Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,608 members, 7,809,224 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 05:57 AM

Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw (1146 Views)

ENI O LE SE BI ALABARU L'OYINGBO, KO LE SE BI ADEGBORO L'OJA OBA. a short story / 200-Year-Old Crocodile Showcased At Ero Okeliwo Festival In Ogun (Photos) / Ogun Awon Bàba Wa (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw by SisiGbeborun(f): 5:15pm On Sep 14, 2015
Kate Henshaw, gbajugbaja osere Nollywood ti gba awon ololufe e niyanju lati ma je ki lilo awon awujo ori ero ayelujara bii Facebook, Twitter, Instagram, ati bee bee lo dari igbesi aye won. O so eleyi di mimo nigbati o n salaye nkan ti oju oun ri leyin ti awon kan fesun kan pe o se afihan awon nkan to lodi si ofin ati ilana oju ewe awujo ero ayelujara kan ti won si tii jade nibe.
http://www.sisigbeborun.com/2015/09/mi-o-le-wa-je-ki-awujo-ero-ayelujara-ma.html

1 Like 1 Share

Re: Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw by abat4real37(f): 5:21pm On Sep 14, 2015
Abi o, bi o ba se wu onikaluku lose le lo igbese aiya re

1 Like 1 Share

(1) (Reply)

Kadara And Ayanmo / Yoruba Eficy And Owe / Is Indiana Jones Bad For Archaeology? [poll]

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.