Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,724 members, 7,809,757 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 02:22 PM

Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan (19728 Views)

One Final Solution To The Incessant Medical Health Workers Strike In Nigeria (lo / Haemorrhoids (JEDI-JEDI) lo ma pa / Ewe Nje (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by Aareago1: 8:07am On Apr 25, 2016
This page is created to demonstrate the power and efficacy in the use of roots and leafs as created by God for the use of mankind to address all physical and spiritual challenges faced in life generally.

The language of this thread shall be in Yoruba as all medicinal herbs' names shall be written purely in Yoruba Language. Efforts shall be made to explain certain things in English Language for the benefits of those who do not understand written-Yoruba very well.

Efforts shall equally be made to answer reasonable questions. Questions that are considered unreasonable and meaningless shall be ignored. Questions could be asked in English Language.

This page is for matured minds; dignity, honour and respect shall be the watch-words of everyone to make the discussion interesting and beneficial to all.

If you need any charm or medicine outside the ones given out freely, then, you shall be charged a token, but be assured that you will get full value for that token. Get it right please- you can request for any charm/medicinal herbs, but where the request is considered extra special, then a token will be charged.

Kindly note that, as the creator of this page, I am not an herberlist, babalawo, Olosanyin or an alfa, so, I do not consult for people. If you explain your physical and spiritual challenges, I will only try to suggest way-out with the use of roots and leafs. It is God that heals- man only tries.

Everyone is free to post here, but please make sure all charms/medicinal herbs are potent, tried, tested and confirmed in order not to make people loose their money or cause serious harm to themselves.

Welcome on board and thanks for taking time to participate.
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by Aareago1: 8:24am On Apr 25, 2016
OOGUN IDI YIYO EYI TI YORUBA NPE NI OROBO(DO DO RE)

Ewe guava tutu. A o gboo pelu omi tutu to mo daadaa. A o fi ase see (sieve it properly). Mimu laaro ati lale bi a se fe. Idi naa yo wole pada pelu ase Olorun.

OOGUN TI ENIYAN BA N YAGBE EJE

Ogede agbagba dudu, a o so sinu ina ti yoo jona bii eedu, a o loo kuna daadaa. A o maa fi fo eko tutu elewe fomu ninu igba tabi aha kekere laaro ati lale. Ise to daju ni. Danwo.

AMUDO TO NJE BII IDAN
Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro

A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re yoo fi maa dide.,
SUGBON BERU OLORUN, TI O BA FI YAN OBINRIN JE,
OLORUN KONIJEKI OSISE.

3 Likes

Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by jentusoul: 10:09pm On Aug 06, 2016
Haa, Baba ewenje eku ise takuntakun ti e n se fun wa lori nairaland ati babaewenje.blospot.com sugbon ope die ti e ti bawa fi ogun si ori blog yii, se aseyin ni, ejowo e continue lati maa saanu wa, OLODUMARE YIO MAA SAANU EYIN NA OOO AMEN

1 Like

Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by skamoh74: 2:16pm On Oct 28, 2016
Aareago1:
OOGUN IDI YIYO EYI TI YORUBA NPE NI OROBO(DO DO RE)

Ewe guava tutu. A o gboo pelu omi tutu to mo daadaa. A o fi ase see (sieve it properly). Mimu laaro ati lale bi a se fe. Idi naa yo wole pada pelu ase Olorun.

OOGUN TI ENIYAN BA N YAGBE EJE

Ogede agbagba dudu, a o so sinu ina ti yoo jona bii eedu, a o loo kuna daadaa. A o maa fi fo eko tutu elewe fomu ninu igba tabi aha kekere laaro ati lale. Ise to daju ni. Danwo.

AMUDO TO NJE BII IDAN
Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro

A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re yoo fi maa dide.,
SUGBON BERU OLORUN, TI O BA FI YAN OBINRIN JE,
OLORUN KONIJEKI OSISE.

Eseun pupo Sir. Ibere mi lori amudo yi nipe kini ale fi dipo Amu fun awa ti angbe EKO
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by denziz: 5:01pm On Oct 28, 2016
E se Baba Ewenje,agbo ale to confirm ni mo nwa,I will be happy if you can oblidge me.
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by Nostradamus: 12:51pm On Feb 12, 2017
Aareago1:
OOGUN IDI YIYO EYI TI YORUBA NPE NI OROBO(DO DO RE)

Ewe guava tutu. A o gboo pelu omi tutu to mo daadaa. A o fi ase see (sieve it properly). Mimu laaro ati lale bi a se fe. Idi naa yo wole pada pelu ase Olorun.

OOGUN TI ENIYAN BA N YAGBE EJE

Ogede agbagba dudu, a o so sinu ina ti yoo jona bii eedu, a o loo kuna daadaa. A o maa fi fo eko tutu elewe fomu ninu igba tabi aha kekere laaro ati lale. Ise to daju ni. Danwo.

AMUDO TO NJE BII IDAN
Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro

A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re yoo fi maa dide.,
SUGBON BERU OLORUN, TI O BA FI YAN OBINRIN JE,
OLORUN KONIJEKI OSISE.

eseun pupo, edakun mo ni awon ibeere kan lori amudo yen ni. 1.se ama lo oruka irin yen mo awon eroja toku yen ni? 2.kini nje amun?
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by deriod(m): 1:31pm On Feb 12, 2017
Aareago1:
OOGUN IDI YIYO EYI TI YORUBA NPE NI OROBO(DO DO RE)

Ewe guava tutu. A o gboo pelu omi tutu to mo daadaa. A o fi ase see (sieve it properly). Mimu laaro ati lale bi a se fe. Idi naa yo wole pada pelu ase Olorun.

OOGUN TI ENIYAN BA N YAGBE EJE

Ogede agbagba dudu, a o so sinu ina ti yoo jona bii eedu, a o loo kuna daadaa. A o maa fi fo eko tutu elewe fomu ninu igba tabi aha kekere laaro ati lale. Ise to daju ni. Danwo.

AMUDO TO NJE BII IDAN
Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro

A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re yoo fi maa dide.,
SUGBON BERU OLORUN, TI O BA FI YAN OBINRIN JE,
OLORUN KONIJEKI OSISE.

Amudo kin se nkan to dara to,bawo lo se ma ri ti won ba lon ni ilo kulo ,iru Ogun bayi ko da kama fi han ni ori ibi ti omode bawa ki won ma back silo .
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by Olu317(m): 6:49pm On Feb 12, 2017
Nostradamus:
eseun pupo, edakun mo ni awon ibeere kan lori amudo yen ni. 1.se ama lo oruka irin yen mo awon eroja toku yen ni? 2.kini nje amun?
Haa“Omoluabi". A fi suuru
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by raymonddodo(m): 8:28pm On Apr 24, 2017
fun Ogun ti anfi di 7 loju otawa ole pemi fun

mio bafi sita amo tiri awon tiwa mafi se ole

toba nilo re lounto pemi 09079098548
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by dgoldboy(m): 1:03pm On Nov 06, 2019
Aboruboye baba Ewenje, ejowo, mo fe ki e ba mi tan imole si ise yii. Ki ni ohun ti o n se ise fun? (Ewe Ominsinminsin ti adi bi osuka, Eyin ibile kan, Atare aja kan, Sugar saint Luis eyo meta.) A o joo po.
Re: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by Apaku: 8:47pm On May 13, 2020
Eyonu

(1) (Reply)

'hospital Too Far' Leaf For Blood Building / JOHESU Heads To National Industrial Court (NIC) / Natural Remedy For Erectile Dysfunction And Low Sperm

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.