₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,328,435 members, 8,435,623 topics. Date: Monday, 29 June 2026 at 05:36 AM

Toggle theme

Skamo74's Posts

Nairaland ForumSkamo74's ProfileSkamo74's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by skamo74: 10:01am On Apr 27, 2016
[quote author=kadunasouth post=33530358][/quote]Baba kadunasourh.Baba heartfirst, Baba Ifankaleluya... etc
iyonu Olohun yio ma ba yin gbe
lailai .
Sir, egbami ooo awon enia kan ma
lo nji oja mi ko nibi ti mo man ko si.
kini mo le se si aye naa Baba


eseun
Christianity EtcRe: Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by skamo74: 9:59am On Apr 27, 2016
salam aleykum Baba kadunasourh. iyonu Olohun yio ma ba yin gbe lailai laye you ati ni ojo alikiyaoma.
Sir, egbami ooo awon enia kan ma lo ji oja mi ko nibi ti mo man ko si. kini mo le se si aye naa Baba

ma salam

kadunasouth:
Bi eniyan bari iyonu oloun gbogbo aye ni ma yonu si iru enibe
Ki oloun eledumare yonu si eni kokan wa kama se dede ibinu re lai lai ati awa ati aromodoma wa Amin ase

Sugbon onawo lalegba ri iyonu olorun oba?
Akoko ipa ofin re ma ati ti tele gbogbo nto ba pawalase.
IWa aforijin lori asise wa lai fi jafara
Ima so ebi po
Itore anu fun awon alaini
Imalosi ile ijosin lorekore latilo josin fun oluwa oba ati bebelo
Kini idahun tire lori ibere yi?
CultureRe: .. by skamo74: 9:03pm On Mar 22, 2016
Thanks Baba. this is what we want sir.
May you live long sir. thanks for the Understanding sir

stay blessed sir


Ifankaleluya:
MO FE RO(urge) WA. E JE KA MU ORO(do do) KURO LORI ORO YEN.

SE EMO WIPE ORO-SISO OBEY HOOKE'S LAW, BI A BA TI N SO,BEE NI YIO MA GUN(do) SI, UNTIL IT EXCEEDS THE ELASTIC LIMIT.

SUGBON TA LO MO IGBA TI YIO EXCEED ELASTIC LIMIT? NO-ONE.

SO,LETS STOP POSTING ABOUT IT. KOSI ENIKENI TO N BA ARA WON JA LORI FANRAN YI.

LETS CONCENTRATE ON THE SALIENT OF THE THREAD.

THANK YOU ALL FOR THE SPOKEN & UNSPOKEN WORDS. I WISH YOU ALL, ALL THE BEST.
CultureRe: .. by skamo74: 6:50pm On Mar 19, 2016
Haba! Sir sorry for saying this I think it's now clear you are not on this forum for the good of it. what are you really teaching people here? Are you using style to sell yourself as the biggest Babalawo? it seems you have a lot of power you want to use or test.

awon agba bo won ni " Igberaga ni siwaju iparun" ati pe " Agba to ba lomi ninu kin pariwo".

Sir can't you start your own forum on IFA or what ever. Everybody has been pleading with you but you still want to pick fight with Baba heartfirst.

sir, since you came on this forum you've managed to create a lot of confusions for us who are learning. the simple truth is that Baba healthfirst and Baba kadunasourh and others has help us alot. we tested what they teaches us and we conformed it to be true.

sir, if you have some just teach and stop urging for war.


sorry my view

Ifankaleluya:
@Healthfirst

I was busy in d morning, So, I could not responded to you post on after the other.


Truely, we have not met in camera,but,if w do. You're still very small to challenge or stop me on any ground cos I no b your caliber, to set proudness apart.

You're very free to invite me to any ground, you w know GOD still exist!
CultureRe: .. by skamo74: 2:56pm On Mar 18, 2016
Baba ajinde ara yio ma jeyin sir. Mo Fe bere bi ao ti se lo ise you ni sir

healthFirst:
IFA IBASIRI TI ENIYAN BA FE SE INAWO TI FI YE ENIYAN Ao da iyerosun sinu aso funfun ao wa teni OTUAMEJI. OFO RE:Amilara, amiloro, iyi ni seru akora baba yin, orunmila o to gege, kowa fun emi lagbaja omo lagbaja niyi temi nibi n kan ti mo fe se yi, ka siri mi o bo, asiri aso funfun ki tuu, ifa moje kasiri temi lagbaja omo lagbaja o tu o, otuameji moje kasiri temi lagbaja omo lagbaja o tu o, kin gba iyi kin gbeye, aso funfun kisi loju oloosa.
CultureRe: .. by skamo74: 7:32am On Mar 15, 2016
Baba pls according to Zenlife teach us any useful things on ewe ati Egbo. since you answered him you've been talking more on Ifa than teaches us ogun and you're more interested in Ifa challenge with Baba health first and most of your useful Ogun is not complete here with the excuse that you don't want people to sell it.

I know you want people to know more truth about IFA, i know you're an intelligent and learned man, so I suggest you start maybe ( IMO NIPA IFA ATI IWULO RE ) or any other name you may think of. You may even make your publication here.

this is my view

thanks


Ifankaleluya:
Maybe you should try to go 2ru my previous posts. You will understand why! You may send an e-mail 2 m nd i'l respond 2 ur request privately. Nd if u av done so,bt,yet 2 received my responds, you shld understand dt there are numerous messages on my e-mail nd urs may went over-sight.

More-over,all my posts here is a prayer 4 u. U may like to say amen 2 it, nd u shall received d blessings in it.
CultureRe: .. by skamo74: 3:59pm On Mar 12, 2016
[
Alfa eke,pastor eke, babalawo eke,adahunse oniro,even fake ore ti. po pupo lasiko ti awa you.

e ni lati bere Lori AJEGUN. eo ri opolopo ni ori ate yii



quote author=skypeme post=43686849]

ni bi odun melo kan seyin mo se alaba pade alfa kan fun iran lowo ati se aseyori, alfa ti mon so oro e yi si se jamba fun mi, gbo gbo aje sara ati iso to wa lara mi ni alfa yi baje. mo wa di eni ti ogun tete ran lese kese.[/quote]
CultureRe: .. by skamo74: 6:38am On Mar 10, 2016
Baba kini Ogun ISETO ( Diabetes)
CultureRe: .. by skamo74: 7:12am On Mar 08, 2016
Baba Ifankaleluya ..... haba !! are you mr. know all? You can't definitely know all. That belongs to the Almighty God. All baba heartfirst and baba kaduna has been giving us is working . I have personally tried more than 15 and all is perfect. about to try one of yours.


why are you always going against others. we have been enjoying this forum before, but you have been confusing pple. pls, just do your own part and leave the others with theirs. or rather you can start your own forum.

Nobody can know all. even Professor can not know all they keep learning and progress.

this is my advice.


Ifankaleluya:
HAAAAAAAA!!!
EJOWO SE KOSI ELOMIRAN YATO SI EMI TO JE BABALAWO LORI FANRAN YI NI? OGUN IRO NI OKUNRIN YIN N FISILE, KOSI OBARA-DAGISE KANKAN. OKANRAN-ADASENU LO WA. OGUN IRO LO KO SILE YI OKUNRIN YI KO DA, MA JE KI AWON ENIYAN SUN(BURN) OWO WON MO.

ATI EWE, ATI EGBO,ATI GBOLOHUN IFA KOSI ELEYI TO BA ARA WON MU!
CultureRe: .. by skamo74: 5:10pm On Feb 10, 2016
baba kadunasouth ati baba healthfirst, eku itoju gbogbo Omo kaaro ojire, ajinde ara yio ma je oo Ejowo kini ale lo fun eniti o my IGBO "India hemp" ati "alaboyun" ti won nleri si pe koni bi layo Apada si aburu koni bayin lailai, amin
CultureRe: .. by skamo74: 5:08pm On Feb 10, 2016
baba kadunasouth ati baba healthfirst, eku itoju gbogbo Omo kaaro ojire, ajinde ara yio ma je oo


Ejowo kini ale lo fun eniti o my IGBO "India hemp" ati alaboyun to won nleri si pe koni bi layo



Apada si aburu koni bayin lailai, amin
CultureRe: .. by skamo74: 6:50am On Feb 04, 2016
healthFirst:
Eleyi kii se Agunmu sugbon e le lo fun Ako Jedijedi;

A. E lo ge Egbo igi ti won n pe ni Udi, ke re sinu omi lojo meta, lehin re, ke bere si mu diedie...Ako jedi yio di ohun igbagbe.

B. E lo ra Ogede Agbagba dudu ti koi ti pon rara, e sun bi boole, ke ma fi Adin Eyan je nigbagbogbo...Eyi tun sise fun Idakole.
e jowo sir se Egbo Igi Udi ni abi Egbo igi Idi?
CultureRe: .. by skamo74: 6:47am On Feb 04, 2016
[quote author=skamo74 post=42602189][/quote]Eseun pupo baba wa healthfirst. ojo yin yio di ale pelu alekun alafia ati ola nla . Olodumare yio ma ba wa dunyin ninu kale

ase ! ase!! ase !!!
CultureRe: .. by skamo74: 6:43am On Feb 04, 2016
healthFirst:
OGUN IDI YIYO
patako ese malu topo, ao jo papo mo odidi atare kan, ao lo kunna dada, ao ma bu sinu adi dudu, eni na a ma yo mu diedie, yio si tun ma bu ebu re soju idi na.
CultureRe: .. by skamo74: 6:39am On Feb 03, 2016
[color=#006600][/color]

eku owuro gbogbo ile. ejowo oo gbogbo ile mofe AGBO ati AGUNMU fun AKO JEDIJEDI. ati fun IDI YIYO.

oju oniti awon agbagba odua ati nairaland

ama ju awon omode se oo... ase

1 (of 1 pages)