Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,383 members, 7,815,812 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 06:47 PM

Dominicson's Posts

Nairaland Forum / Dominicson's Profile / Dominicson's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (of 7 pages)

Culture / Re: .. by dominicson: 8:07am On May 01, 2022
yunqdady:

Hmm, do these things have repercussions?





It has no repercussion.

Most things we think have repercussions do not. Most times, they coincide with faults in our stars, so to say. Our numbers, our destinies and our everyday actions and steps definitely produce results accordingly.

I've learnt long ago not to say or write whatever may bring negative or harmful consequences. About three decades ago, four youngsters, including the present writer, went to a centenarian mystic. And while the man was teaching us what we went there to inquire about delved into some deeper mysteries. He freely opened his mental archive for us. But how could he have known we would 'test' every new mystery we learn immediately, even those we didn't need at that time. And just one hour after we left his house the man was in our family house looking for us. Everyone was looking for us not because the man was an old man but because they knew the man didn't just go out if it wasn't very important. He told them they should look for us by all means that we were preparing something at that moment, and that if we finish it we would want to put it into test, and that could be fatal.

Ours is a machine time!


Whatever I post, especially in a public space like this, is safe.

Like last time someone asked for a recipe for HBP. I only mentioned mistletoe and water leave. These are the safest. They cure both hypertension and hypotension. No need for a physician to guide you. There are herbs that can control HBP and hypertension in a few seconds though.


And for anything, spiritual, you might have used in the past that you are afraid may have repercussions, fret not! Get a handful of peperomia pelucida/ewe rinrin and 16 black pepper, grind and use to cook two snails with a pinch of salt and a little palm oil. Do not wash the snail with alum.

Peace profound!

4 Likes

Culture / Re: .. by dominicson: 10:20pm On Feb 16, 2022
DadaLord:
I need your phone number please

08145802864
Culture / Re: .. by dominicson: 8:36pm On Oct 30, 2021
sharpwriter:


O ga o


Any side effects?


No. No side effects.
What's more, it increases your vibration.

2 Likes

Politics / Re: Oredegbe Worldwide Association Empower Women With 150k In Ondo State (Photos) by dominicson: 11:38pm On Feb 21, 2021
Great one at Oba ile

1 Like

Culture / Re: .. by dominicson: 3:27pm On Jun 01, 2020
It freezes my blood anytime I see oshole or ise owo that can bring a fixed amount like 50k, or awure 9k or oshole 200k, or oso gbe wa 5m. I would think what kind of charm or oshole would now fetch me 100m. Yes, 100m. And yes too, for those that would say 'just 100m'. Why 100m? The first day of this year I had a very strong feeling someone is going to bless me with that amount before the last day of this year. This, I'm very sure those scam babalawo won't have ise to bring such amount. I know. I have that conviction. There's nothing like oshole 50k, osole 1m. I'm not saying such ise won't work, but telling me it brings a particular fixed amount for everyone who uses it is what I won't concur with. I was born into this. Parents and grandparents are into mysticism. African science! None of these forebare ever mention such. There was a particular incidence that involved this present writer that uphold my belief in this. It even changed the minds of those who believed such. In the midst of initiates, n old man was encouraging us to prepare a particular charm that would fetch 100k that very day which nothing would stop it. Everyone was preparing his own, so was I. I joined the train for just one reason: I participated because I remember an incidence that happened one day with my late father. We visited a close friend of his, an awo. Met him eating, offered us water to wash our hand, meaning we should join him. I was surprised my father collected the water, signifying his intention to eat. While would my father want to eat when we barely finished eating pounded yam and bush meat before we came. I was more surprised because my father was a meat eater. I and my other siblings did bet on number of morsels he would swallow during a meal. Some would bet on 2 and some on 3. No one ever bet on 4 or more. There was even a day none of us won, he swallowed just a morsel, but plenty meats. Now the food the man offered had just two meats. Father extended the water to me, and made face before I could protest. I was literally playing with the food, while father swallowed 4 morsels in the course of the meal. None of my siblings and cousins believed me that papa could swallow 4 morsels when later I told them.

He later told me he forced himself to eat it because some other time you may need the food badly and once they see you as classy people now, you may not be invited. It's not only food. You may need something desperately from them...

So, I used the said oshole that could fetch 100k. It was during those period I do use imule like my life depended on it. Barely 5 minutes after, a young man called me, he introduced himself, his name and his friend who gave him my contact. I said jokingly, "omo mi daada ni" meaning his friend (who linked us) is my good son. He said "yes, that's the very reason I am calling. I also want to be one of your good sons. Please, store my number, so I can call you anytime. And please send me the other number... I mean your account number, I want to give you something to buy recharge card."

And in less than 2 minutes, a seven figure amount strolled in as recharge card money.


There are several factors that determine how much a particular work will fetch...


These works/charms/oshole are like seeds. Where a seed is planted determine the harvest. A seed planted in well prepared fertile land will definitely surpass those planted in desert, or amongst thorns, in yield.

Kannakanna Kan, kowe Kan, eyin ororo oojo Kan, atare Kan, ewe afeloru, if burnt and used once, everything, the same day, with gin, will definitely bring whoever uses it money. No doubt. But I will never tell you it can bring 10m because it has once done for someone, because it has also returned just the capital invested for another person.

2 Likes 1 Share

Health / Re: For Men With Small Diick: Cry No! There Is Solution by dominicson: 9:30pm On Apr 25, 2020
Oluwaseyifunmi07:





Good day sir!
I saw your comment on nairaland post,although the post has been posted a long while,pls how can you help me on issue of small penis.I am really depressed by this.pls reply as soon as you get this message.





let's discuss it on WhatsApp, brother.
08145802864
regards
Health / Re: Sister Has Fibroid But Afraid Of Surgery, Help With Alternative Solutions by dominicson: 8:42pm On Jun 11, 2019
9ja4eva:


Please stop deceiving the young lady- SURGERY is the only way to go for fibroid removal. Natural medicine/diet can be used for prevention after surgery.





... natural medicine for prevention after surgery, you say! lol. can't another surgery take care of that too. yeyenatu!
Health / Re: Sister Has Fibroid But Afraid Of Surgery, Help With Alternative Solutions by dominicson: 5:48pm On Jun 11, 2019
9ja4eva:


Please stop spreading "fake news".


Be inclined! I am a member of NCPNM, Nigerian Council of Physicians of Natural Medicine. And I can boast of well over one thousand members(professors/'eggheads') in the council who can treat ANY fibroids with natural medicine(homeopathy, herbal medicine, etc), even free of charge for your kinds!
Health / Re: Sister Has Fibroid But Afraid Of Surgery, Help With Alternative Solutions by dominicson: 3:02pm On Jun 11, 2019
There are herbal and African traditional ways of getting rid of fibroids, perfectly. It's high time we stopped believing anything we don't know don't exist! We had known fibroids before 'they' came.
Culture / Re: .. by dominicson: 11:17pm On May 17, 2019
Ire2:


Hello please can you drop your whatsapp nunber let's talk privately?



08145802864

1 Like

Romance / Re: 'I Can't Date A One Minutes Man' - Nigerian Lady by dominicson: 2:10pm On Jan 23, 2019
ybalogs:
be like that weak erection nah the trend ooo. Any viable solution?


herbs
Culture / Re: .. by dominicson: 12:07am On Jul 17, 2018
dominicson:
Indications: diabetes, typhoid, general infections, Hormonal imbalance, mensural disorders.


contact: 08145802864, 08072331475

Culture / Re: .. by dominicson: 12:05am On Jul 17, 2018
Indications: diabetes, typhoid, general infections, Hormonal imbalance, mensural disorders.


contact: 08145802864, 08072331475

Education / Re: Creative Writers’ Association Of Nigeria (CWAN) New National Executive by dominicson: 5:17pm On Apr 15, 2018
Great men! Congrats

1 Like

Romance / Re: Pre-Wedding Photo Of Physically Challenged Couple by dominicson: 9:50pm On Feb 05, 2018
pyyxxaro:
Wow
Congrats to them

The disable is able




...are
Culture / Re: .. by dominicson: 10:30am On Dec 06, 2017
fredo360:
ekun deede asiko yi o oruko mi no Taye eejo kini eniyan le lo ti nkan omokunrin ba kere ju ojo orie lo. ejowo mo fe kii edami lohun ki oju maba timi oooh




check here, o daju bi iku!

1 Like 2 Shares

Romance / Re: I Am Impotent & Frustrated by dominicson: 11:34am On Mar 19, 2017
idakole, simply. not impotence, not an attack. nothing! herbs cure!
Culture / Re: .. by dominicson: 10:25pm On Nov 05, 2016
Asegbe Odi-meji

Ogun-Lakaye nii se ibi, ti je ibi, tii sanra yo bamubamu. Esu odara nii se odi, nii je odi, ti sanra yo borokoto. Orumila baba Agbonmeregun nii s'oju eleru k'eru, ni eleru tun ki pe baba e seun ana, ti tun ba won gbe ile aye, ti won ko si ri fi se nkankan. Ologbo-finni, Ologbo-finni, Ologbo-finni sa to Eledumare lo. O ni oun ki Ogun-Lakaye, Ogun ko da oun l'ohun. Oun ki Esu-odara, Esu gbo ko dahun. Oun Ki Orunmila baba Agbonmeregun, Orunmila naa ko, ko da oun l'ohun. Eledumare ni ki o lo ba Ogun, ki o bi Ogun leere wipe bawo ni se n se ibi, ti nje ibi, ti n sanra yo bamubamu ti won ko si fi bi. Ki o lo bi Esu-odara naa leere wipe bawo ni se n se odi, ti n je odi, ti n sanra yo borokoto, bee ti omo araye ko ri fi se nkankan. Ki o tun bi Orunmila baba Agbonmeregun bi o se n se, ti o fi n ko eru l'oju eleru, ti eleru tun nki pe o seun ana, ti tun ba won gbe ile aye, sibe, won ko ri fi se nkankan. Emi Lagbaja omo Lagbaja naa sa to Eledumare wa loni o, mo ti se ibi, mo ti je ibi, mo ti yo bamubamu, Eledumare ma je ki omo araye fi ibi bi mi o. Mo ti se odi, mo ti je odi, mo ti yo borokoto, Eledumare, ma je ki omo araye fi odi ti mo je bi mi o. Mo ti ko eru eleru ni isoju eleru, eleru si ti dami mo, sugbon ma je ki won fi bi mi o, kaka ti won i ba fi bimi, ki won tun ma kimi ni mesan-mewa ni o, ki n ma ba won gbe ile aye yi ki won ma le fi ibi kankan se mi. Odi-meji, Odi-meji, Odi-meji wa lo bami di gbogbo awon ota mi lenu o. Ota mi okunrin, ota mi obinrin, oso, aje, emere, ajinnilese, abbl.

3 Likes

Culture / Re: .. by dominicson: 8:54pm On Oct 22, 2016
Lero70:

Modupe pupo lowooyin, aamaariiyinba aso teefi npidan konii faya lagbara Onnile.
Ejowo email yin nko? Efunmi ni ohun naa. Eseepupo.

benige4@gmail.com
Culture / Re: .. by dominicson: 8:06pm On Oct 22, 2016
Lero70:


Ekuise o, Eledumare yio maatiyinleyin, eosiniisaseti lagbara Ogaogo.
Edakun efunmi ni email ati phone number yin, nitori eyin agba naa lesope gbogbo aso ko ni a nsa loorun. Eseepupo. Email temi niyi tailadoriginal@gmail.com

08145802864
Culture / Re: .. by dominicson: 9:12pm On Oct 17, 2016
Lero70:


Baba mi agbalagba, eseun pupo mo mooloore, Eledumare koniije kee wale (come down) laelae, iwaju iwaju leemaalo, omoaraye onii fowo ibaje kan okankan ninu awon eeso yin, ibanuje kere otobi koniikanyin. Esee modupe gan ni,
edakun Baba moni ibeere bii meji nipa ise tiefunmi yen ni,
ekinni, se aha taafi nmemu tabi foko-tutu ni tabi iha taafi ndana?
Ekeji, se ewe ni damonito ni tabi egbo atipe oruko miran wo lotun nje?
Eseepupo unomaa retiresi lati odo yin. Eseepupo yio maa juse o. Ase.



Iha(re mi) ti a fi n da'na(da ina).

Ewe ni Damonito(mi re mi mi). Damonito naa ni sawerepepe.

1 Like

Culture / Re: .. by dominicson: 12:07am On Oct 14, 2016
Lero70:

moki gbogbo eyin agbalagba ti Eledumare jogun ogbon fun ni abala yi, lagbara Eledua ogbon na konii dope, kosiniitan nibiti eti nmuu.
Ejowo mose akiyesi pe eyin agba wonyi kofibee kobiara si abala yi mo, ISESE LAGBA GROUP lorii whatsapp ti boo mole patapata, mosifekeemope awa ti a nje anfaani abala yi, sugbon ti phone wa kogba whatsapp application sipo gan, nitorinaa ejowo ebawa fun abala yi ni ijelogun bii tateyinwa. Yio maa juu yin se o ase.


O seun gan. Adura re yoo gba. Oju ko ni tie. Omo araye ko ni binu re. O o ni te oju ile mo'le. O o ni si oko ja je. Porogodo aye ko ni lu fun o jo. O wi're! Agbekale oro re fi han pe omoluhabi ni o. Oo ni je ibaje nigba kookan.

Ba mi fi omi lo kekere yi:



House arrest

Iha, damonito, koleorogba, ose dudu, a o gun papo, ita gbangba nibiti elomiran ko le ti we ni a ti ma n we. Ko si igba ti a ko le we.


Psalm:
Damonito kan kii fi ito tie dola, warawara ni koleorogba n s'oje, gbogbo eniti ba n p'ori mi nibi, oso ni, aje ni, emere ni, kenimani, babalawo, pastor, ala-laafa,abbl, Iha lo ba mi ha won mole ki won ma le jade mo. Ki won ma a gbe yara pe omo alakara.

1 Like

Culture / Re: .. by dominicson: 11:56pm On Oct 13, 2016
Nostradamus:
edakun gbogbo ile mo ni ibeere ranpe kan,ti won salaye pe ki a gun ogun kan mo ose dudu,shey a le ko ose ati ogun na si ori olo(grinding stone)ki a lo papo?mo fe se ose ebe awon agba kan ni sugbon mi o ri aye si odo but olo wa niwaju mi bayi.


A ma n lo olo. Asi tun ma n lo odo. Nigba miran ohun ti a ba fe gun le kere ti o je wipe ti a ba lo odo, odo yoo ko je. Fun idi eyi, a ma lo olo. Nigba miran ewe, ohun ti a ba fe gun le po ju olo lo ti o je wipe odo la ma lo. Sugbon o, awon ise kan wa ti o je wipe o ma n pan dandan ki a lo ohun ti won ba ni ki a lo lati fi gun, boya odo tabi olo.

Ohun ti o tun da bi re ni wipe, a koko ma n gun eroja kunna ki a to da ose abuwe si, ki a to wa gun papo. Ohun ti o fa sababi eleyi ni wipe ki o le ba rorun lati gun papo. Isese a gbe wa o!

1 Like

Culture / Re: .. by dominicson: 5:01pm On Oct 01, 2016
Ola4ple:
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese I Mean D Meaning Of Iri



Dew
Culture / Re: .. by dominicson: 11:45am On Sep 30, 2016
elegushichilling:


our God Jehovah is alive, he is fighting for us and will continue to do same. Better give ur life to christ now, tomm may be too late. Iku lo'n keyin oungbo gbo. Kini yo je erere ti oba jere gbogbo aye yi, ti osi so emi renu. Ranti wipe aye loja, orun nile. Kilode toje wipe a'un gba owo iyebiye lowo ara wa, ki ato ran ira wa lowo pelu agbara, ipo ati oye wa. A'un tan ira waje wipe okan niwa, omo ile kaaro ojire. Sioo, Iwo ti oko, ti oko se ore, seranti wipe elomiran ni olorun yo lo lati se ore eyi ni ofe, ti oun olorun fe se. Iru eni na sini yoo gba iyi re fun ogo olorun ati imuse oro olorun. Olorun ki se eniyan ti yo fi puro, tabi omo eniyan ti yo fi yipada. Otiso, unje ko ni se, otiso oro, se koni muse. Fi igbagbo re le Oluwa eledumare, ki ogba laye, ki ose iyanu layere. Igbagbo lai si ise, oku ni. Ise pelu igbagbo, emi ni. Gba olorun laye ki odari re si ibi ti igbala re wa pelu ise igbagbo re ninu oruko Jesu. Emi, Ara Olodunmare.






K
Culture / Re: .. by dominicson: 10:59pm On Sep 28, 2016
olusegunakintol:


gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s
e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo


Join Isese L'agba!

1 Like

Culture / Re: .. by dominicson: 11:07pm On Aug 29, 2016
Atayese


Efun, osun, oori, oyin, aadun, eko tutu, ewe rinrin, tete abalaye, ewe abamoda, ewe orokojiya, ewe ogbo, ewe odundun, iyo. A o ko gbogbo awon nkan yii si inu igba nla, a o pe gbolohun re si, a o gbe sinu iri di ojo keji, leyin ti a ba lo gbe won ni ojo keji, a o gun gbogbo re papo pelu ose dudu. A o ko sinu igba olomori. A o da iyere-osun le ose ti a ko sinu igba naa lori. A o te ni eji-ogbe. A o tun wa pe gbolohun re si leekeji. A o ma fi we. Oyin ni a fi ma n po ose yii, kii se omi.





Psalm:


Efun ni tun ori Olugbon se, osun ni mu iwa osun toro. Awon ni won sa igede fun Orunmila nigbati oro re daru tan. Orunmila wa to Eledumare lo. Orunmila ko ejo o ro fun Eledumare. Eledumare ni ki Orunmila lo wa Esu wa. Orunmila de ile Esu, ko ba Esu. O de ile Lapara tii se baba Esu, ko ba Esu nibe. Orunmila lo si ile Gbaroje tii se eru Esu, o ba Esu nibe. Orunmila ba ko ejo o ro fun Esu wipe oro aye oun ti daru, beeni ko si dogba mo. Esu fun Orunmila ni esi wipe: iwo ko rubo ni koje ki oro re dogba, ohun ni oro aye re ko se toro. Esu ni ki Orunmila lo wa Aadun, Osun, Efun, Oyin, Iyo, Eko-tutu, Ewe rinrin, Ewe abamoda, Ewe tete abalaye, Ewe orokojiya, Ewe ogbo, Ewe odundun, Oori. Orunmila ni ki Esu wa ba oun lo si odo Eledumare. Nigbati Esu de odo Eledumare. Esu ni mo de, Oba Alamonmotan, Oba amatiwaiye ojo, Oba amogbeyin oro, Oba ti o n tun ori eniti ko sun won se si daradara. Eledumare bi Esu lere wipe: kilode iwo Esu? Esu ni Orunmila lo wa ba oun wipe oro oun daru tan patapata, beeni oun ko ri ojutu re mo, gbogbo ohun ti oun se koje oun mo, bi oun se ogun ko je mo, oun kori owo, oun kori iyawo fe, oun ko ri omo bi, oun kori ohunrere kan gbese. Eledumare wa bere lowo Esu wipe: se iwo ko gba nkankan ni owo orunmila ni? Esu ni mo gba nkan ni owo re. Esu ni mo gba Aadun lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ma dun ni. Esu ni mo gba Eko-tutu lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ro, ko ni le fun mi laye. Esu ni mo gba Iyo lowo re. Eledumare ni aye mi yoo layo kale ni. Esu ni mo gba oyin lowo re. Eledumare ni aye mi yoo dun ni, ko ni koro, ko ni kan fun mi laelae. Esu ni mo gba Odundun lowo re. Eledumare ni laye mi ohun buruku ko ni dun ni ile mi. Esu mi mo gba Tete-abalaye lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma te mi lowo. Esu mi mo gba Rinrin lowo re, Eledumare ni ile mi yoo ma tutu ni rinrin, ko ni gbona. Esu ni mo gba Abamoda lowo re. Eledumare ni gbogbo aba ti mo ba da ni araye yoo ma gba, ohun(voice) mi ni won yoo si ma fe gbo. Esu ni mo gba Orokojiya lowo re. Eledumare ni emi Lagbaja omo Lagbaja ko ni jiya mo laelae. Esu ni mo gba Ogbo lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma gbo temi. Esu ni mo gba Efun lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma fun mi ni ire temi. Esu ni mo gba Oori lowo re. Eledumare ni gbogbo omo araye ni won yoo ma ri mi yonu si. Esu ni mo gba Osun lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma sun mi bo. Ebo naa ni emi Lagbaja omo Lagbaja gbe wa yio. Ki ara o de mi fun ire gbogbo, ki nri na, kin ri lo, kin rije, ki n ri mu (Adua)

4 Likes 1 Share

Health / Re: Help!!! My Husband Is A One Minute Man, I Am Frustrated! by dominicson: 7:30am On Aug 24, 2016
I can be of help.
Culture / Re: .. by dominicson: 10:42am On Aug 11, 2016
Arobi/Aseta/hunt-the-hunters

Ori aparo mokanla, orogbo mokanla, obi ipa oloju-merin mokanla, obi ifin olojumerin mokanla. Atare mokanla. A o jo papo. A o te ejiogbe si. A o ro sinu seere. Ko gbodo kan'le mo. A o ma fi fo eko tutu mu, a si tun le fi omi tutu lo.


Psalm:
Egun ni ti Onimulu, 3ce. Igede ni ti Ikamesan, 3ce. Ekaebiti lo ni ase lenu. Oro-meji, iwo lo lo difa fun won lode-orun. Nigbati won gbe ifa de ile aye tan, won wa fe fi ba ti Oro-meji je. Won ni Oro-meji ko mo o se mo o. Oro-meji ni ti o ba se bi ise temi ni won ba n wi, o ni egun Onimulu nii pa Onimulu, igede enu Ikamesan nii se iku pa Ikamesan, ase ti n be lenu Ekaebiti naa ni se iku pa Ekaebiti. Gbogbo eniti nba pe ori mi nibi, iwo(do mi) ni ki o lo re wo ile oluwa re. Gbogbo otakota, enikeni, eyankeyan, adahunse, onisegun, oso, aje, ni n ro ibi ro mi, iwo ni ki o lo re wo ile oluwa re. Obi ni ki won fi bi oran si oluwa re lorun. Orogbo ni ki won fi gbo oju oluwa re mo le. Atare ni ki won fi ta oluwa re latapa. Ota po lorun mi yeeye. Egbesi oko, ee si ba mi s'ikan kuro lorun mi; e s'ikan kuro lorun mi. Igbo onigbo ni aparo nku si o. Gbogbo eyin ota mi ni ki e ku iku oro, iku aimodi, iku esin. Oro ti e o mowo, ti e o mese ni ki won o pa yin le lori. Ki n segun ota, ki n reyin odi.

4 Likes

Culture / Re: .. by dominicson: 3:53pm On Aug 06, 2016
jentusoul:
Hmmmnn eku ise @baba domonicson. Olodumare yoo ma bukun yin o ase. Ejowo bawo ni a se ma te odu owonrinmiki



Oworinmiki/owonrinirete/oworin-irete


Two-two-one-one at the first side, and one-one-two-one at the second side. But remember, odu ifa, just like arabic, starts from the right side.


So, two-two-one-one is at the right side, the first ese. And then one-one-two-one at the left side. Ese kan owonrin and ese kan irete is Owonrinmiki or Owonrinnirete.

Regards.

2 Likes

Culture / Re: .. by dominicson: 8:48am On Aug 03, 2016
Imule-Ebe-Eyonu(Owonrinmiki)


Ako Okete aye kan, eepo erun(eepo obo), imi ojo, odidi atare meta, a o jo, a o te ni odu oworinmiki, a o ro itan/ifa/psalm re si, a o ma fi ahon la ninu awo taasa lale ki a to sun ni ihoho pelu epo pupa.


Itan/psalm/Ofo

Orunmila lo ji ni owuro yii, lo gba ojude awon aje lo. Nigbati o de be, o joko, o da ifa owonrinmiki nitori awon alaboyun ti won de mole lori ikunle ti won kole bi omo, tori ki won o le bi omo. O tun da ifa owonrinmiki nitori agan ti won ko loyun, ki won o le ti owo ala bo osun, ki won o ba le di olomo laye. Orunmila tun da ifa owonrinmiki nitori awon okunrin iduro ti won n rin kiri ti won ko gbadun ara won, ki won o le gbadun ara won. Orunmila tun da ifa oworinmiki nitori okunrin idubule, ti won kole sun, ti won ko le wo, ti won ko le je, ti won ko le mu, ki won ki o le rije-rimu. Orunmila tun da ifa owonrinmiki nitori awon alaseiri, ti won n fi osan(noon) won n sise, ti won n fi oru(night) won n sise, ti won ko ni akojo. Nibe ni awon iyami aje ba n bi Orunmila, won ni iwo orunmila, se o mo wipe agan ti ko ni oyun, se o mo wipe ounje wa ni? Orunmila ni oun mo, a ma oun wa sipe fun won ni. Se iwo ko mo wipe alaboyun ti o de ori ikunle ti ko le bi mo, se o mo pe ounje wa ni? Orunmila ni wipe oun mo, a ma mo wa sipe fun won ni. Se iwo ko mo wipe awon okunrin iduro ti won n rin kiri, ti won ko gbadun aye won, se iwo ko mo wipe ounje wa ni won ni? Orunmila ni wipe oun mo, a ma mo wa sipe fun won ni. Se iwo o mo wipe okunrin idubule ti won ko le sun, ti won ko le wo, ti won ko le je, ti won ko si le mu, se iwo ko mo wipe ounje wa ni gbogbo won ni? Orunmila ni wipe oun mo, a ma mo wa sipe fun won ni. Se iwo ko mo wipe awon alaseiri ti won fi osan won sise, ti won n fi oru won sise, ti won ko ri je, ti won ko ri mu, ti won ko ri na, ti won ko ri lo, bee won ko ni akojo, se iwo ko mo wipe ounje wa ni? Orunmila ni wipe oun mo, a ma mo wa sipe fun won ni. Awon iyami ni gbogbo ipe ti Orunmila ba ri ko se, awon ko ni gba ipe naa. Orunmila ni e ba ko ti e ko ba gba ipe, oun yoo p'itan fun yin nisinsinyi. Won ni gbogbo itan ti Orunmila ba mo ko ma pa. Orunmila ni se bi Olupowo ni yeye eyin aje, se bi eyin ni Owewelakasa, se bi eyin naa ni Arinhohojedun. Won ki orunmila dakun(please) ki o duro ni be yen. Orunmila ni ki e ranti adehun ti a jo se ni ijokinni ana, ki e ranti pe aje kii je imi ojo, won ni enikan ki i di ojo lowo koma yo. Se e ranti wipe aje kii roro ki o je eepo eerun. Oro ti okete ba ba ile so ni ile n gbo. Nibe ni awon iyami aje ni awon ti gbo, awon si ti gba. Won ni ti alaboyun ba lo ninu ogun yii, yoo bi tibi-tire. Agan ti o ba lo nibe yoo ti owo ala bo osun, yoo si bi ni alaafia. Okunrin iduro ti o ba lo nibe yoo ri iwosan. Okunrin idubule ti o ba lo nibe yoo ni alaafia. Alaaseiri ti o ba lo nibe, yoo ri se tosan-toru. Ona ire gbogbo yoo si ma a la fun lati odo gbogbo omo araye patapata. Ona ire gbogbo yoo ma la fun emi Lagbaja omo Lamorin naa lati odo gbogbo omo araye patapata. (A o se adura si).

2 Likes

Culture / Re: .. by dominicson: 3:17pm On Jul 29, 2016
As herbalists, our duty is to prepare medicine that are not only effective but also safe. Safety first. We shouldn't cure impotence/weak erection and acquire stroke in its place(in the process); we shouldn't say because we want power, ki a wa se ogun ti paagun yoo fi ma da wa laamu. Desire is not bad; surfeit is. We should be safety conscious. The fact that herb-A can cure malaria and herb-B too can cure it does not mean that the combination of the two herbs will cure malaria. There are certain combinations that go together, and there are those that don't 'meet'(they rather produce adverse effect, sooner or later). So we shouldn't stop learning and researching.

2 Likes

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (of 7 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 81
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.