Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,729 members, 7,851,514 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 09:09 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (155) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377445 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (152) (153) (154) (155) (156) (157) (158) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 2:19pm On Dec 17, 2008
farotika

eebu o wa poju? Agbalagba ma ni ogbeni steven ti o nba soro bayen o! Ma je ki o fi enu agba sepe fun e o. Oya kunle ko toro idariji lowo alagba steven ki o ba le dara fun e lojo iwaju. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 3:39pm On Dec 17, 2008
farotika:

Ode ni iwo omo yi. Oniranu buruku si ni e. Ti o ba nise, o se so fun mi kin ba le ba e wase. Gbogbo eeyan ni o ro pe o ri bi tie, ti won o ni ri nkan se ju ki won maa pe e. Dajudaju asewo, oniranu ati alaini laakaye ni e. tongue

Ogagun Farotika ti binu grin grin grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 3:41pm On Dec 17, 2008
farotika:

Si Chamotex,

Ore wa, ti ibadi ba ndun e; iwo saa ti kan simi ti o ba wale kin le ba e ki agbo jedi ti o lagbara. Emi fi da e loju wipe ti o ba muu fun ojo meji pere, nkan omokunrin re a kan maa gberi ni gbogbo igba ni. wink

Ese modupe, ti e bale bami fi shepe ati opa eyin gan ranse simi, inu mi adun gan ni.

Gbogbo ibadi mi kan romi ni, bi eni wipe mo gbe irin ni . . . . . . . . Ese modupe!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:53pm On Dec 17, 2008
debosky:

farotika

eebu o wa poju? Agbalagba ma ni ogbeni steven ti o nba soro bayen o! Ma je ki o fi enu agba sepe fun e o. Oya kunle ko toro idariji lowo alagba steven ki o ba le dara fun e lojo iwaju. grin

Buroda gbewudani, ewo ni tie naa. Won ni ki gbogbo eranko to niwo jade; igbin na sare bo sita. Se iru tie la wa nwi. Se iwo o mo pe alagba sitivini nse langba langba ni; agba to ba nse langba langba, orisirisi iwosi ni o ma nwo iru won. Nitorina, emi o le kunle be oponu agba kankan o. O je bo se je
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 4:02pm On Dec 17, 2008
chamotex:

Ese modupe, ti e bale bami fi shepe ati opa eyin gan ranse simi, inu mi adun gan ni.

Gbogbo ibadi mi kan romi ni, bi eni wipe mo gbe irin ni . . . . . . . . Ese modupe!

O ye mi ju bo se so lo. Kii se sepe ati opa eyin nikan ni mo maa fi ranse, sungbalaja ati sagbadiwere maa pelu komubinesan (combination) awon nkan ti mo maa fi ranse cool Joo mo fi Olorun be o; ma do awon omo olomo pa ti ogun yi ba bere si sise o wink Ti o ba si do ado fadiya, jowo mase daruko mi fun awon olopa o.

O dabi wipe o fe wale fun odun Keresi; bi o ba jebe iwo saa ti fi adiresi re sowo simi grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 4:03pm On Dec 17, 2008
Kilon whazzup ni bi bayi? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 5:04pm On Dec 17, 2008
o gbiyanju gan ni Moyo, pamari 4 kweshun lasan ni o gbe lugi yen. patewo fun ra e! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:27pm On Dec 17, 2008
farotika:

Si Ebony-Silk,

Bawo ni ore. Se o n gbadun ibi ti o wa lohun ni, ti o ba je bee, ope ni fun Olorun. Emi kan ni kin fi to e leti wipe Okunrin lanti lanti nimi; emi kii se obirin rara. Nitorina, eru Chamotex o bami rara.

Lafikun, mo wo aworan re mo si rii pe omo to rewa ni o. Tubo maa toju ara re o. O digba kan naa
lol, ese n grin grin wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 8:18am On Dec 18, 2008
mo n gbiyanju lati ranti ikan lara awon poem JF Odunjo ti mo ka ni Alawiye pamari 1, e jowo eni ti o ba moo ki o ran mi leti o:

Tepa mose ore mi
ise ni a fi n deni giga
bi a ko ba reni fehinti
bi ole laa ri
bi a ko ba reni gbekele
a tera mose eni
iya re le lowo lowor
ki baba re lesin leekan
bi o ba gboju le won
o te tan ni mo sor fun o
eko si tun n soni doga
mura ki o kor or dara dara
bi o si ri opo eniyan
ti won n fi eko serin rin
dakun mase fara we won
iya n bor fomo ti ko gbon
ekun n be fomo ti n sa kiri
ma fowuro sere ore mi
mura sise ojo n lo

Ibi kan wa ti o ti so pe

'baye ba n fe o loni . . .(cant rmbr again). .
je ki o deni n rago
ki o rii baye ti n yinmu si e. .

eni ti o ba moo, ki o sor e jowo cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:12am On Dec 18, 2008
goodass:

o gbiyanju gan ni Moyo, pamari 4 kweshun lasan ni o gbe lugi yen. patewo fun ra e! tongue

Olodo rabata ni iwo alara. O ye ko so bayii: Ibeere ile iwe kerin puramari ni o gbe lugi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:17am On Dec 18, 2008
goodass:

mo n gbiyanju lati ranti ikan lara awon poem JF Odunjo ti mo ka ni Alawiye pamari 1, e jowo eni ti o ba moo ki o ran mi leti o:

Tepa mose ore mi
ise ni a fi n deni giga
bi a ko ba reni fehinti
bi ole laa ri
bi a ko ba reni gbekele
a tera mose eni
iya re le lowo lowor
ki baba re lesin leekan
bi o ba gboju le won
o te tan ni mo sor fun o
eko si tun n soni doga
mura ki o kor or dara dara
bi o si ri opo eniyan
ti won n fi eko serin rin
dakun mase fara we won
iya n bor fomo ti ko gbon
ekun n be fomo ti n sa kiri
ma fowuro sere ore mi
mura sise ojo n lo

Ibi kan wa ti o ti so pe

'baye ba n fe o loni . . .(can't rmbr again). .
je ki o deni n rago
ki o rii baye ti n yinmu si e. .

eni ti o ba moo, ki o sor e jowo cool

O gbiyanju gan ni o. Emi naa a ronu jinle lati le ranti awon ewi inu alawiye ti puramari. Je kin ronu ikan ooooooooooo,

Iyan funfun balau
owo bata egunsi
aje boko doweke
aje digbo loko
aje boko rerin ofofo
,
gbegiri nikan lewo re
, ati bee bee lo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 10:11am On Dec 18, 2008
goodass:

o gbiyanju gan ni Moyo, pamari 4 kweshun lasan ni o gbe lugi yen. patewo fun ra e! tongue

kpa kpa kpa kpa kpa!! iwo mo fi jo naa. . . tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 10:19am On Dec 18, 2008
Emi na ngbiyanju lati ranti lara awon Ewi ti mo ka ninu 'Iwe Akewike' js1. . .

errm. . .

Bi'na ba njo,
ma so'tito
Bo'le ba nja
ma so'tito
Otito ni gbe ni leke
Otito ni gbe ni de'po giga
Bi'ro ba lo'gun odun
ojo kan ni otito yo ba,
Bi'ro ba ni ese gigun
Otito ma. . . kant rememba dhat jo. .
Bi'ro ba yo terere. . .
Otito a si duro wamu wamu!

Ema so Otito! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 2:24pm On Dec 18, 2008
farotika:

Olodo rabata ni iwo alara. O ye ko so bayii: Ibeere ile iwe kerin puramari ni o gbe lugi.
kini puramari ni yooba? mo n korin fun e o .  .olodo rabata oju eja lo moor je, oo ni lo beba sileti loo maa lo baba johnbull, eba tutu lo moor je, ajiyan-wo  wink (ore mi ma binu o, mo kan n ranti awon orin igba yen ni)  cheesy

ewi e yen n mebi pa mi sugbon mi o le jeyan losan yi ki n ma ba lo maa toogbe nidi ise. ipade emi ati iyan+emu di ojo keresi

@ Moyo
igbakeji-kilasi monitor, e maa gbiyanju gan ni o. E ti bo si pamari 5 nisiyi. e ku oriire o. bawo ni?  cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by origina9ja(f): 2:42pm On Dec 18, 2008
orisirisi

yoruba ko
igbo ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 2:44pm On Dec 18, 2008
goodass:

kini puramari ni yooba? mo n korin fun e o .  .olodo rabata oju eja lo moor je, oo ni lo beba sileti loo maa lo baba johnbull, eba tutu lo moor je, ajiyan-wo  wink (ore mi ma binu o, mo kan n ranti awon orin igba yen ni)  cheesy

ewi e yen n mebi pa mi sugbon mi o le jeyan losan yi ki n ma ba lo maa toogbe nidi ise. ipade emi ati iyan+emu di ojo keresi

@ Moyo
igbakeji-kilasi monitor, e maa gbiyanju gan ni o. E ti bo si pamari 5 nisiyi. e ku oriire o. bawo ni?  cheesy

Iwa olodo wa lara tie no ogbeni goodaasi to pa jesu oyingbo nitori obo  grin

pepa ni won pe, kii se beba. se oro obo naa lo wa fa ki e ma soro bii dindirin ni? undecided grin

Kini itumo 'primary' ni ede Yoruba? E je ki n'fi to yi n'leti

Primary = ile iwe akeko ese keji.

Ti a ba fe juwe 'primary 4' nkan ti a o so ni ile iwe akeko ese keji apa kerin.

Oya e patewo fun mi.

Ogbeni Farotika, ko da ki e pe Alagba Sitivini ni Oponu o, ara n'yun won ni, won si fe f'owo pa omidan lara ni. Kii se ese fun agbalagba lati fe gbadun ara won.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 2:58pm On Dec 18, 2008
debosky:

Iwa olodo wa lara tie no ogbeni goodaasi to pa jesu oyingbo nitori obo grin

pepa ni won pe, kii se beba. se oro obo naa lo wa fa ki e ma soro bii dindirin ni? undecided grin

Kini itumo 'primary' ni ede Yoruba? E je ki n'fi to yi n'leti

Primary = ile iwe akeko ese keji.

Ti a ba fe juwe 'primary 4' nkan ti a o so ni ile iwe akeko ese keji apa kerin.

Oya e patewo fun mi.

Ogbeni Farotika, ko da ki e pe Alagba Sitivini ni Oponu o, ara n'yun won ni, won si fe f'owo pa omidan lara ni. Kii se ese fun agbalagba lati fe gbadun ara won.

Eemo! shocked Emi ma ro pe goodaasi to pa Jesu ti ku ni; emi o mo pe o tun maa farahan ninu tireedi yii o. Yeeeepa! Nje mi o ti soro koja aye mi bayi. E joooooooo buroda Goodaasi, ti nba ti bu yin, e ma binu si mi o, omode lo nse mi. E jowo e ma pa mi be se pa Jesu o. cry

Buroda Ogbufo,

E jowo, e tan imole die si itumo ti e fun puramari yen. Ko mu ogbon wa rara. Ni paapaa ese ikeji ti o wa ninu itumo yin ohun. Ewo ni ese kin ni

Yoruba o ni itumo fun primary. Ayalo ede ni won maa npe. Nitorinaa, won a maa lo ede yoruba lati pee bi oyinbo se npe. Fun apeere: Bread ni ede Yoruba a je: Buredi.

Se o ye eyin omo mi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by geolabious(m): 3:05pm On Dec 18, 2008
[size=13pt]Tgirl where are you
U are needed her[/size]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:15pm On Dec 18, 2008
Ogbeni Farotika

Rara o, emi o gbagbo wipe oro ayalo ni o ye ki a fi se apejuwe 'primary' ninu ede Yoruba.

E je kin dahun ibeere yin - ese ikini je 'nursery'. ese ikeji was je 'primary' iketa wa je 'secondary', ki a to wa de 'university' ti a n'pe ni ile eko giga.

Se oti ye yin nisiyi?

Sugbon ti oro ayalo lo ba rorun fun yin lati lo, iyen naa ko l'aburu. Ona miran ni a le gba de Oyo. cheesy

Eso ra fun Goodassi o, omo yen o buru gaani. Pele pele ni ki e fi ba soro
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 7:39pm On Dec 18, 2008
eje ki emi na ranti awon ewi ti a ma nke ni ile iwe:

Ti a ba ndobo lowo ki a ma pariwo bi eniti won fi ata rodo pa ni idodo cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 8:08pm On Dec 18, 2008
@ Dobosky
beba ni yooba n pe 'paper'. oo le pe 'pepa' ni 'paper' o. nitori naa odo poki ni o gba. mo ba e ya eti ati enu e sii pelu!

@ farotika
ma da dobosky lohun, itan omoge lo ti dahun, nitori e lo she nko 'ese kini', 'ese keji'.

nipa ti eni to pa Jesu, iwo naa mor eni to pa Jesu. ma je ki dobosky ati okoeleshin mu e shina o. awon to mor mi mor pe gudass ni mi (_!_)

@ chamo
iru awon ewi e yen lo yen ki won maa fun ni Oscar. lojo iwaju ti o ba n dobo ki o maa je dodo. ki o si maa fi owo dodo pa omo onidodo nidodo!

poemu to sa pa mi lori leekan yen, mo ti ranti awon ese ti mo fo:
goodass:

Tepa mose ore mi
ise ni a fi n deni giga
bi a ko ba reni fehinti
bi ole laa ri
bi a ko ba reni gbekele
aa tera mose eni
iya re le lowo lowor
ki baba re lesin leekan
bi o ba gboju le won
o te tan ni mo sor fun o[b]
apa lara, igunpa niyekan
baye ba n fe o loni, bi o ba lowo lowo
aye a fe o bo dola
je ki o deni ti n rago
ki o rii baye ti n yinmu si e
[/b]
eko si tun n soni doga
mura ki o kor or dara dara
bi o si ri opo eniyan
ti won n fi eko serin rin
dakun mase fara we won
iya n bor fomo ti ko gbon
ekun n be fomo ti n sa kiri
ma fowuro sere ore mi
mura sise ojo n lo!

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:46pm On Dec 18, 2008
debosky:

Ogbeni Farotika

Rara o, emi o gbagbo wipe oro ayalo ni o ye ki a fi se apejuwe 'primary' ninu ede Yoruba.

E je kin dahun ibeere yin - ese ikini je 'nursery'. ese ikeji was je 'primary' iketa wa je 'secondary', ki a to wa de 'university' ti a n'pe ni ile eko giga.

Se oti ye yin nisiyi?

Sugbon ti oro ayalo lo ba rorun fun yin lati lo, iyen naa ko l'aburu. Ona miran ni a le gba de Oyo. cheesy

Eso ra fun Goodassi o, omo yen o buru gaani. Pele pele ni ki e fi ba soro

rotflmao. . . .Iwo gan lo ye ki Farotika sho'ra fun.

Eduro nan, mo ni ibeere kan. . . .se obirin t'abokunrin no farotika? Nitoripe mo sha n wonder kini reason ti Chamotex fi nle kakiri. undecided tongue grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 11:02pm On Dec 18, 2008
Goodasi jewo ese re ki o le gba idariji. ma tun paro, ese ti o se nigba ti o pa jesu oyingbo nitori obo si wa ni le, otun wa d'ese sii?

Aya ma ko e o.

Talo n'fun ni odo poki? Abi oju n'dun e ni? Emi debosky ma lo n'bawi bayii. . . .ajigijaga fun ra re. hmmm, maa fun e ni asiko die sii lati ronupiwada ki n'to binu patapata.

Ti mo ba de binu, ki enikeni ma wa di mi mu o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:04am On Dec 19, 2008
ewo bi Debosky se n fo yooba bi "Village Headmaster". Akigijaga baba!!! cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 6:59am On Dec 19, 2008
goodass:

@ Dobosky
beba ni yooba n pe 'paper'. oo le pe 'pepa' ni 'paper' o. nitori naa odo poki ni o gba. mo ba e ya eti ati enu e sii pelu!
@ farotika
ma da dobosky lohun, itan omoge lo ti dahun, nitori e lo she nko 'ese kini', 'ese keji'.

nipa ti eni to pa Jesu, iwo naa mor eni to pa Jesu. ma je ki dobosky ati okoeleshin mu e shina o. awon to mor mi mor pe gudass ni mi (_!_)

@ chamo
iru awon ewi e yen lo yen ki won maa fun ni Oscar. lojo iwaju ti o ba n dobo ki o maa je dodo. ki o si maa fi owo dodo pa omo onidodo nidodo!

poemu to sa pa mi lori leekan yen, mo ti ranti awon ese ti mo fo:

Iro nla le pa sa. Beba ko ni yooba npe "paper"; kalamu ni won maa npe nigbati won a maa pe "biro" ni gege.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:05am On Dec 19, 2008
chamotex:

eje ki emi na ranti awon ewi ti a ma nke ni ile iwe:

Ti a ba ndobo lowo ki a ma pariwo bi eniti won fi ata rodo pa ni idodo cool

Haaaa!! kamoteesi, o o se jawo ninu iwa palapala ti o nwu yii. Emi o gbo tabi ka nkankan ti o jo iru ewi yi ri o. Se baba Fagunwa abi Faleti lo koo ni. E saa ma ja emi lawe o. Oro obo ati oko ti e nso yii ti fe maa yi mi lori grin cheesy

E ti e gbo naa eyin ore mi: kini won npe ni oko ati obo naa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:44am On Dec 19, 2008
Ebony-Silk:

rotflmao. . . .Iwo gan lo ye ki Farotika sho'ra fun.

Eduro nan, mo ni ibeere kan. . . .se obirin t'abokunrin no farotika? Nitoripe mo sha n wonder kini reason ti Chamotex fi nle kakiri. undecided tongue grin

Ma fi lo mi ndasi, ewo lo kan e naa? Se o njowu mi ni Ti o ba nifesi Kamoteesi, je ki a gbo o maa fi tife tife so eyin mejeeji papo.

Ni idakeji, ti o ba je pe omi ni o ni ife si, mo wa fun e tigbatigba nitoripe ese meta shandi ni mo ni, mo si se ileri wipe mo maa te e pelu nkan omokunrin mi grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 9:15am On Dec 19, 2008
Iwa olodo wa lara tie no ogbeni goodaasi to pa jesu oyingbo nitori obo

pepa ni won pe, kii se beba. se oro obo naa lo wa fa ki e ma soro bii dindirin ni?

Kini itumo 'primary' ni ede Yoruba? E je ki n'fi to yi n'leti

Primary = ile iwe akeko ese keji.

Ti a ba fe juwe 'primary 4' nkan ti a o so ni ile iwe akeko ese keji apa kerin.

Oya e patewo fun mi.

Ogbeni Farotika, ko da ki e pe Alagba Sitivini ni Oponu o, ara n'yun won ni, won si fe f'owo pa omidan lara ni. Kii se ese fun agbalagba lati fe gbadun ara won.

nkan to funny ju latijo ti mo ti wa ni nairaland niyi.
ahhh, emi o mope thread wa fun tiwa n tiwa wa nibi yi.
ogagun farotika, mo gbedi fun yin o

lateni lo, ibi yi ni mama gbe grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:12pm On Dec 19, 2008
tkb417:

nkan to funny ju latijo ti mo ti wa ni nairaland niyi.
ahhh, emi o mope thread wa fun tiwa n tiwa wa nibi yi.
ogagun farotika, mo gbedi fun yin o

lateni lo, ibi yi ni mama gbe grin grin

Ogbeni 419, ah! shocked ema binu sa. Ogbeni 417 e se gan an ni o. Inu wa dun pe a wa darapo mo wa awa naa si kii yin ku abo, se oko o jepo? Bi o ba ri bee, ope ni fun Edumare.

Lakotan, emi o fe ki e maa gbe nikan o, mo nfe ki o je bi le ma ku si, bi ti mario grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 1:45pm On Dec 19, 2008
Ogbeni farotika
ahh, emi oleku sibi yi bi mario lailai

mo kan fe darapo mo awujo awon omo oduduwa ni. kilode te n wape mini 419
she mowa sori igba yin wa ji nkan je ni?
eso ara yin o kin maba binu sinyin o
ibinu mi ko daara rara osi le farajo ibinu sango olukoso oko oya grin grin
ema minu bimi o

mo fe yara se gafara die
mon bo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 4:53pm On Dec 19, 2008
debosky:

Goodasi jewo ese re ki o le gba idariji. ma tun paro, ese ti o se nigba ti o pa jesu oyingbo nitori obo si wa ni le, otun wa d'ese sii?

Aya ma ko e o.

Talo n'fun ni odo poki? Abi oju n'dun e ni? Emi debosky ma lo n'bawi bayii. . . .ajigijaga fun ra re. hmmm, maa fun e ni asiko die sii lati ronupiwada ki n'to binu patapata.

Ti mo ba de binu, ki enikeni ma wa di mi mu o!
mo ti dariji e, dobosky nitori iwo ko mor ohun ti iwo nshey.

ma she fiwa jor ajigijaga omo-ita. abe mi lo ti ko ishe ni Idumota ati Mushin. nitori pe o gba odo poki nigba ti mo ni ko spell a-j-i-g-i-j-a-g-a ti oun lor n spell j-a-g-i-d-i-j-a-g-a-n ni mo shey yor kuro ninu awon ehin mi.

Nje iwo ti gbo nipa Itu Baba'ta ri? emi gan ni mo n ba e soro bayi and imoran mi si e nigbakugba ti o ba setan lati binu ni pe ki o pade mi ni aajin ooru ni ese-ko-gbeji ni orita meta ona idi-iroko. Maa fun e ni ero ibinu ti Oriadetu Abiwa-pele aya Orunmila fun mi ninu igbo irunmole. N o maa reti e o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:04pm On Dec 19, 2008
farotika:

Ma fi lo mi ndasi, ewo lo kan e naa? Se o njowu mi ni Ti o ba nifesi Kamoteesi, je ki a gbo o maa fi tife tife so eyin mejeeji papo.

Ni idakeji, ti o ba je pe omi ni o ni ife si, mo wa fun e tigbatigba nitoripe ese meta shandi ni mo ni, mo si se ileri wipe mo maa te e pelu nkan omokunrin mi grin
lmao. . . .beeni, mo n jowu e tongue grin Mo ni ife fun Chamotexi grin grin grin grin hehehhe, is that okay for you? tongue

lmaoooooo, dude, you're crazy. . . .oya, mo ni ife si e nan. tongue grin grin

(1) (2) (3) ... (152) (153) (154) (155) (156) (157) (158) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 92
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.