Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,740 members, 7,817,041 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 12:25 AM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (23) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (97440 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by abimbawealth(f): 7:20pm On May 06, 2016
razor123:
eyin eyan omo yin kiyin o.






owo omode o to bo akpe....
Tagba o wo akeregbe...

1 Like

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Erickthewreck: 11:06pm On May 09, 2016
Epon agbo to n mi loke, ko ni jabo.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 12:58pm On May 18, 2016
modath:


Awon ti won fe je iwo o ni ye beere ..


@ OLADEEGBU

Tiwa n Tiwa niyin? shocked shocked shocked

Mo ro wipe awon Araabi ti won fi yoruba boju ni o..

Omo ile kaaro ojiire ni mi o. Eba wa pari owe yi.

A'iyan f'eyin le le,__________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:05am On May 23, 2016
abimbawealth:


Tagba o wo akeregbe...

O kare! E fun wa ni owe 'miran. smiley
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by abimbawealth(f): 8:15pm On May 23, 2016
OLAADEGBU:


O kare! E fun wa ni owe 'miran. smiley

...mo mbo grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:22am On May 25, 2016
Amigoz:


I knew one day it will hunt me not studying yoruba until SS1 undecided sad

Ema sunkun mo, o ba ni ko iti b'aje. wink
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 2:52pm On May 29, 2016
OLAADEGBU:


Omo ile kaaro ojiire ni mi o. Eba wa pari owe yi.

A'iyan f'eyin le le,__________________________

A'iyan f'eyin le le Ifa pin.

Alangba to f'oju di ere,__________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 1:15pm On Jun 17, 2016
OLAADEGBU:


A'iyan f'eyin le le Ifa pin.

Alangba to f'oju di ere,__________________________________

Alangba t'o fi oju di ere ikun ejo ni yio ti ba ara re.

Eni ti o ba ma a je Osakala a je Osakala_________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 7:52pm On Jul 18, 2016
OLAADEGBU:


Alangba t'o fi oju di ere ikun ejo ni yio ti ba ara re.

Eni ti o ba ma a je Osakala a je Osakala_________________
. Osakala sokolo ni ko dara.


Ore ti ko se oore fun ni ati ota ti ko se ni ni oja _________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Fabulous0019(m): 5:11pm On Jul 21, 2016
Pasha paara laa n sinto -__________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:16pm On Jul 21, 2016
Remii:


. Osakala sokolo ni ko dara.


Ore ti ko se oore fun ni ati ota ti ko se ni ni oja _________________

Eku ojo meta oga Remii cheesy

Eni ti o ba ma a je Osakala a je Osakala; eniti o ba ma je Osokolo a je Osokolo , ewo ni Osakala-sokolo?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by professore(m): 11:18pm On Aug 12, 2016
Eku ise,alejo tuntun ni mi nibiyi,sugbon mo f'eran owe pupo

Edan eyi wo

Foriti foriti___________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by professore(m): 11:22pm On Aug 12, 2016
steeving:
aito eyin ka,
Aitu eyin ka,ka tun ma wa da owo bo.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by professore(m): 11:26pm On Aug 12, 2016
OLAADEGBU:
Bi aja ba wo agbada ina, ti amotekun wo ewu eje, ti ologini san akisa mo idi _______________________________
Mo ro yin pe ki e ba wa pari owe to j'oju yii.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 7:46pm On Oct 31, 2018
professore:


Mo ro yin pe ki e ba wa pari owe to j'oju yii.

Bí ajá wọ agbádá iná, tí àmọ̀tẹ́kùn wọ ẹ̀wù ẹ̀jẹ̀, tí ológìnní sán àkísà mọ̀ ìdí, ẹgbẹ́ apẹranjẹ ni wọ́n ńṣe.

1 Like

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Nobody: 11:15am On Nov 01, 2018
Àgbò tó feyìn rìn, agbára ló lo múwá

1 Like

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:46am On Nov 01, 2018
Ní tútù là ńká ẹja kò; ẹja gbígbẹ ò ṣeé ká
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 12:52pm On Nov 01, 2018

1 Like 1 Share

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by professore(m): 2:21am On Dec 06, 2018
OLAADEGBU:


Bí ajá wọ agbádá iná, tí àmọ̀tẹ́kùn wọ ẹ̀wù ẹ̀jẹ̀, tí ológìnní sán àkísà mọ̀ ìdí, ẹgbẹ́ apẹranjẹ ni wọ́n ńṣe.
E se gaani o
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:48am On Dec 09, 2018
professore:


E se gaani o

Kò t'ọpẹ́. smiley
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 8:02pm On Dec 18, 2018
Get Connected To Hope: Feasting after the Famine at Deeper Life National December Retreat 2018

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Nobody: 8:08pm On Jan 01, 2019
Xhj

1 Share

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 2:51pm On Sep 06, 2019
Remii:


1. Iyawo ti a fe ni egan, ti o fi iyan mole; yoo ba nbe lomo re yoo maje.
2. Iyawo ti a fi ijo fe, iran ni yoo wo lo,
3. A n ki, a n sa; o so wipe oko mo eni t'o ku, won so wipe o ni isu gbooro gbooro l'oko, agbado booku la 'la, o tun bere wipe ode ni tabi agbe.
4. Arise ni arika, arika ni baba iregun
5. Oromo adie o fo piriri, won ni eran lo ake; eran kini nbe l'ara eye.
6. Gbon gbon kan o si, a fi eniti ban ti ara e.
7. Ikun n je ogede, ikun n re idi; ikun ko mo wipe oun to dun nii p'ani.
8. A o ri iru re ri, a fi deru ba oloro ni.
9. Bi eni ti ri, ola ko ri be; ni babalawo d'ifa ojojumo.
10.  Ohun ti omo o je, ni o pa oju awo de; ____________________

11. Epa n pa ara re, o so wipe oun pa aja bi aja baku se yoo wa laye.


E pari eleyi:

Mo rii tan, mo maa tan, ______________________________

7. Ikun n je ogede, ikun n re idi; ikun ko mo wipe oun to dun nii p'ani. grin grin grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Bosun13: 6:50pm On Sep 06, 2019
Pari owe wonyi...
(1)Eegun atiro wole,eniyan atiro jade________
(2)Omo ti eniyan yio na, ti yio di ejo tabi ijongbon _______
(3).. aaya n bu e je,otun wa n gba ni ipako ______
(4)..ikoko kii gbona giri giri ________
(5)...eru ti ketekete koleeru _________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 2:05pm On Jan 22, 2020
ÀMỌ̀TẸ́KÙN NURSERY & PRY SCHOOL, IGBÓ IRÚNMỌLẸ̀, NEAR OKE-LANGBODO!

New Enrolment starting first week of February. 2020.
Course Contents include six years of learning how to make and deploy the following traditional weaponry:

Gbètugbètu (Google earth)
Ọkarabata (Voice robotic)
Olùgbohùn(Voice jammer)
Ayẹ-ẹta(unseen bullet deflector)
Òkíígbẹ́(anti-bullet/shrapnel)
Atamọ́tàsé(precision munition)
Ìfúnpá(Treated arm band)
Ìgbàdií(treated waist band)
Olúwẹri (Submariners)
Àfòṣẹ(robotic command signals)
Àgádágodo(spiritual padlock)
Egbé (teletransporter)
Àyájó̩(Weather forecaster)
Kánàkò(spiritual Google maps)
O̩fà (Treated poisoned arrow)
Ata( spiritual hand grenade)
Ṣakabùlà( locally sourced Rifle)

Upon graduation, students will take advanced college work in the making of Àdó-Iku (grenades) and Ẹ̀tù-Ìparun (bombs) and be employable with the S/W Amọtẹkun security outfit.

Bring your children NOW!!!
School fee: Only N250,000 per academic year.

https://www./ondoconnectnewera2012/permalink/2622186134546487/

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 8:02pm On May 07, 2020
Ẹ Kọ'rin Sí Olúwa Wa, Ẹ wá F'ayọ̀ Kọ'rin


https://www.youtube.com/watch?v=wQAPYpPZRro
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 3:19pm On May 09, 2020
Àbẹjoyè Season 3 (Part 1)


https://www.youtube.com/watch?v=j6qgWEgpqA4
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 4:12pm On May 10, 2020
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 12:45pm On Dec 12, 2021
Agbo to feyin rin? _______________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:21am On Jan 08, 2022
Impact 2022 || Day 4 Morning Session || January 08, 2022


https://www.youtube.com/watch?v=IBq9GkE3mgQ
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 4:27pm On Jan 09, 2022
Impact 2022 || Day 5 Evening || Jan 09, 2022


https://www.youtube.com/watch?v=tYxH6lW2qIY

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 27
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.