Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,420 members, 7,850,493 topics. Date: Tuesday, 04 June 2024 at 11:06 PM

Bi Aselemo Iru Irwo Ti Agbewaye - Adverts - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Business / Adverts / Bi Aselemo Iru Irwo Ti Agbewaye (716 Views)

We Need Pet ( Plastic ) Supply On Bi-weekly Bases / I Sell Egusi, Ogbono, Stock Fish, Dry Fish, Crayfish, Iru, Bitterkola (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Bi Aselemo Iru Irwo Ti Agbewaye by adigunttt: 12:03am On Sep 06, 2022
Eyini bi aselemo iru irawowa pelu date of birth
ati iru saara ti obaisedawa mu

IRAWO AFEFE NI AFE SORO NIPA RE LONI

AWON OMO TI ABA BI NI, JAN-20 SI FEB-19, AQUARIUS NI ORUKO AWON IRAWO YI,MAY- 20,SI JUNE -19, GEMINI NI ORUKO AWON IRAWO YI, SEP-20,SI OCT-19, LIBRA NI ORUKO AWON IRAWO YI

SERI AWON OMO OSU YI NI IRAWO AFEFE,AWON IRAWO YI SIJE KOSE MANI,FUN GBOGBO IRAWO TOKU,AWON IRAWO YI MA NSE OGE KAN,WON SI MA NJO ARAWON LOJU PUPO,WON SI MA NKO IWOSI,IBINU WON PO DEBI WIPE,WON MA NFE BA GBOGBO NKAN TI WON TI FI OWO WON SE NI DADA JE NI,IBINU WON KO DARA RARA,TI WON BA NBINU,WON O KI TIJU ATI SORO SI ENIKENI,ENU WON SI MA NDUN GAN,BENI ENU WON MA NMU GIDI GAN NI,ABEBE LUBE NI WON,ARAWON OKI NBALE SI OJUKAN RARA,WON SILE RIN KU,WON SI MA NLOJU KOKORO ASO WIWO ATI ESO ARA,WON OSI MON OWO NA ,TI WONBA NI OWO LOWO,SUGBON AKO TILE TA NIWON,TORI TI WON OBA NI OWO LOWO, GBOGBO NKAN TI WONFI OWO KOJO NI WONYIO MA TA DIEDIE,WON SI LE JE GBESE KU,WON OKI NBERU GBESE RARA,OWO OSI KI NDURO NI OWO WON,

TI WON OBA NI OWO LOWO WON MA NRONU GAN NI,SUGBON TI OWO DIE BATI TEWON LOWO ,IGBAYEN NI WON YIO MA SE ISE OBA,IKA KAN O KI NWO WON NIDI MON NI ASIKO TIWON BA TI LOWO LOWO,WON SI MA NJE OLOOTO ENIYAN,OWU ARAWON OLEGBE RARA,WON JOWU KU,WON O KI NDOKO,SUGBON WON MA NDO AFOJUDI,WON SI MA NSUN MO OKO OLOKO TABI AYA ALAYA GAN NI,SUGBON ENI TOBA SUMON OKO TABI AYA WON WON YIO GBOGUN TI DEBI WIPE,WON YIO FE GBEMIN LENU RE,TORI WON NI AWOMON GAN NI,WAHALA WON SIMA NPO GAN NI,TORI WON OKI NFE DURO LOJU KAN,TABI LORI ISE KAN,WON SI MA N NI EBUN ORIN GAN NI,AWON KAN NINU WON ,WON KI LEMIN IDARIJI,TI ENIYAN BA SEWON,AWON KAN NINU WON SIMON BI WON SE NFI OGBON YAN ALE,TIWON YIO SI SE OJU FURU,WON SIMA NFI ENU TENBELU NKAN GAN,WON SI LE BU EBU OLA SILE,ALAWADA SINI WON, OPOLOPO NINU WON NI OMA NMON IJO JO GAN,WON KISI TIJU,ORO SIMA NDUNWON GAN,KI ENIYAN NA WON TEWON LORUN JU KI OSORO SIWON LO,AWON KAN NIWON OFERAN, IBALOPO RARA,SUGBON TORI WIPE WONBE GAN,AWON ENIYAN MA NRO PE BE NANI WON SAGBERE TO,SUGBON IRONI,WON OKE RARA,AYAFI AWON KAN NINU WON,TI WONBA TI NDAGBA TIWON TI NMON ADUN IBALOPO LOTUN KU,OJO ORIRE WON NI,
TUESDAY, THURSDAY FRIDAY, SATURDAY, SUNDAY,KOSI IRAWO TI WON OLE FE,NINU IRAWO METETA TOKU PELU SUURU,ATI IRAWO AFEFE BI TIWON,SUGBON KIWON MA NI SUURU,TORI OLORUN O YONDA SUURU FUN WON,TI WON OBA SI FI SUURU KUN IWA WON,ATI GBE ILE OKO,TABI NI AYA NILE YIO LE O,KOSI ASO TI WON OLE WO,YATO SI DUDU ATI PUPA,TI WON OGBUDO WO RARA,ORIBIBO ATI ISE TOBA NI NKAN FIFO NINU DARA FUNWON LATI MALO,WON DE TUN LE MA TE ISE SI AFEFE FUNWON,ISE ASELA WON NI,ISE
���
SOROSORO,ORI RADIO TABI ORI TELEVISION,MC,ALAWADA,OSERE TIATA,ADAJO,AGBEJORO, KATAKARA,KARA OJA NI ILU KAN KATA SI ILU ODI KEJI,TABI ALAJAPA,FAYAWO,TABI KI ALO MA SISE LOKE OKUN,TABI ISE ORI AFEFE,TABI TETE TITA,ALAJOTA,AWAKO OJU OFURUFU, TABI TOTI ILE TABI YI OJURIN,TABI TORI OMI,ISE BOLU GBIGBA,TABI ORIN KIKO, WONLE SE NURSE,TABI OGUN TITA,WON LESE ALAGBATA,TABI KI WON MATA GAS,TABI KI WON MA SE GAS MOTOR,ATI GBOGBO ISE TI WON OFI NI JOKO SI OJUKA,MODEBI MODURO,EJE KAFI SOKAN WIPE,

�GBOGBO IRAWO TI OBA BERE LATI OJO KOKANLA OSU SI OJOKOKAN DINLOGUN OSU,11TO 19,ONI RAWO MEJI NIWON,-

Ti ebafera awon iwe wa
ti anta fun imonipa iruirawo ti onlo tabi iru ogunti oleseti olefisise larare, elebamisoro lori��

WHATSAPP ,08058717198

(1) (Reply)

Do You Know That: / Lagoshost Promo, Domain Names As Low As N1,200 Etc / New Phones For Sale. Nokia, Motorola And Sony Ericsson

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.