Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,525 members, 7,954,989 topics. Date: Saturday, 21 September 2024 at 01:42 PM |
Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Ekún Ìyàwó (2550 Views)
Ìyàwó Wa (our Bride) (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Ekún Ìyàwó by oloriireomo(m): 10:17am On Jan 03, 2014 |
EKÚN ÌYÀWÓ. Ati dá ara lékòó nípa" ràrà sísun "l'órí ètò yìí sáájú àkókò yìí. Ní òní yìí e jé kí á gbé ohun tí wôn n pèní ekún ìyàwó wò. Ní ilè yorùbá,ìyàwó titun tí ó ku bí ojó márùn-ún láti losí ilé oko ló n sun ekún ìyàwó káàkiri ilé òbí àti ebí rè láti gba ìre lenu won àti láti dágbére fún won pé 'ìlo tiyá, oníbodè apòmù. •ìyàwò yóò má a ki oríkì-orílè òbí rè •ìyàwó yóò má a sòrò nípa ilé oko rè,ìyá oko,bàbá oko tàbí orogún. E jé kí á wo àpeere yìí: ìyàwo yóò kúnlè sí iwájú àwon òbí rè tàbí ebí rè,tí ó bá jé iwájú òbí rè yó sì má a wí báyìí pé. " ilé oko yá, mo wá gbare è mi Èmi Àdùké òpómúléró moja lekàn, Bàbá tí mo ní mo dúpé kíké tée ké mi, ìyà tí moní mo dúpé gígè tèe gèmí.(abbl). Léyìn náà,ìyá á gbówó lé e léjìká.yó wà súre fún pèlú omijé lójú. " Àdùké òpómúléró moja lekàn. ilé oko lo n lo kélédà ìyá mi má a sìn o lo.ìkó kìí kéjo lésé.ní ilé oko wà á bí okúnrin àbiro,obìnrin àbíyè...(abbl). Gbogbo àwon àdúrà yìí ni kìí jé kí omo ó kàgbákò tàbí bá elénìní pàdé n lé oko.wón á boko gbé dojo alé. sùngbón láyé òde òní nko?gbogbo àwon àsà wònyí tí d'ohun àmúpìtàn. YORÙBÁ DÙN GBÓNGBÓN!!!! I love it plenty plenty. •omo yoòbá àtàtá |
(1) (Reply)
[story] I Called It R.*.p.e (rated 18+)… Part 5 / The First Time I Made Love By Olayemi Olanike Ajewole / It Wasn't A Lie- A Novella By Kayode Odusanya
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7 |