₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,283 members, 8,425,817 topics. Date: Saturday, 13 June 2026 at 07:32 AM

Toggle theme

Ayanjide's Posts

Nairaland ForumAyanjide's ProfileAyanjide's Posts

1 2 (of 2 pages)

CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:21am On Aug 24, 2007
ojumo oni mo, ojo ayo lo mo emi
se alaafia ni lagboole yi
mo f'ope f'eledumare fun anfaani
ojo tuntun ti o fi jinki aye mi loni

se mo ba eeyan ninu abule yi

Richy, o see pupo
mo rii bi anfani nla rapata lati gbo OHUN ENU
re, nitori idi eyi, nko nii kuna lati fun o ni nomba
gegele isoro alagbekaa mi
laipe yoo kan o lara
O SEE FUN EKO TO MOYANLORI
ATI ANFAANI TI KO SEE F'OWORA
IPO AGBA LA N BAGBA
AGBA KAN KII SE LANGBA LANGBA
AGBAA RE O NII DI YEPERE.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 6:03pm On Aug 23, 2007
richy, o see pupo, mo gbadun oriki naa
sugbon mo ni idojuko die ninu itumo
awon oro die ninu e
awon oro bii :

AKORAYE AKEJI OMO-1st to see d world, d 1 dat second a child

OJU MI YESO, OJU RABESA- beauty adorns my face, my face ran away from(avoids)knife

LEMBEBE- wots d meanin

BI O BA TORI ONI KEKE KU E PE KU AREWA LO POGO- if i die cos of a bicycle owner, say it is d death of a beautiful 1 dat kills GLORY

PERENSE- wots d meanin

e ma ni wahala mi po o , e o ko wa je pe, e o ri un amufiboju ati amusagba
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 4:36pm On Aug 23, 2007
ENU AGBA NI OBI TI N DUN "HAUN" . Mo ti gbo, mo si gba pelu !!

iru owe ti o fee pa yi pin si ona meji
ENU AGBA NI OBI TI N GBO
tabi
ENU ONI KAN LA A TI N GBO PON-UN

misho darijimi to ba dabi ayonuso o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:54pm On Aug 23, 2007
tafari, kaabo o
oode o daa bi

richy richy, o see mo dupe
kee pe baba o
nje o lee ran mi lowo pelu
oriki ILE IFE
MO NI LO O RE FUN KANKAN NI KANMO N KOBO
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 2:31pm On Aug 23, 2007
RICHY, omo ogbomosho gan ni mo je ni oyo st8
ise ilu lilu si ni ise awon baba nlaa mi
sugbon ai f'oju f'okan si lo je ko yi mi
legbiri. ki olorun ki o ran mi lowo
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 2:27pm On Aug 23, 2007
richy, o see, o ku ilaloye
mi o f'owo kan kongo 'lu ri
se ati sin gbenre s'eyin eti
o ti waa pe ju bayi
ko buru, maa to awon agba lo
a o si wa nkan se sii
aa ju se fun wa o. ase
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:56pm On Aug 23, 2007
mishoo ohun temi naa n bebe
fun niyen o, ki richy jowo
san igbo didi yi fun wa o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:44pm On Aug 23, 2007
richy ma fa 'rin simi lese
iwo naa mo pe
ogun odun ti reluwe ti n sare
e ku 'waju lo ma n kile
iwaju ni mo baa yin
mi o lemi ati tumo ede ilu naa rara
looto o dun mi pe n ko mo
sugbon a kii fi 'pa le oko to ku
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:32pm On Aug 23, 2007
richy, ti mo ba pe o ni omo ODE_OMU
se mi o jinna sii
mo gbe oriki naa ye wo
ode omu lo jo loju mi o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:14pm On Aug 23, 2007
erin yanturu
nitoripe mo ri akosile oree mi ka
richylaw o see pupo fun oriki yen
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:04pm On Aug 23, 2007
omo Oyo ni emi o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 1:00pm On Aug 23, 2007
e kaa san lorii waya yi o
se alaafia ni e wa o
mo rii wipe a n le sii
lori waya yi
ao nii p'edin o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 12:51pm On Aug 22, 2007
mishoo mo dupe lowoo re fun bi o ti beere mi
oba edumare o ni gbagbe 'wo naa
o ni pare m'aye bi 'so
o si nii d'eni awati
ee koo kan towo ba dile ni mo man fi
ero komputa pa 'wo da
mo sese n ka awon ohun ti mo padanu (miss)
nigba ti n ko si lori waya yi ni
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 5:37pm On Aug 14, 2007
richy law, bawo ni irin ajoo yin ?
se gbogbo nkan lo ni melomelo
e ku asiko yi o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 5:35pm On Aug 14, 2007
se daada ni oode yi wa
TV/MoviesRe: Gulder Ultimate Search 4 (IV)! by ayanjide(m): 11:29am On Aug 13, 2007
when in this world can we stop been who we are?full of criticisms,lets stop apportioning blames to neither nb nor the organisers of the show,this is not the first reality show in the history of gulder ultimate search,we are talking about gus 4 here,it has all been successful. why don't we see it that, it's when tragedy wants to struck,no one is to blame here.the only thing necessary here is to commit his soul to eternal rest. may your soul respect in perfect peace brother.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:10pm On Aug 09, 2007
ko si laburu kankan lori tiredi yii
ko baa le ni 'yanju naa la n seto
o si di dandan ko daa.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 11:17am On Aug 09, 2007
Alaafia fun yin labule yio
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 6:55am On Aug 08, 2007
debosky e see mo dupe gan ni o. E de kuu ilaloye ti e n fun ogbeni debosky afi ki Oluwa ko ko won yoninu oro E PA NA, E PA NA ti won ko raa won si yii.


OBOWUNMI. e jowo kinni itumo oruko yin, se OBO bii VIRGI, abi OBO bii MONKEY nitori ko ye mi ni mo se beere o. E ma fi se 'binu rara o. eni beere kii sina. Nigba ti mo wa aso iboraa mi9 ti n korii mo pe nombaa yin 0900007777 wonni ko si lawujo awon nomba lorii gegele isoro alagbekaa mi. Se kii se p e e ko mo nomba yin lori? E MAA GBADUN LABULE YI O
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:01pm On Aug 07, 2007
@

DEBOSKY

o see pupo fun bi o ti pe akiyesii baale abule yi si oro mi. O dun mi pe o pe die ti mo ti yoju si aafin. Sugbon morii pe lai si n le mi aafin si n dun. Edumare o nii ba ise owoo wa je o. ASE

Sugbon nisinyi maa se akitiyan lati fara moo yin daada, ki a le baa fowowewo ni abule yi.


@
RICHYLAW
ooto ni, un o faramo yin daada nitori abule yi dun. A o nii p'edin, a o si nii te. E see gan ti e ko je ki oruko mi o pare labule yi
BusinessRe: Robert Kiyosaki: His 'Rich Dad' Does 'Not Exist'? by ayanjide(m): 12:39pm On Aug 07, 2007
@poske

tnx 4 ur enlightenment on d game i tink d game is as good as d book. You av just wet my appetite for the game with ur lucid explanation
I would love to know where i can get it in Lagos NIgeria
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 8:00pm On Aug 02, 2007
si bodsibobo
aayan ongbufoo re dun ka
o yo kululu bi elubo ti a jo daada
sugbon O TAKE ADVANTAGE tumo si O LO ANFAANI
opolo e o nii ku
AMIN
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:44pm On Aug 02, 2007
@ola2k
Mo gbadun akosile ede yorubaa re gan ni o. Nje o le ko mi bi a ti se n lo ero komputa lati fi aami si ori ati idi oro yoruba. Nitori mo gbadun lati maa yan awon akosilee mi pelu ami ti o ye
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:40pm On Aug 02, 2007
@borrado
LOL ni edee yoruba tumo si ERIN NI YANTURU tabi OPOLOPO ERIN
BusinessRe: Robert Kiyosaki: His 'Rich Dad' Does 'Not Exist'? by ayanjide(m): 3:46pm On Aug 02, 2007
first time somebody ll cast aspersion on my financial idol. Well, no grudge! all i know s DAT f u r Doin something that people cant criticize, u r not making any impact. Am sure RKs books must av made certain impact on Reeds that could have elicited such articles on on RKs view

@mentorman tnx 4 Ur view and am so glad u r currently running an investment club. Are there still vacancies 4 me i want to join. pls send me the details

@poske The rat race is as real as it is an unfortunate race working like an elephant and eating like an ANT

@segedoon tnx 4 giving me an opportunity to read RKs reply to REEDs views. i ll read it as soon as it is available cos av opened d site but not available yet.
Jokes EtcRe: I Owe My Mom. by ayanjide(m): 2:11pm On Aug 02, 2007
txlonghorn, u kept my eyeballs wet by rekindling my love 4 my sweet mother

1 2 (of 2 pages)