Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,441 members, 7,846,812 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 01:15 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (159) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377211 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (156) (157) (158) (159) (160) (161) (162) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:56am On Jan 06, 2009
Toooyin,

Ki lon wa okunrin lo si ile fun?

O ti fe bere irikurin niyen.

Shina/Agbere ko dara ninu odun titun!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 8:22am On Jan 06, 2009
dayokanu:

Toooyin,

Ki lon wa okunrin lo si ile fun?

O ti fe bere irikurin niyen.

Shina/Agbere ko dara ninu odun titun!!!

E tun ti de bi abbi?? shocked shocked

e ma ku ise oo, Bro Dayo, grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:26am On Jan 06, 2009
Toyosi
iyawo mi da? mio fe ki oma ba omo Dayo yen soro o?
iwa burku wa lowo e

Dayo
ahh, se Deboski ni ile ise agbere ati pansaga ni?
ahh, de de mera ho ooo

eyin eniyan mi
ni odun tuntun yi, aani san ku o o
gbogbo adawo le wa ma bosi aseyori o
amin ase ni tedumare
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 8:28am On Jan 06, 2009
tkb417:

Toyosi
iyawo mi da? mio fe ki oma ba omo Dayo yen soro o?
iwa burku wa lowo e

LOL!!!!

E ku Odun and iye dun too, cheesy

Ba wo ni everything naa??

I ya wo yin to miss yin pupo, oo tongue

o ni kin ma kin yin too, smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 8:34am On Jan 06, 2009
LOL!!!!

E ku Odun and iye dun too,

Ba wo ni everything naa??

I ya wo yin to miss yin pupo, oo

o ni kin ma kin yin too,

ose jare omo daadaa, bami so fun wipe telifoonu e ko kin connect oo
sofun wipe emi ti pada si ilu yi oo and mo de ti missss e gaaaaaaaaaaaaannnnn
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 8:38am On Jan 06, 2009
tkb417:

ose jare omo daadaa, bami so fun wipe telifoonu e ko kin connect oo
sofun wipe emi ti pada si ilu yi oo and mo de ti missss e gaaaaaaaaaaaaannnnn

Ma gie ise yin oo, smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:15am On Jan 06, 2009
dayokanu:

Toooyin,

Ki lon wa okunrin lo si ile fun?

O ti fe bere irikurin niyen.

Shina/Agbere ko dara ninu odun titun!!!

Booda gboromideleru, ewo ni tiyin naa Iwo gan an ni a ba pe ni onirinkunrin, mofilomindasi, gbeborun ati oniranu cool

Se iwo fe so fun mi pe o o mo pe toko tiyawo ni emi ati omo adumaradan yen ni

Ka sora o tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:21am On Jan 06, 2009
tkb417:

Toyosi
iyawo mi da? mio fe ki oma ba omo Dayo yen soro o?
iwa burku wa lowo e

Dayo
ahh, se Deboski ni ile ise agbere ati pansaga ni?
ahh, de de mera ho ooo

eyin eniyan mi
ni odun tuntun yi, aani san ku o o
gbogbo adawo le wa ma bosi aseyori o
amin ase ni tedumare

Booda 419, tani iyawo yin naa E gbe si wa leti ka ri gbo, abi grin grin onishina buruku[s][/s]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:24am On Jan 06, 2009
*Toyinrayo:

Nkan ti emi nan bere ni ye o. Ibo lo gba lo? angry angry

Se ni mo kan leku titi, mo ke gbo gba, sugbon ko se ni to da mi lohun.

Dada ni mo wa o, Iwo nko? se awan obirin ni be ye o sa tele e? grin grin

Rara o shocked shocked Ta lo maa ni iru e lobirin ta loun tun nwota E je pe ori onitoun ti daru. Nitooto, ife re ti fe maa dami lopolo ru.

Jowo onitemi, ma foju mi sona sad sad
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 9:41am On Jan 06, 2009
booda farotika
iyawo kan pere ni mo ni laye lorun
sumoofu loruko re. ama je ke rigbo bi gbogbo eto ba sen lo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 3:22pm On Jan 06, 2009
dayokanu:

Ero ayarabiasa (computer)

Ogbeni debosiki, Ile ise Agbere ati Pansaga yin ko ni jona oh

Awon Iyawo yin won o ma se daada Awon Iyawo yin won o bi Ibeefa ni odun yi o

Ma je kin fi enu ojo titun sepe fun e o!

Ta lo n'se Agbere ati pansaga? Abi iwo o mo pe oniwaasu ni mi ni? Bi o se ri mi yii, mi o ti f'owo kan obo tabi oyan rara. Oniwaasu ihinrere ni mo je. Mo f'oruko Farotika be e, ma ba mi so iru oro rirun yen mo o.

Iwo gaan ni o n'se agbare ati pansaga - jawo nbe ki o ma gbeyin lo orun apaadi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 6:42pm On Jan 06, 2009
isekuse ti fo won lori . . . . . . . . . . . . oro oko ati obo ni won ma ma so ni gbogbo igba . . . eje lo ronu piwada.

emi ti pinu pe ninu odun tuntun yii, mi o ni lu obinrin ni jibiti obo mo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 6:55pm On Jan 06, 2009
isekuse ti fo won lori . . . . . . . . . . . . oro oko ati obo ni won ma ma so ni gbogbo igba . . . eje lo ronu piwada.

emi ti pinu pe ninu odun tuntun yii, mi o ni lu obinrin ni jibiti obo mo.
bobo yi sha! ahn ahn oye ko code kini yen now

ati emi na o, mo ti ronupiwada ni year 2009 yi, but awon alasewo fe ba aye mi je ni Texas. olorun ati adura awon eni bi eni, eyan bi eyan bi dayo, smurf and co lo yomi ni gbogbo wahala yen.
kosi isekuse mo ni odun yi rara grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 10:10pm On Jan 06, 2009
Arakunrin Farotika,

E nle ni beun. Eyin Olowo nabi. Eyin len fi guguru ati epa tan afesona mi wa si ile yin.

Mo ti mon ohun ti ma se. Ma Le ni MAGUN ni . Iwo Alaida eniyan yi. Ti o ba ta okiti leemeta ti o si ko bi akuko ni wa to mo

Mafilomindasi Abi ojugun legbe eti!!! Ti mo ba gba e mu, ma fi imu re danrin. Nitori egbe isu ko ni iya, Aju ara wa lo ti ijakadi ko

Arakunrin Debosiki,

Iru Oniwaasu ati Wooli eke wo ni e gan na? Ti o n pe Oko ati Obo lenu!!! itakun to so igba na ni o so elegede
O da mi loju pe ara awon dodidodi (gay) Oniwasu Ijo Aguda(Catholic Bishops) ni oma je.

Ti owo awon agbofinro ba te e. She o ro pe California lo wa ni? ti o ti le ma ba Okunrin lo po tongue tongue tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:04am On Jan 07, 2009
dayokanu:

Toooyin,

Ki lon wa okunrin lo si ile fun?

O ti fe bere irikurin niyen.

Shina/Agbere ko dara ninu odun titun!!!
Rara na. ko n se nkan ti e nro jare.

Mo kan fe lo ki farotika ni. Iyawo e pke mi la nan, o so fun mi wipe, Farotika n sick die die, so mo kan fe lo ki ni smiley

farotika:

Booda gboromideleru, ewo ni tiyin naa Iwo gan an ni a ba pe ni onirinkunrin, mofilomindasi, gbeborun ati oniranu cool

Se iwo fe so fun mi pe o o mo pe toko tiyawo ni emi ati omo adumaradan yen ni

Ka sora o tongue
grin grin grin grin rotflmao, take am slow na grin

farotika:

Rara o shocked shocked Ta lo maa ni iru e lobirin ta loun tun nwota E je pe ori onitoun ti daru. Nitooto, ife re ti fe maa dami lopolo ru.

Jowo onitemi, ma foju mi sona sad sad
awww, how sweet. . . .omu inu mi din grin grin

ema ronu pawada, mi ni foju yin sonu kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:30am On Jan 07, 2009
dayokanu:

Arakunrin Farotika,

E nle ni beun. Eyin Olowo nabi. Eyin len fi guguru ati epa tan afesona mi wa si ile yin.

Mo ti mon ohun ti ma se. Ma Le ni MAGUN ni . Iwo Alaida eniyan yi. Ti o ba ta okiti leemeta ti o si ko bi akuko ni wa to mo

Mafilomindasi Abi ojugun legbe eti!!! Ti mo ba gba e mu, ma fi imu re danrin. Nitori egbe isu ko ni iya, Aju ara wa lo ti ijakadi ko

Arakunrin Debosiki,

Iru Oniwaasu ati Wooli eke wo ni e gan na? Ti o n pe Oko ati Obo lenu!!! itakun to so igba na ni o so elegede
O da mi loju pe ara awon dodidodi (gay) Oniwasu Ijo Aguda(Catholic Bishops) ni oma je.

Ti owo awon agbofinro ba te e. She o ro pe California lo wa ni? ti o ti le ma ba Okunrin lo po tongue tongue tongue

Yeepa shocked shocked shocked Ewo omo kekere yi to fe maa ba emi agbalagba du iyawo. Haa!!! Aye nbaje, ogede nsoyinbo. Iwosi gbaa ni mo ka eyi si.

Je ki n so fun o iwo omo dayokunu abi ki lo ti npe o tongue Asa re, nkolugi, nkolope, o si fe ko lu orule o. Eye akala to see lojosi nse ni o yo gege lorun.
JAWO NBEEEEEEEEEEEEEEEEEEE angry angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 7:53am On Jan 07, 2009
farotika,
Mo ro pe oruko lo nro o , Ifa ro ti ika. Danwo lo bi iya Okere! Ti o ba dan eleyi wo, adantan ni o ma je fun o.

Mo le fi ohun gbogbo ba eniyan sere sugbon bi ti adumaradan, omoge rumurumu eyinfunjowo to nje Toyin ko.

Laiku egiri, enikan kan o gbudo fi awo re se gbedu. Laiku mi o si fe fi owo ila gba mi loju.

Abi eyin eeyan e wa ba mi wo ni; Faarotika ni iyawo tire ni ile o tun bami du eyokan soso ti mo ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:21am On Jan 07, 2009
dayokanu:

farotika,
Mo ro pe oruko lo nro o , Ifa ro ti ika. Danwo lo bi iya Okere! Ti o ba dan eleyi wo, adantan ni o ma je fun o.

Mo le fi ohun gbogbo ba eniyan sere sugbon bi ti adumaradan, omoge rumurumu eyinfunjowo to nje Toyin ko.

Laiku egiri, enikan kan o gbudo fi awo re se gbedu. Laiku mi o si fe fi owo ila gba mi loju.

Abi eyin eeyan e wa ba mi wo ni; Faarotika ni iyawo tire ni ile o tun bami du eyokan soso ti mo ni

Aja to ba ma sonu ni oro re, koni gbo fere olode. Se emi ni iwo nba leri beyen. Haaaaaa, sangba fo!!! Ti kii ba se ero ayarabiasa ti fa arifin, se iru e le maa ba emi du aya

Boya lomo pe ode ti o ba gboju le fi awo egiri se gbedu laiku re. Loni, emi ati iwo ti jo wo sokoto kan naa; mo de ma fi nkan ti won npe ni agba won e. Maa je ko mo pe eran ti won fa ti ko ja ni won npe ni namo.

Nipa ti Toyin (onitemi tooto), ati toje boloosa lowo, o ku baba eni ti o bo tongue tongue tongue Mo ti lo ri awon obi re asi ti da ti a maa lo se mo-mi-n-mo-o sona. Ma si se seyonu, ma fi iwe ipe ranse si o ti o ba to akoko cool

ODE NLA tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 10:42am On Jan 07, 2009
he he.

Bi iya nla ba gbe ni sanle kekere a ma gori eni. Abi e wa ri farotika ni? Iwosi , Arifin

Ati oje bo olosa lowo? Ti oje ko ba se yo ni owo Olosa, Gige ni owo na yo je
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 4:38pm On Jan 07, 2009
ewo bi awon agbalagba yi se npa ofo nitori obinrin

Fadeyi oloro ati kukute grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tkb417(m): 4:42pm On Jan 07, 2009
eyin oniranu dede
ase ogbon ori gbogbo yin ko tonkan rara
ewo ni ija ajakudorogbo laarin awon ti arope opolo won sise deede.

ija obinrin loku yinka lodun tuntun? boya ke bere lowo ori tofije wipe, ko si nkan mere mere te le gbese ju ija lori obinrin
opolo yin ti yoro eyin booda agbaya meji
elo wase se
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:24pm On Jan 07, 2009
dayokanu:

farotika,
Mo ro pe oruko lo nro o , Ifa ro ti ika. Danwo lo bi iya Okere! Ti o ba dan eleyi wo, adantan ni o ma je fun o.

Mo le fi ohun gbogbo ba eniyan sere sugbon bi ti adumaradan, omoge rumurumu eyinfunjowo to nje Toyin ko.

Laiku egiri, enikan kan o gbudo fi awo re se gbedu. Laiku mi o si fe fi owo ila gba mi loju.

Abi eyin eeyan e wa ba mi wo ni; Faarotika ni iyawo tire ni ile o tun bami du eyokan soso ti mo ni

farotika:

Aja to ba ma sonu ni oro re, koni gbo fere olode. Se emi ni iwo nba leri beyen. Haaaaaa, sangba fo!!! Ti kii ba se ero ayarabiasa ti fa arifin, se iru e le maa ba emi du aya

Boya lomo pe ode ti o ba gboju le fi awo egiri se gbedu laiku re. Loni, emi ati iwo ti jo wo sokoto kan naa; mo de ma fi nkan ti won npe ni agba won e. Maa je ko mo pe eran ti won fa ti ko ja ni won npe ni namo.

Nipa ti Toyin (onitemi tooto), ati toje boloosa lowo, o ku baba eni ti o bo tongue tongue tongue Mo ti lo ri awon obi re asi ti da ti a maa lo se mo-mi-n-mo-o sona. Ma si se seyonu, ma fi iwe ipe ranse si o ti o ba to akoko cool

ODE NLA tongue

angry angry angry angry I no like the cursing na. ah ahn. . . . smiley
Farotika, se ni awan eyan nso fun mi wipe awam obirin nwa a wale. se tooto ni? cry cry

@Dayokanu
Awww, Dayo, lol, wetin be rumurumu? aww, you're such a sweetie kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 10:54pm On Jan 07, 2009
Rumurumu means well shaped.

Farotika Toyin so wipe ohun ko nife re abi se won fi obinrin she e ni? Ti apa ko ba se san a o si ka le ori.
Mo fe ki o mo pe Kukute o se mi, eni to ba mi kukute, ara re ni o mi. Farotika ma ba lo.
Aja ti o ba fe sonu, ko ni gbo fere olode.
Ohun ti agaba fi n jeko, abe ewe ni owa
ati wipe ohun ti a ba fi ju omode lo a ma fin han ni a o kin fi le lowo

@Toyin, bi eniyan o ba je osakala ki o je osakala, bi yo ba ye osokolo ki o je osokolo ewo ni osakalasokolo?

So fun Farotika ti o ba fe fe!!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:13pm On Jan 07, 2009
dayokanu:

Rumurumu means well shaped.

Farotika Toyin so wipe ohun ko nife re abi se won fi obinrin she e ni? Ti apa ko ba se san a o si ka le ori.
Mo fe ki o mo pe Kukute o se mi, eni to ba mi kukute, ara re ni o mi. Farotika ma ba lo.
Aja ti o ba fe sonu, ko ni gbo fere olode.
Ohun ti agaba fi n jeko, abe ewe ni owa
ati wipe ohun ti a ba fi ju omode lo a ma fin han ni a o kin fi le lowo
Dayo, Dayo, Dayo. . . .ere melo ni mo pe e?
se o fe k'oro simi lenu ni? Igba wo ni mo so eleyi? tongue tongue

Dayo, sebi iwo nan moh eni to je ololufe mi, ewo lo wa nba e leru? grin cheesy

dayokanu:

@Toyin, bi eniyan o ba je osakala ki o je osakala, bi yo ba ye osokolo ki o je osokolo ewo ni[b] osakalasokolo?[/b]

So fun Farotika ti o ba fe fe!!!!
Lmao, ewo lo nje osakalasokolo? lmaooooooo, sounds funny sha
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 12:51am On Jan 08, 2009
Oda Toyin Tani o fe ninu awa mejeji.

Soro ni isinyi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by pie1ect(m): 1:44am On Jan 08, 2009
Novice to Yoruba language here and I can't start rifling through 159 pages (of this thread) for a possible answer to my question.

Can someone provide me translations for the following words/phrases urgently:

English to Yoruba

[list]
[li]Travel[/li]
[li]"Come and See"[/li]
[li]Nature[/li]
[li]Welcome Home[/li]
[/list]

Make them as short as possible, please.
Thanks in advance.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:32am On Jan 08, 2009
dayokanu:

Oda Toyin Tani o fe ninu awa mejeji.

Soro ni isinyi
hmmm, dayo dayo, you/farotika should know na.

How was ur day sha smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 2:55am On Jan 08, 2009
English to Yoruba

Travel - Iri ajo
"Come and See"- Wa wo
Nature - No idea
Welcome Home - Kaabo si ile
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by pie1ect(m): 4:39am On Jan 08, 2009
@Dayo

God bless you, Bro.
Really apreciate that.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:29am On Jan 08, 2009
Ogbeni farotika,

Mo yonda fun e. Nitori Toyin gan on sheku sheye. Ko mo ohun to ohun fe.

E ma gbadun ara yin.

@pie1ect, ko to ope. A kin dupe ara eni (Dont mention)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:32am On Jan 08, 2009
dayokanu:

Ogbeni farotika,

Mo yonda fun e. Nitori Toyin gan on sheku sheye. Ko mo ohun to ohun fe.

E ma gbadun ara yin.
Lol, ouch! I didn't tell you for you to burn me cry cry cry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:42am On Jan 08, 2009
Lol, ouch! I didn't tell you for you to burn me

Kini itumo gbogbo eleyi? emi o gbo oyinbo oh!!!

(1) (2) (3) ... (156) (157) (158) (159) (160) (161) (162) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 58
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.