Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,156,744 members, 7,831,373 topics. Date: Friday, 17 May 2024 at 05:52 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Business / Oriki Iseyin (2588 Views)
Best Qualities And Designs Of Aso Ofi Fashion Designers From Iseyin Oyo State Ni / Advans La Fayette Microfinance Bank launches cashless centres in Offa, Iseyin / Free Logs And Firewood At Iseyin. (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Oriki Iseyin by jejelawlar(m): 1:12am On Aug 29, 2019 |
Iseyin oro, Omo ebedi moko.
Omo ase tin mumi to dara.
Ilu eye kiki egan, kiki aponle.
Nibi oju ti n buni to jenu lo.
Bere ki o to WO
Nibi ti ewe
Gbe n je ariyeke.
To popo o n je belewo.
Ti igi oko n je oluwanran.
Se bi nibe lagbado ojo, ti n je topabodi.
Eni ba fe aso atata
Ile yoruba.
Eni ko kori si ilu-iseyin
Nibi ti won ti n hun gidi ninu aso.
Eni ba feran ija.
Ko kori sodo asabari ni saki.
Eni ba fe tare ko wa si ile ebedi moko.
Bi a ba se gege ote.
Ka mu ta seyin kuro.
To ba dojo are
Ka ran ni somo ebedi- moko.
Agbo gambari.
Agbo sokoto.
Agbo 'lorin
Agbo Oyo
Agbo 'badan pelu.
Sun gbon ao gbo ohun ti ilu mokin wi.
Awa lomo oro to n Jo.
Awa lomo oro to n yo.
Awa lomo oro ti n kun yunmuyunmu Lori oparun.
Ogun kan ko ja
Ko ja ilu iseyin
Lati ojo alaye ti daye. By: Jejelola OpeyemiIseyin oro, Omo ebedi moko. Omo ase tin mumi to dara. Ilu eye kiki egan, kiki aponle. Nibi oju ti n buni to jenu lo. Bere ki o to WO Nibi ti ewe Gbe n je ariyeke. To popo o n je belewo. Ti igi oko n je oluwanran. Se bi nibe lagbado ojo, ti n je topabodi. Eni ba fe aso atata Ile yoruba. Eni ko kori si ilu-iseyin Nibi ti won ti n hun gidi ninu aso. Eni ba feran ija. Ko kori sodo asabari ni saki. Eni ba fe tare ko wa si ile ebedi moko. Bi a ba se gege ote. Ka mu ta seyin kuro. To ba dojo are Ka ran ni somo ebedi- moko. Agbo gambari. Agbo sokoto. Agbo 'lorin Agbo Oyo Agbo 'badan pelu. Sun gbon ao gbo ohun ti ilu mokin wi. Awa lomo oro to n Jo. Awa lomo oro to n yo. Awa lomo oro ti n kun yunmuyunmu Lori oparun. Ogun kan ko ja Ko ja ilu iseyin Lati ojo alaye ti daye. By: Jejelola OpeyemiIseyin oro, Omo ebedi moko. Omo ase tin mumi to dara. Ilu eye kiki egan, kiki aponle. Nibi oju ti n buni to jenu lo. Bere ki o to WO Nibi ti ewe Gbe n je ariyeke. To popo o n je belewo. Ti igi oko n je oluwanran. Se bi nibe lagbado ojo, ti n je topabodi. Eni ba fe aso atata Ile yoruba. Eni ko kori si ilu-iseyin Nibi ti won ti n hun gidi ninu aso. Eni ba feran ija. Ko kori sodo asabari ni saki. Eni ba fe tare ko wa si ile ebedi moko. Bi a ba se gege ote. Ka mu ta seyin kuro. To ba dojo are Ka ran ni somo ebedi- moko. Agbo gambari. Agbo sokoto. Agbo 'lorin Agbo Oyo Agbo 'badan pelu. Sun gbon ao gbo ohun ti ilu mokin wi. Awa lomo oro to n Jo. Awa lomo oro to n yo. Awa lomo oro ti n kun yunmuyunmu Lori oparun. Ogun kan ko ja Ko ja ilu iseyin Lati ojo alaye ti daye. By: Jejelola Opeyemi 1 Like 1 Share |
(1) (Reply)
The Real Reason GSK Left Nigeria / Help A 23yrs Old Student Who Was Scammed Of $500 Btc / Get Paid To Give Away Free Ebooks
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12 |