Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,153 members, 7,818,483 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 05:04 PM

.. - Culture (17) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828994 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (14) (15) (16) (17) (18) (19) (20) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Isholex1love: 2:50pm On Aug 01, 2015
Baba E Jo Mo Fe Ogun Ije Lotto Tabi Nairabet
Re: .. by Isholex1love: 5:23pm On Aug 01, 2015
healthFirst:
34 OOGUN AFETA IBON
Ao te aso funfun sile, a o ko oju ologbo, atare,
, ati.......ao ko won sinu aso yen, oye ikan ko gbodo jura won ninu awon nkan wonyi, a
o di ni owu dudu ati funfun, a o ran ni awo funfun, fifi sara rin.

kan simi lori e-mail fun iyoku eroja
E Jo Kini Email Address Yin?

1 Like

Re: .. by virginary: 8:53pm On Aug 01, 2015
Isholex1love:
E Jo Sir Kini Ale Lo Ti Eyan Yio Fima Je Ayo Bi Lotto Ati Nairabet? E Se Pupo Oodua A Gbe Wa Oo
lolx
Re: .. by bosrote: 10:10pm On Aug 01, 2015
Aboru aboye month ke awo ati ogberi o. Ewe ama je fun wa o ejo. Eni to ba month ogun pile idi yiyo ati ogun somororo bi eyan obirin ban se omi lai ni oyun ta bi omo lowo ko fi ta mi lere, ewe ama je fun wa o
Re: .. by KEHINDE633(m): 11:00pm On Aug 01, 2015
[color=#000099][/color]ejowo nilo ogun ada ati obe to confamd pls
Re: .. by sheikhIsmailIdr(m): 11:52pm On Aug 02, 2015
Ejo gbogbo ile.......Edakun nitori olohun,mo nfe Ogun ti eniyan file ba asasi tabi ogun buruku je.Tin ba logun,ko kin sa baje to lara mi....Ogun ti nfi mu gbogbo idiwo yi duro leyi todaju saka ni mofe.Ejooooo eyin agbagba ile yi mojuba yin oooo esanu mi
Re: .. by Bosville(m): 11:20am On Aug 03, 2015
Isholex1love:
Baba E Jo Mo Fe Ogun Ije Lotto Tabi Nairabet
Mi olero pe ogun tete wa rara...gambling is all about luck.
Re: .. by Isholex1love: 1:50pm On Aug 03, 2015
baba e jo nitori eleduwa, e jo kinni email address yin ,mo nilo ise kan lowo yin, oodua yio gbewa o

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 1:55pm On Aug 03, 2015
Bosville:
Mi olero pe ogun tete wa rara...gambling is all about luck.

Eyin na ti ri itakun yi? #ibile

Eba mi so fun won o.
Re: .. by Lionhearted: 1:56pm On Aug 03, 2015
Isholex1love:
baba e jo nitori eleduwa, e jo kinni email address yin ,mo nilo ise kan lowo yin, oodua yio gbewa o

E lo si oju iwe kini ti itakun yi.
Re: .. by scholes0(m): 2:02pm On Aug 03, 2015
Lionhearted:


E lo si oju iwe kini ti itakun yi.

Ejowo, nje eyin naa ni atokun oludasile fun itakun yii ni, tabi eni oto ni Ogbeni "healthfirst" ?
Re: .. by Lionhearted: 2:13pm On Aug 03, 2015
scholes0:


Ejowo, nje eyin naa ni atokun oludasile fun itakun yii ni, tabi eni oto ni Ogbeni "healthfirst" ?

Rara o. Eni oto ni ogbeni healthfirst.

Idaun mi biyin ninu ni?

Oun ti eniti mofe si oro si nwa wa ni bi ti mo so.
Re: .. by Bosville(m): 2:22pm On Aug 03, 2015
Lionhearted:

Eyin na ti ri itakun yi? #ibile
Eba mi so fun won o.
I was once like him, nigba to ya ni mo se ri wipe omode ni nse mi.
Re: .. by scholes0(m): 2:23pm On Aug 03, 2015
Lionhearted:


Rara o. Eni oto ni ogbeni healthfirst.

Idaun mi biyin ninu ni?

Oun ti eniti mofe si oro si nwa wa ni bi ti mo so.

Rara o. Idahun yin ko bi mi ninu rara o...
Mo kan nse ayewo ranpe ni.. Ko ju bee lo. E seun pupo.
Re: .. by Isholex1love: 2:48pm On Aug 03, 2015
baba mo ti kan siyin nibe, e seun pupo
Re: .. by Isholex1love: 4:05pm On Aug 03, 2015
baba e jo e fesi si idahun mi
Re: .. by Nobody: 6:55pm On Aug 03, 2015
Isholex1love:
baba e jo e fesi si idahun mi

e-mail mi wa ni oju iwe kini ...page 1
Re: .. by dewda: 9:50pm On Aug 03, 2015
healthFirst:
5. KI OKUNRIN MIRAN MA LE BA IYAWO WA SUN
Ao ja ewe ewura meta ti aba yagbe, ao fi
nu idi wa, ao wa jopo mo odidi atare kan. ao po mo ori, ao mo fi pa oko ba
iyawo wa sun..

Okunrin miran ko ni le ba sun mo.
Ejo sir Healthfirst se Ewe ewuro ni epe ni abi Ewe Ewura?

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 10:15pm On Aug 03, 2015
kadunasouth:
IBA OMIN O!, OMIN TI INA MU TOKU

OHUN NA NI OMO ENIYAN MU TOLA,

MOBOJU WO APAMI OTUN WONJU BINNBIN
NI, MONI BOLEJU BINNI KOJU BINNI,

AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN,

MOBOJUWO APAMI OSI WONJU BINNI

BINNI MONI BOLEJU BINNI BINNI KOJU

BINNI AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE

ORUN AGBALAGBA BABALAWO KOLEBINU

KOFI OMO BIBI INURE BOFA AJIBOWU

NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA

ISEGUN KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE

BO OSEYIN, AJIBOWU NISE ALAGBEDE

ODE ORUN AGBALAGBA ALUFA ABI EWU

GEREJE KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE

PA ILEYA, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE

ORUN WONNI KIN MASU SEPO MOSU

SEPO WAN OBAMI WI RARA, WONI KINMA

TO SALA MOTO SALA WAN OBAMI WI

RARA, MOWAFI IKO ODIDERE NUDI OMO

OYEBE YEBE AYAMI OGBIRIGIDI MODI

IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI MODI

OMO OBANILE IFE ONI AYAMI OGBIRIGIDI

MODI IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI INU

KIBI BABALAWO KOFI AJA BO IFA INU KIBI

ADAHUNSE KOFI ELEDE TE ODU , EFUN

OMO OGERE IDE, EEDI OMO OGERE OJE,

OGANNA NI ORUKO OGERE IDE EFUN ATI

EDI WONJE ERU OBA NILE IFE, ONI NI IGBA
IWASE, ERU KISIPA OMO OHOWOREJE,

EDUMARE MAJE KI EFUN ATI ED OMO

ARAYE OMUNMIN POPO OKUN KONI ENINI

IRAWO OSA KONI GBOGBO, AKIGBE

AWORAN GEGE KAMOFI OWORE BA

IBIKAN LODIFA FUN YEWANDE TOFI

ODUNMETADINLOGUN WASE OGBURU,

OGBURU OGBARA MORE NITI APA OKUN

OMOLAYO OMO AJOMITAN WUWO OSO

GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, AJE

GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, IKU

GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO ARUN
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO etc

OMIN WO YANRIN GERERE OMI OLAPA

OMIN OLESE OMIWO IYANRIN GERERE

GBOGBO ENIYAN TIN BA NDOJU OTA KOMI

KI OMI AYE BAMI GBEWON LO MOBA OMIN
MULE LONI, ENIKAN KIBANI MULE

KOTUNSE IDANI, EWO ORISA.

Ise yi dara pupo

3 Likes 1 Share

Re: .. by Isholex1love: 10:21pm On Aug 03, 2015
mo ti kan siyin lori email yin
Re: .. by Nobody: 12:55am On Aug 04, 2015
dewda:
Ejo sir Healthfirst se Ewe ewuro ni epe ni abi Ewe Ewura?

Ewu Isu Ewura ni o, kii se Ewuro o!

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:56am On Aug 04, 2015
Isholex1love:
mo ti kan siyin lori email yin

O da, ma lo ye wo.
Re: .. by Sobandemojisola: 4:24pm On Aug 04, 2015
e
Re: .. by greatolusegun: 4:55pm On Aug 04, 2015
Ejowo ta lo mo oruko miran fun ewe tupinmu
Re: .. by kadunasouth(m): 10:49pm On Aug 04, 2015
Eyonu odaju
Ewe imin esu epo obo ao gun papo month ose dudu ao mafi we, iseyi kere loju sugbon odara pupo

4 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 6:08pm On Aug 05, 2015
E ku ise oluwa o.

E jowo kini eniyan le lo lati ma ranti daradara ohun ti a ba ka ninu iwe, ki a si ma gbagbe ohun ti a ba ka rara. E seun.
Re: .. by Isholex1love: 8:24pm On Aug 05, 2015
E KU ISE BABA,EWE AMA JE O , E JO MO NEED OGUN KI OGUN MA TETE DAUN LARA
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:02pm On Aug 05, 2015
[color=#990000][/color] OGUN MARAN OGUN
oku elena mesan pelu eyo atare mesan ati oju olongbo mesan ao lo papo ao fisingbere mate meta si rikerke ara wa ..joint of body

1 Like 1 Share

Re: .. by Emilokoiyawon: 12:13am On Aug 06, 2015
E ku i se. A kin fi o ju o loju sowo ka jere.
Re: .. by Isholex1love: 1:09am On Aug 06, 2015
e seun gan e jo mo need ogun agbepota to gbona na to je pe ti won ba ori eniyan ara ofuyan ki a to da pada si eni na
Re: .. by kadunasouth(m): 10:20am On Aug 06, 2015
Eyonu Awon Agba
Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo pupa lalale pelu adua odara pupo atude nipelu

3 Likes 1 Share

(1) (2) (3) ... (14) (15) (16) (17) (18) (19) (20) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 25
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.