Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,825 members, 7,813,722 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 05:00 PM

.. - Culture (96) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828193 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Yode138: 2:35am On Nov 13, 2018
Moki ara iwaju o. Edakun esanu no o. Aburo mi no oko re ati iyaoko we da abilu buruku lu. Edakun egbami mi o. A ti gbiyanju sugbon pabo ni o si njasi o. SOS!!!

1 Like

Re: .. by consato009: 10:51pm On Nov 13, 2018
Hello
Re: .. by dplanner: 1:47pm On Nov 16, 2018
MO KI GBOGBO ILE OOO, A KU OLA JIMOH ONI , ASIRI KAN NBE TO LAGBARA FUN GBOGBO EYAN TO BA NWA IPO OSELU NI TABI IPO TO KO JE , TO JASI TI A BA PARI RE WALLAHI GBOGBO AWON TO N BA WA DU IPO NINU PARTY ABI PARTY TO KU NI WON O NI GBO RA WON YE MO , TI NKAN MA FI DARU TI YI O SI JE TI TI ENI NA, LAPEJUWE OWO ISE ENI TO N WA IPO COUNCILLOR YATO SI GOVERNOR ATI BE BE LO , WALLAHI ASIRI NBE LODO AWON AGBALAGBA TO DAJU . PE 07067796292, 07055595911 TO BA NI FE SI KA SORO . MA SUN KO LE BA SUN SI WAJU , AYE KO SE WO LASAN OOOOOO
Re: .. by Yode138: 9:39am On Nov 21, 2018
OGUN TI WON KI FI DA EYAN DURO NI IBI ISE: ori ako alangba kan ati ase re, atare eyo kan. Ao Ki ase yen ati atare kan yen si lenu, Ao sa gbe. Ao WA we ni aso waji, Ao fi owu dudu ati funfun we. Odi awo(re re) ni ao fi ran. Ao wa ibikan ninu ile ise yen fi ise yi pamo si. Opari. O le my kuro nijo ti oba wun e lati fi ile ise na sile. Iba gbogbo eyin agba. Iba Iyanda, Omo Olowu oduru.
Re: .. by biometrics: 7:50pm On Nov 27, 2018
Canme4u:

Se omo odun mokandinlogbon naa le WO agbo yii?

Aboru boye...
Eyin agbalagba itakun yi, se eni to ba wani igbekun, le tura re sile fun rare pelu ogun itude tabi atuwo ati eni toba bii ni ninu irawo eran {leo} lelo ninu awon atude to wa ninu ikan yi?
Re: .. by biometrics: 7:56pm On Nov 27, 2018
08101646045atwp:
MOKI GBOGBO EYIN ENIYAN WA KUU DEDE AKOKO YIO, MOGBADUA FUN GBOGBO WA WIPE: GBOGBO IGBA KUUGBA TI YIO BAMA BAWA LAYE NI AO MAARI OPE RERE DA’O!
ADEKU’IMUNRA ODUN’O, AYO ATI ALAFIA NI AO FISE’O ¬¬(AMIN)

PATAKI ORO MI SI GBOGBO EYIN OLOLUFE IKANNI YI LOKUNRIN ATI LOBINRIN TI AN GBIYANJU LORI ASIRI EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI NI WIPE: MOSE AKIESI WIPE OPO AWON ASIRI KAN WA TI AKIISE AKIESI NIPA’E, TABI KI NSO WIPE AKOKAASI PATAKI GEGE BI AWON BABA WA SE NKAASI PATAKI NIGBA TI WON.
FUN APERE: AWATI OLOHUN FUN NI ANFANI LATI MON NIPATEWE’TEGBO LONA KAN TABI IKEJI, ODAJU WIPE AKOGBODO MAAFI OJU DI AWON NKAN AGBARA TABI KI AMAAFI OJU RENA AWON OGUN TABI AWON ASIRI BII:
IMULE
ETUTU
ABEGBEPE
ISOYE
AFORAN
AROBI
ERO
AWISE
OHUNMO
AKOYA
ATI BE BE LO!!
SUGBON EYI TI MOFE KI AJO JI RORO LORIE NI IMUNLE.
OPO AWON ENIYAN LO MA NRO WIPE BI ABA TI NSORO TI ATI DORI IMULE YI, WON MA NRO WIPE KIA WO INU EGBE KAN TABI IKEJI NI ORO YI TUMON SI, SUGBON TI KODE RI BEE RARA, TI ABA NSORO LORI IMULE AJE WIPE ORO TI DE ORI IFA NIYEN
ORUMILA BABA AGBONMIREGUN LOMA NBA AWON IYAMI ELEYE MULE NITORI IDIKAN TABI EKEJI.
FUN APERE BAKANNA: ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN LO NKI IFA OHEREMEKI LOJUDE AWON ELEYE LOJOKAN, NI AWON ELEYE BAYO SI ORUNMILA, WON NI KILODE TI ORUNMILA FI NKI IFA OHEREMEKI?
ORUMILA WIPE:NITORI AWON ALABOYUN KI WONLE BA BI WERE, ATI NITORI AGAN KI OLEEBA TI OWO ALABOSUN ATI NITORI AWON OKUNRUN ILE KI OLEE BA DIDE NILE, KI SISESISE LEBA LOWO ATI KI AWON ISOWO OJA KI WONLE BA RI ERE OJA.
AWON IYAMI ELEYE HA MON ORUNMILA WIPE KAI!
SE IWO KOMON WIPE SISESISE TI KONI OWOLOWO ERAN WA NIISE NI?
BE SINI SOWOSOWO TI KORI ERE OJA NA ERAN WA NIISE,
ALABOYUN TI KOBI ERAN WA NIISE
AGAN TI KORI OMOGBEPON ERAN WA NIISE
OKUNRUN ILE TI KODIDE ERANWA NIISE
ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN DAHUN ONI MOMON
SUGBON MOWA BAWON BEBE NI!
ORUMILA BEWON TITI WON’OGBO
ORUNMILA SIPE TITITI WON’OGBA
ORUNMILA NI TI ONBA BEYIN TI EKOBAGBO NOKI IPONRI (…..) FUN YIN’O
WON NI TI ORUNMILA BAMON KI OMA KII’O!
NI ORUNMILA BA BERE SINI WI BAI PE: (…………..)
AWON IYAMI ELEYE BA WIPE: ODARA AWON TI GBO!
ORUNMILA NI TI EBAGBO TI OHUN WIPE TI AWON OMO OHUN NKO?
NITORI AWON OMO (AWO) OHUN PO NI ODE ISALU AYE
AWON IYAMI ELEYE WA SE APEJUWE AWON EWE IFA KAN FUN ORUNMILA EGE BII IPINHUN TI AMON SI IMULE WIPE TI OBADI WIPE AKOFE DA AWON OMO RE MON MON KI OMAFI SE IFA FUNWON WIPE TI AWON BATI NRI AWON NKAN WONYI WIPE GBOGBO NKAN TI AWON BATI NTANI KOKO NI AWON YIO SI MAATU!
AKIESI KOKO ORO WONYI NTOKA SI PATAKI OJUSE IMULE
NITORINA EYIN ENIYAN MII ODAJU WIPE> IMULE KIISE NKAN TI ENIYAN LEFI OWORO SEYIN FUN AWA TI ANI ANFANI LATI MAALO EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI.
FUN IDI EYI EJEKI AJOJE ANFANI IFA IMULE TI OREMI KAN FI SE EMINA NI ANFANI KI OSE ELERI ORO NA

IMULE
Eyie adan,eyie onbe, atare odindi kan,a o Jo papo,ao wa ro sinu ado,lehin naa ao wa lowa Awo Sobi,Ao bu ebu yii sinu e pelu epo pupa lilo e ni ago kan oru ni ihoriho omoluabi ao fi ESE OSI ti ara ogiri ODAJU:::OFORE--BI OSO BADIN AJE NI TU NI,/ BI AJE BA DE NI OSO NI TUNI,/BI EMERE BA DE NI TOSO TAJE NI TU NI,/BI TOSO,TAJE,TEMERE,BA DE NI EYIN IYA MI OSOROGA NI TU NI SILE TO BA WA RI BEE GBOGBO IDE KU DE TI E DE EMI L OMO L KO MA TUU BAYI
IBA AWO TI OFUNMI NI ASIRIYIO

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?

Aboru boye...
Eyin agbalagba itakun yi, se eni
to ba wani igbekun, le tura re
sile fun rare pelu ogun itude tabi
atuwo ati eni toba bii ni ninu
irawo ina {leo -fire} lelo ninu awon atude to wa ninu ikan yi?

2 Likes

Re: .. by biometrics: 9:15am On Nov 30, 2018
why the silence on this thread. Are there no more elder?
To, iba akoda, iba aseda, iba olukosi, iba olukotun, iba awon orisa, iba awon agbalagba t'olorun ko ile aye si lowo.
Iba arawaju, iba ero eyin o, iba awon agba to wa ni ikan yi, iba awon agba tosi ni ikan yi mo.
Ki iba mi ose o, Iba! iba!! iba!!!
Aboru boye....

1 Like

Re: .. by biometrics: 9:07pm On Nov 30, 2018
Aboru boye....? Ema bami ka lo...
Re: .. by biometrics: 8:14pm On Dec 01, 2018
thank God today is December 1st
Eni ni ojo akoko osun titun December.
Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'.
I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread?

1 Like

Re: .. by biometrics: 8:01am On Dec 02, 2018
Atude/Atuwo/Ebe Agba
¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤
Ao fi ogede omini 3 ti o pon dada, atare odindi 7, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yi fiba atare yen ni gbogbo ara re. Ao she ogede 3 yen be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fingun iyan bo ogede omini/atare yen mole di ojo keji. Ao wa k'ogede 3 pelu atare yi sinu agbada, ao wa jo. Ta ba ti jo tan, ao wa lo kunaa dada. Awa da sinu
igo funfun.
Lilo re: Ao ma busi eyin owo wa, ao ma fi owo gba y'o si ma wole pelu ase olohun. Ki e to lo ise kankan fun alaisan, e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na lomi mu lasan pe kolo yio sise fun. Edanwo!
Re: .. by biometrics: 1:49pm On Jan 04, 2019
Happy New Year to you all. Eku odun titun o.
Re: .. by Nobody: 9:05pm On Jan 04, 2019
biometrics:
thank God today is December 1st
Eni ni ojo akoko osun titun December.
Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'.
I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread?
Does pandoro and ori amo work for enlargment of breast and penis?
Re: .. by Fm007: 11:22am On Jan 05, 2019
Ejowo kini je ijoka adie
Re: .. by Yode138: 1:46am On Jan 10, 2019
Ejowo e post Imule Asefijin yen pada.
biometrics:
thank God today is December 1st
Eni ni ojo akoko osun titun December.
Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'.
I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread?
Re: .. by Yode138: 1:50am On Jan 10, 2019
"thank God today is December 1st
Eni ni ojo akoko osun titun December.
Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'.
I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread"

Dplanner, ejowo e repost ise Imule Asefijin na. Eseun.
Re: .. by Yode138: 2:10am On Jan 10, 2019
Ago Aleko ati Moko Tobi learnt from this thread tode shaprapra.
Pandora tutu, odidi atare kan to gbe dada, eru alamo, eru awonka. Ao wa gbogbo re sinu pot, ao bu omi si ao se ni agbo. Idaji stainless cup. Mimu ni aro ati ale.
NB: You must warm it before you drink. Tested and confirmed!
camobri:

Does pandoro and ori amo work for enlargment of breast and penis?

2 Likes 1 Share

Re: .. by Funmiladey(m): 6:22am On Jan 11, 2019
E jowo, se ise yii ni ma mu ki oko tobi si, ati wipe ojo melo ni eniyan yoo fi loo ki ato da owo re duro?




Yode138:
Ago Aleko ati Moko Tobi learnt from this thread tode shaprapra.
Pandora tutu, odidi atare kan to gbe dada, eru alamo, eru awonka. Ao wa gbogbo re sinu pot, ao bu omi si ao se ni agbo. Idaji stainless cup. Mimu ni aro ati ale.
NB: You must warm it before you drink. Tested and confirmed!

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:29pm On Jan 12, 2019
Yode138:
Ago Aleko ati Moko Tobi learnt from this thread tode shaprapra.
Pandora tutu, odidi atare kan to gbe dada, eru alamo, eru awonka. Ao wa gbogbo re sinu pot, ao bu omi si ao se ni agbo. Idaji stainless cup. Mimu ni aro ati ale.
NB: You must warm it before you drink. Tested and confirmed!
odidi Pandoro ni a yio lo abi a yio ge? Ejowo, nibo ni motile ri Eru alamo ati eru awonka ra?
Re: .. by dplanner: 7:42am On Jan 17, 2019
EYIN TI WA , MO KI YIN PE AKU ODUN TUNTUN EMI YI O SE PUPO RE ASE OLORUN OBA ,ISE PO NI E FI RI OWO MI LATI OJO DIE ,EYI TI MO TUN MY WA NI YI OOO
OLUGBOHUN RIRISE TO CONFIRM TESTED AND TRUSED KO SI ISE TI ALE LO FUN , ISE NA LO BAYI
EWE INA, EWE ESINSIN , EWE ARAGBA , EWE OLOYIN , A O GUN PO MO OSE DUDU, A O FI EMU AILA PELU OGURO AILA PO PAPO PELU OTI SCHNAPP PO PAPO DADA, A O FI OGA AYE ATI EJA OJIJI AYE KAN TELE TELE IHO MALU YEN , A O WA KO OSE YEN LELORI , A O FI ASO PUPA BO LORI , A O WE MO LARA , A O MA SI ASO PUPA YEN LOJU TI A BA FE LO , GBOGBO ENI TO BA NIFE SI KO PE , 07067796292 TABI KO WHATSAPP MI LORI NUMBER YEN NA, NKAN TO FA TI MI FI SO ISE NA KALE TAN, TORI ISE TONI AGBARA NI, KI AWON EYAN MA LO MA SI LO FUN NKAN MI , AMO ENI TO BA PE MI TABI WHATSAPP TI MO RI PE LO OTO O NEED FUN KO LE MA RISE GBA DADA , MA FUN PELU MAJEMU TORIPE OF DAJU PUPO . FUN PIPE TABI WHATSAPP 07067796292.
Re: .. by dplanner: 11:29am On Jan 17, 2019
FUN AWON ALFA ATI AWA OMO KEU ELEYI NI OSE ISEGUN , ASINA TIAFIRIAYESE TO KA JUE
A o gun ori oka pelu epo obo ati kafura pelebe mo ose dudu , a o Han suratul masad tamo si tabatiyada 71 , a o fi omi die fo, ohun la o fi po ose yen pelu oronro malu ati lofinda bintu , a o ma we laro ki orun o to yo tabi lale ta ni jade mo .Fun ibere 07067796292 tabi ki e whatsapp mi lori number yen na .
Re: .. by biometrics: 4:48am On Jan 27, 2019
This Imule Asefijin reposted;
dominicson:

Imule: Asefijin
A o fi ikoode kan ha adaripon kan l'enu. A o fi atare kan naa ha. A o jo, a ko ni so kale ti o ba ti jo tan, a o fi omo olo lo mo inu ape, a o wa da epo pupa die si, a o fi ekiri aran malu kan si. Ti o ba ti din(fried), a o pa ina ni idi re, sugbon a ko ni so ikoko na kale. Ti o ba ti di agogo kan oru, a o da oogun yi si enu ona, a o bo ara sile ni ihoho, a o dobale, a o so wipe:
Psalm/nafdac
Asefijin, asefijin, asefijin, ti alangba ba se igba eniyan, idobale kan soso bayi ni nfi tan. Idobale mi re o, gbogbo enia ti mo ba ti se, oso ni, aje ni, emere ni... e fi orijin mi o. E je ki ona o la fun mi, ki n ri temi se o. Plus personal prayer.

2 Likes

Re: .. by dplanner: 11:44am On Feb 01, 2019
AKU OLA JIMOH ONI , EMI YI O SE PUPO RE , ELEYI NI ,
AWURE OWO ATI ONFA NEW CLIENTS FUN ENIKENI : Ako alangba kan , abo alangba kan , a o la mejeji laya , a o yo ifun won jade sori olo , a o lo pomo ose , a o fi eyin agric po ose na dada bi ose yen base posi ni ase malo eyin na , alelo eyin meji tabi meta ko sa ti dun ose na dada , a o wa ko ose na sinu ike funfun , a o ma we laro kutu kutu , awon alangba tayo ifun re , a o fi obi ipa sinu ako , a o fi obi ifin sinu abo , a o wa da aya mejeji korawon ninu ape , a o fi odindi atare kan si legbe , a o wa ko ewe sawerepepe bo mole ti ko ni Han Sita mo , a o jo po lai yipada , a o ma oti schnapp tabi oyin gidi lo , ti a ba ti we ose de lati ilewe, o daju ooo.Fun ibere tabi Nipa akosejaye ati irawo aye ko mo ibi to n lo whatsapp mi lori 07067796292
Re: .. by dplanner: 9:17am On Feb 02, 2019
MO KI GBOGBO ILE , A O NI DAMU LAYE WA O OOO AMIN , ETO YE RA RE WO TO NLO LOWO NI MONI KI N FI TO LE .
FUN AYEWO AKOSEJAYE ATI IRAWO RE KO LE MO SE TO BA O LARA MU, ATI GBOGBO NKAN TO ROMO AYE RE, TORIPE ELOMI TI LO OGUN DUDU TI KO SISE FUN, TO JA SI WIPE ADUA ATI SARA LASAN LORO GBA, ELOMI NKAN FUNFUN NI SOLUTION AYE RE , O TI WA LO ORISISI ISE , KO WA JE FUN , ELOMI IDIWO LO FA , TI ISE KO FI DAHUN, AYAFI KI KO FI NKAN MU IDIWO NA KURO PELU ADURA ATI SARA KI ISE TO LE MA JE FUN ATI BE BE LO , IWO TO BA FE JE ANFANI NI YI, PROMO NLO LOWO BAYI LATI YE RA RE WO PELU 3K PERE , TORIPE TELE 5K NI , AMA PROMO TI BERE LATI 31 DECEMBER 2018 TO MA PARI NI 311ST MARCH, 2019 LEYIN NA YI O PADA SI 5K RE PADA , IWO TO BA NIFE SI ,KAN SI MI NI WHATSAPP NUMBER 07067796292 , PELU ORUKO RE ATI AWON OBI RE MEJEJI PELU OJO IBI RE , PELU OGO OLORUN GBOGBO NKAN LO GBO LEKUN RERE NI PA GBOGBO NKAN TO ROMO AYE. WHATSAPP NUMBER 07067796292 .
Re: .. by dplanner: 5:31pm On Feb 10, 2019
FUN ANJO OMO BIBI TO CONFIRM INSHALLAH, WHATSAPP 07067796292
Re: .. by biometrics: 8:39am On Mar 06, 2019
Happy new month - March. God let the good of life begin in our life, amin.

AWORO - ABOMOLE TO DAJU.
=====================
Eyin ororo 8
Alabahun nla 1
Iyo isebe
Ao wa gbele lenu ona shop wa ti yo gba odidi alabahun naa. Ao koko fi omi tutu won inu iho ti a gbe yen. Ao wa bu iyo si. Ao wa gbe ijapa naa lelori, ao wa tun bu iyo si ti yo bo gbogbo ara ijapa yen mole. Ao wa to eyin ororo yen bi wipe atefa ejiogbe si ori iyo ti a bu si eyin alabahun naa ibi sonso eyin yen la fi gun o. Ao wa tun bu iyo si lori eyin naa ti eyin ko ni han sita. Ao wa fi hunkan bomole pako tabi pannu, ao wa ro yee pe bomole dada. O tan. Lesekese ni yoo bere ise o daju pupo o.
Re: .. by ayogabriel(m): 7:21pm On Mar 19, 2019
Mo ki gbogbo ile. E Jọwọ e ṣe iranlọwọ fun mi, oga mi oyinbo fe damidiro Leui ise. O san fu n HR manager wa pe, ni Friday o ma damidiro. O Fe gbe eyan ti ti e wole. Ejo, ajo wo mo le se?
Re: .. by dplanner: 8:13pm On Mar 29, 2019
ASIRI TI A FI NKO ILE MEFA LARIN ODUN KAN TESTED AND CONFIRMED
Omo eye ega meji , ti o wa ninu Ile loke , a o ja won tile tile , ewe esisi ojoo lopolopo, a o su losuka, lona meje , a o gbe agbada kana, a o to osuka meta , sori ara won ninu , a o wa ko awon omo eye ega na le lori tile tile , a o tun wa gbe ewe osuka to seku le lori , a o wa jo po ,a o lo kuna dada , a o ro ebu na sinu ado ide tuntun Kan, a o wa fi igi orijin ati Ikode kan di ado na Lenu pa , ti a ba ti wa pari ise na, a o gbe ado na sinu apoti lesekese , a o fon ekuru funfun si idi ise na fun ojo meta gbako , leyin ojo keta yi , a o lo aso awon agba meta, a o da sinu ise yi leyin igba ti a ti fon ekuru yen , a o wa fi ideri re de pada .
LILORE
A o din akara elepo nla kan , a o lu akara na ni iho (a o da lu ) a o da ebu inu ado yi sinu akara na , a o si je lesekese lobatan . Daju daju a o ko odindi ile kookan lona mefa larin ODUN KAN , to daju ti o si iyemeji nbe.
EWO RE
EWO meta nibe fun ise yi ,Akoko , a o gbudo fi enu kan akara elepo mo laelae , ekeji a o gbudo ko ile ju mefa na lo , bi o se gbogbo re ni yi o wo loju aye wa , te o si ni ko ile mo Titi , e o fije olorun ni pe , eketa , a o gbudo su mo obinrin fun osu meta gbako .
AKIYESI PATAKI
E se akiyesi, ti ise na ba bere ise , eye kan Ma ke ninu ikun wa, sugbon , a o gbudo beru , ko si wahala kankan o ti bere ise niyen .
T I A BA FE BA ISE NA JE
Leyin igba ti a ti kole tan , a o lo ewe ekuku tutu , a o fi se igbin agbonu nla kan je, a o lo ya igbe si ori akitan , a o si fi oju wa mejeji ri eye funfun kan ti yi o fo jade nibe , ogun ti baje ni yen ooo.
IWO TO BA FE SE ISE YI GBIYANJU KO KAN SI MI LORI WHATSAPP 07067796292 TABI KO PE KA LE SORO , TO RI OKU LEYIN LEYIN NI IBON N RO, O OOO.
Re: .. by biometrics: 1:35am On Apr 09, 2019
Aku new month moni aku osu titun olohun ada wa si o.
Re: .. by biometrics: 7:57am On Apr 09, 2019
IFERAN ATINUDENU FUN OBINRIN TODAJU
====================
Tobadi ago 12am oru -midnight- ni ao se ise yi o. Ekuru elewe kan ati iyereosun. Ao da iyereosun sori opon ifa, white paper tabi white plate kan ao te ni ejiogbe. Ao pe ofore si.
==========
Gbolohun re
==========
Okara 3x,
okooro 3x,
ifa iwo loko somo niye, lo ko ife emi lagbaja omo lagbaja si iye lagbaja omo lagbaja. Nitoripe ni ojo ti elekuru bakiri ekuru ni fobore tore fomo araye oni ibonbo ekuru. Ki lagbaja omo lagbaja fobore tore fun emi lagbaja omo lagbaja.
Ko di iyawo mi loni, ko male sun ko male wo, bio ba joko ko ma ranti mi, ohun kohun toba nse koma ranti mi, iyereosun loni kio male sun.
Ejiogbe oba lorun lo bami gbe ife emi lagbaja omo lagbaja si okan lagbaja omo lagbaja loni.
Ao da iyereosun naa sori ekuru naa ao ko je.
Iree o.
Re: .. by biometrics: 4:59pm On May 04, 2019
Happy New month - May.
Ajeogun
====<=
Ao ra ewe esisi, ewe ina, eyin ina - ao mu ogun ina. Ao sare so si pelu atare mesan. Ao lo. Ao wa fin singbere si owo ati ese wa.
Ire o
Re: .. by Nobody: 2:40pm On May 17, 2019
dominicson:




Things like this are always abused. But I will find a way of answering you privately. Best Regards


Hello please can you drop your whatsapp nunber let's talk privately?

1 Like

Re: .. by dominicson: 11:17pm On May 17, 2019
Ire2:


Hello please can you drop your whatsapp nunber let's talk privately?



08145802864

1 Like

(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 55
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.