Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,444 members, 7,846,845 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 03:35 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (157) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377213 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (154) (155) (156) (157) (158) (159) (160) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 6:17pm On Dec 22, 2008
Ifyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyyy ma love, my aunt et all tongue
I don miss u dieeeeeeeeeeeeeeeeeeeeee embarassed cool

How are ma niece/nephew, how are doing, I wish u a wonderful holiday, and a very prosperous new year to u and ur entire family, ma sweettttttttttttttttttt sister kiss kiss kiss kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ifyalways(f): 6:22pm On Dec 22, 2008
Toyo,na Okurin boys meji eji tongue
Mother,daddy and boys are safe and doing great.Thanks kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 6:26pm On Dec 22, 2008
Ahhhhhhhhhhhhhhhhhhhhh!!!!!!!!!!!!!!!!!!

U truely are blessed oo, ma sister, may God be with then oo, take it easy sis, kiss kiss kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 7:03pm On Dec 22, 2008
e ku oriire o, Ify. kip d sun shinin'
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:05pm On Dec 22, 2008
awon wo lawon ton so ede geesi nibiyi
ehn. ewo ni ify to n so yoruba sef? ede yoruba ma ti di meta ten kobo ke grin grin
oda naa

ogagun farotika
se emi ni olodo rabata? emi rope 'funi' je ede ayalo ni mo se bere
eyin lemo brother agabya grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:54pm On Dec 22, 2008
@TOYOSI
no be you I meet for here? grin grin

@ oko mi owon
farotika:

Ololufe temi nikan, ma fi oju mi sona sad sad sad Tete fun mi ni aago ilewo re ki nba le tete kan si e. Oju nro mi o cry
kini nkan ti wan pke ni ago? shocked shocked shocked shocked

abi o mean "Agogo ewu?"

goodass:

tongue
you're not slick wink

MrCrackles:

Mo fe gba anybody le ti! grin
Igbati oloyin! grin cheesy
then wa, je kin fun e ni igbati!! wa like e. . . . wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dean2725: 9:53pm On Dec 22, 2008
TOYOSI20:

Ahhhhhhhhhhhhhhhhhhhhh!!!!!!!!!!!!!!!!!!

U truely are blessed oo, ma sister, may God be with then oo, take it easy sis, kiss kiss kiss


Eyin na e jara mo ti yin naa. . . . sisi tee se na toooo. lipsrsealed
abi ko ti ya ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:19am On Dec 23, 2008
goodass:

rara o, mi o ni. ile-iwe alakobere kerin or ikarun ni mo ti ka awon iwe yen. mo n pongbe lati tun ri won ka leekan sii. won maa n ka Ireke Onibudo ni Choice FM 1030pm ni ojoojo aje. won ko i ti lo jina rara, o dabi oju ewe 50 or 60 ni won wa nisiyi.

E dee ku oriire igbeyawo o. ehin iyawo ko ni mor bed o. Ta lo ba mi ri chamo? o to ojo meta.
tongue

O se ore mi tooto. Mo ti ka ireke onibudo daadaa ni kekere. Mo ti ka ADIITU ELEDUMARE naa sugbon o ti pe gan an, atipe awon oro ife inu re po gan an. Se o de mo pe mo ti nnife Ebony, mo si nfe awon oro ife nla nla ti mo le fi da ori re ru.

Emi ati Ebony o tii se igbeyawo o. A kan si n sere ife ni cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:24am On Dec 23, 2008
TOYOSI20:

ROFLMGBO!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!

@Faro Talika grin grin grin

emi ode abi, brother agabya oshi, lol. . . . . ole ee wa iya wo abi, e sho ra yin gi di gan oo, ahn ahn ki lo wa de e de wan bu yan, Emagba mi ke Emi TOYOSI na, o di igba ti mo ba mu yin, ode # 2 grin

@ smurf

I'm good sweets, happy Holidays to ya, kiss

@ Nike na this kin place we go dey find u trouble maker, tongue kiss

Mo se rii daju pe ODE NLA ni e. Bayo lo se ma pe olowo nla bi temi ni talika. O dabi pe eje ti ta si e lopolo grin Wa ki nko e ni bi won se nko ede Yooba tongue grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:31am On Dec 23, 2008
tkb417:

awon wo lawon ton so ede geesi nibiyi
ehn. ewo ni ify to n so yoruba sef? ede yoruba ma ti di meta ten kobo ke grin grin
oda naa

ogagun farotika
se emi ni olodo rabata? emi rope 'funi' je ede ayalo ni mo se bere
eyin lemo brother agabya grin

Se emi ni buroda agbaiya. Iwo naa omode ise tongue Yooba ni "bi omode ba mo owo we, a ba agba jeun" emi ti rii daju pe o mo owo we rara, mi o de rope o le ba awa agba jeun. Ti kii ba se onitemi (Ebony) ti o be mi ni, nba ti le e kuro ni tireedi yi.

O le eeeeeeeeeeee
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:39am On Dec 23, 2008
Ebony-Silk:

@TOYOSI
no be you I meet for here? grin grin

@ oko mi owonkini nkan ti wan pke ni ago? shocked shocked shocked shocked

abi o mean "Agogo ewu?"
you're not slick wink
then wa, je kin fun e ni igbati!! wa like e. . . . wink



Aago ilewo ni oyinbo npe ni: GSM number. Pele onitemi atata. Se o n filenijo nibi ti o wa yen? Jowo ma fi oju mi sona o. kiss kiss kiss

E jowo e ba mi wa Debo ati kamoteesi ooooooooooooooooooo sad sad sad
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:46am On Dec 23, 2008
dean2725:


Eyin na e jara mo ti yin naa. . . . sisi tee se na toooo. lipsrsealed
abi ko ti ya ni?

E ma da bebi yen loun jooo. Ko mo nkan ti o se rara. O digba ti o ba wa juba lodo mi ki o to le mo nkan ti o nse cool grin

Olori odo tongue grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:22am On Dec 23, 2008
Se emi ni buroda agbaiya. Iwo naa omode ise Yooba ni "bi omode ba mo owo we, a ba agba jeun" emi ti rii daju pe o mo owo we rara, mi o de rope o le ba awa agba jeun. Ti kii ba se onitemi (Ebony) ti o be mi ni, nba ti le e kuro ni tireedi yi.

O le eeeeeeeeeeee

emi omodo agba ni emi. emi ti bagba jeun tipe tipe. Te ba sope e fe lemi ni tireedi yi, emi na ma fejosun modurator or alakoso tireedi yi nitori nairalandi yi, mo le lo si ibi to ba wumi. se tigbo grin grin

sese n lo sha ogbeni farotika.
eni nice day o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 8:25am On Dec 23, 2008
TOYOSI20:



@ smurf

I'm good sweets, happy Holidays to ya, kiss


I'm great oo, where the heel you been, kiss dont mind them o, they say we have to stay speaking our ede, and I'm trying so hard to learn, so imma stay tuned to this tread,  tongue cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:27am On Dec 23, 2008
I'm great oo, where the heel you been, don't mind them o, they say we have to stay speaking our ede, and I'm trying so hard to learn, so I'm going to stay tuned to this tread,
ooooh Jesu kristi
shey eyin omode yi ko le so yoruba ni? kinla?
afira, ekuro nibiyi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 8:38am On Dec 23, 2008
tkb417:

ooooh Jesu kristi
shey eyin omode yi ko le so yoruba ni? kinla?
afira, ekuro nibiyi

ROFL!!!!!!!!!!!!!!
Oda, a ma ma ko die e die abi, practice makes perfect too, kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:49pm On Dec 23, 2008
tkb417:

emi omodo agba ni emi. emi ti bagba jeun tipe tipe. Te ba sope e fe lemi ni tireedi yi, emi na ma fejosun modurator or alakoso tireedi yi nitori nairalandi yi, mo le lo si ibi to ba wumi. se tigbo grin grin

sese n lo sha ogbeni farotika.
eni nice day o

O se jare ore mi. A n gbiyanju ki ise maa lo. Bawo ni odo e lohun Se ise nlo bose ye Jowo ma fi aye gba awon omoge elese teere yen lati mu e se irewesi lenu ise o grin cheesy

Eni a san e o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:54pm On Dec 23, 2008
tkb417:

ooooh Jesu kristi
shey eyin omode yi ko le so yoruba ni? kinla?
afira, ekuro nibiyi

Ma da awon ode meji yen loun joo. Opolo won ti yoro grin grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 1:58pm On Dec 23, 2008
Ma da awon ode meji yen loun joo. Opolo won ti yoro
hehehehehe grin grin
oku die ko yoro buroda mi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 2:46am On Dec 24, 2008
Odomokunrin Farotika,

asiri yin ti tu . . . . . afefe ti fe, moti ri furo yin

sepe obinrin lewa wa si ori threadi yi, mo ma ni ki Seun ban yin for life ni.

Ebony te fe mu yen ju agbara yin lo o. E ti dagba ju fun gbogbo iru isekuse yen . . . . . e jawo nbe, e ma se ru e mo o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tope2000(f): 2:48am On Dec 24, 2008
rofl. . . . . . grin cheesy grin cheesy
tkb417 ti gba smurf lo owo e cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 2:51am On Dec 24, 2008
kosi anybody to gba anybody, chamo is on a celibacy course until further notice cheesy grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 7:09am On Dec 24, 2008
chamo padi mi
maje ki obinrin koda ija sile laarin wa jare
omo pe we are UTD on all fonts (cant say that in Yoruba)
ko si enito gba anybody lowo e jare, iwo lo fun mi personally. abi na lie grin grin grin

Tope
ahh, she iwo na man se amebo ni?
morope J-girl nikan loma n se amebo ni. so u are akproko too grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:49am On Dec 24, 2008
chamotex:

Odomokunrin Farotika,

asiri yin ti tu . . . . . afefe ti fe, moti ri furo yin

sepe obinrin lewa wa si ori threadi yi, mo ma ni ki Seun ban yin for life ni.

Ebony te fe mu yen ju agbara yin lo o. E ti dagba ju fun gbogbo iru isekuse yen . . . . . e jawo nbe, e ma se ru e mo o.

Kii se obinrin ni mo wa wa o. Sugbon bo se wu Olorun lo nse ola, bi mo se de ori tireedi yi ni mo beresi n nife si omo Ebony yen. Mi o mo nkan omobirin yen fun mi je o cry

Oruko e nikan ni mo maa nje lenu ni enu ojo meta yii. E jowo e ba mi waa ooooooooooo. Bi bee ko mo ma pa ara mi sii yin lorun ni o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:58am On Dec 24, 2008
tkb417:

chamo padi mi
maje ki obinrin koda ija sile laarin wa jare
omo pe we are UTD on all fonts (can't say that in Yoruba)
ko si enito gba anybody lowo e jare, iwo lo fun mi personally. abi na lie grin grin grin

Tope
ahh, she iwo na man se amebo ni?
morope J-girl nikan loma n se amebo ni. so u are akproko too grin grin

Eyin omode wonyi, ki lo n seyin naa angry Obinrin po nigboro ta tie ri nkan fiwon se le wa nja lori omo kan ti won pe ni sumoofu lori tireedi yi.

E je ki ori yin pe o ti e o ba fe ki n le yin kuro nibo. Eyin oloju kokoro yi. Shioooooooooooooooooooooooooo cool grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 8:07am On Dec 24, 2008
tope2000:

rofl. . . . . . grin cheesy grin cheesy
tkb417 ti gba smurf lo owo e cheesy
TOPE, I NO UNDERSTAND OO. JA MISI
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:14am On Dec 24, 2008
Eyin omode wonyi, ki lo n seyin naa    Obinrin po nigboro ta tie ri nkan fiwon se le wa nja lori omo kan ti won pe ni sumoofu lori tireedi yi.

E je ki ori yin pe o ti e o ba fe ki n le yin kuro nibo. Eyin oloju kokoro yi. Shioooooooooooooooooooooooooo

eyin agbalagba yi sha. se eeni amojukuro ni?
eemo pe olorun lopa lofin fun wa wipe kama bisi kasi maresi. besides, emi at chamo ore ni wa, awon elemi esu na kan so isokuso.
ema dawon lohun jare ogbeni farokita. esa gbo orin nice to sowipe, oun to ba wun anybody lole fenuwon so, efiwon sile, eje kan mo solo .   .   .   .


babsongudus
she okunrin ma n se amebo ni? ejawo niwa ibaje grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by babsongudus: 8:22am On Dec 24, 2008
babsongudus:

TOPE, I NO UNDERSTAND OO. JA MISI
AAA EYIN OMO ENIYAN ADAMU SEBI ATI RI TEMI JE NAA NI MO NWA KIRI
tkb417:


eyin agbalagba yi sha. se eeni amojukuro ni?
eemo pe olorun lopa lofin fun wa wipe kama bisi kasi maresi. besides, emi at chamo ore ni wa, awon elemi esu na kan so isokuso.
ema dawon lohun jare ogbeni farokita. esa gbo orin nice to sowipe, oun to ba wun anybody lole fenuwon so, efiwon sile, eje kan mo solo .   .   .   .


babsongudus
she okunrin ma n se amebo ni? ejawo niwa ibaje grin

AAAAA EYIN OMO ENIYAN ADARI WU IRUN SEBI ONA ATI RI TEMI JE NI MO NWA KIRI. JEMBE, JEMBE LAYE YI SA GBA. tongue tongue tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:45am On Dec 24, 2008
babsongudus:

AAA EYIN OMO ENIYAN ADAMU SEBI ATI RI TEMI JE NAA NI MO NWA KIRIAAAAA EYIN OMO ENIYAN ADARI WU IRUN SEBI ONA ATI RI TEMI JE NI MO NWA KIRI. JEMBE, JEMBE LAYE YI SA GBA. tongue tongue tongue

Ki Olorun ma je ko je eleyi to ma ha e lofun tongue grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:48am On Dec 24, 2008
AAAAA EYIN OMO ENIYAN ADARI WU IRUN SEBI ONA ATI RI TEMI JE NI MO NWA KIRI. JEMBE, JEMBE LAYE YI SA GBA
wonbiliki wobia ni e. ahhhhhh, ki olorun maje ki o je nkan to mapa e ooo
koyami lenu, bi awon omo london se man se niyen
iwa ibaje yin ti poju. grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:56am On Dec 24, 2008
Eyin ara mi ninu foroomu yii,

Mo fe fi akoko yi ki gbogbo yin ku odun keresi o. Aseyi samodun o. Odun o ni diwa mo eru lo o. Gbogbowa la tun ma peju sibi ni odun to nbo pelu alaafia ati ayo ati idunnu pelu igbega.

E ba mi mu nkan ti e ba jeku fun odun wa o

Si Ebony,

Jowo iyawo mi tooto, mo se nreti re nile mi leni o. Obe ti o se ni o wu mi ki nje ninu odun keresi yi. Ose pupo o si ku ife aisetan ti o ni si mi grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 9:16am On Dec 24, 2008
Eyin ara mi ninu foroomu yii,

Mo fe fi akoko yi ki gbogbo yin ku odun keresi o. Aseyi samodun o. Odun o ni diwa mo eru lo o. Gbogbowa la tun ma peju sibi ni odun to nbo pelu alaafia ati ayo ati idunnu pelu igbega.

E ba mi mu nkan ti e ba jeku fun odun wa o

Si Ebony,

Jowo iyawo mi tooto, mo se nreti re nile mi leni o. Obe ti o se ni o wu mi ki nje ninu odun keresi yi. Ose pupo o si ku ife aisetan ti o ni si mi

ese pupo alakoso foruumu.
odun ayabo fun gbogbo wa o
aseyi semi oo
odun keresi yi ko ni di gbogbo wa leru lo oo

ni odun tonbo gbogbo wa ma pejopo se hapi new year ooo grin
kai ma yoruba is grade A now cheesy

(1) (2) (3) ... (154) (155) (156) (157) (158) (159) (160) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 65
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.