Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,775 members, 7,955,961 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 07:42 PM |
Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Egbe Onkawe Ede Yoruba (2872 Views)
Ede Yoruba Dun Ka / Orin Orile Ede Naijiria Ni Ede Yoruba Ati Ni Geesi (2) (3) (4)
Egbe Onkawe Ede Yoruba by synw: 5:45pm On Nov 30, 2013 |
EGBE ONKAWE EDE YORUBA Egbe Onkawe Ede Yoruba je egbe fun awon onkawe ede Yoruba. Lososu awon onkawe ti won ni ife lati maa ka awon iwe ti won fi ede Yoruba ko maa n pade lati se itupale awon iwe ti won bam un fun iru osu bee. Eyi ko seyin bi Egbe Onkawe Ede Yoruba se pinu lati polongo ati lati je ki ti awon ara ilu feran lati maa kaa awon iwe eyi ti won fi ede afinibi eyi ti o se Yoruba ko. Igbagbo awon eniyan ni wipe ede, ise ati asa Yoruba ti n parun. Egbe Onkawe Ede Yoruba wa pinu lati se gbogbo ohun ti o wa ni ikapa re lati ri wipe kika iwe ede Yoruba je koko ati didan fun ojulowo gbogbo omo karo o jire (nile Yoruba). Die ninu iwe ti Egbe Onkawe Ede Yoruba ti gbe yewo ni wonyii: • Ireke Onibudo • Ogoju Ode Ninu Igbo Irunmale • Irinkerindo Ninu Igbo Elegbeje • Taiwo Ati Kehinde • Efusetan Aniwura • Ole Ku Fun Alaye - 08072673852 |
Re: Egbe Onkawe Ede Yoruba by Drniyi4u(m): 5:55pm On Nov 30, 2013 |
e se pupo, olootu. Emi na ti n gbiyanju lati wa PDF awon iwe D.O Fagunwa, sugbon mi o ti ni anfaani lati ri. Inu mi a dun ti mo ba le ri 'download'.....inu mi a si tu dun ti mo ba le mo daradara nipa egbe naa |
Re: Egbe Onkawe Ede Yoruba by Nobody: 5:59pm On Nov 30, 2013 |
Inu mi dun pupo fun agbekale gbagede ayewo yi. Ma se gbagbe lati ye awon iwe yi wo. Nkan Asiri, Owo Eje, Kuye, Je nlogba a.b.b.l (ati be be lo) |
Re: Egbe Onkawe Ede Yoruba by OkikiOluwa1(m): 6:53pm On Nov 30, 2013 |
O dara. Nigbati ti mo ba farabale, maa pada wa si agbo yi. Ota ti o gbeyin: Mo n bo! |
Re: Egbe Onkawe Ede Yoruba by Ashley2389: 3:38pm On Dec 01, 2013 |
Emi na ti wa awon iwe ireke onibudo, akoni meje ni igbo irumole kiri, sugbon mi o ri won ra, ti enikeni ba month ibi ti month ti le rii, inu mi adun gan! Ese |
Re: Egbe Onkawe Ede Yoruba by Africaman: 12:19pm On Dec 02, 2013 |
Eyin ara mi gbogbo e ku ipalemo odun keresimesi ti o nno lona o, odun titun a dara fun gbogbo wa o, l'oruko Jesu Kristi, Amin. E seun olootu egbe 'SYNW'('Society of Young Nigerian Wtiters' -> 'Egbe Onkowe Odo Orile-Ede Naijiria'), fun tireedi yi. Mo fe ki e se akiyesi iwe yi: 'Igbesi Aye Okonkwo'. Iwe naa je atunmo si ede Yoruba, iwe 'Things Fall Apart' ti Omowe oloogbe Chinua Achebe, lati ede oyinbo Geesi. Oloye oloogbe Wale Ogunyemi ni won se itunmo naa ni odun 1997, ti won si tee jade ni odun 2000. E le ye e wo nibi yi: http://www.hebnpublishers.com/files/prod.php?id=226626 E ku oju lona o. O digba kan na |
(1) (Reply)
Writers Make Money, Readers Too..get In Here / The Regret By Osakpamwan Osadolor / Adventures Of The Village Idiot
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21 |