Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,162,459 members, 7,850,599 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 05:24 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377417 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (155) (156) (157) (158) (159) (160) (161) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 9:29am On Dec 24, 2008 |
farotika:KO NI HA MI LOFUN. NITORI AMOJE LODIFA FUN ORUNMILA NIGBA TI BABA KO ENOUGH EBO JE TI O RO PE MC DONALD'S BURGER NI. E JO WO PADDY MI, FUN MI JE MA JE TAN PATA PATA TITI KAN PATA |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 9:32am On Dec 24, 2008 |
tkb417:HAAA EYAN MI, KO RI BE OO OMO LONDON O KIN SEBE RARA AWA MA NTOJU OUNJE DARA DARA TORI O JO MIRAN TI EBI BA NPA OKO. u know. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 10:15am On Dec 24, 2008 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 11:10am On Dec 24, 2008 |
HAAA EYAN MI, KO RI BE OO OMO LONDON O KIN SEBE RARA AWA MA NTOJU OUNJE DARA DARA TORI O JO MIRAN TI EBI BA NPA OKO. u know.ore mi, ko si wahala. mo ti gbo o se jeje ni asiko odun yi o. odun ayabo o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 11:13am On Dec 24, 2008 |
E ka ro ooo! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 11:27am On Dec 24, 2008 |
tkb417:be ni eyan mi gidi, odun to nbo yi ma san wan si ola at ola repete. a ko ni ba obo lo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 11:30am On Dec 24, 2008 |
Brash ka a roo se dada loji. Iyawo ko, omo nko? ma mu oti to ba tin drive o nigba odun yi o bami ki gbogbo family o chei, i love this thread like mad be ni eyan mi gidi, odun to nbo yi ma san wan si ola at ola repete. a ko ni ba obo loadura nla. Amin ase edumare |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 11:50am On Dec 24, 2008 |
MrCrackles: O se jare omo daa daa. Eni a san e o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:15pm On Dec 24, 2008 |
Ebony te fe mu yen ju agbara yin lo o. E ti dagba ju fun gbogbo iru isekuse yen . . . . . e jawo nbe, e ma se ru e mo o.rotflmaoooooooo. . . .efi mi sile se e n jealous Farotika ni? eje stop e o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:19pm On Dec 24, 2008 |
Se emi ni buroda agbaiya. Iwo naa omode ise Tongue Yooba ni "bi omode ba mo owo we, a ba agba jeun" emi ti rii daju pe o mo owo we rara, mi o de rope o le ba awa agba jeun. Ti kii ba se onitemi (Ebony) ti o be mi ni, nba ti le e kuro ni tireedi yi.lmaooo. . . .jorrrr, maa le egbon mi kuro ni tireedi yi o. oko mi owon, ejor, ema binu |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:24pm On Dec 24, 2008 |
O se ore mi tooto. Mo ti ka ireke onibudo daadaa ni kekere. Mo ti ka ADIITU ELEDUMARE naa sugbon o ti pe gan an, atipe awon oro ife inu re po gan an. Se o de mo pe mo ti nnife Ebony, mo si nfe awon oro ife nla nla ti mo le fi da ori re ru.Ese sir o. . . .ee ni lati wa oro ife fun mi, eewa enough (you're enough. sorry o, my yoruba is not that good ) sugbon, eduro na, emi ti mo n se wedding, mii ma ni ring o. . . |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:27pm On Dec 24, 2008 |
farotika:#giggles# jor, si leku, mo ti nbo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Skidoc(m): 3:06am On Jan 02, 2009 |
E jowo,Yoruba nikan ni ki a maa so nibi. E ma fi oyinbo kankan si RARA. Apeere: Gbogbo ROTFLMAO yen, e ma so iyen mo, e ma so wipe YNIRIEJ. Eyi tumo si - Yi Ni Ile Rin Idi E Jade |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 3:26am On Jan 02, 2009 |
awon omo asewo ti wa ba threadi yi je. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:51am On Jan 02, 2009 |
Ebony-Silk: Ma da bobo yen loun jare. O ma ku soro owu jije ni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 7:54am On Jan 02, 2009 |
farotika: Agba ya ni yin oo, ni nu new year too. . . . . |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:59am On Jan 02, 2009 |
TOYOSI20: Iwo omo yi, o je bowo fagba ki o baa le pe laye |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:24am On Jan 02, 2009 |
Ebony-Silk: O se gan ni iyawo mi atata. Iwo naa si to fun mi. Nipa ti oruka igbeyawo, iwo sa je ka pade ni ile igbafe ti o ba fe ki nba lee fun o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:35am On Jan 02, 2009 |
Ebony-Silk: Ololufemi, ki lo de ti o wa tan mi Mo duro titi ni ojo keresi, sugbon o ko, o ko wa rara Se kii se pe o fe ko oju mi si orun ale bayii |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:40am On Jan 02, 2009 |
chamotex: Kamoteesi, nibo ni iwo lo lati ijo yi. Iwo gan si ni oga awon asewo o. Ki Olorun dari agabagebe re ji o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:46am On Jan 02, 2009 |
Eyin olufemi ninu tireedi yii, odun titun yii a san wa sowo, a san wa somo, a san wa si aiku baale oro. Gbogbo idawole wa a yori si rere o. Amin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:25pm On Jan 02, 2009 |
farotika:Amin, ese n o. farotika:ta lo n tan yin? emi ko o. mo kan leku titi, shugbon ee dami lo hum farotika:ewo lo n je ile igbafe? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:57am On Jan 03, 2009 |
farotika: ori obo ni mo wa o, won ni ki n ma ki yin. Eku odun o. Ori obo a gbe yin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:57am On Jan 03, 2009 |
farotika: Amin!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 1:28pm On Jan 05, 2009 |
*Toyinrayo: Ebony mi owon, nibo ni mo wa gba lo nigba ti o n kan leku O ga o. Laifa oro gun sa, ile igbafe ni eebo npe ni hotel or guest house Se daa daa lo wa sa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 1:31pm On Jan 05, 2009 |
chamotex: Ore, mo gbaa ladura pe o o ni ku sori obo o. Haba!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:02pm On Jan 05, 2009 |
Eyin ara mi mo kii yin ku orire o, nitori orire nla ni fun gbogbo wa ti a f'oju ri odun titun yii. Bii Ogbeni Farotika ti gbadura, gbogbo idawole wa ni odun titun yii a yori si rere o. ako ni foju ri ibi o, rere nikan ni ama ri. Nigba ti isoro ba de, Olodumare a fun wa ni agbara lati la isoro naa koja. Ako ni s'abamo ni odun yii o. Bata a pe lese wa o. Gbogbo ife okan wa, Oluwa a mu se o. Odun 2009 a je odun to l'adun fun gbogbo wa o. Amin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:20pm On Jan 05, 2009 |
Ni odun titun yi, Mo gba yin niyanju pe ki e rora gan Ife ori ero ayarabiasa ti on gbode yi on ba mi leru lopolopo. Ti e ba fe ba ara in lopo, ki e ma lo roba idabobo. Nitori Arun Kogboogun po nita Iwo Shamotessi ni mon bawi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:36pm On Jan 05, 2009 |
Oga o! Emi o mo pe ede Yoruba ti ni itumo fun 'internet' (ero ayarabiasa) Ogbeni dayokanu egbiyanju ti e tun fi eyi to wa l'eti. Ile ise yin ko ni jona o, owo yin a ma roke, aya yin mukinatu si ma bi omokunrin lantu lantu fun yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 7:40pm On Jan 05, 2009 |
Ero ayarabiasa (computer) Ogbeni debosiki, Ile ise Agbere ati Pansaga yin ko ni jona oh Awon Iyawo yin won o ma se daada Awon Iyawo yin won o bi Ibeefa ni odun yi o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by fireangels(f): 9:29pm On Jan 05, 2009 |
amin e ku odun ni bii yii o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:21am On Jan 06, 2009 |
farotika:Nkan ti emi nan bere ni ye o. Ibo lo gba lo? Se ni mo kan leku titi, mo ke gbo gba, sugbon ko se ni to da mi lohun. Dada ni mo wa o, Iwo nko? se awan obirin ni be ye o sa tele e? |
(1) (2) (3) ... (155) (156) (157) (158) (159) (160) (161) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37 |