Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,804 members, 7,956,057 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 10:53 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842112 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (18) (19) (20) (21) (22) (23) (24) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by omoaribaba1(m): 11:01pm On Aug 31, 2015 |
omoaribaba1: pelu (OLUGBOHUN) sugbon akin ngbe eleyi sile ooo afi yara idalejo lohun nikan nia le gbesi. 1 Like |
Re: .. by Lionhearted: 8:16am On Sep 01, 2015 |
omoaribaba1: See ooto le so bii? Kosi ogun ti ko ni ero. Ibi ti agbara enikan pari si i be niti elomiran ti bere. 4 Likes 1 Share |
Re: .. by omoaribaba1(m): 8:30pm On Sep 01, 2015 |
omoaribaba1:maani eso bee ooooo, mio kin ba eniyan jiyan oro oo |
Re: .. by Frayo93: 11:08pm On Sep 01, 2015 |
omoaribaba1:. . eeju sitaa |
Re: .. by Nobody: 12:24am On Sep 02, 2015 |
omoaribaba1: Abala yi ko si fun iru iwa ika bayi o... Ao fe rara ati rara. A ko gbe eto yi kale lati ba ti omo enikeji je. Eto yi wa fun igbega ati itusile fun awon ti aye de mole. A ko fi aye gba Oogun Ika rara. 2 Likes 2 Shares |
Re: .. by Nobody: 12:34am On Sep 02, 2015 |
E jowo Eyin oluka, E sora nipa awon Oogun lati owo awon ti won n ba wa da si eto yi, awon Oogun ti ko pe ti po losri abala yi lati owo awon ayederu Oloogun. Awon Ayederu Oloogun ti n fi awon Oogun to je ayederu si ori abala yi pupo ju. Ao bere si fi ejo won sun awon to n dari eto abala yi. Ao si ma pa awon ayederu Oogun ti won ba ko re. 3 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 7:56am On Sep 02, 2015 |
healthFirst:Kare ore imule ododo oro leleyi 4 Likes |
Re: .. by Truck01: 2:44pm On Sep 02, 2015 |
healthFirst: E Se pupo fun ekanna ipako yi. Mo fe beere wipe kilode ti ero alageka yin ki lo?ati wipe e ti yo ero na kuro lori whatsapp? Se ko si nitoriwipe opolopo eniyan lo ti fe te yin laago fun alaye kan tabi omiran abi lati ri yin paapa. |
Re: .. by Teebob: 3:52pm On Sep 02, 2015 |
ejo Kinni a pe ni, ewe igbonse ? |
Re: .. by Nobody: 12:15am On Sep 03, 2015 |
Truck01: Ero alagbeka mi ti n sise pada...o ni iyonu ranpe ni sugbon a ti tu se bayi. |
Re: .. by scholes0(m): 3:30am On Sep 03, 2015 |
Lionhearted: |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:01am On Sep 03, 2015 |
OGUN OWO TODAJU(respect) Ewe Owo tutu ao so ogunna eyokan sinu omin ao fi ewe owo yi gba ao tunwa fi owu tutu gba legbe ao we lowu dudu ati funfun ao ma fi sapo odaju NB owo yi wa fun lati dabobo arare lona eto ti oko bati fi se aburu odaju pupo ati omo ita ati dana dana wan aman fi owo wo e ni sugbon olewu lati lo fun iwa kiwa ijona ni yio baje ti koni sise mo 3 Likes 1 Share |
Re: .. by kadunasouth(m): 11:40am On Sep 03, 2015 |
Ogun eyonu Eyin ororo kan ewe ewuro 100 ao fi tele koko ao fi eyin ororo le ao tun ko ewe ewuro 100 le lori ao fi atare kan si ao ma jo to bati jotan dada ao sokale ao wa sadua si ewe ewuro eyokan ao waju si leyin tati sokale ao lo ao pin si ona meje ao bere lilore lojo sunday fun ojo meje Nb ojo sunday nikan lale jo ise yi odaju Yio je funyin o+++++++++++++++++++!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!! 2 Likes |
Re: .. by virginary: 2:47pm On Sep 03, 2015 |
kadunasouth:Mo ju ba o,ejowo kini ao fi ma lo ise yii,se ao ma la ni abi ao fi fo eko mun. |
Re: .. by kadunasouth(m): 9:13pm On Sep 03, 2015 |
virginary:Ale lo eko tutu tabi omikan agbado funfun asi lefi omi lasan lo laro laro ni lilore daraju sugbon to basepe ale lofe malo epo pupa ni walo 3 Likes 1 Share |
Re: .. by Maleekridwan: 11:36am On Sep 04, 2015 |
Mojuba eyi agbagba lori eto yi ,eni to ma tomi ati eni ti oma jumilo ,mojuba omode ,mojuba agbalagba eje ki iba mi o seo iba ni mose. Esi dakun ki e gbami laye kie fi mi kun ijo olorire jubi moti ro lo ? |
Re: .. by Ade231(m): 1:48pm On Sep 04, 2015 |
kadunasouth:Mo ki yin lopolopo,eku ise ewe ama je fun yin lagbara eledua,ejo Eyonu ti e fun wa yi kini ao fi ma lo abi ao kan ma la lasan ni ejowo e la yewa ese pupo. |
Re: .. by Ade231(m): 1:58pm On Sep 04, 2015 |
kadunasouth:Ese pupo baba moti ri lilo re ni isale emi ni mio ka lo si isale esehun,ejowo mo ma need ogun ti eyan fi ma ni omo ekose (aprentise)lopolopo ese ma ma reti idahun yin. 1 Like |
Re: .. by Eddygrate: 2:03pm On Sep 04, 2015 |
PETS CONTROL FUMIGATION
For fumigation of your home, office spaces,
apartments, open lands,
etc.
We offer a quality and affordable services such as
fumigation and
cleaning. and we take responsibilities on all our
jobs and we have a
single goal in mind in our jobs, that is CUSTOMER
SATISFACTION.
We charge as low as N5,000 per job, depending on
the size of the apartment
For More info Please Contact
SPOTLESS SHINE CLEANING SERVICES
25 mabawonku Stresst oworonshoki Lagos
07033491967
Spotless.shinec@gmail.com
|
Re: .. by Ade231(m): 2:25pm On Sep 04, 2015 |
healthFirst:Oda bi ese se yi ajinde ara yio ma je yi ewo se oogun na lowa di nkan ti a mu ni yepere be ni oni kaluku sa n so orisi risi ti owu na ni ewo baba mo ti send msg si yin ni e.mail address ejowo mo n reti esi yin sir and again ejo mo ma n fe ogun ti eyan fi ma ni omo ekose pupo pupo ese gan ewe yio ma je fun wa o,ase edumare... |
Re: .. by Ade231(m): 4:07pm On Sep 04, 2015 |
healthFirst:Baba aboru boye o eku ise eledua yio so imon yin di otun ejo se oruka yen se ao na gbooro ni abi bi o se wa na ni kika ni ao lo ni ati pe se ao pa akuko yen si ile ni abi ao gbe eje re si inu igba kan ese pupo. 1 Like |
Re: .. by Maleekridwan: 5:29pm On Sep 04, 2015 |
Mose iba agba o. Edakun baba mo fi eleduha be yin eni subu danu . Bawo lese bawa fi ami si awon ti won ko pe ninu eyi ti o wa lori eto. Nitori wipe afani ti o wa nibe ko kere rara. Edakun ese anu wa olohun yio ranyin lowo . (Amina) |
Re: .. by oracle009(m): 4:26pm On Sep 05, 2015 |
Too... Eyi wa leni ko si nkan? Ori mi wu ni riri ti mo ri awon omo ile oodua tin won gbe asa, ise ati egbo igi wa laruge. Nitooto, emi o kin pa owo da. Amo, mo gbanju ba ise isegun (ewe ati egbo) nile ni. Inu mi si dun wipe mo tun lo ko eko nipa re ni ile iwe giga Fasiiti. Fun eyikeyi ninu ilo ewe ati egbo fun IMULARADA, e le kan si mi ni ori ila yi. A o ni fi dudu pe funfun fun ara wa... Ewe wa, Aye si tun wa. Ewe ni emi ro mo, ewe a si tun maa je fun mi. Healthfirst, e ku ise ribiribi, oodua a gbe wa o. Ase |
Re: .. by omoalade144(m): 8:12pm On Sep 05, 2015 |
Aboruboye ooo gbogbo ile.Moki gbogbo agbagba lori ikanni yio, ewe ama jeooooo.ASE. |
Re: .. by Nobody: 11:08pm On Sep 05, 2015 |
oracle009: E kaabo saarin wa. Ajagunmole, Awo ode Orun yio fun gbogbo wa se. Ase. |
Re: .. by Nobody: 11:09pm On Sep 05, 2015 |
Ade231: Eje Adiye na la fe lo. Oruka Ogun yen yio wa bo se wa ni o. |
Re: .. by Isholex1love: 11:16pm On Sep 05, 2015 |
healthFirst:e jo sir ise wo ni ao lo eje adiye fun |
Re: .. by gawab: 11:23am On Sep 07, 2015 |
healthFirst:E jowo kini enia le lo lati bo ninu ide awon eleye ti nwo ko je ki enia ni agbega ati aseyori. E se pupo. |
Re: .. by Davidifa(m): 3:32pm On Sep 07, 2015 |
Inu mi dun lati wa ni bi |
Re: .. by Davidifa(m): 3:38pm On Sep 07, 2015 |
Ero agbaina:oori oka,ewe pasa,odidi atare kan,ikoride kan,ao jo ao fi sin gbere yi orun owo mejeji ka |
Re: .. by Ade231(m): 7:41am On Sep 08, 2015 |
healthFirst:ese pupo baba eledumare yio ma funyin se o ejo mo beere fun ogun omo ekose e o si ti si nipa re rara edakun... |
Re: .. by sammyjay76(m): 10:01am On Sep 08, 2015 |
healthFirst:@healthfirst, ejowo gege bi omo yoruba to mo nipa ewe ati egbo, kini e ri si iwosan nipa lilo ito ara wa? Urine. nje o n sise bi? ti o ba nise, iru awon nkan wo la le li fun ati bi a se le lo? Ejowo gbogbo eyin ojogbon inu ile yi e bawa da si o. Eseun. |
(1) (2) (3) ... (18) (19) (20) (21) (22) (23) (24) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44 |