Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,165,326 members, 7,860,786 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 04:23 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1834033 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 5:34pm On Dec 24, 2015 |
owonoko: |
Re: .. by Nobody: 5:43am On Dec 25, 2015 |
E wo ori ikani yi fun orisirisi ebe Agba sugbon bie ba fe Ipese tabi Eyonu Nla ti a fi n tu awon agba loju, e kan si mi lori e-mail. kii se inkan ta le fi sori afefe. |
Re: .. by admolfemx(m): 8:38am On Dec 25, 2015 |
healthFirst:E jo baba healthfirst, elo ni iwe na fun tita mean(price of the book) ati pe nibo ni a ti le rira, ni ipinle osun state, e se pupo.[color=#006600][quote author=healthFirst post=41238894]Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade |
Re: .. by Nobody: 10:13am On Dec 25, 2015 |
admolfemx: Kii se Iwe ta le fi sori ate fun tita sugbon eni to ba nife si yio kan si wa lori e-mail tabi whatsapp, ao fi ranse si ibikibi to ba wa. |
Re: .. by omoerimama(m): 4:11pm On Dec 25, 2015 |
healthFirst:Baba, E Jowo, Kini Won Pe Ni Odidi Kolobo Kan? 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:41pm On Dec 25, 2015 |
omoerimama: isasun kekere. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Diamond666(m): 2:38am On Dec 27, 2015 |
Aboruaboye nile awo....!!! Iba omode ileyi, iba agbagba ileyi, tokunrin tobinrin ileyi iba ooooo inu mindun pupo pupo nigbati mori ikani yi,Iba eyin agbalagba ton be ni ikaniyi tio jeo baje,ile ati ona teyina konibaje lase edunmare.inumin dun lati darapomon ikani yi kosini baje lase eledua. Iba ooo.... |
Re: .. by Naturewonders: 3:11pm On Dec 27, 2015 |
Ejowo gbogbo ile.ogun wo ni omokunrin le lo ti yio fi ri iyawo fe. |
Re: .. by Naturewonders: 3:13pm On Dec 27, 2015 |
Ati eyi ti obinrin lelo ti yio fi ri oko fe |
Re: .. by faray: 1:18am On Dec 28, 2015 |
hehehe...ibile things |
Re: .. by Nobody: 2:51am On Dec 28, 2015 |
Diamond666: Aboru Aboye, Abo sise nile Awo. |
Re: .. by Nobody: 2:52am On Dec 28, 2015 |
Diamond666: Ki le fi kan? |
Re: .. by MANPOLO(m): 8:50am On Dec 28, 2015 |
BABA EJOWO E FUN MI NI OOGUN ATOSI TO TI PE NINU ARA TO BI ODUN MARUN, ABI AGBO ATOSI TI ENIYAN MA MU TO FI MA TO GBOGBO RE DANU, EJOWO MAA MA RETI ESI OODUA AGBE YIN O |
Re: .. by Diamond666(m): 9:38am On Dec 28, 2015 |
Mofi ogbo ato apala afole afayafa mofikan |
Re: .. by MANPOLO(m): 10:40am On Dec 28, 2015 |
EJOWO E RAN MI LOWO NIPA ATOSI YI OUN KAMI LARA E SANU MI ENI FI AISAN LOGBA,ENIKENI TO BA NI OOGUN YII SOWO KIO RO TI OLORUN ATI OLA OODUA KO RAN MI LOWO, OODUA AGBE YIN O E SEUN. |
Re: .. by olabisiazeezish(m): 3:41pm On Dec 28, 2015 |
Ejo se ele fi ogun yi si ori aff lati lema dabobo awa tiki sepanle, ejo efi ogun apaji ati ogun abilu yio ma ju yin se baba. |
Re: .. by fbabs(m): 5:24pm On Dec 28, 2015 |
Naturewonders:Cc ; Healthfirst, Kadunasouth keyguy, |
Re: .. by MANPOLO(m): 5:35pm On Dec 28, 2015 |
ejo baba helthfirst ati kadunasouth eranmi lowo kie fun mi ni agbo atosi olodun marun(5year ) ati eyi ti ao mamu e ni damu e seun pupo |
Re: .. by enigstil(m): 7:35pm On Dec 28, 2015 |
Epada seyin ki e lo ka abala yi lati oju ewe kini, ikan nine baba kaduna south tabi healthfirst ti fisi ori abala yi RI. MANPOLO: 1 Like |
Re: .. by MANPOLO(m): 10:21pm On Dec 28, 2015 |
kin se wipe mio ri iyen sugbon iyen agunmu ni, agbo eleyi to je wipe a ma se lori ina ti ao sin ma mu ni mo un bere kie jo |
Re: .. by heritagesat: 10:32pm On Dec 28, 2015 |
Ejo mo ni di aworo si ile ball (view center) eyi to gbona gan |
Re: .. by Nobody: 12:36am On Dec 29, 2015 |
MANPOLO: Ki le wo lo...odindi odun marun!.... |
Re: .. by Nobody: 12:37am On Dec 29, 2015 |
Diamond666: kare awo...ogbo akokoniko...je ka fi sile beyen...ori afefe la wa. |
Re: .. by Nobody: 12:39am On Dec 29, 2015 |
olabisiazeezish:Eyin o ki n se ipanle sugbon e n fe ka fun yin ni Abilu? Ki le fe fi Abilu se? |
Re: .. by Nobody: 12:40am On Dec 29, 2015 |
heritagesat: Aworo ti wa lori ikani yi sugbon tio ba te yin lorun, e kan si mi lori e-mail...ke ranti wipe te ba ti wa sori e-mail, ao gba owo lowo yin o. |
Re: .. by Maleekridwan: 9:59am On Dec 29, 2015 |
Agbo atosi, eda , inu kikan fun obinrin,bi ori ba yo kokoro . E .t.c. Ao wa bara odidi kan ao wa fi obe ha gbogbo ara re danu ao ge kekeke lehin igba ti ati yo egusi inu re danu tan ao wa omi osan orombo ti atun masi omi osan wewe ati kanhun bilala die ao da gbo re po sinu ike olomari fun ojo meta lehin ojo keta ao mamu ni sibi imuko meta lojun mon. IBA EYIN AGBA OOO. YO JUWA SEO.AMINA 1 Like |
Re: .. by Nobody: 10:14am On Dec 29, 2015 |
Wow. very interesting... |
Re: .. by MANPOLO(m): 11:21am On Dec 29, 2015 |
e seun pupo sugbon eni to ba tun ri imiran to gbona ju eleyi ko fun mi, nitori wipe moti lo to bi orisi risi meta si merin, idi niyen ti mo fin bere fun agbo to gbona dada,sibe eni toba ni imiran to tun gbona ju eleyi kio fun mi, mo un be yin ni baba helthfirst ati eyin egbon mi gbogbo edakun layo lama fi sodun |
Re: .. by Shomar: 11:30am On Dec 29, 2015 |
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye. |
Re: .. by Nobody: 12:54pm On Dec 30, 2015 |
Shomar: E kaabo saarin wa. Aye wa lati ba wa da si eto yi lati gbe asa ati ise ile wa laruge. inu wa yio dun ti e ba ba wa da si. Sugbon awon ilana wa niwonyi; A ko fi aye gba itumo awon oogun wonyen ni ede geesi rara. Ede Yoruba nikan ni ki a ma fi ko won. Gbogbo ogun te ba fe fun awon eeyan, ke ri wipe kii se ayederu oogun ati wipe ko je oogun ti e ti se ri. A ko fi aye gba ogun to ba nilo eya ara eniyan rara A ko fi aye gba ero ibanisoro rara. Awon to ba fe kan si yin le ko iwe si yin ni idakonko(PM) E seun. |
Re: .. by Nobody: 1:15pm On Dec 30, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by fbabs(m): 1:50pm On Dec 30, 2015 |
healthFirst: Baba kinni oun je "gerugeru idi" 1 Like |
(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33 |