Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,162,767 members, 7,851,621 topics. Date: Thursday, 06 June 2024 at 01:23 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377462 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (153) (154) (155) (156) (157) (158) (159) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by UNLEASHED(m): 12:25pm On Dec 20, 2008 |
hmmm Orisirisi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 4:09pm On Dec 20, 2008 |
goodass: gbogbo agbaiye se e ri n'kan ti ogbeni goodassi n'so bayii? Nigba to pa jesu onyingbo lori obo aya re, otun wa fe ba mi ja? Emi o ni ba e ja o, obo iyawo temi dun gaan ni, mi o de ni je ki enikankan bami gbadun lara e. Oda, dakun oga awon omo-ita Idumota ati Oshodi, emi o ba e ja mo. Maa fi ebun ranse si e fun odun Keresimesi. Sugbon ti mo ba gbo pe e tun pa elomiran lati gbadun obo aya eni naa, mo ma lo fi ejo yin sun awon olopa ni panti, won si ma ti yin mole fun odun iyebiye. E teti si ikilo yii o ki e ba le gbadun odun keresimesi lai si idamu. Alufaa Farotika O dabi n'pe omo Ebony(ti a n'pe ni alagolo nitori shikishiki aya re) ti n'gbadun oro didun ti e ti n'so sii leti. Bobo Kamoteesi yen ko l'agbara rara o. E joo e gbiyanju ki e mu ebony mole. Emi o fowo si iwe naa lati se ijeri (witness) si igbeyawo yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 6:01pm On Dec 20, 2008 |
debosky: iwo ore mi dobosky debe-debe, mi o ba e ja o, mi o si ki n gba riba bee si ni olopa ko le mu mi odun lo de la n shey. aito ehin ka la n fowo boo. oje mi ga ju gbogbo iyen lo. oun ti mo so ni pe maa fun e ni ero (antidote) ti mo gba bo irinkerindo mi ninu igbo irunmole. ma je ki eru ba e rara. iwo lo maa lo aya re gbo gbo gbo kanrin kese. n o maa reti ebun keresi ti o sor. bawo ni wknd? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Hauwa1: 6:22pm On Dec 20, 2008 |
mukulu mukeke ma jo fun Olorun mi mukulu mukeke ma jo fun Olorun mi omukulu omukeke omukulu omukeke mukulu omukeke mukulu omukeke ijoing ati korining and humming |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 1:32am On Dec 21, 2008 |
TÓJÚ ÌWÀ RE Tójú ìwà re, òré mi! Olá a ma si lo n'ilé eni, Ewà a sì ma sì l'ára enia, Olówó òní 'ndi olòsì b'ó d'òla Òkun l'óla, òkun nìgbì orò, Gbogbo won l'ó 'nsí lo nílé eni; Sùgbón ìwà ni 'mbá'ni dé sàréè, Owo kò jé nkan fún 'ni, Ìwà l'éwà l'omo enia. Bí o l'ówó bí o kò ní 'wà 'nkó, Tani jé f'inú tán o bá s'ohun rere? Tàbí bí o sì se obìrin rògbòdò, Bí o bá jìnà sí 'wa tí èdá 'nfé, Taní jé fé a s'ílé bí aya? Tàbí bi o jé oníjìbìtì enia, Bí a Tilè mo ìwé àmòdájú, Taní jé gbé 'sé aje fún o se? Tójú ìwà re, 'òré mi, Ìwà kò sí, èkó d'ègbé, Gbogbo aiye ni 'nfé 'ni t'ó jé rere. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 7:02am On Dec 21, 2008 |
o ku aigbagbe Remii. mo gbadun ami ti o tun fi se ewi yen loge. nibo ni eeyan ti le ri iru keyboard yen ra l'Eko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 12:21pm On Dec 21, 2008 |
goodass: Ye abuja yi wo : http://groups.yahoo.com/group/yorubaworld/message/1428 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:56am On Dec 22, 2008 |
debosky:Why am I just seeing this now? Sorry o, you're not my father, you don't get to give me away. . . . |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 7:46am On Dec 22, 2008 |
Why am I just seeing this now? oole so yoruba ni? eleyi ti gbagbe yoruba o ede geesi ti molara. shior |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 7:47am On Dec 22, 2008 |
~Hummm Subscribing to thread~ |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 8:33am On Dec 22, 2008 |
TOYOSI20: Same here oo, I see I can learn a couple of things too, B.T.W, how u dey? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:02am On Dec 22, 2008 |
tkb417: E ma binu sir, 419 kan wa simi lenu ni. Won o komi ki nmaa yaju si agbalagba. E jowo sir, E fori ji omo yin. Eyin agba le npa lowe pe: "Omode o le mo eko je ko ma yi lowo". Tooto, o se bi owe eyin agba. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:41am On Dec 22, 2008 |
Ebony-Silk: Ebony mi owon, Looto, oro ife dabi oro adawo ni. Lati igba ti mo ti ka iwe pelebe ti o ko simi yii ni ife re ti ngun mi bi esin. Nse lo dabi ki nri e ki nsi ma fi ara lo e bi ologbo. Jowo ololufe mi, bawo ni mo se le ri e ki a ba le bere ere ife wa loju paali. Oloomi, onitemi, ore mi, alabaro, oju kan saa lada ni, lolaoluwa ko seni ti o ya wa (Kamoteesi). Mofe ba e darugbo, mo fe ba e kale, iwo leni ti mo fe ri lojojumo aye mi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:51am On Dec 22, 2008 |
debosky: O se ore mi atata, emi naa mo pe eyin mi ni o wa lojokojo. Emi naa ti n nife omo yen o. Mo fe ma fi enu fa kini ti o wa ni aya re yen. Jowo se o le ko mi bi mo se le se ti o ma gba lati fe mi laisi wahala rara. Jowo mo nreti esi re o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:58am On Dec 22, 2008 |
goodass: Judaasi, Jowo se o ti ka iwe baba Fagunwa ti o ni akole yii: ADIITU ELEDUMARE? Bi o ba je be, se o si nii lowo atipe bawo lo se le fi sowo si mi. Jawo ninu riba JUDAASI!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:02pm On Dec 22, 2008 |
Remii: Mo kan sara si e Remi. O se pupo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:15pm On Dec 22, 2008 |
Ebony-Silk: Haba ololufe mi, ma doju timii. Yooba ponbele ni mo fe ki a maa so nibi yii. Jowo ma se je ki awon omo kekere wonyi wenu si e lara o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:21pm On Dec 22, 2008 |
~smurf: Abi ode ni awon alawe meji ti won npe ara won ni Toyosi ati Sumoofu yi ni? Se oju yin fo e o rii pe Yooba lanso nihanyi ni. E ma so ede ajeji nibi ti e o ba fe ki a leeyin kuro ni ori tireedi yi o. O digba kan na. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 12:59pm On Dec 22, 2008 |
Abi ode ni awon alawe meji ti won npe ara won ni Toyosi ati Sumoofu yi ni? Se oju yin fo e o rii pe Yooba lanso nihanyi ni. E ma so ede ajeji nibi ti e o ba fe ki a leeyin kuro ni ori tireedi yi o.erin fepami sibiyi oti foni ju. kini yoruba foni na? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:40pm On Dec 22, 2008 |
TOYOSI20: Stop playing hide and seek with me jor, I no like am. Come out come out wherever you are |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 2:43pm On Dec 22, 2008 |
tkb417: Itumo foni ni: o pani lerin tabi o darin pa ereke Olodo nla. Olodo rabata, oju eja lo mo je. Sileeti lo o ma lo o oni lo pepa. Poki!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:46pm On Dec 22, 2008 |
tkb417:Lol, talo so fun e wipe mii le so ede mi? Emi o ki nse akata o Mo f'eron ede mi bi mo se f'eron owo farotika:lmao. . . . debo don start trouble o. To ba je wipe o f'eron mi nigbati mo ko post ye si e, oba ti so fun mi lol, I like your poem sha. . . .shugbon to ba fe ri mi, ba debosky (my PA) soro farotika:lol, ejo oga, ambinu. Yooba ni ma ma so la te ni lo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 2:49pm On Dec 22, 2008 |
Ebony-Silk: Ebony temi owon, O de fe maa doju timi sa. Ani ko ye so ede ajeji nibiyi. Bami so ede abinibi. Ti o ba jawo ati maa so awon ede eru buruku yii; mo ma ja iwe ikosile fun e o. Emi o de fe ki nkan beyen sele tori ife ti mo ni si e. Ka sora gidigidi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moonstone(f): 2:56pm On Dec 22, 2008 |
E gbami! Ebony, se iranu ede geesi ti sun e ni? O tu bere pelu yoruba. Ki la ma se si oro iwo omode yii nisin? Ma lo fi ejo e sun "Uncle". Sa ma se jeje o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:02pm On Dec 22, 2008 |
farotika:Oko mi owon, jo ma binu simi. Mo ti nkunle lowo lowo fun yin, ejo, e dari jimi Moonstone:ejor ejor ejor, efi mi sile Tani "Uncle" yin? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:08pm On Dec 22, 2008 |
Ebony-Silk: O se iyawo mi atata. Emi naa mo pe omo daadaa ni e ati pe omo Oodua tooto si ni e pelu. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:16pm On Dec 22, 2008 |
Moonstone: Eeee anti gbeborun. Ta lo pe yin si oro oko ati iyawo Jowo ma ta si iyawo temi o. Emi o fi oro re sere rara. Ti oko ti o dara bi temi ba wu o, tete wa oko tire siwaju o. To ba fe mo le saye Kamoseeti fun o. Olodo buruku |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:28pm On Dec 22, 2008 |
Ebony-Silk: Ololufe temi nikan, ma fi oju mi sona Tete fun mi ni aago ilewo re ki nba le tete kan si e. Oju nro mi o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 4:51pm On Dec 22, 2008 |
farotika:rara o, mi o ni. ile-iwe alakobere kerin or ikarun ni mo ti ka awon iwe yen. mo n pongbe lati tun ri won ka leekan sii. won maa n ka Ireke Onibudo ni Choice FM 1030pm ni ojoojo aje. won ko i ti lo jina rara, o dabi oju ewe 50 or 60 ni won wa nisiyi. E dee ku oriire igbeyawo o. ehin iyawo ko ni mor bed o. Ta lo ba mi ri chamo? o to ojo meta. Ebony-Silk: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 4:53pm On Dec 22, 2008 |
Mo fe gba anybody le ti! Igbati oloyin! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 5:30pm On Dec 22, 2008 |
ROFLMGBO!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!! @Faro Talika emi ode abi, broda agabya oshi, lol. . . . . ole ee wa iya wo abi, e sho ra yin gi di gan oo, ahn ahn ki lo wa de e de wan bu yan, Emagba mi ke Emi TOYOSI na, o di igba ti mo ba mu yin, ode # 2 @ smurf I'm good sweets, happy Holidays to ya, @ Nike na this kin place we go dey find u trouble maker, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ifyalways(f): 6:15pm On Dec 22, 2008 |
TOYOSI20:Toyo kilode?where have you been hiding your sweet self?ka oda oo missed you babe,compliments of the seasons,wishing u all the best of the season Omo dada |
(1) (2) (3) ... (153) (154) (155) (156) (157) (158) (159) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 68 |