Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,586 members, 7,820,115 topics. Date: Tuesday, 07 May 2024 at 10:00 AM

Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni (12412 Views)

Osole Gbewa 15 Million Tabi 9million. / Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Ogun Ti Okunrin Tabi Obinrin Koba Lori Oko Tabi Aya (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni by Laniretiawoagba: 9:44am On Feb 28, 2018
ofo ree idi Ogun gan nbo , inu kibi baale ile Kofi aso ori oro da agbada, inu kibi iya le ile Kofi akisa ori akitan da ewu, eewo orisa, omode kifi aso awo aja bora, agba kifi awo aja bora, ojo to mode atagba ba foju kan idin inu imi, inu won ma nruu nii, gbogbo okunrin tabi obinrin toba ti nfoju kan lagbaja ki inu won oma ruu, kiwon o ko sile fun emi lagbaja lati oni loo, IKILO PATAKI: gbogbo eniti ako bani fee kama sise yii sii, ki aberu olorun Lori gbogbo oun ti aba NSE, Otito ti eniyan ba koo tolohun ko sogun ika Mon, eniti yoo jewo koni salai Mon beeree . IRE OOO

(1) (Reply)

Igbo Names In At Least Three Separate Dialects / Yewa Land Lagos History (anagos, Eyos, Ogu (egun), Ifonyin, Ije, Sabe And Ketu) / Respect For Elders: Who Does It More/better?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.