Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,162,656 members, 7,851,249 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 03:47 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377439 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (158) (159) (160) (161) (162) (163) (164) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 9:46am On Jan 13, 2009 |
Jarusi, Owo eni la fi n tun iwa ara eni se. Iwo funra re ni oo lo pe Funmi wa si ihayin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:34am On Jan 14, 2009 |
E je ki a gba adura, "baba wa tin be ni orun, ki a bowo fun oruko re, ki ijoba re de, " |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:01am On Jan 14, 2009 |
Biowande: Se bi won se ngbadura niyen. Olodo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by allboyz(m): 11:25am On Jan 16, 2009 |
emi o mo pe a ni iru threadi bayi ni ibi bayi o mo ba ti soro pupo lati aro. mo ki gbo gbo yin o0o ewe so(ijebu) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 4:49pm On Jan 16, 2009 |
allboyz: A n je Omo daadaa, a si ki e ku abo. Tireedi yi ni won pe ni tireedi akagbadun Sugbon o leewo o Akoko: Iwo ko gbudo yaju si awa agba Eekeji: Iwo ko gbodo soro kunba kungbe si awon iyawo wa. Ti o ba ti se eleyi, a je pe o ti mo owo we niyen wa si le ba awa agba jeun Bi beeko, igbo rere ni tagbe |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 4:54pm On Jan 16, 2009 |
A dupe lowo Olorun fun odun titun.E jowo e je ki a se ara wa nikan. Ki e si rora se ere ni iwotun-iwosin ni opin ose yi. Yoo see se o . |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 5:59pm On Jan 16, 2009 |
kola oloye:eni to ba sere gele, OYO lo wa, abi abuja ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:25pm On Jan 16, 2009 |
Eyin temi bawo ni o, se ewa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 1:27am On Jan 17, 2009 |
allboyz: wa gbayi se wipe Ijebu ni re wa (something like that sha) Ode abi Igbo?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jarus(m): 5:57pm On Jan 18, 2009 |
farotika:@ eyi ti mo kun loda dudu, Mo juba eyin agba o ;DMRS |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 11:57pm On Jan 18, 2009 |
@Jarusi, Ooto oro ni Farotika so yen. Nitori lowelowe ni a n lu ilu agidigbo, Awon ologbon ni o ma ye, Awon Omaran ni yo mo idi re Soki ni obe oge, Aabo oro ni an so fun omoluwabi, Ti o ba de inu re yo di odindi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 11:39am On Jan 19, 2009 |
uhmmn! eyin omo yoba o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 4:47pm On Jan 19, 2009 |
Moyola:Ahon re yi ma rewa, bawo ni nkan Gbogbo ile- e kaasan, se nkan nlo deede |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FunmyKemmy(f): 5:18pm On Jan 19, 2009 |
Suliat kan, Ayetoro kan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 6:02pm On Jan 19, 2009 |
kola oloye: Booda Kola, E se ya oponu bayi. Se ahon obinrin lo wa wo nibi tabi ndan Ti o ba ni nkan gidi iso, o je yaa sa kuro nibiyi Oniranu, orobinrin dori, ako isu, ode nla |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 6:21pm On Jan 19, 2009 |
FunmyKemmy:itumo, anty orisaFunmyKe? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kolaoloye(m): 8:17am On Jan 20, 2009 |
@ farotika, Ase lotito ni ibi ma nro eniyan. O ma se o,ase eniti ko ba ni iru eni lotito ni pe ko le mo iyi eni. Ti aja ba nsinwin o ye ki o mo oju ina. Arakunrin se pele,ma se ri agba fin (gegebi amoran re) ki o ba le dara fun o di ojo ale. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 5:11pm On Jan 20, 2009 |
kola oloye: E wo oro ni igboro enu Se emi ni iwo nsoro kunbakungbe si beyen. Ti kii ba se ti Toyin iyawo mi to nbe mi ni, mba ni ki n soro agba si o. Sugbon o, ti iwo ba ko ti o ko bowo fun agba, nigbanaa ni emi ati iwo jo ma wo sokoto kan naa. Ki obinrin rarinto, ki okunrin rin arinto, ka wa wo eyi to maa ni omi leyin ese ju Ode nla. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 6:43pm On Jan 20, 2009 |
ogbeni farotika yi rope ohun kan le soro saka si gbogbo eniyan emi ko ni aye tire nisinyin rara abowaba ni oro re shior |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:08am On Jan 21, 2009 |
419 abi ki ni won ti npe o Oro re dabi oro omode ti o so oko lu iroko, ti o behinwo, ko mo pe oojo ko ni oluwere nja. Iwo sa maa sanra sile de iya |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 2:49pm On Jan 21, 2009 |
kola oloye: Nko mo pe ahon ma nrewa o! dada ni nkan wa! awon mo'lebi nko? farotika: Ah ahn! erenle nau! se inu nbi o ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 2:51pm On Jan 21, 2009 |
Ogbeni TKB! eku ijo tiwee! sewa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 5:08pm On Jan 21, 2009 |
Moyola: Asewo, odoko, haba se oko ni won ni ko wa wa sibiyi ni abi ndan Se o fe so fun wa pe iwo ati 419 o ri ara yin lana ni Laise aini aini, ile bobo yen ni o sun lale ana. Je ki nso fun o: oniranu ponbele ni bobo ti won npe ni tkb yen o, ti o ba nwa oko, o maa dara ti o ba le fe Kamoteesi, omo daadaa ni o si mo bi won se ntoju obinrin. Ti kii ba se pe mo ti nfe toyin ni, nba ni ki nmaa fe o sugbon o ti pe ju bose ye lo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 6:16pm On Jan 21, 2009 |
Brother Faro, afi ke ma run enu yin yi le mo, e sho ra gidi gan ni oh!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 6:23pm On Jan 21, 2009 |
sisi smurf bawo ni o? bata ko-ko-ka yin ye ko eazy rara. ti iru iyen ba lor sheshi te mi ni toes penre, chei! massage ti o maa fun mi ko ni kere o shey alaafia lo wa jo? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 7:40pm On Jan 21, 2009 |
Haaa Goodass didnt get all u said ooh, but me sef dey hail you oh, how things naw? EKU SE OH! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 7:44pm On Jan 21, 2009 |
Moyola aburo mi toda, bawoni, shey ise nlo? bawo ni igboro london? maje kin ri e pelu awon omo yahoo yahoo o ese jeje. emi na ma wa sibeyen laipe smurf aya to dara, bawo ni. shey o wapa. ade ku orire oga agbanla aye ni, Obama orire na akari o. mase dekun ko fi aworan ti oya lana nibi igbeniga Obama na egbon re nko? ki ille fun mi farotika oni katikati ni awe yi sha, kini mo ra ni igba re ti mio sanwo? ejo egbe mi jusile, emi kin se omo owo moyola ati smurf yen, oju e lori, ete re kole ba ole oloju kokoro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 7:48pm On Jan 21, 2009 |
tkb417: Awww, Oko mi, my one and only, bawo nkan, she dada le wa, ese oh, awa ni yen jare, erm. . .thats about all i can say oh, and mo ti miss yin ju too! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by goodass(m): 7:56pm On Jan 21, 2009 |
~smurf:e shey o. bawo ni lyf too. said 'ur high-heel poker no eazy.if dat heel puncture my toes, d massage u go giv no go small' |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by smurf1(f): 8:00pm On Jan 21, 2009 |
oh i see, my bad, hehehehehe, i know too understand, but thanks for translating, hope all is well wiff u sha, laterz |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 1:10am On Jan 22, 2009 |
farotika: Ni tani?!! Ogbeni oun try me o se ilara na lo to yi ehn?!! ko lo so ara e gidi gan, else ma doti e criously! farotika: So nitoripe oun fe Toyin lo se fe kin reti gboran? wo to ba lo so ara e. . . won ma gba omo yen mo elowo By_d_wey. . . 'Kamoteesi' ta lawon? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 1:18am On Jan 22, 2009 |
tkb417: Dada ni o. igboro lndn dey. emi ke? ki lo fe pa emi ati awon omo yahoo yahoo papo. . . . esa mo na, omo jeje nimi Ama reti yin o! |
(1) (2) (3) ... (158) (159) (160) (161) (162) (163) (164) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44 |