Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,286 members, 7,957,742 topics. Date: Tuesday, 24 September 2024 at 06:44 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842235 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:26pm On Jul 03, 2015 |
[color=#000099][/color] GENERAL LOVE ewe amunimuye ewe alupaida, eyo atare meta ao jo po ao pomo ose dudu ao fimawe ...eniyan kan nioo 1 Like |
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:32pm On Jul 03, 2015 |
[color=#000099][/color] OGUN ANU obi ifin kan ao gesi 201, obi pupa kan ao gesi 201, eyo atare 201, ao fi omi amu po papo ao ro si inu ado ijamo kekere kan ao fi awo ijimere ran ao ma fisapo..ODAJU . 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:33pm On Jul 03, 2015 |
KEHINDE633: O kare omo odo agba....Oogun itusile to je bi idan ni sugbon lehin ti a ba fi nu ara pelu iwure tan, ao fi eyin na sinu apaadi kekere kan, ao bu epo ojeere le lori ao gbe sori aatan tabi orita meta...beeni, a kii wo ehin tabi ba eeyan kankan soro titi ao fi pada de ile. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 2:46am On Jul 04, 2015 |
x 1 Like 1 Share |
Re: .. by avsnet: 8:49pm On Jul 04, 2015 |
healthFirst: ('Inu agbada' (re mi mi) cloth wear or inu agbada (re re re) big earthen pot). 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:36am On Jul 05, 2015 |
£ |
Re: .. by kadunasouth(m): 1:56pm On Jul 05, 2015 |
OGUN ISOYE Ewe akoko 16 ori akuko adie togbo dada odidi atare kan aojo ao ma fi oyin la 4 Likes 3 Shares |
Re: .. by kadunasouth(m): 2:35pm On Jul 05, 2015 |
ISOYE TA NFI RANTI GBOGBO NKAN Akuko to batobi dada ao tu iye abiya re ti apa otun ao lomo eyo atare meta tapa osi eyo atare meta ao fi tapa otun sin gbere meta si abiya otun tapa osi si abiya osi ti aba gbagbe nkan kan ao fi apa lu apawa lemeta bi adie pelu ofore ao ranti nkan nan lese kese odaju OFORE Bi adie bafi apalu apa pipi iyere aso 3times kin ranti nkan bayi bayi opari. Fun ibere kansimi lori email mi 4 Likes 2 Shares |
Re: .. by iahmed(m): 3:55pm On Jul 05, 2015 |
Ba ba o! Edakun kini ema nipa ifa owo at pei kini awon ewo to so po mon ifa owo ni bibo |
Re: .. by Nobody: 6:36pm On Jul 05, 2015 |
avsnet: earthen pot...ko je dandan ko tobi...iwonba ti a le fi jo Oogun na 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 6:43pm On Jul 05, 2015 |
x 3 Likes 2 Shares |
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:51pm On Jul 05, 2015 |
MARAN ADA obi lakiriboto kan pelu eyo atare mesan ao lo je lori igi ti ese wa ko ni kanle MARAN IBON ASASI ewe irosu kan ao fisi abe wa moju tio ba di ni ojo keji ao lo jo pelu odidi atare kan ao fi singbere yida inu wa ikun wa IBA AGBA ILU 1 Like |
Re: .. by KEHINDE633(m): 11:00pm On Jul 05, 2015 |
[center][/center][/color][color=#000099] OFO OWO(RESPECT) ao ko atere mesan si enu ao ma pe ofo yi bayi pe...iwaju ori ohun ni gbayi lowo ori (3x) Atele ese ohun ni gbayi lowo ese (3x) aso funfun ohun ni gbayi lara oku (3x) emi lagbaja omo lagbaja gbogbo ibi to moba de loni kin gbayi ao tusi iwaju 3 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 11:39pm On Jul 05, 2015 |
Ogun iyonu ati aranse Koro owu akese topo eyin ororo ati atare ao jo ao lo kuna ao ma fi miliki olope lo die die 4 Likes 2 Shares |
Re: .. by jades5050(m): 9:52am On Jul 06, 2015 |
Inu mi dun gan ni nigbati mo ba irufe eto yii pade. Ise takuntakun le nse oooo ewe a ma je egbo a ma je fun yin ni ase EDUMARE 1 Like |
Re: .. by kadunasouth(m): 1:06am On Jul 07, 2015 |
jades5050:Amin pupo |
Re: .. by KEHINDE633(m): 2:02pm On Jul 07, 2015 |
[color=#000099][/color] MARAN..ADA,OBE,IBON .AIKE.AYETA..ATI FORI FOGO ...IS COMING SOON .........it me your boy kenny shitta.a.k.a senior kay. respect |
Re: .. by Nobody: 5:08pm On Jul 07, 2015 |
Oju Okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele awalawulu oju orun o ni wu koriko awon lo difa fun olokun seniade lojo ti gbogbo omi so pe awon ko niba se mo won ni ki o rubo ki gbogbo awon ti won lawon o ni ba se le maa ba se won yan lebo o rubo laipe laijina gbogbo awon omi ti won lawon o ni base yi ohun pada won wa nba olokun se wo si fi joba won won teriba fun un olokun seniade njo, o ni yo ooo ni bee lawon babalawo to se fa fun oun wi awon oju okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele awalawulu oju orun ko ni wu koriko awon lo difa fun Olokun Seniade lojo gbogbo omi so pe awon o niba se mo nje e ba mi se loni atewe atagba ewe asesere loni ki e ba mi se eku olose loni ki e ba mi se ogbo loni ki e maa gbo te mi ewe apada loni ki e padi ire gbogbo da si odo mi loni nitori ti moriwo ope ba yo a koju si Olodunmare Atewe Atagba e maa ba mi se 5 Likes 1 Share |
Re: .. by jades5050(m): 7:37pm On Jul 07, 2015 |
healthFirst:. Mo se iba eyin Agba ooooooo |
Re: .. by KEHINDE633(m): 8:07pm On Jul 07, 2015 |
[color=#000099][/color] IBON TODAJU ewe ailu to po die pelu eyo owo (15) ati omi osan wewe ao gun pomo rawon ao da si inu omi osan yen ao ma mu die die.. 1 Like |
Re: .. by KEHINDE633(m): 8:13pm On Jul 07, 2015 |
Iba akoda aiye..iba aseda aiye,. iba agbagba merindinlogun lotu ife..iba oja tokun tio lero.iba obinrin arin ihoho woja..awon loni akiki odidi made kuro ju ano. ojo ti akerejupon ba fenu kanle ojo na ni kanlepa.ojo ti keregbe batenu bo omi ololo ni fohun....,... 2 Likes |
Re: .. by KEHINDE633(m): 11:36pm On Jul 07, 2015 |
IBA EYIN IYA MI LORITA META ONA ARA EGBO OHUN MI LONI O ogbo loni kie gbohun loni, alupiada loni kie ma pahun mi da loni. ogba loni kie gba oro mi loni. abamoda kan oni da tie kio mase . gbogbo obirin ilu okunrin ilu egbo hun me sire loni 4 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 4:56am On Jul 08, 2015 |
E ku ise, egbogi wo lo da fun eyin didun ati ara riro |
Re: .. by Nobody: 5:00am On Jul 08, 2015 |
KEHINDE633: Se ko ni gbolohun tabi ofo kankan fun. E se |
Re: .. by Kulrunner: 2:12pm On Jul 08, 2015 |
Ejo ogun awure obinrin nimofe ejo efunmi |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:32pm On Jul 08, 2015 |
Mode lobi ile ile lobi mode ogere afoko yeri afoko yeri lobi atepe atepe lobi arososile ife Arososile ife lobi Ajomisara Ajomisara lobi Agbanmiregun nje emi di Agbanmiregun gbogbo eni tobagun ori ile tofe sasimi abi semi laburu ile baja kodalamu tikobajawo ile lanu kogbemi kodi ero ORUN 2 Likes |
Re: .. by bosrote: 4:32pm On Jul 10, 2015 |
Aboru aboye ejo ki ale lo fun HOMONAL INBALANCE BI OMU OBIRIN BA NSE OMI LAI LOYUN TABI OMO LOWO? TE BA NO EJO EFUN WA . EWE AMA JE |
Re: .. by sammyjay76(m): 10:58pm On Jul 10, 2015 |
healthFirst:GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN AE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju. |
Re: .. by KEHINDE633(m): 12:00am On Jul 12, 2015 |
[color=#990000][/color]IBA saki loni oro. awo ijale loni epe. ijebu loni ase.ati oro saki ati awo ijale apa kankan otu kawa mo iyen madi eworisa..ayi ile aiye ka loruko tanpe aro. etu loruko tanpe osan. okuku birimu loruko tanpe oru. igba nla loruko tanpe aye.majedun loruko tanpe ile. ife omo jeje ki iku ma to e pami . ohun lo difa ile. eni gori ile oba gori eni ade go ri oba esinsin gori ade. esinsin to gori ade lojo kinin ano yen won dariji. Iya lode o iya lode o iya lode o .. otun. otunba. osi. gbogbo won dariji mi .kehinde. aro nimi mio lorukun ejo. aafin nimi mio lese eya go lona........COMING SOON MORE 1 Like |
Re: .. by sammyjay76(m): 7:51pm On Jul 12, 2015 |
healthFirst: GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN APE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:16am On Jul 13, 2015 |
sammyjay76: Mo da yin lohun awon ibeere yin, to ba ni awon eyi to ku; Suuru loba iwa. E se suuru, Ikookan la n yo ese le'ku. |
(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40 |