Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,195,446 members, 7,958,332 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 12:33 PM

Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry (811 Views)

The Cost Of Uprooting The Ekiti Sacred Tree In Odo, Oja (Snapshot) / Watch Beautiful Rendition Of Ogbu Oja Igbo (igbo Fluitist). You Will Be Thrilled / Ooni Of Ogunwusi Visits Badagry, The First Storey Building In Nigeria (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry by SisiGbeborun(f): 2:46pm On Jul 26, 2015
Awon ohun ini ti o to opolopo milionu naira lo ti jona l'ana ni iso pako kan ni Badagry ni'lu Eko. A dupe pe eni kankan o ku nibi ijamba ina naa. Ina yi tun jo ile ijosin St Anthony Catholic Church kan to wa ni itosi iso pako naa. Awon panapana tete de ibi ina yi sha lati paa ni nkan bi aago mefa abo irole. Eni kan ti o ngbe itosi iso pako, Hamed, so wipe sa dede ni won ri eefin ti o n jade lati inu awon pako ti won ko jo, ti 'Thinner' si gb'ina ni eyi ti o fa ina nla yi.

(1) (Reply)

RE: I Have No Apology To Worshiping God - Ooni of ife (Pics) / Consideration For 2016 / For The Love Of Africa. Grabs Yours Now

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.