye wa to wole de.

Inu mi dun wipe awon eyan wa ba wa layo ati alafia ooo, ayo wa ko ni din ku.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 10:55am On Jun 18, 2007
So Oloye Tafari,

Baale lo fun Ipade ni the third State from base won, grin

Se ko le ooo, ele ran mi si won, ma de te won ni ago ti oba je pe ise were were ni.
CultureRe: If Your Wife-To-Be Can't Cook by segoye2(m): 10:48am On Jun 18, 2007
Well, love is all that matters,
Since no one is perfect,
And because you can't get a perfect match on earth,
Everyone has to beat his partner into the best tool he/she wanted him/her, though is pretty hard, but just like the iron, the results are always great.
So, if you love her, you could spend time working on teaching her the cooking aspect.
Moreover, just like Seun said, it is better to have a woman full of potentials to having a woman that is high time liability.
Food is not the 80 percent area of marriage, is just, some few necessity of it all.

@ Thread Author,
Is pretty great to contribute on such a wonderful topic, keep the good words moving.

Cheers,

Segoye2
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 10:17am On Jun 18, 2007
oloye segoye2,

ki emi ola o gun o, inu mi dun pupo wipe eyin len soju baale.
mo so fun baale wipe mo fe da ile ise igbalode ti won tin se oti lile(biya ati ogogoro) sile ninu ilu wayi.
baale ko ti fun mi laye ati ile lati da ile ise naa.
nje a o lo ipo yin lati fun mi ni ile ki baale ko to de. mo se ileri oun meremere fun yin.

egbe egba je egbe ti yio mu ki ilu wa ki o toro bi omi afuwuro pon.
awon to gbajumo bi eyin le le darapo mon wa.
Ore mi Tafari,

O seun ooo, sugbon igbagbo mi ko gbami laye lati gba abetele lowo enikeni, ati wipe, baale wa rin rin ajo ni, kin se pe won ku, ati wipe won iti fun mi ni ase lati ma daba ti te mi ti karami, nitorina, ase ti baale ba pa ni awan tele.

Ati wipe, Oba nairaland wa si ha yi ni osan ana, ele bewon lati bayin se eto lori ile ohun, ani lori ile ni ori threadi yi fun ile ise na, ama, mo fe fi ye yin wipe, ile ise ti e fe da yi, ohun ayo and ohun gidi ni, sugbon, a mase fi owo abetele ko ooo, nitori ojo oni ko oo, nitori ojo ola ile ise yi niooo,

Baale wa o ni pe de ooo, eku oju lona ooo.


Si ore mi Ikomi,

Bawo ni, se daada ni iwe mi yi ba oo, bawo de ni oro iwo ati iyawo re? jowo, ma fi sinu adura, nitori, ohun gbogbo ni n fe adura, ati eyi to dara ati eyi ti ko dara, adura ni a, de re. Ma si je ki enikeni da si oro yin mo, ani, eniya o fe ni foro, afi ori eni.

looto, aya re, omo rere ni, mo de mo iwo tikare re na wipe eyan daada ni ire, fi ogbon se oo, ko de ni bu mo o lowo oo (Amin)

Si Iyawo Ikomi,

Jowo gbo ti oko re ooo, nitori wipe, oko rere sooro ri ni awujo oni. Ati wipe, ohun kohun ti, ogbeni ikomi ba se si oo, jowo, fo wo denu ki osi dariji, ranti igba daadaa ti o ti koja, si ranti wipe ko si ki ikose ma wa, ma si je ki orun wo ba ibinu ninu re, Ju gbogbo e lo, ni alafia ni baale fi wa sile, mase je ki baale pada wa ba ile ni ituka.


Si oremi Debosky,

Ife kin yi ori ooo, nitori ni ati agbala eledumare ni o ti se wa, ohun ti ode ti odo eledumare san wa ki n pa ni lara rara, Ife omo Igbo is 4 real, ani 1 love grin

Si Ore Iyawo mi (Nana)

Se eyi wa lori ijoko, tabi eti jade lo si ibi ise cheesy
CultureRe: Urhobo Waado. by segoye2(m): 7:16pm On Jun 17, 2007
Ono uwei? mi kia, mi gwono paza grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 7:10pm On Jun 17, 2007
Nana bawo ni sunday re?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 7:10pm On Jun 17, 2007
Mo kaabo sa.[quote][/quote]grin

Ore mi Seun, kaabo ooo. I nu mi dun wipe gege bi mo se so fun yin pe, eto n lo nipa iwuye mi ati wipe Oloye Agba, Oba Tabritabri 1 of nairaland.com ma wa ni ha yi pelu wa, Inu mi dun lopo lopo.

Kabiyesi ooo, kara o le oo, ekaabo oo, ile ni le yin ooo, ile baba omo kin bomo leru, ile yoruba ti a wa yi, ti inu wa sin dun, yi yio gbe wa ooo, e seun ooo, baale wa ni ki a ki yin ooo, won sare jade fun ipade ranpe kan bayi, be gege si ni Iyawo mi sare lo si ile wa ni Nigeria lati ba awon eyan wa se eto lori ayeye Oye ti won fi mi je.

Eka bo le ken si.

Ki le ma je sir, ounje wa, otin oyinbo wa, emu yoruba si wa pelu; tabi sapele water ni efe ni grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 6:57pm On Jun 17, 2007
Egbe Agba! Egbe Agba!! Egba Agba!!!

ikede yii wa fun gbogbo eyin ara ilu ti e ba wo egba agba ninu ilu wa yi.

egbe agba wa fun gbogbo awon okunrin ati obinrin  to gbajumo ninu ilu yii.

kowe pada si mi tio ba fe wo egbe naa.

anfani nla wa fun gbogbo eni tio ba dara po mo wa.

egbe agba tumo si egbe awo. awo funfun ni o!


olukede: oluwo tafari
Ogbeni Oluwo Tafari,

Kara le ooo, e ku ise ki lu oda na. Oro kekere kan kon mi ni omi nu lowolowo.

Nje Baale ti gbo si oro egbe si en soro re yi tabi nitoripe baale rin rin ajo fun ipade ni e fin se eto lehin won lai je ki won mo si? ati wipe, ni baale ba mo si, wa ti fi to mi leti, nitoripe, emi ni Ab' oba jiro of yoruba land, ati wipe, ohun ko hun ti o ba ma gba afin ko ja, ma n to mi ni eti ni, e jowo, esala ye fun mi ni ekun rere ooo.


Si gbogbo wa,

Eku ile ooo, e de ku oro ilu wa na, ayo ilu wa yio kari oooo, iwa omo luwa bi ti a ti bere yi, e jowo, e je ki a ma see lo, ayo wa ko ni baje, ayo wa joni din ku, ola wa yo bujade, irawo wa yo tan dale, ibukun wa yo ma le si, anu oluwa yo wa wa ri, ogo wa ko ni wo ile, Ni ORUKO JESU (AMIN)

Si iyawo mi,

Bawo ni, awon ero ile n ko, se alafia ni awon daddy ati mummy wa, mo gbagbe lati so fun awon ore re pe o sare rin rin ajo lati fi to awon eyan wa leti wipe a ni ajoyo kekere kan to n bo lona.

Ma gbagbe pe ore re, Nana n reti re, o de ti n miss e ooo,

I love you (mo ni ife e)
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 6:47pm On Jun 17, 2007
Ogbenni Olofofo, ki ni koko ofofo re? salaye fun mi yo.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 5:13pm On Jun 16, 2007
Ore wa Al Raheem!,

Oda na, eyi keyi ti eba lo ni o da. Ati paapa julo, oruko rere san ju wura ati fadaka lo.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 1:08pm On Jun 16, 2007
Ikomi, ki ni oti ko mi ni owuro yi grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 12:16pm On Jun 16, 2007
Baale, E seun wa oo, ma de ma kon si yin ni nkan bi ago meta osan oni grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 4:06am On Jun 16, 2007
Baale se ewa ni afin bi? ni deede ti mo dele ni aya mi jise fun mi pe e n wa mi ni afin ooo, ni gbati mo de de afin mo ba olori agba, won de fi to mi leti pe eti wo ibu isun, won ni ki wa riyin ni hai lowuro oni, baba, se ko le ooo, ? cheesy
CultureRe: Urhobo Waado. by segoye2(m): 4:01am On Jun 16, 2007
Mavo desorlah,? oma garin? vredo aye me,!, we we ukwo urhobo gbani ukwo yoruba?, didi ode we,? mi kia, mi gwono damee! grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 1:09am On Jun 16, 2007
Ore mi kan pemi lati Nigeria, ode n bemi pe kin ran owun lowo lati ko Cover Letter,

Oda na, mo nigbagbo pe ire wa ni hayi lowolowo yi, nitorina,

BAYI ni WA Se KO!

I am an enthusiastic, loyal and clearly dedicated individual who has
an ambition to succeed in any given environment. I have a desire to
learn, and am always up to a challenge whatever the situation. I get
along well with others, while also working efficiently on my own. I am
seeking a position where I can develop and excel while giving my best
to an employer.

I would like to thank you for your interest in my inquiry for
employment. I have worked directly with lenders, assisting in a number
of ways ranging from facilitating answering phones, filing, data entry
and many other duties that are commonly associated with a Loan
Processor.

I have demonstrated the skills that make an individual like myself an
excellent candidate for this position. Skills like leadership, a
positive and professional attitude, good punctuality and attendance,
detail-orientation, command of written and oral communication, the
ability to work efficiently in a fast pace environment and most
importantly, excellent customer service and public relations skills.
In addition to these skills, I have over five years of combined
experience and, knowledge of Microsoft Word, Excel, Power Point and
Access, internet exploration and managing cash and credit
transactions.

Along with this cover letter, I have enclosed a copy of my resume for
your review. Thank you once again for your time and consideration. I
look forward to working with you soon


I haven't updated my resume yet but I have been working for London College of Business and Computer Studies as a in house consultant for 2 years, 4 months now.

Thanks

Lander, Segoye2
Clampham Common
London
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 12:38am On Jun 16, 2007
Eyin Eyan mi,

Eku ile ooo, ore mi, jowo, mo jade lo fun ipade ranpe kan bayi ni oooo, e mi ki n mu emu mo.

IYAWO Mi, Se Owa ni ILE?

Eyin Eyan mi, eku aduro ti oooo!

Emi ni omoyin, ore yin,

Segoye2
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 11:53am On Jun 15, 2007
Minute, oma pe ti arin yin oo, se ko le oo grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 11:31am On Jun 15, 2007
Ekaro ooo, ema binu pe ope kin to de! se daada le wa?

Iyawo mi atata, bawo ni, ku oju mo ooo, bawo ni ara re?

Baale, se ara le oo, mon bo lafin, se ewa ni afin bayi bayi? grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 8:58pm On Jun 14, 2007
Bawo ni Ore wa champredd , I nu mi dun pe, ede abinibi wa ti an so yi wu ori re.

Si Queen2,

A gbiyanju lati se bi ose so, be gege, iwo gbiyanju lati so ede re daadaa, O se pataki, ota koko grin

Baale, Mo de Agbala, e ti jade, se ara le oo, igbagbo mi ni pe, lori eto wa le den baka oooo
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 8:49pm On Jun 14, 2007
Nana mo wa, mo ro pe Iyawo mi wa ni ile e made ni, nitoripe, oni wipe oun fe lo ba egbe awon obirin lori oro eto iwuye mi, boya ode de ile, ti ko de ba e nile, mo de ni gbagbo pe ko ni pe de. Ebi ti le n pa mi, sugbon ma duro. grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 7:47pm On Jun 14, 2007
Nana, bawo ni? se o wa pa!? bawo ni oko re?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(op): 7:41pm On Jun 14, 2007
Ore mi Mishoo,

Inu mi dun pe daadaa ni oba ile oo, looto, mo ni mo n wa obirin to sanra ni gba yen, sugbon, mo sese ri wipe, ise ni ade gbogbo re, ju gbogbo re lo, emi ati iyawo mi desorlah ni ife ara wa daadaa, ati wipe, e jowo, yowo ranti wipe, o n ba aya mi soro wipe ki o ko mi sile, ki osi lo fe fani?  huh

Koda, oro re, ore mi, bimi ninu gidigidi, sugbon, lai binu jina, ore ni wa, mi o de fe ki e da si oro ilewa mo, ohun ti o ba nile ni ki o dasi, jowo, oro ti o wa nile ni oro iwuye mi, ki n se oro ati gba iyawo mi lowo mi, tabi ti oba gba lowo mi tan, se wa fe mi ni?  angry

Si Baale,

Mo ti ba oga Seun soro, mo ni gbagbo pe yio bawa ni biyi, yio si daasi oro yi tale tale oni.

Si Iyawo mi,

Iyawo mi Owon, O seun oo ode ku itoju ile ooo. Se daadaa ni owa, jowo, je ka pade ni owuro ola lati soro lori ayeye wa, nito ti oba se ti temi, tiwa na ni ooo!  grin

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 22 pages)