Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,701 members, 7,820,452 topics. Date: Tuesday, 07 May 2024 at 03:11 PM

Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) (1680 Views)

Ogun Awon Bàba Wa / Awon Koko Inu Iwe Iroyin To Jade Loni (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by BRAV0O(m): 8:49pm On Sep 22, 2014
Mo ro wipe won ti ni ki okada marin ni oju ona marose moO ni ilu eko ?

Ewo ni si yi bi mo se (shay) soro yii , okada kan ti onbo lati wrong way ti she omo kurin kan leshe ni oju ona mangoro (new abeokuta express road)
O dun mi pupo wipe won o ri olokada ye ri mu , nishe ni ogba omokurin na ti ofe sonda jeje ti ko mo pe okada bon ni ona ibo miran ,

Akiyesi mi ni wipe , awon ti won ba ni ebi ni area ye ki won shora oO , nitori kodi gba ti won ba to pa nkan ninu awon ti won sunmo wa ki ato mowipe iru nkan ti won tolerate ni area yee O da rara

Atipe , awon agbofinro wa gbodo sun shokoto won soke , mo gbo wipe awon agbofiro kan ti lo gba rigba lowo won ni bi ti won ti ma kero ni ikeja along ,

Ejowo oO , olorun a maa showa oO
Ki awa na ma shora wa oO

Iwa ti awon omo olokada ye wu ni agbegbe ye oda rara, nishe ni won ma gba wrong way lati ikeja along titi de dopemu underbridge.

Emi ni molebi ni area ye oO
Ti okada ba gba molebi mi ni experess ye , fashola ni emi maso lokun lorun oO ...

2 Likes

Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by aryzgreat: 8:52pm On Sep 22, 2014
Seun, oam4j, mynd44

Please move to cultural section. Thanks
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by Ramnon2: 8:55pm On Sep 22, 2014
WTF is this? Is this some spirit language? grin grin
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by aljharem(m): 8:59pm On Sep 22, 2014
Egbon, Okada ti pada nitori pe Fashola ati Tinubu ti re pe ode ni awon yoruba ni di yi lo fi mu okada pada.

Ema dibo fun APC mo o.

Make una hear word

1 Like

Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by BRAV0O(m): 9:03pm On Sep 22, 2014
Gbogbo wa la month idi ti won shay da okada pada shugbon ewo ni ti wrong way bayi ? !

Eni ti oba mo fashola rii, kiwon kilor fun won oO

aljharem: Egbon, Okada ti pada nitori pe Fashola ati Tinubu ti re pe ode ni awon yoruba ni di yi lo fi mu okada pada.

Ema dibo fun APC mo o.

Make una hear word
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by aljharem(m): 9:08pm On Sep 22, 2014
BRAV0O: Gbogbo wa la month idi ti won shay da okada pada shugbon ewo ni ti wrong way bayi ? !
Eni ti oba mo fashola rii, kiwon kilor fun won oO

Adura wa ni pe ki PDP sha gba ijoba lo wo APC. Wo ta wa fun awon ole nigeria. cry cry
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by BRAV0O(m): 9:11pm On Sep 22, 2014
Ati pdp ati apc , kosi iyato ninu gbogbo won jare , ki won sha ma fi tiwon ko ba wa

aljharem:

Adura wa ni pe ki PDP sha gba ijoba lo wo APC. Wo ta wa fun awon ole nigeria. cry cry
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by aljharem(m): 9:15pm On Sep 22, 2014
BRAV0O: Ati pdp ati apc , kosi iyato ninu gbogbo won jare , ki won sha ma fi tiwon ko ba wa


Hahahaha LOL

Otoo lo sor egbon sugbon eyin agba na le so we pe "Aja lo ma n je ebi e" (A dog going back to eat its vomit)

Ni kan ti APC shey ni yen
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by BRAV0O(m): 9:19pm On Sep 22, 2014
MomO pe opolo lasan ni apc nlo fun wa ni ilu eko shugbo nkan ti won she da po ju eyi ti won she da loO , shori pdp to soO ye , emi oti ele fi owo sanya fun won rara , olohun mo pe pdp ole gba eko sha ...

aljharem:

Hahahaha LOL

Otoo lo sor egbon sugbon eyin agba na le so we pe "Aja lo ma n je ebi e" (A dog going back to eat its vomit)

Ni kan ti APC shey ni yen
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by aljharem(m): 9:33pm On Sep 22, 2014
BRAV0O: MomO pe opolo lasan ni apc nlo fun wa ni ilu eko shugbo nkan ti won she da po ju eyi ti won she da loO , shori pdp to soO ye , emi oti ele fi owo sanya fun won rara , olohun mo pe pdp ole gba eko sha ...


Well, ka ma wo

Ti Oluwa lo ma se smiley
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by BRAV0O(m): 9:37pm On Sep 22, 2014
Abi . ..

aljharem:

Well, ka ma wo

Ti Oluwa lo ma se smiley
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by Handsomeemmy(m): 9:38pm On Sep 22, 2014
Asiko ibo didi ti sumo, ti tori be ni ese ri awon olokada ni ori titi marose.

Oluwa oni gba fun eni ti obafe ba ilu Nigeria je mo wa lowo, e se akiyesi gidi gaan ki eto dibo.

Nigeria a gbewa ooo ... A se.
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by kweenkong(f): 4:45pm On Sep 25, 2014
ki a ma so ara ni adugbo yen agaga ti ile ba ti su. nitori sunkere fa kere oko ni adugbo yen awon eyen se gun okada. okada ni kan ko o, motor no ma gba odi ikeji ono nitori ono yen. Ti e ba le bawa be Federal Govt ki wan wa se ibi iyanna buststop yen , awon eyan to gun okada a diku, okada no o ni ma gba one way repete bayen.
( i hope what i wrote was readable) smiley
Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by 2prexios: 7:31pm On Sep 25, 2014
mo ranti ojo kan bayi ti mo nkanju lo si obalende. Aaro kutu hai, mo ji, mo mura. Bi mo se de under bridge, Olokada naa ti nduro de mi, O dabi enipe "AK" ni man naa. kia, mo gbe baagi igbalode ti a maa npon seyin yen wo bi ewu ode, mo joko, inu mi dun. Lesekese, olokada fina si okada re, eruku lala tu jade lenu salensa bieni pe ero ilogi faragbota.

beeni inu mi ndun siin bi okunrin to ri olomoge. wo, ti mo ba ri power bike lori 3rd mainland bridge, nse lo maa nwunmi pe emi ni mo nwa power bike naa ni, ere iku maa nse ara mi bakan, nko ever kilo fun olokada pe o nsare ri, ere yen gaan ni mo fe, mo maa nso pe, awon oyinbo mo nkan ti won nse kon to se okada, won fe nkan to maa sa ere asapajude ni, emi naa de fee be.

So lojo yen, bi mo ti de ibudoko, ti a nlo si oshodi, okada naa bere sii sare, mi o tie care, kilokan mi, ani ko speed si. So traffic wa mu ni Ikeja along, but igba ta de ehn, iyana airport, ona yen ti free. Olokada mi bo si fast lane, o wan jalo bii irawo to ja ni oju orun. Emi naa reke si eyin e bii enipe moti ni emi mii ni inu bag.

Base de sam ethnam airforce base bayi, bad man kan kan nsare bo leyin wa ni, o gbe camry car, o fi funwa mo arin oun ati danfo pa. Ko foni rara, aya mi ti jah! Moto mejeji fun emi ati demana yen pa ni. Olorun lo ni ki owo dimana olokada yen magbon, aijebe, a maa subu saarin tamac, moto tonbo leyin akon grill wa ni, ni suya bade.

Aimoye awon eeyan to ti ku si ori tamac yen. Bi ase de iwaju entrance awon soldier yen, man evil driver yen wan so pe, "maa payin danu ni, wo maa payin danu lasan ni" Ah, Yoba ni man naa o, O Kola kongba-kongba s'eke bi omo ti funny pesin kon gbe si ori tred kan nibeyen. Atigba yen ni mo ti so pe mi oni gun okada ni express mo titi aye maa fi pare.

but eyi to foni ju ni awon to maa ngan oko reluwe ni ikeja lale lati ebute metta. Ko nse nkan to dara rara, ori won maa ngba irin nigba mii. ijokan, mo try train lati Island, kinto de agege, ifun mi ti lepor morawon. mo fee bi nijo naa. oorun awon eeyan bi won se nmi siranwon, olorun lo le ko awon ara eko yo ninu hilahilo.

1 Like

Re: Akiyesi Pataki Fun Awon Agbofinro!!! (yoruba Only) by Howmanage: 10:12pm On Sep 25, 2014
BRAV0O: Ati pdp ati apc , kosi iyato ninu gbogbo won jare , ki won sha ma fi tiwon ko ba wa

emi o gba pe ikankan naa ni won o! Afoju nikan ni ko le ri wipe APC si san ju PDP lo ....

(1) (Reply)

Metamorphosis: Alaafin Of Oyo, Oba Adeyemi On His Coronation In 1971 And Now. / Other tribes / The Story Of The Benin's Kingdom In Connection To Oduduwa's Dynasty In Ile Ife!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 29
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.