Sammyjay76's Posts
Nairaland Forum › Sammyjay76's Profile › Sammyjay76's Posts
healthFirst:Iba agba o, a ma juse o. Eku ise lada, edumare a ma ran yin se o. E dakun ape obinrin to lo ti ko si ni odo eyan mo to daju ejowo fi sita fun mi. Eseun fun awon dahun wonyi ooooo. |
healthFirst:GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN APE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju. |
healthFirst:GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN AE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju. |
healthFirst:EJOWO FUN WA NI OGUN ARA DIDA SHAKA NINU EGUNGUN TABI KI O TETE MA RE ENIYAN NINU EGUNGUN KO MA LE DURO PE PATAKI FUN EGUNGUN. ESE |
[quote author=healthFirst post=35136583]ORISIRISI OOGUN Oogun funfun Oogun dudu Oogun pupa Kiyesi oogun toba romo eleda re.[/quote [color=#006600][/color] Ejowo se alaye dada nipa awon oogun ti e daruko naa, ki olukuluku le mo bo ti ye ka se si. Leekan si edakun efi oogun Sickle Cell miran ranse si bi fun anfaani awon to ni awon eniyan bee lowo to si gbagbo ninu ewe ati egbo, awa naa ni ona ewe ati egbo ti a n lo sugbon karin ka po yiyeni ye ni oooo. olorun a ma fun yin se o. |
healthFirst:EJOWO MO FE PE AKIYESI YIN SI NKANKAN LORI OGUN SCKLE CELL TI E SO NAA, ESO RERE. WADI MI FI HAN PE EWE RERE PE MEJI AKO WA ABO SII WA PELU. NJE EYI TI O SO BI EWA NI NJUWE RE NI ABI BAWO NI ESO NA TI RI? EJOWO TAN IMOLE SI DARADAR. IDI NIIWIPE, AWON EWE NA NI ORUKO ORISIRSI ATI BI WON TI NPE WON KAKLIRI ILE KARO O JIRE. ILE ANAGO TI BENIN REPUBLIC NI EMI WA SUGBON OMO BIBI ILE EGBA, ABEOKUTA, NIGERIA NI MO JE. PELUPELU, EJOWO FI OGUN SC MIRAN SITA FUN WA FUN IRANLOWO DIDEKUN AISAN NA ESEUN PUPO. |
healthFirst: |
kadunasouth: |
[quote author=kadunasouth post=34726734]ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun Iba akoda iba aseda iba agba merindinlogun lotu ife iba baba iba mama iba omode iba agbalagba iba okunrin iba obinrin efi oju rere womin o! Ase edumare Contact me 08028358926a@gmail.com[/quote |
healthFirst:GBOGBO ILE NI MO KI O..... EJOWO EFUN WA NI OOGUN TI RIRU EJE BA WA LE JU, TI A MO SI HYPOTENSION I DAKEJI HYPERTENSION.............................................................................................................................................. |
healthFirst:EDAHUN SI AGBEYEWO YII SE LEHIN TI ATI JO AGBADO AKOKO PELU ORUKO TI A KO SI PAPER TI A DI MO NI A O TUN DI ORUKO MIRAN MO EBU ATI ORUKO TI A O TUN KO NI? ABI A O TUN WA AGBADO MII? E DAKUN SE ALAYE KO LE YE WA DADA. ESEUN. |
healthFirst:EJOWO SE NIGBA TI A BA TI TI TANNATANNA NAA BO YIO WA NINU RE TI A O FI BU IBE JE NI ABI A O YO KI A TO BU OKANKAN I BE JE? |
healthFirst:E n le ni beyen, Bawo ni oro wa? Mi o tun ri esi oro email ti a so pati mo? Fun ti oogun SCD ti a so naa eso (RERE)ni ede yoruba se amin isale ti a npe ni d d ni abi amin oke ti a ne ni m m, abi amin arin ni? Nitoripe pipe re se pataki. Ejowo dahun oro asotele wa. Eseun. |
healthFirst:Eku ise o, olorun a ma ran yn lowo.... Amin Awon ona kan ni mo fe ki e fi kun awon eto ati ilana lati je ki forum yi (IWULO EWE ATI EGBO) ki o le ye awon eniyan daradara......... Bi awon ewe tabi egbo ti e n ko sita fun wa lati le je ko ye awon eniyan ati lati mo pipe re pelu fun anfaani ati ma se asise ninu awon oogun ti e n fi sita......... Akoko ni pe ti eba le ma se afiyan awon ewe wonyi tabi ti aba le da whatsapp group sile pelu tai le ma pe awon oruko ewe tabi egbo naa (as voice message on whatsapp) a je ki o ma si asise kankan asi tun ran gbogbo wa lowo lopolopo. Edakun gbogbo ile ki le ri si oro mi, eyin naa pelu egbe oro na ye wo daradara. Fun apeere.... Ewe rere na nnu oogun (sickle cell) opolopo ibi ni mo ti beere sugbon ti won ko le ri aridaju re bi ase pee. Oro mi ko lopin....... Eseun fun gbogbo akitiyan yin. |
healthFirst:Mo kiyin o, E dakun esi awon ibere mi ti e so wipe e t f ranse naa, mi o ri nnu email mi rara. E jowo bami fi ranse si email mi naa lekan si.....sajolive6@gmail.com E jowo eseun ooooo. MO TI WA RI NI ISINYI, KO DA O SE SE WOLE LOWO LAIE NI...... ESEUN GAN MA TUN FI ESI RANSE LAIE YI..... ESEUN GAN. |
healthFirst:Mo ti fi atejse kan ranse si yin lori email yin naa, e yewo ki e le ri...... Ngo ma reti idahun yn ni ekun rere. E pe fun wa ooooo. Amin. |
E ku ise o, edumare oba oke a ma fun yin se o.... Ejowo e fun wa ni ogun ti eniyan o ni le fi ko arun lara obinrin tabi okunrin, boya magun, eroo, ati awon arun miran. Ati oogun ti a fi n so ile eni tabi ayika wa di eewo fun emi buburu tabi awon nkan aransi. A ma jhu yin se ooooo...... Amin. |
healthFirst:ESEUN GAN O, AJINDE ARA YIO MA JE. O. LEKAN SI LORI OOGUN SICKLE CELL YI...... EJOWO BA MI SE ALAYE IYE IGBA TI A LE LO OOGUN NAA DA, ABI TITI LKO NI? EJEJI, ESO RERE TI E DARUKO NAA, E SE ALAYE DIDAMO DARADARA, SE RENRENni? ABiI RERE? EDAKUN TI OOGUN MIRAN TABI ONA MIRAN BAWO LATI DEERO AISAN YI PATAPATA E BA WA FI SITA. E O NI SUBU DANU O, EDA GBOGBO AWON ENIYAN TI WON RI OREOFE NIPA IWULO EWE ATI EGBO YI AFI IRE AJENJETAN FUN AYE YIN. ESEUN PUIPO. |
healthFirst:Eseun fun dahun yi....... Ejowo se dan dan ni o gbodo je. Pe eegun itan adie ni won yio ma fi mu ni? Se a o toju eegun adie naa ti a o ma fi mu ni igba de igba ni abi ekan soso naa nbi yio fi mu eko abi, ao ma pa adie ni gbogbo igba ti a ba fe fi oogun yi mu eko ni? E dakun e se alaye naa daradara fun wa. |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... |
wtech:DOES IT BROWSE-ABLE? HOW CAN IT IT BE RECHARGED? I WISH TO PATRONISE YOU IF IT'S EFFICIENT AS WITH THOSE OPERATIONS!!! |
Do not be dismayed there is no sickness without cure. Believe me, there are herbs capable of doing that, its just the combinations or preparations we dont know..... As for asthma i want to give you free of charge and i want those who are patients or have patients to come back here and testify.... Pls its important. Get a house rat that was killed without piosion , i mean the one you kill by normal means, by trap or by hiting it with stick or something, burn it completely till it become powder, get a pure honey and put the whole burnt powder in it and beginning to lick it morning afternoon andnight. Wiiithin a month or two you will be surprised. Its acure not prevention just that you have to do it to complete three stages. There is greater knowledge in herbs and there ancient secret of healing all those deadly alments....... For any diseasses or ailment contact me i will assist. |
unclesamtech:how? ok pls do this for me pls.......ALCATEL ONE TOUCH, OT908F IMEI-860126011167352 GOD BLESS. |
+22966088270..... |
PLS HELP ME WITH THE CODE TO UNLOCK THIS ONE TOUCH X090S X090S-2AM1BJ3 IMEI NO-355249043094907 PLS. |
PLS HELP ME WITH THE NCK CODE TO UNLOCK THIS ONE TOUCH X090S X090S-2AM1BJ3 IMEI NO-355249043094907 |