Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,584 members, 7,958,805 topics. Date: Thursday, 26 September 2024 at 01:56 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba Incantations. . . . . (97987 Views)
Yoruba Incantations (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply) (Go Down)
Re: Yoruba Incantations. . . . . by farotika(m): 3:41pm On Feb 25, 2009 |
jamace: Bawo ni jare booda jagbado (jamace) Emi o sa o. Ise kan po die ni owo mi ni. Ofo si po nile oluwere, beeni ogede o le tan nile awo. Ki awon amofin ipinle ogun maa se nkan ti won nse. Ase ntedulare |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by hajifaty: 2:12am On Feb 28, 2009 |
I respect you guys |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 11:49am On Mar 02, 2009 |
Yeeppaaa! |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by oronna: 3:29am On Mar 07, 2009 |
Iba aridegbe Balogun Orun, iba aresegba Balogun Isalu, Iba Arogunmatidi baba mi. Ina agbere kii jo Sango lawujo, otutu odo kii mu eja ninu osa bori amo ba foju kan oorun yiyo ni i yo, bi oba fi oju kan Toyin ki o ma woo sun sun bi Aguntan. Emi lo so be. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by TOYOSI20(f): 5:34pm On Mar 07, 2009 |
jamace: Ma exact sentiments too!! |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 6:18pm On Mar 07, 2009 |
which sentiments are you talking about? |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by TOYOSI20(f): 6:29pm On Mar 07, 2009 |
Abeg forget sentiments jare, u are the main the main naa. . . . . |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 9:14pm On Mar 07, 2009 |
Just like the way I feel about ya |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by TOYOSI20(f): 9:43pm On Mar 07, 2009 |
dayokanu: Ummm. . . .what else is new oo?? |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by dayokanu(m): 10:25pm On Mar 07, 2009 |
Tha feeling cant change na. Its always the same |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 3:55pm On Mar 09, 2009 |
The IFA chief priest, Farotika has gone on AWOL. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by okokomeji: 5:32pm On Jun 23, 2009 |
Opa odu gbedu, pomu odu bara, Oro bale kende kita, ofe gbemi paa. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by okokomeji: 5:33pm On Jun 23, 2009 |
Oparu jekejeke awo Inu gbo, Eyin jekee jekee awon Idi ona, Oro mo te mi o teku. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by nosmas: 1:34pm On Jun 24, 2009 |
E GBE ORI YIN SOKE EYIN ILEKU KI A SI GBE YIN SOKE EYIN ILEKU AYERAYE JE KI OBA OGO KI O WOLE TA NI OBA OGO NAA? ENI TI ODA ILE OUN AYE TI OFI IDE RE SOLE LORI OMI TI O NI KI BIBE MABE TI ONI KI ORUN KI OWO TI ONI KI IRE MA WA MI WA OYA EGBE ORI SOKE EYIN ILEKU IRE IKE ALAFIA KI OMA TO MI LEHIN KI OJURERE KI OMA JE TEMI OJO MOPE OOOO OOO KI OMA JE MI NIPE LOGAN LOGAN KI O FI OWO OTUN FARE WA BAMI KI O FI OWO OSI YE IBI SONU I NO TRY UP ME [flash=200,200][/flash] |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 3:16pm On Jun 24, 2009 |
jamace: Ologinni t'ajo de, gbogbo ekute ile e paramo Ipadabo abija re. Ode ti o ba gb'oju o gbodo duro de kinniun. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 3:19pm On Jun 24, 2009 |
Moruru ni s'awo nile moruru, morere ni s'awo nile morere, oro ti okete ba ba ile so, ni ile ngba. Gbogbo eyin ota mi o, e maa wole beeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeee |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by Witi(m): 3:45pm On Jun 24, 2009 |
Pese lese un pa ekolo oju ona, ona okin un di mo omo ejo ko ma ro na lo, aje o ki un buruburu ko bori ile, Akin un bori ojo,# Akin un bori oorun, Nigba ti orumila un wa isale aye awon kan ko ara won jo pe orunmila o no ri ona ola Orunmila wa fesi wipe enikan un borile, E ki yo bori mi Nitorina emi WITI mo wi loni wipe eki yo bori mi ooo |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by sholasys: 4:53pm On Jun 24, 2009 |
7 aligator pepper mark eji ogbe on the grand shew the pepper for 30sec then say 0' sha imole x3 ti didi ba di a'ba di ti ologbo sese ba se a'ba se reku reku koni ja ko fi oju ona si le , let me stop this is life. It works, Its owo. no matter the violent or trouble it will not come near u. after the incantation jst pour it on the eji ogbe. U can use it if u r going to a party ot a dangerious place 1 Like |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by adetunrayo(f): 5:35pm On Jun 24, 2009 |
This is serious o |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 9:04am On Jun 25, 2009 |
Eyi a ba wi f'ogbo ni ogbo ngbo Eyi a ba wi f'ogba ni ogba ngba Oro ti okete ba ba ile so ni ile ngba Adetunrayo oooooooo mo pe o l'oni o nitori bi a ba pe oku ni popo alaye ni ndahun latoni lo, bi o ba ri mi, ki o ma le sun igbe topsy ni ko ma fi ba enu ooooooooo Ase gun un |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by skyone(m): 9:20am On Jun 25, 2009 |
topsy25: Kai iro lopa emi skyone oloro emi ti a fi oba lo to ko si le bi ounje anaa oya egbiripo eberipo ko ma yii ko mayii otele otele ko ma ro ko ma ro gbo' un ti topsy25 ba so ko ma do mi oya ko ma mi |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 10:59am On Jun 26, 2009 |
skyone: Tani o Iwo ti gbagbe ni Wipe t'omode ba dari s'apa, apa a paa T'omode ba dari s'oroko, Iroko a koooo Ti arigidsegi ba segi, ori ara re nii fi ru Ki ogiri alapa ko maa wo lu e pa |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by jamace(m): 5:39am On Jul 05, 2009 |
See me , see something! Farotika, are you still here? Some senior boys are ursuping your job o! Abeg see this link: https://www.nairaland.com/nigeria/topic-291127.0.html |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 10:57am On Jul 06, 2009 |
jamace: |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 11:02am On Jul 06, 2009 |
jamace: Jamy my man. How u dey nau? I still dey o. As for dos dishonoured morons, dey dont know anything about our traditional rites. Notwithstanding, I'm not surprised cos in every 12, there'll always be a Judas NB: They are doing it the wrong way my bro. |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by alimat2(f): 11:52am On Jul 06, 2009 |
una de try 4 dis place oooooooooooooo, kudos u all, Anyway i nid sum1 to help me out cos my boyfriend dun run go, so if u can help me to u incantation on him, i go appriciate alot, maa dupe lowo ifa. contact me on 08012345678 |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 5:09pm On Jul 06, 2009 |
u don need us to call you; we can do it right here Olupe mo pe, olupe mo pe Iba akoda, iba aseda, iba ile ogeere afoko yeri Ololo olohun gbedu, iwo lo ma ngbeni mi bii kalokalo |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 5:22pm On Jul 06, 2009 |
u don need us to call you; we can do it right here Olupe mo pe, olupe mo pe Iba akoda, iba aseda, iba ile ogeere afoko yeri Ololo olohun gbedu, iwo lo ma ngbeni mi bii kalokalo Ikun iwaju ti kekere y'oke, adifa f'agunlenu be agogo, Odu alabahun pelu ileke lorun, adifa fun adifa f'eni a soro fun To lohun o ni gba, p ohun o ni gbo. Iwo orekunrin Alimat ti o fe ja ju sile, mo pe o loni o nitoripe Alimat ti sa to awa agba wa Irukere si re, me b'ohun ni ngbomo orumila Eyi a fi sowo otun, owo otun ni gbe eyi a fi sowo osi, owo osi nii gbe Oro ti okete ba ba ile so ni ile ngba Nitorinaa mo pe o loni iwo orekunrin alimat ti o ba wa lodo omo birin miran, ki kinni omokunrin re ma sise ti o ba ri alimat ki o ma le sun, ki o ma le je, ki o si ma le mu Bi ori ba ri oorun, inu re maa nyo ni; Bi o ba ri Alimat, ki inu re maa yo sii (hope the boyfriend u're talking about is Ifeleke ) |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by bintab(f): 9:21pm On Jul 06, 2009 |
topsy25:Tope you also had become iyalawo he, he he , |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 2:44pm On Jul 07, 2009 |
Bintab, emi o ki se tope2000 o, asewo ni omo yen emi ni farotika ti o yi awo pada si topsy25 |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by alimat2(f): 10:48am On Jul 08, 2009 |
@topsy25 Ha no no se u be baba/iyalawo, anyway thank u for u concern and dnt be suprise that u are the boyfriend that am talking about. topsy25ooooooooooooooooooooooooooooo Ife loni koma femi,ife loni koma ri mi, ti o ko bari mi o ko ni sun ohunfa loni ko fa mo mi ohundi loni ko di mo mi ohungbe loni ko gbe mi ni iyawo kosekose ni ti ilakose koribe kosebe poo poo pooo. ase gun |
Re: Yoruba Incantations. . . . . by topsy25(m): 12:01pm On Jul 09, 2009 |
alimat 2: Iro lo paaaaaaaaaa Nitoripe ape ni pelepe Asasi ni pa alasasi Ti elulu ba fa ojo ori ara re nii faa le Mo mo oruko ti aje nje nitorinaa aje o le je mi Mo mo oruko ti oso nje Oso o le so mi Mo mo oruko ti alimat nje nitorinaa alimat o le do mi |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply)
Yoruba, Igbo And Acculturation (or Multiculture) / Top 10 Most Spoken Nigerian Languages / List Of First Class Kings In Nigeria By ThisTrend
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37 |