Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,778 members, 7,837,827 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 11:16 AM

.. - Culture (24) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831531 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (21) (22) (23) (24) (25) (26) (27) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by edrys(m): 9:22pm On Sep 25, 2015
Eku Ise takukun lori Ikanna yi, Eledua A pelu gbogbo wa. Ejowo mo ni lo, elo Ose Ero fun tita, igbonna, ati Eyin fun Omo ikoko. Ati Irufe Ogun to le se Omo Owo l'afani. Ese ngo ma reti.@ healthfirst, kadunasouth.
Re: .. by orisafemi: 8:11am On Sep 26, 2015
iba omode iba agba iba okunrin iba obinrin ejowo gbogbo agba ologbon oni mimon oloye gbogbo yin pata pata ni moju ba yin ejowo gbogbo eyin ti eba mon nipa ogun (adesun)gbogbo yin patapa ni mope ejowo se ogun adesun se owo ti eyan bafi si orire ti eyan fida ajo se ti eyan bamu se owo ye amapada si ori oga yeni abi bawo ni ase mamu ni ojo jumon ejowo gbogbo eyin agbalagba ologbon onimi mon ti emon nipa ogun adesun yin dada ejowo mofe jeki efiye mi dada seti awa ti ojewipe afi ogun sise jeun akan mase ogun ni tori afa ni arara wa ati awa eyan wa ejowo ti irun awaba bayi base irun ogun yin se omo wa koni kun ejowo ese alaye re fuwa dada olohun ni mofi beyi o

1 Like

Re: .. by olabode800(m): 4:26pm On Sep 26, 2015
baba keepe o.
Ejo kini ogun ti o daju fun ofa ara.
Re: .. by isdula: 2:49pm On Sep 27, 2015
ewe ama je ooooooooo....eju wo kini ogun ti eniyan koba le ni kanlee dada.....
Re: .. by Davidifa(m): 4:25pm On Sep 27, 2015
Ejo Adeesu yi se ti a ba se fun eniyan se omo eni tose ose yi fun eniyan lo ma ku ni abi eni to loo?
Re: .. by Ade231(m): 9:58pm On Sep 27, 2015
healthFirst:
56

OOGUN ADEESU
Ewe akerejupon ao gun mose ao fi oyin po ao wa fi oga aye kan ti owo ti a ba fe bi 1000 tabi 5000, ao wa je ki o gba awo owo yen, ao wa mu owo yen kuro ao le ose yen mo ori oga na tiko n ifi ku ti yio ni aye ti ko fi ni ku ao wa fi owo na le lori pada ao ma sope ajo temi niyi o, ao ma mu ni ojojumo, elomiran ko gbodo fi oju ri ise yio.

IKILO PATAKI: Oogun yi daju sugbon oni eewo o...O lewu fun ogberi lati se, nitori awon omo eni naa yio ma ku to ba pe to ti n na owo yi...sugbon omo awo to ba mon owo we yio ba agba jeun.


Eku deede asiko yi o baba eku ojo meji o asi ku odun o,ejowo tori eledua kini eewo Adeesu yi eso fun wa mo fi eledua beyin,tori eru ma n ba emi fun irufe awon oogun bayi.

1 Like

Re: .. by Sobandemojisola: 5:49pm On Sep 28, 2015
E e
Re: .. by Nobody: 3:09pm On Sep 30, 2015
x

4 Likes

Re: .. by Nobody: 3:10pm On Sep 30, 2015
Ade231:



Eku deede asiko yi o baba eku ojo meji o asi ku odun o,ejowo tori eledua kini eewo Adeesu yi eso fun wa mo fi eledua beyin,tori eru ma n ba emi fun irufe awon oogun bayi.

E ka daada..mo ti so eewo re sibe.
Re: .. by Nobody: 3:15pm On Sep 30, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 3:38pm On Sep 30, 2015
x

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:45pm On Sep 30, 2015
x

2 Likes

Re: .. by sammyjay76(m): 4:06pm On Sep 30, 2015
kadunasouth:
Ogun ta nfi pe obirin/okunrin to salo pada
Adan 1 eye onbe 1 akeke 1 atare 1 ao jo papo pomo ose dudu kosinu igba olomori gbesi nu apo aso fun fun odi wiwe kia kia ni yio de
Ofore adan kilori ade obe kilorun atokunbo akeke kinidi aga lagbaja omo lagbaja koma nidi aga komalesun komalewo koma sare pada bowa sodomi

NB ise yi wafun obinrin tosalo tabi okunrin tosalo fun iyawo tabi okore tia ko ba jebire yio de larin ojo meje ti kobade ye arare wo iwo koloto odaju
IBA ARA IWAJU O, IBA EYIN AGBA GBA, E JOWO ISE YI SE FUN ENI KAN LO LE LO NI? ABI ELOMII LE LO NINU E?
EDAKUN EFOYE YE NI O.
Re: .. by Davidifa(m): 4:43pm On Sep 30, 2015
Ejo ki ni mo le fi ta okada mi ni kiakia tori mo need owo nikiakia
Re: .. by Davidifa(m): 4:46pm On Sep 30, 2015
Ewe ama je ooo,ejo adeesu yi ti a ba se fun eniyan sebi eni to ko owo ori alagamo ni omo re a ma ku?
Re: .. by jamiu3209(m): 6:25pm On Sep 30, 2015
Eku deede asiko yi, ewe ama je o....ejo wo moni nidi Ogun Ariran ati Ki Ogun maa ran Eniyan tiwon ba naa yan ni nkan...e seun mojuba
Re: .. by kadunasouth(m): 6:57pm On Sep 30, 2015
Awure Owo Olosekan
Ao wa oga gbigbe ti irure ka dada ao ra isasun tuntun olomori kekere odidi atare kan ao fi atare kan si legbe ao jo ao lo ra aso funfun opa kan kio te sile ki owa fi miliki olope kan lo lori aso funfun ati koko ati aso yi loju si ori atan. Ona owo yio si fun o kosi aburu kan kan lori iseyi
NB ti yio ba je funo isere koju osekan lo, Ale se ise yi lojo lasan sugbon ojo sunday lodaraju ijo tabajo lagbodo lo

4 Likes 1 Share

Re: .. by Ade231(m): 8:10pm On Sep 30, 2015
kadunasouth:
Awure Owo Olosekan
Ao wa oga gbigbe ti irure ka dada ao ra isasun tuntun olomori kekere odidi atare kan ao fi atare kan si legbe ao jo ao lo ra aso funfun opa kan kio te sile ki owa fi miliki olope kan lo lori aso funfun ati koko ati aso yi loju si ori atan. Ona owo yio si fun o kosi aburu kan kan lori iseyi
NB ti yio ba je funo isere koju osekan lo, Ale se ise yi lojo lasan sugbon ojo sunday lodaraju ijo tabajo lagbodo lo


Mojuba eyin agbalagba o ewe a ma je o ejowo se inu isasun titun yi ni ao ti po ebu yen pelu milk ni abi in nkan miran bi cup abi abo eseun gaan ewe o ma je fun wa o.

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 8:21pm On Sep 30, 2015
Ade231:



Mojuba eyin agbalagba o ewe a ma je o ejowo se inu isasun titun yi ni ao ti po ebu yen pelu milk ni abi in nkan miran bi cup abi abo eseun gaan ewe o ma je fun wa o.
Ele lo ninu cup asile lo isasun ye na kafilo sugbon akogbodo fi isasun yi jo isemiran ao lore jusi ori akitan nio

1 Like

Re: .. by Ade231(m): 8:22pm On Sep 30, 2015
healthFirst:
IWE OWO BURUKU AIYE DANU LARA

Ao gun epo obo kunna dada, ao te gbogbo odu ife si lori, ao gbe kale bi wakati kan, ao wa gbo ewe ewuro topo laifi omi gbo, ao fun omi e sibikan, ao mu die ninu sakiti ewe ye die, ao bu die ninu epo obo tatefa le lori ye, ao pomo ose talewe fun ojo meje, ao wa gbe omi ewuro ye wole, ao du eje penpeye si Pata Pata, ao da epo obo yoku sinure, ao ropo dada, ao wa gbe losile iwe ni dede ago mejila oru, ao fipa gbogbo ara wa latoke dele, ao wa joko sori apoti fun bi wakati kan, lehin wakati kan, ao bu die Totowe nibi ose tagun ye, ao fiwe pelu omi lasan, ao wa fi ose yoku we fun ojo mefa toku pelu omi lasan ni dede ago kan oru ni o. Odaju

Baba health eseun pupo eledua koni fi yin sile nigba kankan gbogbo nkan yin koni dojuru
lola eledua ejowo se ao ni fi kainkain we rara ni abi ao lo kainkain ti aba ma lo titun kankan ni ao ma lo ni ojo kankan ni abi eyokan ni ao fi we iwe na tan ema pe fun wa o...Ase.

2 Likes 1 Share

Re: .. by Ade231(m): 8:27pm On Sep 30, 2015
kadunasouth:

Ele lo ninu cup asile lo isasun ye na kafilo sugbon akogbodo fi isasun yi jo isemiran ao lore jusi ori akitan nio

Ese gaan baba ao ma ri yin ba lola eleduwa ko si ni pada leyin gbogbo wa,ema binu o se ihoho ni ao wa ti ao fi lo ise yi ni abi ale wo aso sorun se ese gaan.

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 8:48pm On Sep 30, 2015
Ade231:


Ese gaan baba ao ma ri yin ba lola eleduwa ko si ni pada leyin gbogbo wa,ema binu o se ihoho ni ao wa ti ao fi lo ise yi ni abi ale wo aso sorun se ese gaan.
Ewo aso sorun aso fufun dara asilewo eyi keyi ninu aso tabani

2 Likes

Re: .. by enigstil(m): 9:07pm On Sep 30, 2015
Iba gbogbo awon agbalagba to n be lori ikanni yi.Edakun mofe mu wa gege bi aba, yato si awon ogun ti o je fun isora ati eto wa, mofe ki ama fi ti ilera na si dada.
Edakun se ari enikeni to mo nipa ogun Cancer bi?
Re: .. by enigstil(m): 9:15pm On Sep 30, 2015
Aboru boye o baba, edakun kini itunmo ti oju orun ba pari?
healthFirst:
IMULE AWON AGBA

Ti osu oju orun ba pari, ao jo eiye ega ako ati odidi atare kan, ni dede ago mejila oru, ta ba jo tan ao lo, ao wa yo okan adie akuko kan si, ao tun lo papo, ta ba lo papo tan, ao wa du eje eiyele kan si... funfun ni o, ao wa fi po dada, ao su kinni yen rodo rodo sona meta.

LILORE:- Ao mi okan ni ago mefa idaji, ao mi ikeji ni ago mejila osan, ao mi iketa ni ago mefa irole.

IKILO:-ao godo jeun ni ojo ye o,odi eyin ago mejila oru ojo talo ise yi kato jeun.

ONA ABAYO:-ale ma mu epo pupa tabi akara elepo nikan dipo ounje jije.

ETUTU RE:-ao mapa eiyele funfun kookan nipari osu oju orun fun osu mefa, ao mafa eje eiyele ye mu ni o. ao si maso awon eiyele ye nu.

odaju

2 Likes

Re: .. by Davidifa(m): 10:15pm On Sep 30, 2015
Ejo kini mo le fi ta okada mi ni kiakia
Re: .. by isdula: 6:14pm On Oct 01, 2015
ewe ama je ooooooooo....eju wo kini ogun ti eniyan koba le mi kanlee dada.....
Re: .. by Nobody: 7:30pm On Oct 01, 2015
Iba Eyin Agba O, Ki A Ri Yin Pe, Ewe A Ma Je O. Ejowo Se Ewe Yi Ni Won Pe Ni '' Rerinkomi "

Re: .. by afeezwaheed8: 4:12pm On Oct 02, 2015
Baba oo ke pe Oo. Ama juse fu n yio. Ejo mo ma n ti n pe ero ibani soro yin ko lo. Ejo mo fe bayin soro
Re: .. by Davidifa(m): 10:16pm On Oct 02, 2015
Ti a ba se adeesu fun ore se inkan ko ni se mi sha
Re: .. by KolaBELIEVE: 3:57am On Oct 03, 2015
healthFirst:
16 IPARA EBE AWON AGBA
Eepo Obo, Eepo Igi Nla, ao gun won po, ao lo won po kuna daada, ao da mo Ori tabi Ipara, ao ma fi para.
eku ise ooooo! Ejowo mo nilo osole

1 Like

Re: .. by enigstil(m): 6:06am On Oct 03, 2015
Benni ohun ni, Yoruba tun ma pe ni, imi esu.
owonoko:
Iba Eyin Agba O, Ki A Ri Yin Pe, Ewe A Ma Je O. Ejowo Se Ewe Yi Ni Won Pe Ni '' Rerinkomi "

(1) (2) (3) ... (21) (22) (23) (24) (25) (26) (27) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.