₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,923 members, 8,447,774 topics. Date: Saturday, 18 July 2026 at 11:41 PM

Toggle theme

Dominicson's Posts

Nairaland ForumDominicson's ProfileDominicson's Posts

1 2 3 4 5 6 7 (of 7 pages)

CultureRe: .. by dominicson: 12:18am On Apr 02, 2016
Zenlife:
@Healthfirst
Baba ejowo e funwa ni oogun ki iyawo mon see bi oko baa ti fe ni gbogbo igba. E seun. Edumare a to ju yin fun wa o. Ewe a je o.
Perhaps you need to pay her dowry again!

But this time to Osumare. It is always found at the riverside. When it is found, the simple ritual is made there, saying: Osumare, Osumare, Osumare, lati ijo alaye ti d'aye ni iwo Osumare ti n se oko odo, ko si si enikankan ti n ba o du. Lati oni yii lo enikeni ko gbodo ba mi du (your wife's name), be it her parents, her work, her boss, her anything. Mo ti mu owo ori re(do) wa fun iwo Osumare loni o, emi nikan ni kin ma ba se loko-laya o, ife t'emi nikan ni ki o ma gbile ninu re, oro mi nikan ni ki o ma wo o l'eti." You will then take one of the moneys paid to osumare, give to your wife to buy you something with it.
Science/TechnologyRe: Meet Alagba, A 330-Year-Old Tortoise Found In Ogbomoso, Oyo State (Pics) by dominicson: 1:40pm On Mar 31, 2016
KayTash:
lie
Brother, it is not a lie. Some beings are not meant to die naturally; except you take their lives, poisoning or otherwise.
Christianity EtcRe: Christianity In Nigeria Today As Practiced By Most Pastors And Their Flock by dominicson: 2:26pm On Mar 28, 2016
Zenlife:
CHRISTIANITY AS PRACTICED BY MOST PASTORS & THEIR FLOCK IN NIGERIA TODAY:

Inconsiderate, disillusioned, abusive, ignorant, loathful, arrogant, wealth-accumulating (shunning the camel/needle), sexual-predators, separating-families, breaking up matrimonial homes (asunder), unemployment encouraging, sloth perpetrating, mind manipulating and destroying, insulting, irritating, fraudulent, selfish, repeling, dangerous, diabolic, vindictive, terroristic, killings, murdering, mis-informing, repetitive/boring (same songs), emptiness, cheap sinful glamour, unhealthful, sickening, counter-productive, shameful, disgusting, unhealthy, ritualistic noise polluting neighborhood disturbing night vigils, PESTS, dangerous, predators, self-deceit, fake, lies, cheap fear-tactics, exploitative, brain-washing, repulsive, excluding, judgemental, condemning, nauseating, uncaring, expensive schools members/their children who donated monies to build can't afford to attend, thieving (tithing), irreponsible, fraudulent, community unsupporting, polluting, criminal, unholy, take take take, money accumulation with no food or water in the 'storehouse' to offer congregation ...NOISY!!!
Zenlife, could you say why my I'm banned from posting at Culture section again, pls?
CelebritiesRe: KWAM 1's Birthday Party, Money Rain (Photos) by dominicson: 11:32am On Mar 26, 2016
K1 de Ultimate
CultureRe: .. by dominicson: 1:59pm On Mar 23, 2016
Yes, for those who have called to ask which one(Imule) I think is best for them or a specific situation. Divination reveals this best. Because what Mr. X uses and later thanks his Babalawo (who in turn would thank Ifa, and Ifa, Eledumare) Mr. Y may not see/feel its impact/potency, or it may not work as effective as it did for Mr. X. However, for those that are predominantly water or more of water(water element/those born under water signs or stars), water plants and animals are the best for them. Crab. Fish. Frog. Toad. Isawuru. Crocodile. Oju-oro. Osibata. Ireke. Ogede. Etc. If these are used to make Imule or Awure or sacrifice or anything for them, it will work very well. While the 'air' people should try birds: vulture, bat, eagle, dove, mistletoe, etc. I'm not saying your Ori/Ipin/Head may not request things outside these boundaries if the oracle is consulted, but efficacy/effectiveness of charms prepared with materials(plants and animals) that are naturally compatible with your star/element is guaranteed, consulting or not. But for those that combine two elements(cusp), say water and air, duck will be very good for you. I'm actually not 'speaking' with neophytes here!
CultureRe: .. by dominicson: 1:56pm On Mar 23, 2016

CultureRe: .. by dominicson: 6:50pm On Mar 22, 2016
Lero70:
Alagba Dominicson, email address teefisita yi, motigbiyaju lati kole ranse sinu re, sugbon esi tiwon ndapada funmi nipe wonkodaamo ( address is not recognized ) eranmilowo. Eseepupo.
benige4@gmail.com
CultureRe: .. by dominicson: 3:50pm On Mar 22, 2016
wale259:
Sir,e fun mi idi isoye yi...
Irunla, that is ila(okra/okro) ti o gbe/dry si ori iya e, owo eyo kan (eyi ti ko lu), oko atare kan, a o gun papo, ao fi fo eko tutu kan mu.
CultureRe: .. by dominicson: 11:13am On Mar 20, 2016
Lero70:
ejowo Alagba se ki ato kunle sidi ipese yi lati ka psalm re sii ni aoti fi ebu ti atenifa awon maami wonan ni abi leyin ti atigbe de ibiti aol gbee kale si. Esee pupo
Ninu iyewu yin ni e o gbe ipese naa si, e o te ifa si egbe re, e o kun le ti (a bi se eyin o le kunle fun awon mami ni?) Ti e ba ti ka psalm yen si tan, e o da ifa naa si ori ipese naa, e o wa gbe jade lo si ibi ti e fe gbe si. Kan ni awon baba mi ni, awon a maa le(bi opele/ifa) ibi ti won ti fe pade yin. But never to worry, just take it at least a bit far to your place. If you have a car, put it in your car and drive to a convenient place to place it! If you don't (Awon ti Olorun fi se opo/pillar aye yoo pese fun yin), just put it in a 'poly bag', stroll out, or take bike if need be, and drop it off! Regards.
CultureRe: .. by dominicson: 11:01am On Mar 20, 2016
Lero70:
edakun aaye ologinni, se ti ao sesepa funrawa abi ti ao gbe sinu agbada laaye? Ejoo ebawatanmonle sii Moseba Agba o.
Ti e ba se n pa tan ni e o gbe sinu agbada, kii se laaye o. Nitoripe ologinni kii se eran be o!
CultureRe: .. by dominicson: 6:09am On Mar 20, 2016
wale259:
E se sir,Agba yin o ni baje
Ase n'Ife!
CultureRe: .. by dominicson: 6:06am On Mar 20, 2016
Lero70:
@Dominicson Ejowo efunmi ni phone no. Ati email add yin
08145802864. 08121751389. benige4@gmail.com
CultureRe: .. by dominicson: 12:31am On Mar 20, 2016
wale259:
Sir,se ale ni lilo ebu yi ati wipe se gbogbo igba ta ba fe lo ni a o ma te ifa eji ogbe si lati pe ohun re si...Aye ologini ni abi Oku re,kini a ma fi lo sir.
Eko tutu la a fi lo. Owuro kutukutu la a lo. Aaye ologinni nla la a lo. Ti a ba ti pe gbolohun si ki a to ro sinu ato, o ti daa.
CultureRe: .. by dominicson: 12:01am On Mar 20, 2016
Imule 4:

Olongbo nla kan, owo eyo ogoji(ailu), ewe oriji oojo, atare kan. A o jo papo, ao te ebu yii ni ogbe meji/eji ogbe, a o ro itan/ofo/gbolohun/psalm re si, a o ro sinu ato/seere/ado.

Psalm:

Iweku-ni-iweku, iweja-ni-iweja, a difa fun okanlenirinwo n'ijo ti won lo re yan ipin l'odo Oodua. Won pin aje(wealth) fun Olubini, won pin okun(re do) fun Olurada, won pin ide fun Osun, won pin oje fun Orisa-nla, won pin irin dudu fun ogun, won pin igba omi fun Agbonmeregun, won pin ile(land) fun Oba l'ode Oyo(do mi), won pin isekuse fun Esu Odara. Asotito bo s'ile, o gba aje lowo Olubini, o gba okun lowo Olurada, o gba ide lowo Osun, o gba oje lowo Orisa-nla, o gba irin dudu lowo Ogun, o gba igba omi lowo Agbonmeregun, o gba ile lowo Oba l'ode Oyo. Won wa ni ki Esu o mu isekuse owo re wa, Esu ni ki won o fi ti oun ji oun. Won ni ee ti ri? O ni se bi oba ni eyin, ologinni ni oun. Ati ile, ati ona ni oba fi n ji ologinni, eyin alaye, e wa fi adun aye gbogbo ji mi. Orijin lo ni ki e fi gbogbo ire ti n be ni ode isalaye ji mi. Nitoripe apejin(do do do) ni ti ogoji, e fi ire nla nla ji mi, e fi asise mi gbogbo ji mi o.
CultureRe: .. by dominicson: 11:07pm On Mar 19, 2016
dominicson:
I think one more can still come out into the light, with a serious warning though.

This Imule, 'Oloherenhere', is very good. Even if one needs a good job. A job of your choice. Or wherever your need is, you will get your choice. But if you wish not to work or do anything, and wish to be living big, try 'Al'apa ma sise, Am'ona owo ma re...' That's another Ifa/Imule entirely.

Back to Oloherenhere, this Ifa/Imule is in two parts. You can do it the same day, but if you can't make it doing the two the same day, it is recommended you do its Ese(do do) before its Etu(do do).

Imule: Oloherenhere (Osa meji, Osa Eleye!)

Ese: the first part.

A o wa akuko adie ti o se se la ogbe (ti ogbe ori re se se yo). A o pa, a o ge si merindinlogun. A o fi epo pupa din(fry). A o ko sinu taasa tuntun.

Ikilo/warning: everything that you use to prepare this delicacy: knife, spoon, pot/pan, and all, should be disposed of into a river, and never be used again. If not, the very many guests that are invited will also share whoever use those cutlery.

Having served it, a o fi ebu re te Odu/Ifa awon mummy mi beside that awo ipese ti a wa eran naa si, a o kun'le, a o so wipe:

(Psalm)

Iba, iba, iba. Ela ro wa, Ifa ti o ba n be l'okun Ela ro wa, Orunmila bi o ba n be l'osa Ela ro wa, Osa Eleye, Ela ro wa. Nko pe yin fun iku o, bee nko pe yin fun arun (wa fi action gidi si ni o; you have to brace yourself, because you may experience the presence of your guests, even if you may not see them. This is because they would have smelled it while it was still on the fire frying.) Nko pe yin fun faari o! Mo pe yin ki aye omo Olufe(Olu Ife) le tuba tuse ni o. Oloherenhere, Oloherenhere, Oloherenhere, se bi eye ori agbon(coconut) ni e n se. Ibe(there) le gbe n pe (congregate), ibe le gbe n je(do), ibe le gbe je(re), ibe le gbe mu, ibe le gbe ro(do). E wa lo ro nitori oro emi lagbaja omo lagbaja. E lo ro nitori a ti l'owo(getting rich) mi, e lo ro nitori a ti bi'mo mi, nitori a ti l'aya, a ti d'olokiki mi. Gbogbo eyin Eleye ni mo be(plead), eyin Aje aye o! Eyin Aje orun o! Eyin a je eegun(bone)! Eyin a je eran! Eyin a je edo! Eyin a je oronro ogalanta! Eyin a mu eje(blood) eeyan(person) ma bi! Eyin Aje(witches) sanmo mejeeje. Eyin Aje ile mejeeje. Eyin aje dudu. Eyin Aje funfun. Eyin aje pupa. Eyin Aje kalakinni (do mi do mi). Eyin Aje batabata(do mi do mi). Emi Lagbaja omo Lagbaja, mo di opo yin mu l'ori a ti l'owo, l'aya... Osa Eleye Oo! Ti o ba je wipe eyin(back) re l'o fi pon awon Aje wa si'le aye, ki o sa ere tete ki o lo gba ire ola(re do) t'emi wa fun mi o.

(To be continued, pls)
Yes, a o gbe etutu yii jina si ibi ti a n gbe. Ekuru meje ti a jo pelu atare kan ni a o fi te odu osa eleye ti a o fi won(bu si ori) ipese yii. Ti o ba se e se, oru ojo yii gan ni odara ki a se ikeji(the second part) ti o lo bayi:

Ebu.

Oromodie (a chick) ati atare kan, a o jo, a o da ebu yii si inu igba olomori kekere kan. A o tun jo alapandede ati atare kan, a o da sinu igba kekere miran. A o jo eye ega kan ati atare kan, a o da sinu igba olomori keta. Ti o ba di agogo kan oru, a o te aso funfun si ile ni gbangba abe sanmo. A o joko le lori ni ihoho. A o wa akara elepo meta. A o fi akara kan je ebu inu igba kan. So, akara meta, igba meta. Ki a to je, a o so wipe:

Eyin alaye, mo ba yin mule loni o. Emi o ba yin fi omo mi mule o. Emi o ba yin mule a n pa ara eni l'aya, l'omo... Emi wa ba yin mule kin le la, kin n le lu, ki n le ri owo se fuja. Ti eran ba n wu yin je, awon ota mi ni ki e ma mu pa je lokokan o.
CultureRe: .. by dominicson: 5:18pm On Mar 19, 2016
skypeme:
The indians are best known for the production of rings, such as Magic ring, success ring, protection ring, goodluck ring and so on, my question is shey our own power neva reach the level of producing such rings ? just like the indians
Bros, we, the Yorubas, have things that are more potent/powerful than the indians. Indians ba wo! Ibi ti olukuluku ba se awo de ni! Me o, I've seen things, only I may never be able to reveal ninety percent of them! Imule la fi se!
CultureRe: .. by dominicson: 4:34pm On Mar 19, 2016
I think one more can still come out into the light, with a serious warning though.

This Imule, 'Oloherenhere', is very good. Even if one needs a good job. A job of your choice. Or wherever your need is, you will get your choice. But if you wish not to work or do anything, and wish to be living big, try 'Al'apa ma sise, Am'ona owo ma re...' That's another Ifa/Imule entirely.

Back to Oloherenhere, this Ifa/Imule is in two parts. You can do it the same day, but if you can't make it doing the two the same day, it is recommended you do its Ese(do do) before its Etu(do do).

Imule: Oloherenhere (Osa meji, Osa Eleye!)

Ese: the first part.

A o wa akuko adie ti o se se la ogbe (ti ogbe ori re se se yo). A o pa, a o ge si merindinlogun. A o fi epo pupa din(fry). A o ko sinu taasa tuntun.

Ikilo/warning: everything that you use to prepare this delicacy: knife, spoon, pot/pan, and all, should be disposed of into a river, and never be used again. If not, the very many guests that are invited will also share whoever use those cutlery.

Having served it, a o fi ebu re te Odu/Ifa awon mummy mi beside that awo ipese ti a wa eran naa si, a o kun'le, a o so wipe:

(Psalm)

Iba, iba, iba. Ela ro wa, Ifa ti o ba n be l'okun Ela ro wa, Orunmila bi o ba n be l'osa Ela ro wa, Osa Eleye, Ela ro wa. Nko pe yin fun iku o, bee nko pe yin fun arun (wa fi action gidi si ni o; you have to brace yourself, because you may experience the presence of your guests, even if you may not see them. This is because they would have smelled it while it was still on the fire frying.) Nko pe yin fun faari o! Mo pe yin ki aye omo Olufe(Olu Ife) le tuba tuse ni o. Oloherenhere, Oloherenhere, Oloherenhere, se bi eye ori agbon(coconut) ni e n se. Ibe(there) le gbe n pe (congregate), ibe le gbe n je(do), ibe le gbe je(re), ibe le gbe mu, ibe le gbe ro(do). E wa lo ro nitori oro emi lagbaja omo lagbaja. E lo ro nitori a ti l'owo(getting rich) mi, e lo ro nitori a ti bi'mo mi, nitori a ti l'aya, a ti d'olokiki mi. Gbogbo eyin Eleye ni mo be(plead), eyin Aje aye o! Eyin Aje orun o! Eyin a je eegun(bone)! Eyin a je eran! Eyin a je edo! Eyin a je oronro ogalanta! Eyin a mu eje(blood) eeyan(person) ma bi! Eyin Aje(witches) sanmo mejeeje. Eyin Aje ile mejeeje. Eyin aje dudu. Eyin Aje funfun. Eyin aje pupa. Eyin Aje kalakinni (do mi do mi). Eyin Aje batabata(do mi do mi). Emi Lagbaja omo Lagbaja, mo di opo yin mu l'ori a ti l'owo, l'aya... Osa Eleye Oo! Ti o ba je wipe eyin(back) re l'o fi pon awon Aje wa si'le aye, ki o sa ere tete ki o lo gba ire ola(re do) t'emi wa fun mi o.

(To be continued, pls)
CultureRe: .. by dominicson: 11:32am On Mar 19, 2016
I intended posting ten confirmed Imule, but now I'm afraid the next eight could make the female ones among us 'fly'.

So helpless I am to help those I know they really need these imule here!
CultureRe: .. by dominicson: 11:17am On Mar 19, 2016
@ Cancioamor, Obe/Aseje ni ise naa.

@Lero70, Gbigbe ni asin ati Oga naa, sugbon asin ti won la ni aya(chest) ni o.

Orangun meji naa ni an pe ni ofu meji, odu yii ni alakoso awon iya mi eleye before osa meji took its position, that's a story for another day. Two-one-two-one at both sides

. . . .
. .
. . . .
. .

And for pronunciation of those words, you can call or whatsapp me, so I can record and send.

@Wale259, Gbigbe ni asin ati oga naa o.

Ati wipe ale patapata ni a lo imule yii.
CultureRe: .. by dominicson: 9:47pm On Mar 18, 2016
Imule 2: Osa Eleye

Igbin apinnu meji, otutu opon, sefunsefun, aluki, ajeobale, iyere.

Psalm:

Alagada nla l'oruko ti a n pe ifa. Araba-tasi l'oruko ti a n pe ile. Ti a ba fi efun fun aye, ara aye a ya gaga. Ti a ba s'epe (curse) so Ogun, ara ogun a le koko. Ogun aseje, awo won lootu Ife, oun l'obi Atepe, Atepe l'obi ile. Nje okunrin l'o ba ni kin ma t'ele yi pe, ki o ku bi aja se n ku ti oun ti ogboro. Agbalagba l'o ba ni ki n ma tele yii pe, ki o ku bi aguntan se ku ti oun ti bolobolo enu re. Ti o ba se pe eyin aje gan ni e wipe ki n ma t'ele yi pe, ki eku bi adire opipi se n ku ti oun ti agada ese re mejeji. Enikeni ti o ba so wipe ki n ma te ile yi pe, ona odi, ona odi ni ki won ma gba lo s'orun. Eye s'eye, o fi apa se eye. Eye s'eye, o fi ese se eye. Eye fo omo owu alagbede pomu. Eye wo(enter) ile Alara, o pa omo Alara. Eye wo ile Ajero, o pa omo Ajero. Eye wo ile Orangun ile Ila, o pa omo Orangun ile Ila. Won ni nibo ni ile awon babalawo to gbo'ju kun si? Won wa k'ori (face) si ile olori Ajangbo-wewe tii se awo ile Alara, eye pa! Bobo-l'aguntan-wo ti se awo ile Ajero, eye pa! Won wa k'ori si ile Aforikori-oke tii se awo Orangun ile Ila, o yan kete, eye pa! Won wa f'abo si ile Orunmila, won ni awon wa wo(pull down) ile re, awon wa pa omo re, awon wa pa aya re, awon wa pa molebi re. Orunmila ni eewo! Orunmila ni oun yoo so oruko yin fun yin nisisiyi. Won ni iro ni, won ni ko si eniti o mo oruko awon laye mo. Orunmila ni sebi Atidisoro l'oruko iya(mother) yin je. Sebi Atedojokan l'oruko ti baba yin je. Sebi Owale-karakara l'oruko ti eyin gan paapa n je. Won ni o di oro imule, won ni ki Orunmila o ke si Otutu-opon, ko kesi Sefunsefun, ki o wa pe Osa meji dani. Won ni ki Orunmila fise Igbin meji yii je. Won ni gbogbo eniti o ba je obe yi ti di eni owo. Won ni ti erin(elephant) ba je oko titi, a fi ewe aluki si le. Bi efon naa ba je oko titi, i fi aluki s'oto ni. Aje kan kii gboju-gboju ko ba sori igi ajeobale, gbogbo ara ni sefunsefun fi sefun aje, ki ile mi o kun fun aje(wealth), ki awon eleye fi owo t'emi wo mi. Oun kohun ti mo ba ti pe ni ko ma je mi.
CultureRe: .. by dominicson: 9:38pm On Mar 18, 2016
Twenty candidates, out of more than two hundred applicants, were sent message to come for interview in a multinational company. These twenty were those who, apart from their academic qualifications, pray and use 'ise aanu/awure'. Only fifteen however could make it there; those that use 'ebe and eyonu' together with their 'awure'. Three of them didn't receive the message sent to them, while two candidates got the message but couldn't make it to the venue for some reasons. Eventually, four of them secured the job after the interview; those that use 'imule'.

Imule 1: Orangun meji

Eku asin meji, oga meji, iwerenjeje igba, eso ido igba, ati igba omo atare. A o jo, a o te ebu yii ni Orangun meji, a o pe gbolohun re si, a o ma fi epo pupa la sun lale.

Psalm/ofo re:

Mo k'eko (learn) k'eko kin to mo ifa da. Mo s'aalo s'aalo kin to mo ibo di. Aalo ni mo se ti mo fi k'eru (load) mi jade kuro n'ile Olofin. Titoro n toro, titoro n toro. O di Oluyonran n yonran. Eyi ona, ona. Eyin ona, afobo s'ona. Eyin ona afobo s'eje. A difa fun Olugbese Ogege, nibi ti won ti n d'ajo esusu, esusu ti won da ni omo won fin nku. Won pa Alara, won pa Ajero, won ni Orangun meji, kini oun kan o. Orangun meji ni nkankan ko kan oun. Emi naa ni aburu aye kankan ko le kan mi. Won ni tori kini o se kan o? O ni ije ti a nje eran gbogbo lenu enikan ki je eku asin be. O ni ije ti a nje eran gbogbo lenu enikan ki je eran oga be. O ni ije ti a nje ohun gbogbo lenu enikan ki je iwerenjeje be. Bee a ki je eso ido bi a ti nje gbogbo eso. Won ni baba, ofo le n pa yii? O ni kii se ofo, o ni oso ile, imule mi le e se, aje ile, imule mi le e se. E ti di imule mi loni. Tori wipe akii bani mule ki a da ise eni ru, akii ba ni mule ki a pon ni loju, a kii bani mule ki a ma le dani l'ola. Eyin eye dudu kekeke ori agbon won yi, se bi eye ile wa le e se, e mu gbogbo aburu kuro lona emi Lagbaja omo Tamado, e wa dami lola, ki e fi adun aye gbogbo fun mi.
CultureRe: .. by dominicson: 2:53pm On Mar 17, 2016
Ogbeguda
Bibinu oba ki i dara
Ija agba meji ko san
Won ni ki enikan ko mu suuru bi okan ba mbinu
A difa fun Osan, a bu fun Oru ti won ni ki won o rubo ki won ma ri ara won fin
Ela boru, Ela boye, Ela bosise!
CultureRe: .. by dominicson: 9:49am On Mar 16, 2016
Ifankaleluya:
@zenlife

With a gaiety,I salute your courage. I think you challenged him(healthfirst) on this thread,but,why he opted to responded on general section?

I'l like him to come out here & named those he reffered as ''semi-iliterate, do-no-good,& ill-will chartalans'' that he stated to quoted your post.

Before,I see him as a chamelon that do change as its surrounding changes,but,now I can finally resolved that he is jst a gadfly.

Let him go ahead to execute his intent. I'l not fold my hands & watch him abusing ifa-verses,& hide under the false pretence that he is ifa-priest to dupe users of this thread.
Ifa, in Iwori meji says:

A pa ewure tan, a yan egungun re lodi

Beeni ninu eran ni egungun n gbe

Won pa esin(horse), won fi esin je, a si yan egungun re lodi...

Ehin/eyin erin l'ola, awo ara re ko n'iyi

Iwo efon ni ola, eran ara re kii n'iyi

A difa fun kiniun, a bu fun ekun, ti oku won yi o d'oku oba

Ekun ru eku ago, kiniun ru eku afe

Nje a kii fi ago b'ori, a kii f'afe b'orisa

Ko si eniti n wipe eran ekun ni ifa oun gba: eewo orisa, a kii fi kiniun b'orisa

Ela boru, Ela boye, Ela bosise!

I think it's time we resolved this issue behind the scene. Or have we anything to gain disparaging ourselves in the eyes of toddlers/neophytes in mysticism? Ete awo, our elders would say, erin ogberi. But ogbo(do-do)/ogberi too should note, before they sneer, as Ifa rightly pointed out in Iworidi, "Iwori wodu, a difa fun ofidan ti ko gba, ti ko te, ti n lo f'oju wo odu, ti oju re yoo fo..."

If we are not very careful, we may end up destroying people whose lives we intend to build by writing/saying things they are not supposed to hear.

So, Ifakunle and HealthFirst, I won't ask you to eat 'Ebure', lest you tell me that ebure is 'eran ohun' but mo fi Orunmila, Olofin ati Onile-Ogboduora be yin, let's talk this out as initiates.
CultureRe: .. by dominicson: 2:34pm On Mar 13, 2016
Ifankaleluya:
O kare jare....iwo nikan loro mi ye.
Ori a gbo, Ori a to ooo.
Ogbo Edan
Ogbo Akokoniko
Ogbo Alawori!
CultureRe: .. by dominicson: 12:19pm On Mar 13, 2016
Ifankaleluya:
Ifa ni,

Eni a ba ba wa ode la ba rele

Eni aja ba wa ni aja ma n ba lo

A difa fun orunmila

Ifa ni ohun o koju si akapo

Ifa koju si mi wo mi ire

Eji-koko iwori.

Eledumare yio koju rere si wa.

Ase-orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmonle yio gba,ase-orisa lenu mi.

Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise.
Ope (do do) te ju mo mi, ko wo mi re

Ela te ju mo mi, ko wo mi re

Ori te ju mo mi, ko wo mi re

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aje

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aya

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni di ogbo

Ope te ju mo mi, ki o wo mi re...

Ela boru, Ela boye, Ela bosise!
CultureRe: .. by dominicson: 1:56pm On Mar 12, 2016
skypeme:
Dominicson se o fe ran mi lowo ni?
Emi ke? Emi aayan lasan! Only God/Light/Knowledge can help you.

You can whatsapp me nonetheless: 08145802864 or 08121751389

1 2 3 4 5 6 7 (of 7 pages)