Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,678 members, 7,955,503 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 07:43 AM |
Nairaland Forum / Entertainment / Music/Radio / Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics (10058 Views)
Shola Allyson Ft Adekunle Gold - Alujanjankijan (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics by ayoolagr8ness(f): 5:54am On Aug 10, 2016 |
Shola allyson - Ayanmo Ife Ololufe woju mi So fun mi pe o fe mi Ayanmo ife laje fun ra wa Lat'odo Eni to da wa Ofi imole re fun mi Ofi agbara mi fun o Ofi idanu sinu wa Lati mo'fe lati mo're Owo mi re fami dani Ase oluwa ni Ayanmo ife laje fun ra wa Lat'odo eni to da wa Ayo wa ti dajo se Ola wa ti dajo ni Irin wa to dajo rin Ibanuje koji na si wa Womi otun mi wo Pelu oju inu Irin wa laye jo ra won ^2 Ayanmo wa jo ayanmo Loro ife wa se se regi Owo mi re fami da ni Ase oluwa ni Ayanmo ife laje fun ra wa Lat'odo eni to da wa Kole se kija ma wa Jowo jajo so asoye Boro ba se bi oro Jowo fi suru bamise Ore kan mi pemi o o bi mi Ogiri wa koma laanu^2 Bi a bafi imo wa sokan Oke oke la o ma lo^2 Owo mi re o fa mi dani... Ololufe woju mi... Bafefe idanwo ba fe de Durotimi girigiri Botiwu ko run mo to, Sanmo dudu a wa dandan ni Iwenumo ma lo je Ka tu le ri anu gba si ni Isoro ni adun ola ni adun ola ni Ayo ati ope lo ma jasi Owo mi re fami dani .... Chorus. 2 Likes 1 Share |
Re: Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics by xedyl(m): 6:39am On Aug 10, 2016 |
I Jux like her voice |
(1) (Reply)
Nigerian Female Singers To Perform At Your Event? / Official VIDEO: Flavour – Champion / Jim Iyke Ft 2face - Who Am I
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 11 |