Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:57pm On Sep 03, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:52pm On Sep 03, 2009 |
IFELEKE: 'seeker,tope ki'in se omo kekere oo, ohun ni oko akoko ti toyin ni lori tireedi yi ki n to gba'a lowo e. . .atiwipe,oko risika omo iya olobi lo n ba soro. Ma da omo ana ti o fe maa w'enu si agba yen lohun jo  Ojo ti o ba fi owo kan toyin lasan, mo maa ko ni eko manigbagbe  Mo maa ni ki o ma sika kiri ni  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:08pm On Sep 03, 2009 |
TheSeeker: Oti pe ti mo ti mo wipe omode to ti baje patapata ni e. Mi o lu kude ri. . . . sugbon mo ma n se apprentice l'odo baba kan ti o mo nipa egbo igi. Looto  E jowo booda agbaya, bawo ni a se le sa awon egbogi ti o ma wo arun kude, nitoripe kamoteesi ti takiti akoko  e tete so fun wa ki o to takiti meji ti o ku  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:45pm On Sep 03, 2009 |
TheSeeker: Awon wo ni won tun so wipe won ti lu kude? Chamotesiii abi Camoranessi l'on je!!!! Eero magun wa oooo ti o ba fe. Se magun a'lakuko ni abi o'lomi? booda sika, se eyin ti lu kude ri ni  bawo ni e se mo ero e  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:36pm On Sep 03, 2009 |
IFELEKE:
 ogbeni jewo! abi o ti lu kude ni? Kamoteesi ti o ti fi oko ko jongbo  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:07pm On Sep 03, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:06pm On Sep 03, 2009 |
chamotex: Eyin Arakunrin ori ile yi, erora ma do obo o, obo l'ewu o. Ikilo pataki lati enu Chamo okunrin meta niyi o. Kamoteesi, se o fe gba ibi ti o gba wa lo ni  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:42am On Sep 03, 2009 |
tubabie: A t'em tika, ayun re so mi gidi Se alafia lo wa? tu, awe gbon ore mi re o ko ba mo fe ri oju pupon mi  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:40am On Sep 03, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:37am On Sep 03, 2009 |
IFELEKE: awe wo tun ti bere abi? mi kuo ja ho lapon ke'e yo kuo gbo'omi ula kana. . .gbon ya mi ku o wele risika lujare! hw u dey? hw work? will holla you wen e buddy allows me se aya ria lomode un. aya kete ria ni awe  jemi tika t'oju re  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:42am On Sep 03, 2009 |
|
Romance › Re: Your First Toasting And How It Went by topsy25(m): 1:32pm On Sep 02, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:58am On Sep 02, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:17am On Sep 02, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:12am On Sep 02, 2009 |
IFELEKE: Ki lo n sele ninu ile yi ? Bee la nbini o ore mi ifelepon ifeleke, omo kekere kan ti won npe ni sika lo fe maa wenu simi nitoripe mo ba wi pe o gbe iyawo wa toyin pamo  Kini seria ti a l da fun naa  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:22am On Sep 02, 2009 |
TheSeeker: Abi o tin mu igbo ni? Awon iya mi ni o da'ruko yen. . . ki lo ma n se iwo baby yi no? Bibeli ati kurani ni: bowo fun awon agba ki ojo ori re le pe ni ori ile aye  Se emi ni o nsoro kunba kungbe si beyen  O ji iyawo temi gbe, mi o soro, o tun nwenu simi  Se o fe to mi sa  Abi o fe ki nfi oju re ri nkan ti oju Bayo ajomogbe ri ni Ka sora o  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:40am On Sep 02, 2009 |
FL Gators: Oti e ti pe ti oju mi ti ri tiredi yi moh.
eekale o, gbogbo yin
Bro dayo, ni bo le ko si? otojo meta o Bawo ni iyawo temi nikan  Won ni bobo kan ti won npe ni sika (abi seeking tie ni  ), lo gbe a salo; se ooto ni  Jowo so fun mi ki nba le ran awon iyami osoronga, atapa jori, atedo jokan si, ki won le se bi ose se nse oju  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:33am On Sep 02, 2009 |
dayo, bawo ni kinni e  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 3:59pm On Sep 01, 2009 |
Remii: E wo ni tie ni didun ninu wipe enikan nfun awon ti o fe l'oyan, sebi eleyin loni eyin to 'mu re ile apon. E ma binu sir. Abi eyin naa fe mu oyan ni  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:49am On Sep 01, 2009 |
E nle nbeun o eyin eeyan mi. Se daadaa le wa  |
Romance › Re: Kó Gbè ómó Wàà, ó Dé Gbè ómó Ló . by topsy25(m): 8:43am On Sep 01, 2009 |
|
Romance › Re: Kó Gbè ómó Wàà, ó Dé Gbè ómó Ló . by topsy25(m): 12:56pm On Aug 31, 2009 |
nike4luv: generalizing, not all girls love owo. the main thing with most down to earth girls [like moi] is dat the man must have vision and aspirations and should be trying to work towards them. thats what attracts me to a man. not money, financial status is unpredictable nike, se wa fe mi nitoripe mo ni aspirations and visions to po gan  Although mi o tii ni owo lowo o  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:49pm On Aug 31, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:46pm On Aug 31, 2009 |
IFELEKE: Orisirisi ma lo n sele lori tireedi yi lenu ojo meta yi oo! leyin igba ti a ti fi adura segun isokuso pafati ati dayo omiran letun gbe yo le te yi! O ga oo, e wo ni miliki ti gbogbo yin n du kiri? ki gbogbo yin sora se o! Omobirin kan ti won npe ni tope2000 lo fe fi oyan pa awon omokunrin ti o wa ni tireedi yi. O dun mi pe emi ati omo yen nje oruko kan naa  tope, se mo le mo e sa  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:35pm On Aug 31, 2009 |
IFELEKE: Orisirisi ma lo n sele lori tireedi yi lenu ojo meta yi oo! leyin igba ti a ti fi adura segun isokuso pafati ati dayo omiran letun gbe yo le te yi! O ga oo, e wo ni miliki ti gbogbo yin n du kiri? ki gbogbo yin sora se o! tu dear bawo ni? se o sun daada?  toyin temi nikan se alaafia lo wa? o to jo meta ooo, je ka pade ni koro wa  @gbogbo ile(ogbeni dayo oni miliki,tubabir,ajenti,No2A,toyin,tope,Remii. . .et al) Eku Ojumo ooo Ara awe, o t'orun  Wo ri d'ami nu bi omo usan o; mo palu ko o naa  Leke, oro kan ma se bi kayefi si mi, inu mi a si dun ti o ba le so nkan ti o wa ni idi oro naa fun mi  O to ojo meta kan ti mo ti wa si ilu wa yi. Lati ale ana ni aayo ilu yi ti mu mi mo si pinu lati wa sihanyi ni aaro yi. Sugbon iyalenu nla lo je fun mi nigba ti mo ka awon isele ti o se lati ojo meta sehin ti mo si rii pe awon oludokudo onisokuso kan ti fe gba tu mo e lowo ti ohun naa si nba won feyin pelu gbogbo owo ti a ti naa lee lori. Eleyi o tun wa dun mi o, igba ti iwo naa tun maa soro, oro miliki tope2000 ni o nso  Emi lo de  Yooba ni ti o ba nidi obinrin o ki nje kumolu  Se o ngburo iyawo wa toyin  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:16pm On Aug 31, 2009 |
E nle nbeun o. Se daadaa le wa gege bi mo se wa  E maa miliki  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 3:27pm On Aug 27, 2009 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:55am On Aug 27, 2009 |
tubabie: Awon omo onisokuso wonyi si wa ni ibi yii?  Mo mope Id iru oro yii lati ma ba Peverti,Tope-lobi ati Dayokanu. tu, so ara re ki o je ki Olorun so e  Se mo jo Ifeleke ni  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:39am On Aug 27, 2009 |
IYA NGBALI: kilode teyin guys yi o le fi pervert lorun sile even lehin igba to decide lati ma yoju sagbo yi mo?mo de wonder why ti e se npe mi ni pervert se e ri username mi ni abi e ko decide lati form clique so that awon alagbara a le lemi kuro nilu yi,ko da be o,anyways e ti dami lohun lori ibere ti mo bere lowo yin nipa agbaDO,gbogbo yin le ma nje agbaDO but e le so "idi" e ti won fi npe agbaDO ni agbaDO,anu gbogbo yin se mi simple question e le dahun afi ke kan ma je agbaDO lasan both day and night,shiooo. Se oju yin o sise ni eyin booda yi. Se e ri pe mo ti dahun ibeere yin ni  |
Christianity Etc › Re: Is It Biblical For Pastors To Advertise Miracles by topsy25(m): 1:34pm On Aug 26, 2009 |
ud4u: When Jesus was on earth did He go into the hospitals to heal the sick?
You rather read your bible very well. Maybe u should go back to that bible again and read well. Then, you'll realise Jesus was going about healing all that were oppressed of the devil. Whereever he saw them (hospital or on street and not just the synagogue) he was moved with compassion and heals the sick. |
Christianity Etc › Re: Is It Biblical For Pastors To Advertise Miracles by topsy25(m): 1:27pm On Aug 26, 2009 |
Hi fellow Nlders,
There's nothing wrong with miracles. It's part of Christ's mission and God's gift to mankind. That is why the scripture said: ", going about doing good and healing all that were oppressed of the devil because God was with him."
God has in the past and at present use miracles to draw unbelievers to Himself and the bible recorded it that many believed on Jesus first because of the miracle they saw and later His words e.g the Samaritan woman and the Samaritans.
Notwithstanding, a genuine servants of God would not have to advertise or fake miracles before people gets to know they can perform miracles. Genuine and God-given miracle will advertise itself. We should also note that these are the last days and fake and pastors from the pit of hell abound to deceive people with signs and wonders; only those with the Spirit of God and good knowledge of the Word will escape.
Beware!!! |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:40am On Aug 26, 2009 |
IFELEKE: Ore mi tope-lobi, bawo ni? se alaafia lo wa? iyawo ati abobo nko? iwo,pafati ati dayo lo le gbogbo awon omoge wa lo pelu awon isokuso yin. Atunbi lemi o. Mi o mo nkankan  |