₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,777 members, 8,423,671 topics. Date: Wednesday, 10 June 2026 at 06:28 AM

Toggle theme

Topsy25's Posts

Nairaland ForumTopsy25's ProfileTopsy25's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 14 pages)

CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:53pm On Jul 24, 2009
IFELEKE:
(having issues logging on, but am still trying to).
Ota mi, so ede ti mo gbo o. Emi o gbo ede eebo embarassed
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:49pm On Jul 24, 2009
Dr Ferlie:
mo ro wipe o ti mu paraga ati igbo ni owuro yii. se emi oloye ASIWAJU ni iwo nba soro ba yen. ti o ko ba so ara re ma niki won ti e mo ewon fun odun mewa. cheesy
Emi o ni ti e mo ewon rara. Ewon awon aye ni mo maa ti e mo cool

Olupe mo pe, olupe mo pe
Eyin iya mi osoronga, atapa jori, atedo jokan,
Atifun jorooro.

Eyin ti eledumare gbe aye le lowo,
Ejo feli ti o npe ara re ni dokita ni mo wa fi sun yin o
Nitoripe ojo ti omode ba f'ori dapa, apa a pa,
Ojo ti omode ba fi ori kan iroko, iroko a ko

Eyin le so wipe: ewe ti a ba fi si owo otun, otun nii gbe,
eyi ti a ba fi si owo osi, osi nii gbe
Oro ti okete ba ba ile so ni ile ngba

Mo pase ki oko Dr. Fali poora nisinsinyi
Aseeeeeeee wa cool cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:18pm On Jul 24, 2009
IFELEKE:
grin awe awawi we'e wi lerun ni.
Mo ti so fun e pe mi o le ma a ba e takuroso lori iyawo mi(toyin temi nikan)
nipa ojo to ti n pa igun e bo tipe tipe, igun e o tokunrin'i se ni nitori to ba tokunrin'i se ni ko ye ki ojo pa e fun ojo pipe.
BTW, emi ati debo ti n gbaradi lati tele e lo si ile awon iya olobi lati lo da'na risika.
Rara o shocked emi o le je ki eyin mejeeji tele mi o, eyin ota bi ore yi angry

awe, abo lori yim, mo ti tirai ati ba o sujo grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:16pm On Jul 24, 2009
IFELEKE:
@gbogbo ile(toyin,debo,ajenti,tubabie,blu,faakay,dokita feli,tope,pafati et al)
Eku Ojumo
A de ku yotomi opin ose
Ota mi atata, opin ose yi maa ni arinrin fun gbogbo wa o. Nitemi, aago mokanla aaro ni mo maa ji, se e mo pe ehunfaromenta wa grin cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:10pm On Jul 24, 2009
tubabie:
@all
Gbogbo ile se alaafia lawa , o to jo meta o
(Debosky, farotika,FL,argent,ifeleke,pevert09,bluespice et al)
Moi dia grin Se daadaa ni o wa. Pele, se jeje o
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:07pm On Jul 24, 2009
Dr Ferlie:
ASIWAJU dee, ki gbogbo ilu pa roro. emi okunrin ogun ti wo ilu, ki gbogbo ota wo igbo lo.

mo ki gbogbo eyin omo oduaaaaaa. e ku ojo meta oooooo.

Baale, iyalode, dobosky, ore mi pataki ###wunmi, o ku ojo meta ooooooo. grin grin cheesy cheesy
Tani o huh Kini o huh Obo lo ti jawa ti o ni okun lorun huh shocked Se awon aye le e wa si hanyi ni. Se o sonu ni? Se won ntan e ni obi o n tan ara re?

Ikilo pataki: Nkan ti owo e to, ma fi gongo fa o cheesy grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:01pm On Jul 24, 2009
debosky:
Kini itumo oro ti o jabo lenu e yii? Se o ti ko ifeleke sile ni abi bawo ni o se je?? grin

Ifeleke sure wa o, gatoosi ti nfi obe je isu e leyin o!!!
Yooba bo won ni: Mi o ri eleyi ri, a fi nderu ba oloro ni. Debo, ti won ba ni omi e ni o maa se eja jina, ma ni iro ni. Emi ni ero pe ore ni atata ni e tele, sugbon pelu nkan ti o so si oke yii, mo ni lati ro oro naa daa daa.

Se ibi ko ni o wa nigba ti mo nfi gbogbo nkan ti mo ni wa toyin, toyin gba lati se aya mi lehin opolopo atotonu a si bere ere ife wa. Ko si eleyi ti o se eyin re ninu gboogbo isele yi o. O wa ya mi lenu pe o le ya enu e paga lati ma tako ife emi ati adumaradan mi.

Sugbon yooba ti pari oro, won ni: ore dani o dun mi, eni abinibi ndani undecided
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 12:51pm On Jul 24, 2009
FL Gators:
@@post
A saying goes like this "You never know what you ave until you lose it". Now I know, where's topsy25 cry
toyin temi,

Iro nla lo ma je ti mo ba so fun o pe ayun e o yun mi nihanyi cry Nitooto, okan mi nfa si e ni ojoojumo sugbon niwon igbati o ti ko jale lati so eni ti o ni oyun ninu emi ati omokekere ti won npe ni Ifelepon yen, mo ti gba kamu. Nitoripe emi o le maa ba omo ana yen maa du obinrin.

Yooba ni ojo ti npa igun bo, ojo ti pe. O pe ti mo ti nfi ife han si o, ti awa mejeeji si ti nba ere ife wa bo; sugbon ni were ti omo yen bere sii jabo si e ni o ti nba so awon oro kunba kungbe. Eyi ni o mu ko ohun naa maa wenu si iru emi embarassed Paga!!! O ma se o. O tun wa gun igi koja ori ewe, o ni ohun ni ohun ni oyun ti mo sise nla le lori.

Oro yi ni mo wa ro ti mo si fi eeni kun eeji pe, kaka ki nfi ojo ori mi yii ma ba omode kan du iyawo, maa fi owo leran maa wo ibi ti oro yin maa ja si. Mo mo wipe eyin mejeeji si nbo wa be mi cool

O digba kan naa
RomanceRe: There Is Not One Girl On Nairaland Who Wont Fall For Me In 3 Days Max! by topsy25(m): 2:28pm On Jul 22, 2009
luxoire:
mai fren - u had better return to Ekiti and let those local/mad women continue falling for you - because your class no dey NL

nonsense!!!!
From which planet did this thing fall from huh shocked What does this thread has to do with Ekiti huh E be like say u don drink sugbalaja huh Which hamlet u from come self.

Be warned, else sango will fire dat ur useless mouth angry
RomanceRe: Why Do matured Ladys Romance Kids Of 2-5yrs, by topsy25(m): 1:59pm On Jul 22, 2009
young_zeal:
my own story sweet pass all ur own. i fu3ked our house help, fu3ked nore than three big girlz n other child play stufff smiley, even now, it still dey happen 4 some houses. i missed all dose day cus i can go for 4-5hours but now highest na six round. thing don change 4 my bodyooooo cool cool cool cool
U just dey start bros, small time u no go fit do at all tongue
CultureRe: How Do You Translate this specific Body Parts In Your Language? by topsy25(m): 10:16am On Jul 22, 2009
FL Gators:
Interesting topic

Hand: Owo
Head: Ori
Eyes: oju
Nose: imu
Mouth: enu
Ears: eti
Teeth: Eyin
Lips: ete
Eyebrow: Irun oju
Neck: orun
Fingers: ?
Cheeks: ?
Forehead: ?

Shoulder: ?
Elbow: ?
Arm: ?
Wrist: ?

Breast: Oyan
Nipples: ?
Chest: ?
Tummy: ?
Navel: ?
Waist: ?
Hips: ?

Buttom: Idi
Legs: ese
Thigh: ?
Patella:?
Knees: ?
Ankles: ?
Toes: ?
Heels:?
Let me feel in the gaps for my wify kiss kiss kiss

Fingers - Ika owo
Cheeks - ereke
Forehead - Iwaju ori / opon ori
Shoulder - Ejika
Elbow - Igunpa
Arm - Apa (as in: re mi)
Wrist -
Nipples - Koko omu
Chest - Aya (as in: do do)
Tummy - Ikun
Navel - Idodo
Waist - ?
Hips - ?
Thigh - Itan
Knees - Orokun ese (ekiti calls it: koko)
Toes - Omo ika ese
Heels - ?
FamilyRe: She Needs A Companion by topsy25(m): 9:00am On Jul 22, 2009
Gudintent:
any takers?
my great grand pa, he's 95 wink
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:26am On Jul 21, 2009
IFELEKE:
;fi iyawo oniyawo lala (instead of dreaming about another man's property)
Se eri oju aye abi e ri huh Otito ti nfara han die die. Eboni mi, se o ri nkan ti o jamo lowo Ifelepon huh "ohun ini" lasan lasan undecided Shio!!! Se o wa ri pe omo yen kan ri e gege bi ohun ini ("puropati" abi kinni eleebo npe) ni.

Nipa temi o, o ju ohun ini lo. Iwo ni eni bi okan mi, ilaji mi ti o dara ju (my better half), oluranlowo mi, angeli mi, iyun mi, alabaro mi, eni ti okan mi fe, abbl (ati bee bee lo) kiss kiss kiss
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:59am On Jul 21, 2009
Eyin ara mi ninu tireedi yi, e bami dupe lowo Eledumare o nitoripe oro mi ti di ayo.

Ni osan ana ni Ifeleke dede pe mi si ori aago ilewo mi (GSM) ti o si bere si nbe mi ti o si ntoro idariji ni odo mi. Oro yi je kayefi si mi, ni mo wa bii pe kilo sele. Lo ba ni ki nma binu pe ohun nba mi du iyawo pe ohun si ti jawo ninu iwa buruku bee.

Iyalenu ni eleyi je fun mi, ni mo ba bii pe kilo ri ninu obe ti o fi wa iru sowo. Gbara to maa dahun, o ni awon agba meta kan ni won yo si ohun ni oju orun ti won si ki ohun nilo gidigidi pe ki nba mi du iyawo o. Ni oju orun yii ni won ti naa ni egba meje shocked shocked Won si so siwaju sii pe bi o ba jawo, bi yio se maa je egba awon aye ni ojoojumo niyen.

E jowo e ba mi dupe lowo baba Goodu cheesy grin
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:42am On Jul 21, 2009
FL Gators:
Okiez Dokiez, got it. But who are you loffing for real? grin grin tongue
Tani o ro pe ifeleke nife e bikose Sikiratu Bebedi tongue

FL Gators:
@topsy
topsy, o ri mi, o si ki mi. se bee ni in un okirin Ondo se n se si olufe wan?
o ti ko mi fun omoge ye, se bee le se ri? undecided
Adumaradan temi nikan, Bawo ni mi o se ni ki e huh Sebi odo mi ni o sun moju ana huh Nkan ti o je ki nki e niyen o, nigbati o jepe a sun ti ara wa moju a tun fi enu ko enu laaro ana, ki lo tun ku huh Sugbon, bi o ba je pe mo ti se o nipa pe mi o ki e lori tireedi, jowo ma binu si mi.

Se iwo o mo pe ekuro mi ni alabaku ewa e ni huh Yooba ni bi igbin ba fa ikaraun a telee; ibi ti oloomi ba koju si nibe gan an ni ona mi gba lo kiss Se iwo ti gbagbe ni, pe ife eyele ni mo ni si e, kii se ti adaba rara. Eyin oju mi lo je o, bi enikeni ba fowo kan o (eeyan bi ifelepon), yio ru igi oyin ni cheesy cool
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:24am On Jul 20, 2009
debosky:
HAAAAAAAAAAA!!!!

Egbon Farotika ko le je bee! Se nkan ti e fe so funmi ni pe kii se ifelopon lo fun Getoosi loyun ni? Talo wa loyun naa? Oro yi ma ga o! Pekele pekele arugbo je gbese tani o san? undecided
Ifelopon Faro ti so ko nla ba e o. Se ko ba e lori sha? grin

Bawo ni ose tun ti ni iyawo si abule pelu Getoosi? Se iwo naa wa lara awon ti won se ise ibi lati ma ko awon omobinrin wa lo si oke okun lati ma se ashewo ni? (human trafficking) grin

Tubabie ngbo se iwo o kin se iya afin ni? Abi iro ni pafaati npa mo e?

Oro gbogbo yin ti su mi gaan. Ajenti aya mi nikan soso, tete wale ki a wo yara lo sere ife titi ti owuro ola. cool
Ohun ko o shocked shocked shocked Emi ni mo ni oyun yen o. Je ki nwa so kini kan fun o, obinrin meji ni o wa ninu toyin bi a se nsoro yii. Emi ni mo mo nkan ti mo to sibe nau cool. Bi a se nsoro yi, mo se je iyan akanilaya kan ti toyin gun fun mi laaro yi ni. Se ewa rii pe ifeleke kan nse lasan ni tongue
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:09am On Jul 20, 2009
PERVERT9:
Eyin ara papa julo eyin omoge ti ifelepon ifeleke nparo fun ni abule yi,eyi ni leta ti iyawo ifeleke towa ni abule won kosi ni nkan bi ojo meta seyin,ede oyinbo ni o fi ko leta na, o dami loju pe gbogbo yin le o gbadun leta ohun,e ma bawa kalo o grin


No 25,alamudo street,
abule mado mi pa,
26-06-2008


Dear Ifeleke,
How is you does?i hope you are does fine?long time no seeing,long time no earing from you,why does you do me like that,you just abadoning me in the village sinse all this deys,are it good like that and you tolded me that you loving me,you efen promise promising me before i gree greeing to goes out with you and marriage you,now that you have lefting the village you are does not caring or get time for me again,you does not write to me,you does not kollling my nomba or efen flashing me like you use to does wen you does not having credit in your fone.ifeleke temi nikan what does i did to desaving all this from you,has you forgeted about me and the plenty loves that i has for you,has you forgeted all what you tolded mama eleko who helps you to toasting me when you are ashaming to even facing me to told me that you loving me,i did not greeing to your loving,you would not leaving me alone,you going to meet iya olobi,broda mukaila,iya luku,buroda kapenta and even my momo to talking to me for you,still i does not greeing for you because i am afraiding of you disappointing me uselesing me and leafing me in the village.i does not greeing you until when you broughted your momo and your olori ebi to our house to come and beging me for you,you frostrated {dobale} for my parent and promising many many thing that day,when i looked at your eyes i tooked pity on you,i even sees in your eye that you loving me and becos you have suffering too mush because of me i gree greeing for you,you tooked me to many playses to see many many pipu,you tooked me to the zoo to see monkey,inaki,ejo,erin,ekun, ijapa and elede,you tooked me to kinsway to buying plenti tins{Things} for me like cloth,pata,shuu{shoe}rist wash,bangu and provisionses you also tooked me to mr bigs and boughted for me iresi and siken{chicken}we enjoying awaself well well before you tooked me to owonikoko hotel,where we goes to enjoys awaself. cry cry cry cry cry cry

Ifeleke temi nikan,you rememba when we gotted to the owonikoko hotel,that day you beged me to greeing for you to fokying me but i rifuse you,you promising me many many thing,like moni,cloth and you promising to taking me to amerika,when i looked at your eyes i tooked pity on you and i allowing you to fokying me you fokying me well well and fokying you too well well,we both enjoying awaself bifore we going back home,we doing it gain in your hause on the mart and you promosing not to disappointing me,but sinc you going bak to lagos i does not sea or hearing from you again, mulika and seri tolded me that they seeing you in nairaland efery day,that you are now marrying anoda wife caling tubrasier,toyosi,mukina ati awon obirin mi,is it truth,ifeleke what you does to me is very very bad and i am not hapi with you i am very very anoying with you,aniway i will look for money to coming to lagos and sees you so that you can telling me if you are not loving me again or you are not interesting in our relationsheep again,but i want you to nose that i stll loves you and i would like to marriage you.

till i comes to lagos takes kia of yorself kiss kiss kiss

yours daling waif,
sikiratu bebedi kiss kiss kiss
Eyin ara mi ninu tireedi yi, ti mo ba so fun yin pe ina njo nibi kan, e ni ki nko eeru e wa. Nigba ti mo so fun yin ni ijo kinni ana pe ifeleke ti ni iyawo (bi o tile je pe kole fun un loyun nitoripe epon e o tii gbo tongue) e ro pe iro ni mo npa. Se o tan abi ko tan huh

Imoran fun ore mi Ifeleke:

Ma se je ki toyin tan e. Bi mo se n te kiboodu yi, toyin ti ngbe ninu ile temi. Iba san ti o ba le lo ba SIKIRATU BEBEDI nitoripe o feran re tokan tokan. Ko si ni dara ki o padanu iru ife nla yi ati awon akitiyan ti o ti se lati rii pe fe omo naa undecided

Ire o cool
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:00am On Jul 20, 2009
IFELEKE:
po kini? awe ipokupo lo fe po yen o! risika lo ro pe mo n so ni?
se eni ti mo ti ro yo, ti mo ti rojo oyun ibeji si ikun e lo tun fe po nkan si? eyin(back) lo fe gba wole ni abi enu? nitori mo ti ro yo bamu bamu! awe, we le risika!
how work?
Iro lo pa joo. Kini e o tii le di omo cheesy grin Nitorinaa emi ni mo ni oyun tongue
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 3:24pm On Jul 17, 2009
IFELEKE:
aya mi atata,aaayo ati iyaafin ifeleke, aya'ba laafin mi kiss
bawo ni? se alaafia lo wa? ma se da awon olote bi tope-lobi ati pafati lohun, won n se lasan ni, won fe e da arin emi ati e ru ni sugbon pabo lo ja si.
orekelewa mi, eleyinju ege temi nikan kiss home is always in the hearts of those who long for it. . .
I'll make sure you speak it as I do,trust me wink kiss
Gberun re soun joooooooooo tongue Emi o ni lati ko o ni ede ekiti rara. Ti mo ba ti le po nkan sii lara, o ma jafafa ninu ede ekiti baje grin cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:51am On Jul 17, 2009
FL Gators:
Inu mi dun wipe o wa dada wink

I feel like you just "bu" mi, ah ahn, sugbon mo n try pelu ekiti mi na embarassed tongue
Emi ke shocked shocked shocked Bawo ni mo se ma bu iyawo temi nikan huh Mo kan gbiyanju ati ko e ni yooba ni o. Jowo ma binu si mi kiss

FL Gators:
Ewo ni iyawo afin toyin? oya, kini afin mean? angry tongue
Itumo afin ni "ile" tabi "ibugbe" (i.e. a place of abode). Nitorinaa, a le ni: Afin oba i.e king's palace or king's place of abode or afin Farotika i.e. Farotika's place of abode wink

Se o ye yin iya afin farotika huh grin cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:37am On Jul 17, 2009
PERVERT9:
eponleke bawo ni se o wa,mo ri careless letter ti iyawo to wa loko ni abule yin nibi kan leni,ti o ko ba mind ma send leta na si e,but plsssssssssssssssssss,ma paro nibi bayi pe o ni iyawo ni abule yin o,mo promise pe mi ko ni so fun toyosi, tubabie tubrasier ati awon other ladies ni nairaland awo mi nie now i promise not to told anyone wink wink wink
Iyen nipe ifelepon ti ni iyawo si abule. Sugbon mo mo pe iyawo yen o tii le ni oyun nitoripe epon ifelepon ko tii gbo tongue
RomanceRe: Why Do We Get Married ? by topsy25(m): 10:53am On Jul 16, 2009
To prevent cold at night
RomanceRe: Lovesick by topsy25(m): 10:51am On Jul 16, 2009
I concur cheesy
CultureRe: A Need To Change The Name Nigeria To Wazobia by topsy25(m): 10:14am On Jul 16, 2009
omogenaija:
i don't agree b/c not all nigerians r yoruba , igbo, or hausa
I don't believe people will look at it that way. The name "wazobia" might have been curved out of the 3 major tribe in the country, but it has been generally accepted as a unifying name by all undecided
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:51am On Jul 16, 2009
IFELEKE:
aya mi atata, iyawo ati iyaafin ifeleke kiss se alaafia ni? bawo ni awon ibeji mi, se wo n kick?
Mo le ro pe o ti jeun sha? nitori mi o fe ki ebi pa orekelewa mi rara. . .just checking on you
Ifelepon, o fe fi gongo fa nkan ti owo e o to shocked Sora o ki o ma ba fi ori k'ole agbon cool
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:49am On Jul 16, 2009
PERVERT9:
come to my bedroom and lets start with a aja b bata d doje o oko o obo and from there we shall begin to speak in tongues o sa mo ru e kissexpress road ta gba waye niye now so ko pa gbogbo wa den grin grin ;

eponleke sorry mo mean ifeleke,mo gbo pe o lo si meeting awon oso ati aje loru ana se loto ni,toyosi ati debosky lo so fun mi pe awon ri e ni meeting won lana won deni o mu "sobo"{blood} gidi gan ni,se looto ni,haaaaaaa o ga o cry cry cry cry cry
Pafaati, ronu piwada nitoripe ijoba orun ku si dede undecided
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:41am On Jul 16, 2009
FL Gators:
bawo ni jare? oti pe ti mo ti rie man
Mo wapa jare. Ise ni o fa ti mi o fi le de odo e ni ijeta. Lai se aini aini, mo maa de ile odo e ni otunla kiss kiss kiss

FL Gators:
iya afin = wife of a king (queen) orrrrrrrrrrr it could mean "ebo"

I think it's an ekiti term
Rara o. O sii monokai cheesy Itumo iya afin ni: Mrs. Ti mo ba fe pe oruko e ni apeja, mo maa ni: Iya afin toyin farotika grin cheesy Ede yooba ponbele ni iya afin je; ekiti nikan ko ni o nso.

Ni ede yooba, olori ni a ma npe iyawo oba (queen).

Ti nba ri e ni otunla, mo maa ko e ni awon nkan miran ninu ede yooba kiss
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:26am On Jul 16, 2009
tubabie:
Ose my dear, mo mo nipe oni interest mi at heart kiss
Se o kii se iya afin ni huh
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:25am On Jul 16, 2009
argent:
Se awon ibeji n kick?
Igba wo ni oko se change of name si Ifelepon? ( oruko fine gan ni grin)
ajeniti, o nwa ibinu mi o angry Emi ni mo ni oyun, Ifelepon ko, o ni epon looto, sugbon epon e o tii le di omo tongue
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:23am On Jul 16, 2009
TOYOSI20:
Ehen, niboni Dayokanu wa?? shocked sad. . . .and Mr Farotika himself undecided, i need to brush up on ma yoruba oo, LOL!!
Mo wa pa jare omotoyosi. Nipa ti dayo, bobo yen ti fi ara pa lori omobirin opelenge kan. O si maa lo osu meta ni osibitu.

E saa je ki a ma fi adura ran an lowo cry
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:21am On Jul 16, 2009
IFELEKE:
tope oko omo iya olobi(a.k.a tope-lobi)
awe, gege bi ore ooto, mo ma a sin e lo si ile awon iya olobi lati lo da'na risika.
ooo ni choice rara,o gbudo gba oyun yen ni nitori iwo lo ro ojo ina si inu iku omo na.
Me ran o luse awe. Yaa jokole grin

IFELEKE:
Ke e se o ran? we ti pari oro risika we e merun l'oya oloya!
so rare o!
Aya gidi li toyin o; ayaba li omo iya olobi wink cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:01am On Jul 15, 2009
argent:
Mr Farotika, oko omo iya olobi tongue
Emi niyen o iyawo wa wink

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 14 pages)