Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,227 members, 7,818,772 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 02:01 AM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (8) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (97513 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bintab(f): 8:56am On Dec 16, 2008
@  ogbeni kola,Awon owe re le pupo,o de gba ogbon ati iro jinle gan ni.O wa da mi lo ju kedere PE omo agba tooto ni e.Mo ngba dun re pupo.Oodua a tun bo ma gbe o ,wa pe pe fun wa ni NL. Nipa owe to pa gbehin yen. A KII NI'GI LAGBALA,, KA WA MA FOWO WA NA.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 3:07pm On Dec 16, 2008
A kii ni'gi lagbala, ki a ma mo eso (fruit) re grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 3:09pm On Dec 16, 2008
O dara na , eyi nko?
[b]Alagbede ti o nlu irin ni oju kanna[/b]_______________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 11:38am On Dec 17, 2008
[b]Alagbede ti o nlu irin ni oju kanna[/b]_______________________
[quote][/quote]
Oni ohun to fe mun jade nibe.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 4:03pm On Dec 17, 2008
E seun eyin temi,


Alagba Kola oloye, bawo lo se nlo?

E gbayi yewo,





Obinrin sowa nu,  _ _ _ _
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Moyola(f): 4:07pm On Dec 17, 2008
KollyJay:

Obinrin sowa nu, _ _ _ _

errm. . . . . leme guess"Obirin sowa nu, nitoripe o wa careless ju" undecided tongue
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 5:06pm On Dec 17, 2008
. .o ni ohun ko rile oko gbe

omo to fowo osi juwe ile baba e . . . .
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 6:01pm On Dec 17, 2008
@ moyola,

ahah, thatz F9 o, lol,

@ goodeass,
E se pupo, A1 niye! grin

Lati pari owe yin,

Bayi na se ma nso. Won a ni, Omo ALE[BASTARD] lo ma nfowo osi juwe ile dad e,

E se pupo,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 6:04pm On Dec 17, 2008
Eyin temi egbayi ye wo


Ere taja ba fogun odun sa?, [The distance wey dog use 20yrs to cover, ]?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by PowerfullK(f): 6:54pm On Dec 17, 2008
Ere taja ba fogun odun sa - Irin fajii ni fun eshin.

Eni to reti ati sun Akan?.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 7:04pm On Dec 17, 2008
.  . yio pe leti omi

KollyJay:


Lati pari owe yin,

Bayi na se ma nso. Won a ni, Omo ALE[BASTARD] lo ma nfowo osi juwe ile dad e,

E se pupo,

ha! emi ro pe won maa n so pe omo to fowo osi juwe ile baba e, o so apo iya ko.
mayb i'm mxin it up wt 'omo ti o lenu agba n run.  .  .'

alagba kola, e jowo e ran mi lowo o  shocked
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 7:12pm On Dec 17, 2008
@ Powerfullk
e se pupo.

Eni to nreti atisu akan, yoo pe leti omi o, big time!!!!! grin

@ goodass,

egbon, o wa a little bit confusing di e, but mo mon pe awon ojogbo wa nibi, awon bi Prof. Kola Oloye, ati Dr. Powerfull, lol grin


Egbayi yewo,


Ko sewu legberun eko, ,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by PowerfullK(f): 7:55pm On Dec 17, 2008
Ko sewu legberun eko, - A Faa duun obe.

Ibi pelebe?.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 8:30pm On Dec 17, 2008
Ibi pelebe , la tii mole e je.


E gbayi yewo,


Bolori ilu ba ngbokiti,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bintab(f): 1:17am On Dec 18, 2008
egbon kola ejo e pari owe yi fun mi, bi otu pa okan ore?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bintab(f): 1:19am On Dec 18, 2008
etun gba yi wo, atere mo atan?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bintab(f): 1:19am On Dec 18, 2008
Another one, opere fo fe
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by bintab(f): 1:21am On Dec 18, 2008
Another one, iku pa edun,owe n yo?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Moyola(f): 10:07am On Dec 18, 2008
KollyJay:

@ moyola,

ahah, thatz F9 o, lol,

. . embarassed
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Moyola(f): 10:08am On Dec 18, 2008
iru awon owe wo ni won yi. . . undecided tongue
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Godalone(m): 11:01am On Dec 18, 2008
goodass:

. . yio pe leti omi

ha! emi ro pe won maa n so pe omo to fowo osi juwe ile baba e, o so apo iya ko.

Emi naa ro be o.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 12:54pm On Dec 18, 2008
@Godalone
Omo t'oba so ile nu ni o so apo iya ko.
Alagbede ti o nlu irin ni oju kanna,aami (mark) ni o nbe nibe
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 12:56pm On Dec 18, 2008
Alagemo ti bi omo re na_____________________ cheesy
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 2:12pm On Dec 18, 2008
kola oloye:

Alagemo ti bi omo re na_____________________ cheesy

. . .aimoo jo o ku sowo omo e
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 2:13pm On Dec 18, 2008
agba to so yangan modi ___________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 5:45pm On Dec 18, 2008
agba to so yangan modi, ni o so ara e di alawada adie grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 5:46pm On Dec 18, 2008
[b]Aito odo to si[/b]___________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:30pm On Dec 19, 2008
Ai to do to si lakere di ju konko di ju mo fee to
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:31pm On Dec 19, 2008
Bi ina ban jo ni nile ______________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by goodass(m): 7:00pm On Dec 19, 2008
Remii:

Bi ina ban jo ni nile ______________________________________

a o pe pana-pana sii
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 9:00pm On Dec 19, 2008
goodass:

a o pe pana-pana sii

O sii oh!!

Bi ina banjo ni ile a ma wu ni ki odo di oko a lo sun (If you have troubled home, you would like to prolong any opportunity to stay away)[b][/b]
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by KollyJay(m): 11:57am On Dec 20, 2008
Eyin temi, e pari owe mi ke? kilo de?

Mo ni, Tolori ilu ba ntakiti, Ans------- Ori igi lo ye ka ti belemonso.

E gbayi wo,

Apa ai mu dele,__________________

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.