Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,874 members, 7,810,327 topics. Date: Saturday, 27 April 2024 at 07:06 AM

Oriki Of All Towns In Ekiti State - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Oriki Of All Towns In Ekiti State (13761 Views)

Oriki Of All Towns In Ekiti State / Oriki - Is There Anything Historical In It For Us? / The Oriki Of Omo Ede - What Is Your Oriki (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Oriki Of All Towns In Ekiti State by Moneyfem: 7:24pm On Jan 25, 2019
ORIKI OF ALL TOWNS IN EKITI
--
AAYE EKITI: Omo eleku lele lele ona Aaye,Eku Senu Omode Aaye o mu kete ö ra gburin.
ADO EKITI: Omo Ado Oora Amukara sabe ewuje, Ikara se meji i temi lukoko, Ado mei yunle oni kobe osilo monu
AGBADO EKITI: omo owa omo ekun omo alagbado orara, aimona gbe sinu agbado
AISEGBA EKITI: aisegba aguda omo apalufin omo olulu orokeiroloru lasura omo odoja supon-na lasura
ARA EKITI: Omo alara tin dara,ara la o mada ,awa o ni daran
ARAMOKO EKITI: omo alaramoko l'ejidogbon agogo ude; alara m'oi pori isa okan i ki mi ' a roko aga o, ara ara pelu ife' jumo k'agbara ga k'ara ye wa' k'ara san wa; Ara ulu ayo
ARAROMI-UGBESHI EKITI: omo elesi adu ile adu oko
ARE EKITI: Omo oyi ajawa nfe murinmurin lule
AWO EKITI: omo alagodo abeni memu,omo oloke ijisun eru ko yu.omo eguru sotita ona oke ijisun.
AYEDE EKITI: Ayede geri attah, osoko ekiti soko akoko, o sakoko rigborigbo.
AYEDUN EKITI: Omo elesun a payiya yeye
AYEGBAJU EKITI: Ayegbaju obalu odagun lule odagun loko omo alale kemun tisan bomi
AYEGUNLE EKITI: Omo amoro epa reni, Omo amuda sile mogun erun pani
AYETORO EKITI: Elo ajana omo agbo o yo erun odi, Omo owa omo ekun, edu iju omo akin,omo ofabere gunyan ki idi gberigbe ona ma mo. Omo oluku k'aso ibo,omo abadin hanran hanran.
EFON-ALAYE EKITI: omo oloke ko moke igun,oke ko malaye i tile ogun,omo edu ule haun efon kumoye, Omo Oke Wa Foona Oke Sora Dotaa,Eji gberekede,Eji gbimorodun
EJIYAN EKITI - Omo Elerii njiyan kan da’de, akun weji weji, Omo alaye more Oko ido ale iye, Omo Elegigun iwaju ji’ tehin nrina, Omo Elegigun le ju ade kan soso, Omo adegigun sori-eko weji weji
EMURE EKITI: Omo Elemure aoro ora, elemure i japari usu, e i jemulolo udi re, aarin usu ni kan mu a kelemure mi aje, Emi lomo eso orita egiri oke, Emure ijaloke afisu foloore
EPE EKITI: Epemuke moale omo elepe lologun igi lasan lara oko unbo
ERINJIYAN EKITI : omo oloja odo omo oloja odo aboyesun, omo erin adigunbo
ERINMOPE EKITI: Omo eridu'ora omokuku be korantan i han omo han ke bi han be i dun han Eeemope Omo Eridu 'ora
ERIO EKITI: Èdú Èrìò ọmọ agbe mùsúù kẹlẹ, ọmọ ọtayeye lugbọn-ọn mibọbọ joye, ibọbọ jolodeode, ibọbọ jọta epo, ọmọ oloke meji takọ tabo, ajoji baa i gori olodeode, ọta epo larosi de a.
ESUN EKITI : omo elesun oyinbo omo elesun orinjeyeweere
ESURE EKITI: Omo Elesure okese.
EWU EKITI: Omo Ewu Ogidi uda, omo amudasile mogun enu pani
EYIO EKITI: omo a muda sile kogun eni pani
IDO EKITI: omo udo oganganmodu ama gbado ekuru resin, iha lomo alagbado ayaiya tan aiha a ya, aire a ya arimona gbe sinu agbado
IDO-ILE EKITI: ile Omo Ajinare mope oye, omo owa omo ekun, omo ajisunhan,omo ajire ni, omo amojo gbogbo dara bi egbin,omo alagogo ajilu gbingbin ni sosi,omo onibata kero kalokabo lona adura omo oni bata kerokalo-kabo lugbi mo rusimi onigbagbo.
IFAKI EKITI: Ifaki orinkinran, omo atijo ogun lele boorun maakin. Esi keejogun ijale udo ona ifaki lii ha. Omo okorobo lila isuko firi ona eyika more.
IGBARA-ODO EKITI: Omo eleye i se weyeweye ati dori ogun
IGBEMO EKITI: omo elefo sigbemo oba yii efo san bi eni rele efo romi oko ra lona igbemo
IGBOLE EKITI: omo olurara agbagba tile oyi biribiri goke lagbe igbole odo
IGEDE EKITI - omo elemi nigede amadiye sereke, elemi igede niwi ki mi gbadiye sin, mowi me i sinye omi, oni laso mo mu kigede soro, agboku mariwo na mi selewo yuyu
IGOGO EKITI: igogo obiri; omo awoko merin tia gbe foruru obe je egberin okele, ekiri oke omo amain urukan jaraba iyan igogo sebora onielaya edese
IJAN EKITI: Omo ijanmodu alagada ogun, omi ki ijan i mu ni ijan we esi; omo elega arisagba.eru ko sagba nibe arija ayaba,ari sagba arija olori
IJELU EKITI: Ijelu mojo omo olodi atalemo, omo alayuwa ajoji ko wese, ajoji koba wese adoni ebo lulera lono ije
IJERO EKITI: omo owa Omo ekun, omo ejio omo oriomu,omo olose meji takotabo,omo amomohoko toutobo udi re
IJESA-ISU EKITI: omo ijesamodu,omo eleni ewele,omo ameo usu dahun se,omo a woro labe usu yaa gbe lolo odikeji,omo ikaka i so'su diro diro loke amu,omo a muda sile mogun erun pani.omo agbagba roke orire yaa lu, omo ehon kitipa ona 'jesa kii'jesa moja kii'jesa modeyo, laka ule ra lona
IJURIN EKITI: Ijurin moje! Omo alaran ojiji, omo amuda sile mogun enu pani, akuku beni lori ya jogun enu lule ijurin omo agbara sa yaya lori eguru.
IKERE EKITI: omo oloke meji takotabo, omo aba gbami eye gbami, agbagba fiafia alapa faari, omo oju kee boju leru omo eleo jeun ree omo ekun omo erukuluji, omo ukere kete oniyan ana olosunta orun ukere orole baba oke.
IKOGOSI EKITI: omo olomi meji, gbigbona ati titu.. nibi o tipade
IKOLE EKITI: Elekole o balaya aso, Ikole to tala bose, e i sepe hon run ma so se, eshi idale ti a ni, Ikole lomo olose meji gbarimi rimi kan le. Ikole run ma aso se kin tala mo sha; atala bose, keru ba adiye funfun.
IKORO EKITI; Omo eso obe so ikoro mudapariko omo eruku yoyo onah obe yajogun enun lobe ooooo, ireke aragan idun bi ogan iyo, ireke aragan idun bi oyinmomo.
IKUN EKITI: Emi lomo ikun amure,omo elero mumu ona oja,omo abeja i se wotowoto enu asoro
ILAWE EKITI: omo alawe ko tori wiwe ko makuro soja,ko wi kun naja-naja kun bomi a lura lona Awe
ILOGBO EKITI: ilogbo okere,abewe usu gbagangbagan
ILORO EKITI: Omo oloro erijugbin Ari jugbin ranje mu karahun muni, omo olotorojo nse ori opalele
ILUKUNO EKITI: ilukuno ose omo a min ranyin bi ogo iyo
ILUPEJU EKITI: Ulupeju la me a, Omo Eso ooruta merun wese,
Omo Oke lila ti moto layaa, omo egiri oke arogunse bi ega
IPAO EKITI: ipao ileji ogbe omo amugbo sodi orogba omo onile imole ajeji kowo ajeji toba fipawobe laimepo laimuyo ammebose
IPOLE ILORO EKITI: ipole omo asewi leremeta kale to le
IPOTI EKITI: upoti ala, omo amewe eni j'iyan, awa lomo eleni ewele,omo amekuru jeko.
IRE EKITI: iremogun omo awuse, omo owu ti n wuko gbinrin-gbinrin lagbede. N ba tete waye omo enimeta ni n ba maa se, n ba jomo, , n ba jomo alakara maa ma roun fi wan enun, n tun jomo alagbede ma finanloju-finanle masagban isale woriwori
IRO EKITI: Uro adidi,omo amugbayeo
IROPORA EKITI: iropora ajija emure ule ewa ubi kan sewa iyun
ISAN EKITI: Isan moge, omo asote monru, oloro agogo, omo amuda sile mogun erun pani.omo owa omo ekun omo olodi, odi re atile mo,ooni ke mo rin un modi mo omo elepa omo awo
ISAOYE EKITI: Isaoye akoko alakoko ororo giro omo amugba buwo
ISE -EKITI- Omo Akin je'Efon. Omo a gbure Agudugbu s'oju odi k'ari j'Efon Use ya yan. Ugbo kan mo'sii si kan si d'Use, a mo foo oun le iijugbo Aje a l'Use. Adabalukosi lo ba loriigi l'oja Odo, kan p'ugba Ode jo. Oni mo tita libe, o ta ogun ifon. A ri mo tita libe, o t'oji akofa. Ugbogbo kukuruku la gbogi l'oja odo, k'Adabalukosi fo lo, Emi omo ogidan,o gun mo gara, Omo at'eran mo ta'ho.
ISINBODE EKITI: isin obi omo olobedu woroworo,obe kan se ke kute ule jerun omo oni simi
ITAJI EKITI: omo Itaji òpó kìtìpà léyìn Èkìtì, mii k'opo ma ja kí Ekiti mó dêyô, Èwí í bèmí ùdì, Ônítâjî í bèmí èsûn'sû ôkô, Èwí mí yoo jùdì, Ônítâjî mí yoo mó ó jóná, un i kôsé ôlójà méjì màá bá tùbá mi Ônítâjî â lô
ITAPA EKITI: Eso oruta ejiri oke,omo onimeya ule meya oko,omo asibeota yayinyo
IWOROKO EKITI: Ihoroko de ile ouro ile ouro omolore la me ia ogun i pa ihoroko omo aroloyen
IYE EKITI: Omo alagere kijipa suko firi ona, omo oloke meji tako tabo
IYEMERO EKITI: OMO ni sedo ewa,omo ori mogun je,awa lomo awo foo sise..ofi omo foko to n ti kini abere, Omo onihun didun lodo di.
IYIN EKITI: Awa lomo eso orita Egirioke. Uyin logun Uyin lota. Ulu kan rije rimu tan ke i deni lora; Omo alaede
KOTA EKITI: Omo Elekota ogunroyin soye, agun soye bi oyinbo. Omo oriire d'ade.
ODOOWA EKITI: omo eleni ewele,omo oke lila ti moto laya, olegin lodoyin ololua lode udogun. omo abu oba ma se, omo ala ideu,omo egin,omo epa, omo otokorojo sori opa lelele
OGOTUN EKITI: omo ologotun ojorube, omo eleni ateeka,omo eleni ewele,omo amuru ekun sere nibuje,Eja gbogbo dade,towena dade akun.
OKE-AYEDUN EKITI: omo adagbalu, omo adelila pa
OKE-ORO EKITI: omo alaure ladao para seji,omo alaure san yaya gunta. Omo amekikun modi,omo alaure la Okeoro para seji aka kan tolokore,okan re ti apetu
OKEMESI EKITI: omo oloja oke ni di ogun,omo fabunmi orara lada. omo afaganja omo arogun yo. omo oke agbonna, omo oke ludi ogun atiri ogun
OMU EKITI: Omo olomu aperan omo oloro,Agogo omo amuda sile mogun erun pani akuku beni lori san jogun erun lo lona omu
OMUO EKITI: Omo eleye meta oro kashakasha, iko ina, iko oorun, iko koku osupa a tani yayaya, Omo olomuo kerejekereje omuo ore,
OMUOOKE EKITI: Omo Olomi Ajire,omo alaroju ja ka, omo gbo gbo bi oro, omo o ba ma aja je tan o a ga ro bo ruu n oo, omo eleye meta o roo ka ta ka ta,meta la pa, meta la un la
ORA EKITI: Omo Olora airijuru ugba, arijuru lora mo yogiri sapo
ORIN EKITI: omo elero ajeja sanra ero sapodi supepe ero kun derun latete eru ibudo
ORUN EKITI: Omo apariko odu ule aro omo ologba arin ko okoroti kion ti moni, ire joba lopoto o orire se ki moba sale ayare,awelejo mo ri lo sagbala yaa senu sogini miki weise libe nii meise ori re meise agbon re.
OSAN EKITI: omo olosan mojo,olosan abedu omo inu odi, omo olosan mojo, omo arowora mo ra hin, omo aladodo,awo gbeseti lodo atiba, omo aforosinu bo atare lowo, omo amebi sinu ko nje
OSI EKITI: Osi asise omo elegberin uwo, omo a meruko ude ba Ooni sala (agbe) ale, omo a muda sile m'ogun enu pa'ni, akuku be lori moyajogunenulo, omo olosimefu, omo afiju agbere suaa omo ameruko oko boonin sagbe ale, olumonle meji werewere
OSUN EKITI: Omo olosun bipesi riro, omo Olosun ri tanna ode, Osun mokun Ijunmu, Omo Ajiboye
OTUN EKITI : Otunmoba, Omo enireke agbejo; omo olodi atile mo, Omo Ireke Aragan Idun TunMayan Idun, Ireke Ria Idun Booyinmonmon, Omo Oloro An Se, Keran Mon Je, Kaaguntan Mon Je, OtunMoba Osere Omo Akinla Lotun, Omo Olorogbo Kiji Lotun
OYE EKITI: omoloye morauife, kei tana osi gangan,mo asoro siku otutu si, omo alago ajilu gboin gboin nijo ose
TEMIDIRE EKITI: omo onisopo omo oloke agunmootadi omo agesiwonwon boko
USI EKITI: Usi oro, omo atoko bo mohun sibi kan ni
USIN EKITI: omo aoyo yo oni gbo, gbo ti n ti eyin eku...

3 Likes

Re: Oriki Of All Towns In Ekiti State by Agarli(m): 7:29pm On Jan 25, 2019
nice one bro... omo iyin-ekiti ni mi o

1 Like

Re: Oriki Of All Towns In Ekiti State by Moneyfem: 7:32pm On Jan 25, 2019
Oye-Ekiti
Re: Oriki Of All Towns In Ekiti State by wealthtrak: 1:14am On May 04, 2021
Moneyfem:

Wow! Mad cool grin

2 Likes 2 Shares

Re: Oriki Of All Towns In Ekiti State by adestay(m): 4:16am
Ira Ekiti, Moba Local Government Area, Ekiti State, Nigeria: Omo Ira Ajojo, omo olodo lalede, oruye omo beni rugba

(1) (Reply)

Why Is Esu Associated With Satan? / Japan's Lady Of Eternal Youth / Lagos Obas Canvass August 20 As Isese Day Holiday

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 54
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.