Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,899 members, 7,956,395 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 11:08 AM |
Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (100233 Views)
Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply) (Go Down)
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:12pm On Jul 08, 2008 |
kokoye: Aalo apamo ni eyi, ki ise owe. Sibe-sibe itumo re ni EWA. |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 5:02pm On Jul 08, 2008 |
Ojo n pa iyo ori n du nun----------------------- |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 5:11pm On Jul 08, 2008 |
bluehorizo:Ojo n pa iyo ori n dunun, ki ori mayo layoju nitori to'jo ba tida orun nbo. @bluehorizo se o wa pa? Agba ti ko ke'wun soro,_________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 5:32pm On Jul 08, 2008 |
Kola mo wa pa. Se alaafia ni? Awon owe e yen ga ju. Nibo lo ti n gbe won wa na? |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 9:25am On Jul 09, 2008 |
bluehorizo:Omo odo agba ni mi .Ede yoruba ma nmu inu mi dun gan an ni. Maa se jeje o. Agba ti ko ke'wun soro,_________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 2:56pm On Jul 09, 2008 |
Agba ti ko ke'wun soro,_________________________ Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SARE Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:18pm On Jul 09, 2008 |
tybanky:Omo odo agba,o kare laye.Mo gba fun o,o peregede. |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 5:25pm On Jul 09, 2008 |
Insert Quote Omo odo agba,o kare laye.Mo gba fun,o peregede. E se sir |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 12:38pm On Jul 12, 2008 |
Alangba to f'oju di ere,__________________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by tybanky(f): 1:25pm On Jul 15, 2008 |
Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________ Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won bi iya adie lati de be lo woran |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:24am On Jul 16, 2008 |
OLAADEGBU: ikun ejo ni yo ba ara e Afopina to ni oun o pa fitila,_____________________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by CH3COO(m): 7:25am On Jul 16, 2008 |
OLAADEGBU: ara re nio pa. |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:45am On Jul 16, 2008 |
Egbirin ote________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:23am On Jul 17, 2008 |
kola oloye: Bi a ti npa ikan ni nkan nru (This was copied from kola oloye) Eni aigbon pa lo po,___________________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 8:15pm On Jul 17, 2008 |
OLAADEGBU: eni ogbon pa o to nkan Eni maa je oyin inu apata,______________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 8:21pm On Jul 17, 2008 |
- - -- - Ki i wo enu aake. @post oo sa igi logbe, oo ta oguro lofa, o wa de idi ope, o gbe enu soke - - - - |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:09pm On Jul 17, 2008 |
mishooo: o fe mu emu Eni a wi fun ko gbo, eni a fo fun ko gba,___________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 5:00am On Jul 18, 2008 |
OLAADEGBU: eyi ti ko gbo yo file bora Maalu ti o n'iru,______________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 7:27am On Jul 18, 2008 |
OLAADEGBU: it continues - - - - - - - - Ofe ko ni yio ro. OLAADEGBU: olurun ni o m ba le esinsin !! |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 9:45am On Jul 18, 2008 |
mishooo: Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. Were dun wo,_______________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Femonjay(m): 12:29pm On Jul 18, 2008 |
Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. Were dun wo,_____ko se bi lomo ile la awo ------------- |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 1:04pm On Jul 18, 2008 |
Femonjay: ile la'wo ka to somo loruko o fi nu we'nu---------------------- |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by nana(f): 1:06pm On Jul 18, 2008 |
bluehorizo:O mo pe inu jin ju orun lo. Larin egun ni- - - |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 2:27pm On Jul 18, 2008 |
nana: Larin egun ni mariwo ti n soge T'eni be'gi loju---------------------- |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 7:33pm On Jul 18, 2008 |
of course - igi a ruwe @post Ata aato (do-re re-do-do) OR oun ta ta ti aa to (meaning something - like an animal, shot but not traced/followed up) - - - Someone must find the answer oo |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:20pm On Jul 18, 2008 |
mishooo: Eni ba ri he lo maa sun je Atele owo eni,________________________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bluehorizo(m): 1:15pm On Jul 20, 2008 |
OLAADEGBU: Atele owo eni,ki tan ni je Ope oyinbo fi dundun sewa--------------- |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by mishooo(m): 8:22am On Jul 21, 2008 |
mishooo: ni o n di eran idin. (becomes meat for the maggots) |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by obuchineme: 9:10am On Jul 21, 2008 |
Agba to rofo ika, |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by olawunmi05(f): 2:13pm On Jul 21, 2008 |
obuchineme: omo re aje ni be gbami gbami ko ye agba |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 3:24pm On Jul 21, 2008 |
olawunmi05: gbami gbami ko ye agba, eranko ni nle mi bo ko ye ode Alagbede t'onlu irin ni oju kan__________________________ |
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:52am On Jul 24, 2008 |
Omo ti yo je asamu,____________________________ |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (25) (Reply)
Lovely Pictures / What Would You Do If? / Match 2 Personalities 2 Make A Couple
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 27 |