Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,166,493 members, 7,865,087 topics. Date: Wednesday, 19 June 2024 at 12:04 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (115) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377874 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (112) (113) (114) (115) (116) (117) (118) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 2:23pm On Sep 10, 2007
iyalaje:

@ nana aworan renimosese wotan ni isin . Ha ha! eyipo ogbesi owo, otungbesori, otunponseyin. Gegebi omo odudua gidi ti obanwa oluranlowo, mosetanlati ran elowo laigba kobo lowore nitori wipe ojuni ounri oju se anu. Bakanna ni ilu -ebo wonki saba mafioriru eru. Eleyi je ajoji simi pupo. Imoranmini wipe ki owa ponpon kan abi omolanke ki ogbe eruyi si, nitoriwipe aranifi abo si. Ise kekere owo nla niki olorun ofijinki re o.
Iyalaje,ki lo mu ero wipe emi ni mo wa ninu awaoran yen? Mo ri awaoran na ni ibi kan,o si ya mi lenu lopo lopo nitorire ni mo se n lo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 2:26pm On Sep 10, 2007
@aloib, Tell  me about your level. Ebi yoruba ni moko ranse. Boya kiotunyiri rewo lekan si oriwiipe iwotunwonsi ni ede timolo. yoruba titemina kogbona yo eruku biti richylaw.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 2:32pm On Sep 10, 2007
@nana, Odabaun, eruba emina beni aragbamita lofati mofirobe. Looto, emina tun nse iyemeji pe koleje nana lonse ise asekara bayi. Mabinu awadamini opoju
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 2:38pm On Sep 10, 2007
Ma ma da nana lohun. Fine girl ni omo yen oh. Gbabeski. In fact igba ti awon admirers ti poju lo tete
change aworan inu profile sharp sharp. grin grin

In fact aworan nana ni screensaver mi. grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 2:39pm On Sep 10, 2007
Baale ati awon ijoye won nbowabaminibi. Ile ni apotijoko de idi. Won orimi, won osi ran omo latiwa bemi wo. Kadi oju ki ase bi eniti oku kialebamo eni ti oferan eni.  Gbogbo nti wonbarilobe tiwonfiwa irusi owo, loni laoogbo. Aiye okunipa enikokan wati gegebi asoti ogbo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 2:43pm On Sep 10, 2007
@bolarge, ounti oda ni ose. Osamape amojuto ose pataki toro bati dabaun. Bosemina, mawa onamigbegba. Kojumari ibi, Omo olomo oyapa awoda. emi oribawi jare.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 2:48pm On Sep 10, 2007
@ Bolarge, iwogan ibolotiri awon kukute ti okosodi. Kape awon omo odo renu, dakun mafi ebi pawon nitoripe odagege bi epe sokoto won ti jabo. Afi aimo koma je pe ebi ni ose okunfa re.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 2:51pm On Sep 10, 2007
Bolarge,wahala yen ti poju fun mi looto jare.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 3:07pm On Sep 10, 2007
Ma worry. Ojo too ba ti declare fun ikan ninu wa publicly, wahala e ti tan niyen. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 3:10pm On Sep 10, 2007
lol. . .declare wipe kinni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:13pm On Sep 10, 2007
aloib:

ebi pan mi
se wa je epon pelu obe koropon?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishooo(m): 3:16pm On Sep 10, 2007
nana:

lol. . .declare wipe kinni?

WIPE O NIFE ENIYAN KAN grin grin grin


iyalaje:

Baale ati awon ijoye won nbowabaminibi. Ile ni apotijoko de idi. Won orimi, won osi ran omo latiwa bemi wo. Kadi oju ki ase bi eniti oku kialebamo eni ti oferan eni. Gbogbo nti wonbarilobe tiwonfiwa irusi owo, loni laoogbo. Aiye okunipa enikokan wati gegebi asoti ogbo.

IWO NI KAN KO NI ORO NA DUN. KO DA KAYEFI NI O JE FUN MI !! angry angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:24pm On Sep 10, 2007
mishooo:

WIPE O NIFE ENIYAN KAN grin grin grin


IWO NI KAN KO NI ORO NA DUN. KO DA KAYEFI NI O JE FUN MI !! angry angry angry
[/quoute]hmmmmmmmm ,a bere e sa ma tami oge epon semi lara o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 3:30pm On Sep 10, 2007
nana:

lol. . .declare wipe kinni?
Wipe o ti ni ololufe tie ni.
eg "Bolarge ni ololufe mi ni Nairaland yi, so gbogbo eyin yoku e joo e fi emi ati e sile o." grin

Mo ti bere campaign temi niyen oh! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 3:33pm On Sep 10, 2007
Bolarge:

Wipe o ti ni ololufe tie ni.
eg "Bolarge ni ololufe mi ni Nairaland yi, so gbogbo eyin yoku e joo e fi emi ati e sile o." grin

Mo ti bere campaign temi niyen oh! grin
Hmm. . .ologbon dori eja mu.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:36pm On Sep 10, 2007
Bolarge:

Wipe o ti ni ololufe tie ni.
eg "Bolarge ni ololufe mi ni Nairaland yi, so gbogbo eyin yoku e joo e fi emi ati e sile o." grin

Mo ti bere campaign temi niyen oh! grin
hmmmmmmmmmmmm,na wa for dis kona kona love o,abi na nairaland love we go call am?abeg sofri sofri o,e ma fadi ya o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 4:58pm On Sep 10, 2007
Dr. Ferlie, booni o? Kini so re? Soo wa pa? Awa naa wa pa ni haahin o. Idun mi dun lati ka oro re si mi. O se mi laanu wipe fife emi ati ire ko le bo si. Sugbon ti o ba je omo gidi, idun mi yio dun lati fi okan ninu awon omo mi obirin fun o. Meta ni won, ojo ori won si je mejidinlogun, merindinlogun ati metala resipektifuli. Egbon won papapata je okunrin, egbe si i ni iwo ati oun (22yrs). Mo fi akoko yi ro kokoro re ko ma se gun igi eleera o, nitori pe o lewu. Aabo oro la nso fun omoluabi , Edumare yio fi kun ogbon, imo ati oye re, yi o si fi emi gigun jinki re. Amin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 8:29pm On Sep 10, 2007
@mishoo, bawoni nkan, se gbogbore ngunrege?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 12:36am On Sep 11, 2007
Hello grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by replenish(f): 12:09pm On Sep 11, 2007
hello gbogbo omo yoruba

se alafia ni e wa.

mo kan ni ki nse epele ni be'hun ni o

e ma ba faaji yin lo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 1:24pm On Sep 11, 2007
@Mishoo, bawoni nkan?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mrferlie(m): 2:19pm On Sep 11, 2007
bolorunfem:

Dr. Ferlie, booni o? Kini so re? Soo wa pa? Awa naa wa pa ni haahin o. Idun mi dun lati ka oro re si mi. O se mi laanu wipe fife emi ati ire ko le bo si. Sugbon ti o ba je omo gidi, idun mi yio dun lati fi okan ninu awon omo mi obirin fun o. Meta ni won, ojo ori won si je mejidinlogun, merindinlogun ati metala resipektifuli. Egbon won papapata je okunrin, egbe si i ni iwo ati oun (22yrs). Mo fi akoko yi ro kokoro re ko ma se gun igi eleera o, nitori pe o lewu. Aabo oro la nso fun omoluabi , Edumare yio fi kun ogbon, imo ati oye re, yi o si fi emi gigun jinki re. Amin.


e se fun idahun yin. emi naa kii se omo kekere. e gba gbe ojo ori(age) ti o wa ninu profile mi. football age lasan ni.
well, family ati ise nko? se alaafia ni. inu mi dun pupo fun ogbon yin o. e si bami ki awon aburo mi.
ki e ni lovely week ahead!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrDre1(m): 2:31pm On Sep 11, 2007
Olorun o!!!!
Ni bo ni mo wa ni land yi ti thread yi fi long bayi? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 3:33pm On Sep 11, 2007
Hallo cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 3:42pm On Sep 11, 2007
O kare lae, broda mi atata. Opolo re ko ni i ku. Kosi wahala. Ba mi ki omo Liberia ti o feran yen o, ti akoko ba si i to lati gbegele lo si ilu won fun idana, mo setan lati ba o lo. Alafia.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 5:38pm On Sep 11, 2007
BOLORUNFEMI O see pupo, alaafia ni mo wa, se gbogbo nkan lo dede, ise, ebi ara ati ojulumo. E ku ola o. Nje o gburo oree mi atata RICHYLAW, o se die ti mo gbo from him. Mo nireti pe daada ni o wa, nitori won ii fibe jinna si wa to bayi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ssRhino: 11:23pm On Sep 11, 2007
na wa oh, see how people are firing yoruba without any grammatical error, i envy y'all oh
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 4:18am On Sep 12, 2007
ojo ibi mi ni lana, e o ti e kimi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Digital(f): 9:26am On Sep 12, 2007
Oga o, mo ma n ro pe mo mo yoruba so ati pe mo mo ka, until ti mo de ibibayi mo gbe osuba kare fun awon omo oduduwa. o ga ju
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrDre1(m): 11:11am On Sep 12, 2007
@ Aloib
Ma binu jo tori Olohun.
To ba je pe emi mo ni, imba ki e o
Se ko ti pe ju lati ki e bayi?
***olojo ibi, ijo kan e o, se were, ko da wa lohun*** grin
Oku ori re o. Emi ashe pupo odun laye o smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 1:38pm On Sep 12, 2007
@digital, morobi eminikan nimonro beeni, ase apopupo lenu e. Mosifila fun awon ara abule yii.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by champredd(m): 4:45pm On Sep 12, 2007
Whatzzzzz up guyzzzzzzzzzzz?

Baaaaaaaaaaaaaawoooooooooooooooo niiiiiiiiiiiiiiiiiiiii?

(1) (2) (3) ... (112) (113) (114) (115) (116) (117) (118) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 36
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.