Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,825 members, 7,820,901 topics. Date: Wednesday, 08 May 2024 at 01:19 AM

Ogbon Agba - Nairaland / General - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Ogbon Agba (1760 Views)

Treasury House Fire: Nigeria’s Financial Records Are Intact, Says Agba / Cross River NUJ Disowns Detained Journalist, Agba Jalingo, National Disagrees / Agba Kii Wa Loja (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ogbon Agba by Knight0777(m): 7:54am On May 01, 2017
Botile je wipe, iru awon koko oro ti mo tori re si ikanni yii po daradara lori forum yii, sibe ose pataki lati fi ikanni OGBON AGBA sita nitori awon idi won yii:
Akoko, awon ogun ti opo eniyan nfi sita ko pe rara ti osi lewu fun awon ti won ba n gbiyanjue.
Ekeji, opo eni ti o nfi ogun sita ko mo bi ati nko ede yoruba to yaayi ti ki so itumo oro nu.
Eketa, ohun ti emi ni gege bi ogbon agba oyato si ohun ti iwo ni.
Ekerin to je pari pari e ni wipe, mo fe fi anfani yii se afihan ogbon ti awon Baba wa fi ma nwa ojutu si isoro won laye atijo ki nsi tun se afihan awon ogbon kokan lati inu Iwe Asiri Nla ti opolopo mo si Sixth & Seventh Book of Moses lojuna ati se iranlowo fun awon eni ti a nni lara.
AKIYESI PATAKI RE O.
Awon ogbon miran ti oba lagbara ju ohun ti ogberi tabi oje wewe le mo, a jo ni le fi gbogbo re sita lori afefe o.

(1) (Reply)

Substance Abuse / 15 Personality Traits That All Successful People Have / Isnt This 2 Much?mustay, I Need Mustay Phone #.and Dont Ask Y.cos He Kwns.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.