Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,194,830 members, 7,956,147 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 05:33 AM

Yoruba Incantations. . . . . - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba Incantations. . . . . (97946 Views)

Yoruba Incantations (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Incantations. . . . . by bintab(f): 11:00am On Jan 28, 2009
Ogbeni Farotika,oda mi loju pe babalawo ni e, iwo ati dayokanu  pelu.O ga ofo yin ti po ju, in shot  eru n ba mi, mi o le tesi waju lati ma ka gbogbo ogede yin o. Bi e ko  ba  kinse babalawo o je wipe omo odo agba ni yin. Abi family ni e je si Fadeyi oloro ati Abija ni?
Re: Yoruba Incantations. . . . . by bintab(f): 11:01am On Jan 28, 2009
Ogbeni Farotika,oda mi loju pe babalawo ni e, iwo ati dayokanu  pelu.O ga ofo yin ti po ju, in shot  eru n ba mi, mi o le tesi waju lati ma ka gbogbo ogede yin o. Bi e ko  ba  kinse babalawo o je wipe omo odo agba ni yin. Abi family ni e je si Fadeyi oloro ati Abija ni?
Re: Yoruba Incantations. . . . . by MrCrackles(m): 11:03am On Jan 28, 2009
You guys have succeeded in turning this place to a jazz and juju shrine abi?
All dis stuff you are all chatting, we dont even have a clue, WTF
! cheesy
Carry all these fetish nonsense a million miles far away from here jare angry
Re: Yoruba Incantations. . . . . by Moyola(f): 11:32am On Jan 28, 2009
farotika:

Si Moyola,

Ti o ba mo awon iya ti mo nso, oriki won ni dayo ti fun o yen o.

Inu mi a dun ti o ba le toro idariji fun oro ti o so si emi ati awon iya yen, nitoripe emi o fe ki nka buruku kankan sele si e o. kiss kiss kiss

Oriki ko. . . . angry Mi o toro any idariji tongue
Re: Yoruba Incantations. . . . . by nana(f): 5:16pm On Jan 28, 2009
Mehn,i cant laugh!
Re: Yoruba Incantations. . . . . by tkb417(m): 7:41pm On Jan 28, 2009
nana
oje rerin sita. kosi enikeni to le mu e si

emi komo any ofo mo. ive exhausted all the incantations i learnt.
i need some ogunde and sokoti alagbede oruns films.
with those i can deal with farotika (babalawo of NL) grin
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 8:56am On Jan 29, 2009
bintab:

Ogbeni Farotika,oda mi loju pe babalawo ni e, iwo ati dayokanu pelu.O ga ofo yin ti po ju, in shot eru n ba mi, mi o le tesi waju lati ma ka gbogbo ogede yin o. Bi e ko ba kinse babalawo o je wipe omo odo agba ni yin. Abi family ni e je si Fadeyi oloro ati Abija ni?

Ma beru aburo mi, iwo saa ti ma tapa sawa agba grin
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 9:17am On Jan 29, 2009
MrCrackles:

You guys have succeeded in turning this place to a jazz and juju shrine abi?
All dis stuff you are all chatting, we dont even have a clue, WTF
! cheesy
Carry all these fetish nonsense a million miles far away from here jare angry

Se na my mamas' handiwork u dey call fetish abi kini Ma je ki nran sanpona si o o angry

Ode nla tongue
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 9:33am On Jan 29, 2009
tkb417:

nana
oje rerin sita. kosi enikeni to le mu e si

emi komo any ofo mo. ive exhausted all the incantations i learnt.
i need some ogunde and sokoti alagbede oruns films.
with those i can deal with farotika (babalawo of NL) grin

Igbagbe se o ni
Pe tomode ba dari sapa, apa a pa won
tomode ba dari soroko, iroko a ko
eni ba si pori mi nibi, ogiri alapa, lo maa wo luwon pa
Ogiri alapa cool
Re: Yoruba Incantations. . . . . by TOYOSI20(f): 8:27pm On Jan 29, 2009
@ OP

Thanks a bunch for this thread now at least we really know whos who amongst us. . .i don begin dey fear too!! shocked shocked
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 9:00pm On Jan 29, 2009
Ogbeni Farotika,oda mi loju pe babalawo ni e, iwo ati dayokanu pelu.O ga ofo yin ti po ju, in shot eru n ba mi, mi o le tesi waju lati ma ka gbogbo ogede yin o. Bi e ko ba kinse babalawo o je wipe omo odo agba ni yin. Abi family ni e je si Fadeyi oloro ati Abija ni?

Paga!!!!!

Emi lo de.

Obatala OOOOOOOOO

Won tun ti de oh
nitori wipe o dabi wipe obinrin ni iwo,

Awo egungun lobinrin le se
Awo gelede ni Obinrin le mo
Bi obinrin ba fi oju ba oro, oro a gbe!!!!

ma je kin binu oh

Mo tun ti de o
Mo se iba awon Iya mi Opake, olake, akoruru, alaruru, alagogo ide

Won ni kin ma su si epo mo su si epo won o ba mi wi rara
Won ni kin ma to si aala mo to si aala won o ba mi wi rara
Nitori owo ipopo ni a fin wo igi, owo orisa la fin wo afin

Oso ile lo ba pe ori mi ni ibi, Ogiri alapa ko ma wo lu won Ogiri alapa
Aje ile ni o ba n pe ori mi ni ibi, Ogiri alapa ko ma wo lu won Ogiri alapa
Bintab ni o ba n pe ori mi ni ibi, Ogiri Alapa ko ma wo lu won Ogiri Alapa

Nuff said tongue tongue tongue
Re: Yoruba Incantations. . . . . by MrCrackles(m): 9:05pm On Jan 29, 2009
farotika:

Se na my mamas' handiwork u dey call fetish abi kini Ma je ki nran sanpona si o o angry

Ode nla tongue

Ur juju wont work on me, trust me
QUit your fetish ways and stop murmuring stupid and meaningless incantations, it wont take you to heaven
! cheesy
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 9:10pm On Jan 29, 2009
Brash,
You get plans to go heaven before?
Re: Yoruba Incantations. . . . . by cvibe: 9:21pm On Jan 29, 2009
Orogbo atanla obetodun ooo!
Re: Yoruba Incantations. . . . . by MrCrackles(m): 9:41pm On Jan 29, 2009
dayokanu:

Brash,
You get plans to go heaven before?

Dk of course, abi u nor wan go?
Bus they load oo
! cheesy
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 9:49pm On Jan 29, 2009
@brash,

na your time dem dey find for there?
Re: Yoruba Incantations. . . . . by MrCrackles(m): 10:43pm On Jan 29, 2009
dayokanu:

@brash,

na your time dem dey find for there?

It will shock you
! cheesy
Re: Yoruba Incantations. . . . . by chamotex(m): 11:30pm On Jan 29, 2009
At least I know the people i can fukc with now. cheesy
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 3:36pm On Jan 30, 2009
dayokanu:

Paga!!!!!

Emi lo de.

Obatala OOOOOOOOO

Won tun ti de oh
nitori wipe o dabi wipe obinrin ni iwo,

Awo egungun lobinrin le se
Awo gelede ni Obinrin le mo
Bi obinrin ba fi oju ba oro, oro a gbe!!!!

ma je kin binu oh

Mo tun ti de o
Mo se iba awon Iya mi Opake, olake, akoruru, alaruru, alagogo ide

Won ni kin ma su si epo mo su si epo won o ba mi wi rara
Won ni kin ma to si aala mo to si aala won o ba mi wi rara
Nitori owo ipopo ni a fin wo igi, owo orisa la fin wo afin

Oso ile lo ba pe ori mi ni ibi, Ogiri alapa ko ma wo lu won Ogiri alapa
Aje ile ni o ba n pe ori mi ni ibi, Ogiri alapa ko ma wo lu won Ogiri alapa
Bintab ni o ba n pe ori mi ni ibi, Ogiri Alapa ko ma wo lu won Ogiri Alapa

Nuff said tongue tongue tongue

Woo dayo, ti enikeni ba ba e soro kunba kungbe kan, so fun mi ki nba le foro won lo awon eleye cool
Re: Yoruba Incantations. . . . . by mafolayomi(f): 3:39pm On Jan 30, 2009
smiley smiley smiley una dey try ooooooooooooooooo. all na fun sha, make una carry go jare grin grin grin
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 3:50pm On Jan 30, 2009
Kamoteesi, ka sora o. U better not Bleep up with me cool Else, mo ma fi e gun ose ni angry
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 12:14am On Jan 31, 2009
farotika,

Mo ni kin kilo fun won ni . Nitoripe , Ma je kin soro ju

Ayalala ni mo ma be lowe
Re: Yoruba Incantations. . . . . by ariblaze(m): 12:49am On Jan 31, 2009
kilode?

she wan biso ni ma eja ni?

eyin people en try mi ooo

ok

ope baba mi titi lia lia

ope baba mi titi lia lia

orogbo ni oju oka wo

boo boo ni aguntan wo

ahsiri ile owo ile lo wa

omi o ni ota

gbo gbo eyin ti eba fe try me

by derailing this thread

ema yo ikun

bai bai
Re: Yoruba Incantations. . . . . by bintab(f): 12:43pm On Feb 07, 2009
Ogbeni Dayokanu ati farotika, mo gbedi fun yin o ,mo si se iba yin pelu. Mo ra owo ebe yin si yin e je ki n ko ire oko de le, omode ni mi, mi o laya akebo je.
Re: Yoruba Incantations. . . . . by argent(f): 12:58pm On Feb 07, 2009
Thread yi si wa alive, men eyin pips yin ntry.

E ti to run out of ofo. shocked
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 8:38pm On Feb 07, 2009
Ogbeni Dayokanu ati farotika, mo gbedi fun yin o ,mo si se iba yin pelu. Mo ra owo ebe yin si yin e je ki n ko ire oko de le, omode ni mi, mi o laya akebo je.

Gbe idi yen sun mo ibiyi, Ki awon Iya osoronga le dariji iwo.

Gbe idi yen sunmo ibi daada ki o si gbe ara duro tongue tongue tongue tongue
Re: Yoruba Incantations. . . . . by minute(f): 8:49pm On Feb 07, 2009
LOL @ Iya oshoronga.
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 8:09am On Feb 09, 2009
dayokanu:

Gbe idi yen sun mo ibiyi, Ki awon Iya osoronga le dariji iwo.

Gbe idi yen sunmo ibi daada ki o si gbe ara duro tongue tongue tongue tongue

Dayo, ijo wo ni babalawo tie di gbedi gbedi. Se o ti gbagbe ni pe ifa o kii nse eke beeni ifa o duro ti ika rara. Mase mu iwa sina wo inu ise awo o, ki ifa ba le gbe o cool
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 8:25am On Feb 19, 2009
OGUN CRISIS:’We’re Now Cursed On Phone’—Speaker
February 17, 2009 15:07 (8 hours ago), 637 views
By Jide Osokoya
Lawmakers in Ogun state have either changed their phone numbers or only pick select calls, to avoid being cursed on phone, a development which they said has become disturbing.

Speaking with P.M.NEWS on why most of them refused to pick their calls, the Speaker of the Ogun State House of Assembly, Tunji Egbetokun, said some people have been cursing them (lawmakers) on phone in recent times.

Said the Speaker: “To be sincere with you, our attitude in not picking calls is not out of arrogance, it’s simply a security measure, because some unscrupulous people now curse us on phone and even go to the point of chanting incantations.
“It is a shocking development, but that is the gospel truth. Most of them call with unidentified numbers and the moment you pick your phone, they will just rain curses on you. It is sad that Ogun state politics has degenerated to that level.”

P.M.NEWS investigation further revealed that most of the lawmakers now communicate through SMS. They no longer receive calls directly. Some of the lawmakers have even acquired new lines. It was further learnt that most of the strange callers often curse the lawmakers for engaging the state governor, Otunba Gbenga Daniel, in a political battle of wits.

A source close to the governor’s office, however, blamed the dirty politicking on a particular commissioner in Otunba Daniel’s cabinet, who has been labelled the governor’s ‘hit man.’ He was said to be involved in every scandal that had attracted negative publicity to the Ogun state number one citizen.

http://thepmnews.com/2009/02/17/ogun-crisis-we-are-now-cursed-on-phone-—speaker

Farotika well done. Your soldiers are doing well. More of that grin grin.
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 8:25am On Feb 21, 2009
Where is Farotika naa?
Re: Yoruba Incantations. . . . . by comfort3: 7:48pm On Feb 23, 2009
:-x
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 6:44am On Feb 25, 2009
Where is Farotika naa?
Na now whey your juju don de work wonders na im you come de tire? grin

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply)

Yoruba, Igbo And Acculturation (or Multiculture) / Top 10 Most Spoken Nigerian Languages / List Of First Class Kings In Nigeria By ThisTrend

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.