Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,624 members, 7,809,325 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 07:51 AM

.. - Culture (19) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827291 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (16) (17) (18) (19) (20) (21) (22) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by tundebadmus(m): 9:48pm On Aug 13, 2015
iba eyin ti eledumare fi asiri ewe ati egbo ran ibayin oo,ejo wo inje ogun ti eni yan baji owo wa ti asi mon eni ti oji owo na inje ogun ti eyen lefi mon eni na inje owa eni ti oba ni iru ogun na ti osi daju ki oba wa fisi ta?iba eyin agba cryiba eyin ti eledumare fi asiri ewe ati egbo ran ibayin oo,ejo wo inje ogun ti eni yan baji owo wa ti asi mon eni ti oji owo na inje ogun ti eyen lefi mon eni na inje owa eni ti oba ni iru ogun na ti osi daju ki oba wa fisi ta?iba eyin agba
Re: .. by dominicson: 10:03pm On Aug 13, 2015
OJOTUNDEFELIX:
Ejowo mo ni lo Atude ati Eyonu ati ajegun todaju. Ewe ama je oo



Ajeegun

Ao fi omi agbon gbo ewe akoko mu aaro ki a to fohun (soro) si enikeni

5 Likes

Re: .. by OJOTUNDEFELIX(m): 10:20pm On Aug 13, 2015
Ese pupo ama je fun wa lola olorun ati awon ton jawe ati awon ton wagbo. Sugbon kind lo ma fa ti mo ba lo ogun ti kind Fi sise fun mi sugbon ti mo ba se fu elomoran ogun naa ma sise fun. Ejowo kilo fa
Re: .. by tundebadmus(m): 9:52am On Aug 14, 2015
healthFirst:
32 OKIGBE IGO TO DAJU SAKA

Ewe apada 7 to ti gbe, Idandan, igo towa lori sare ao fo ao lo die ninu e, eepo atare kan ati eyo 7, ewe osan wewe 7 toti gbe...
ao lo papo ,ao fi singbere meje si isale idodo wa!
ao tun fi otin ibile lo die ninu re
sugbon oni ewo kan!
ewo wo ni oni eje ka mon ewoye ki atoda owole,ewe yio maje o

4 Likes 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 10:12pm On Aug 14, 2015
AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE AWE-EPE etc
Efun ni baye osun je
Osun ni baye efun je
Atefun Atosun edu ni baye awon mejeji je.
Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe, idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi mu tin be lara oni kaluku wa koba je, kopa ibi da, koso dire, ki ona owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase odumare

5 Likes 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 10:19pm On Aug 14, 2015
AJEGUN
Egbo lapalapa ati odidi atare kan ao jo ao lo ao ma fi epo pupa la, lalale

2 Likes

Re: .. by bigfatthing(m): 10:32pm On Aug 14, 2015
kadunasouth:

Oruko miran to nje ni ewe rerinkomi tabi imi eran apakan nisale wan aman peni ewe kuo ati bebelo iwulo ewe na po pupo kolonka

Eseun pupo Baba
Re: .. by kadunasouth(m): 10:44pm On Aug 14, 2015
AJEGUN
Owo alangba mererin eyo atare 7/9 epo obo die ao jo papo ao fi singbere yipo orun owo wa mejeji
Mojuba awan Agbagba

3 Likes 2 Shares

Re: .. by kadunasouth(m): 10:58pm On Aug 14, 2015
ise ajegun todaju aowa oga kobaje aye kobaje eyiti otiku agan owo re otun afi eyo atare kasi aojo loto ao gan owo re osi aojo pelu eyo atare kan loto afiti otun si gbere yika owo otun afi ti osi sin gbere si owo osi ajegun todara ni

2 Likes 1 Share

Re: .. by tundebadmus(m): 10:21pm On Aug 15, 2015
bigfatthing:

Baba e jowse ise yi ko ni nkan buruku leyin
iba agba iba omo,baba ekuse ewe yio maje.ejowo baba kini ikan ti omafa ti ogun kifi je fun eni yan abi kini ikan ti eyan lese ti gbogbo ogun ti eyan se fun ara re tabi eyi ti won ba sefun eyan ti yofi je fun eyan,ese pupo oluwa aran yi lowo,
Re: .. by Frayo93: 7:40am On Aug 16, 2015
kadunasouth:
Aseje Owo togbona
Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju


.
ewe imi esu eyokan tojo, (tojo) yii ko ye mi. e joo kini o tunmo sii

1 Like

Re: .. by tundebadmus(m): 11:43am On Aug 16, 2015
KEHINDE633:
[color=#990000][/color] OGUN MARAN OGUN
oku elena mesan pelu eyo atare mesan ati oju olongbo mesan ao lo papo ao fisingbere mate meta si rikerke ara wa ..joint of body
ejowo ogun wo ni nije, ogun maran ogun.ejo e se alaye re fuwa..yio maju yin se oo
Re: .. by Isholex1love: 10:20pm On Aug 17, 2015
E jo kini elena
Re: .. by Nobody: 6:31am On Aug 18, 2015
E Jo mo fe mo oruko ewe yi ni Ede yoruba ati Ede gesin ( English). Ese pupo

1 Like

Re: .. by bolorunfem(f): 8:29am On Aug 18, 2015
Isholex1love:
E jo kini elena

Elena ni oruko miran fun Alantakun (Spider)

2 Likes

Re: .. by bolorunfem(f): 8:32am On Aug 18, 2015
E jowo se e le ba wa fi aworan "Ewe Imi Esu" han? Mo ti gbiyanju titi sugbon nko daa mo, ki nma loo fi aimokan ja ewe miran paapa julo nigbati kii se ohun ti a le ra lowo alagbo.

A dupe.

1 Like

Re: .. by Nobody: 11:44am On Aug 18, 2015
bolorunfem:
E jowo se e le ba wa fi aworan "Ewe Imi Esu" han? Mo ti gbiyanju titi sugbon nko daa mo, ki nma loo fi aimokan ja ewe miran paapa julo nigbati kii se ohun ti a le ra lowo alagbo.

A dupe.

E le ri Imi Esu ra lowo awon alagbo omo...O po kaakiri

1 Like

Re: .. by Nobody: 11:53am On Aug 18, 2015
Bi e ba fe dara po mo wa lori whatsapp, e fi number yin ranse si e-mail yi binaryteck@gmail.com, ao fi yin sori whasapp wa. Ao da whatsapp group sile fun awon ibeere sugbon eni to ba fe ibeere lori asiri, yio kan si wa ni idakonko.(private).

1 Like

Re: .. by Isholex1love: 12:34pm On Aug 18, 2015
e seun pupo
Re: .. by bolorunfem(f): 3:33pm On Aug 18, 2015
healthFirst:

E le ri Imi Esu ra lowo awon alagbo omo...O po kaakiri

E seun, sugbon ti a ba fee jaa (Ewe Imi Esu aka Rerin ko mi) fun eyonu ti a sii nilo lati baa soro ki a too jaa (i.e pee ni orukoo re "rerin ko mi''), se e mo pe ko nii dara ki a raa lori igba.
Re: .. by Isholex1love: 12:44am On Aug 19, 2015
E jo sir mo need ogun adabipada to gbona e jo ama juwa se o
Re: .. by avsnet: 4:19am On Aug 19, 2015
healthFirst:
Bi e ba fe dara po mo wa lori whatsapp, e fi number yin ranse si e-mail yi binaryteck@gmail.com, ao fi yin sori whasapp wa. Ao da whatsapp group sile fun awon ibeere sugbon eni to ba fe ibeere lori asiri, yio kan si wa ni idakonko.(private).

Email ti e fi sori afefe yi ko lo, mo ti ngbiyanju lataro, X lo nda pada funmi, e bawa ye arin yi wo.
Re: .. by Ojotundefelix1: 8:22am On Aug 19, 2015
Se leyin ta ba Jo tan latun ko sinu epo obo naa abi bo.
Re: .. by bolorunfem(f): 11:17am On Aug 19, 2015
avsnet:


Email ti e fi sori afefe yi ko lo, mo ti ngbiyanju lataro, X lo nda pada funmi, e bawa ye arin yi wo.

O lo ni odo temi, boya e ko ko adiresi yen daadaa ni, e tun yewo ki e tun gbiyanju re leekan si. Ire o.
Re: .. by dytex: 8:39pm On Aug 19, 2015
ekuse takun takun o olorun amabu kun isapa yin o ejowo bawo leyan she le mo ogun to ba eleda re mu

2 Likes

Re: .. by Nobody: 2:15pm On Aug 20, 2015
dytex:
ekuse takun takun o olorun amabu kun isapa yin o ejowo bawo leyan she le mo ogun to ba eleda re mu

Ona meji ni a le gba lati mo iru Oogun to ba Eleda wa mu; Ikini ni nipa wiwadi lowo Ifa wipe Oogun wo lo ro mo Eleda wa, ikeji ni nipa akiyesi bi a ba lo Oogun dudu, pupa tabi funfun, ewo ni a kiyesi wipe o n sise tabi ko sise. Eleyi se pataki pupo ninu sise Oogun...Idi niyi ti o fi je wipe, ki a to se oogun fun enikeni, ao koko se awon iwadi wonyi daada...ao pe Eleda eni na, yio si so fun wa iru Oogun to fe.

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 9:36pm On Aug 20, 2015
shoyemiayodeji:
E Jo mo fe mo oruko ewe yi ni Ede yoruba ati Ede gesin ( English). Ese pupo
Ewe abamoda (scientific name:: Bryophyllum Pinnatum )

2 Likes

Re: .. by Nobody: 10:49pm On Aug 20, 2015
kadunasouth:
Ewe abamoda (scientific name:: Bryophyllum Pinnatum )



E se gan oooooo.......much thanks.
Re: .. by scholes0(m): 2:19am On Aug 21, 2015
shoyemiayodeji:


E se gan oooooo.......much thanks.

Ki ni Iwulo ewe naa?
Re: .. by Nobody: 7:12am On Aug 21, 2015
scholes0:

Ki ni Iwulo ewe naa?



- Leaves used as astringent, antiseptic, and counterirritant against poisonous insect bites. - Pounded fresh material is applied as a poultice for a variety of conditions: Sprains, eczema, infections, burns, carbuncle and erysipelas. - Leaves, made pliable by hold over fire, are applied to wounds, bruises, boils; also, used as poultice or power in bad ulcers. - Juice is mixed with lard and used for diarrhea, dysentery, cholera, and phthisis. - Pounded leaves are applied as poultices to the soles of the feet to stop hemorrhages. - Leaves are used as topicals in dislocation, ecchymoses, callosities. - Leaves, pounded and mixed with salt, used as plaster and applied to stomach to relieve enuresis - For boils, the whole leaf is pressed by hand, to and fro, until it becomes moist with the leaf extract. A small opening is made in the middle of the leaf which is then placed on the boil with hole over the pointing of the abscess. - For asthma, leaves of leaves places in hot water for 15 minutes, then juice squeezed out of the leaves, and drunk. - Juice of leaves used in bilious diarrhea and lithiasis. - In Ayurveda, useful in vitiated conditions of vata and pitta, cuts, wounds, hemorrhoids, menorrhagia, boils, sloughing ulcers, burns and scalds, diarrhea, dysentery, headaches, vomiting, bronchitis. - In Puerto Rico, leaf juice used as diuretic. - Leaves are rubbed or tied on the head for headaches. - Leaf decoction usually taken to lower blood pressure. - Leaf juice used for earache and ophthalmia. - In Sierre Leon, cough medicine is made from the roots. - In Brazil leaves, heated over fire and mixed with oil, are used as emollient and refrigerant for facial swelling associated with neuralgia or tooth trouble. Also, used for asthma and bronchitis. - In Jamaica, leaves used for coughs and colds. Sometimes, it is mixed with salt or honey, for headaches, colds, bronchial affections, and hypertension. Heated leaves used for swellings and abscesses. - In Africa, used for earaches, eye problems, and as diuretic. - In China used for rheumatoid arthritis, bruises, burns and ulcers. • In Bangladesh, used for diabetes, wounds, boils, and insect bites. Also, used as diuretic, dissolving kidney stones. (27) - In Nigeria, plant is considered sedative, wound- healing, diuretic, anti-inflammatory, and cough suppressant. Leaf juice used to treat boils and skin ulcers. Plant used for intestinal parasites, bronchitis, pneumonia. (21)
Re: .. by abacusbabababa1: 6:07pm On Aug 21, 2015
Ewe a ma je fun yin ooooo.ejowo kinni itunmo obi ajoopa
Re: .. by Nobody: 11:28pm On Aug 21, 2015
[quote author=shoyemiayodeji post=37175973]




- Leaves used as astringent, antiseptic, and
counterirritant against poisonous insect bites.
- Pounded fresh material is applied as a poultice for a
variety of conditions: Sprains, eczema, infections,
burns, carbuncle and erysipelas.
- Leaves, made pliable by hold over fire, are applied
to wounds, bruises, boils; also, used as poultice or
power in bad ulcers.
- Juice is mixed with lard and used for diarrhea,
dysentery, cholera, and phthisis.
- Pounded leaves are applied as poultices to the soles
of the feet to stop hemorrhages.
- Leaves are used as topicals in dislocation,
ecchymoses, callosities.
- Leaves, pounded and mixed with salt, used as
plaster and applied to stomach to relieve enuresis
- For boils, the whole leaf is pressed by hand, to and
fro, until it becomes moist with the leaf extract. A
small opening is made in the middle of the leaf which
is then placed on the boil with hole over the pointing
of the abscess.
- For asthma, leaves of leaves places in hot water for
15 minutes, then juice squeezed out of the leaves,
and drunk.
- Juice of leaves used in bilious diarrhea and lithiasis.
- In Ayurveda, useful in vitiated conditions of vata and
pitta, cuts, wounds, hemorrhoids, menorrhagia,
boils, sloughing ulcers, burns and scalds, diarrhea,
dysentery, headaches, vomiting, bronchitis.
- In Puerto Rico, leaf juice used as diuretic.
- Leaves are rubbed or tied on the head for
headaches.
- Leaf decoction usually taken to lower blood
pressure.
- Leaf juice used for earache and ophthalmia.
- In Sierre Leon, cough medicine is made from the
roots.
- In Brazil leaves, heated over fire and mixed with oil,
are used as emollient and refrigerant for facial
swelling associated with neuralgia or tooth trouble.
Also, used for asthma and bronchitis.
- In Jamaica, leaves used for coughs and colds.
Sometimes, it is mixed with salt or honey, for
headaches, colds, bronchial affections, and
hypertension. Heated leaves used for swellings and
abscesses.
- In Africa, used for earaches, eye problems, and as
diuretic.
- In China used for rheumatoid arthritis, bruises,
burns and ulcers.
• In Bangladesh, used for diabetes, wounds, boils,
and insect bites. Also, used as diuretic, dissolving
kidney stones. (27)
- In Nigeria, plant is considered sedative, wound-
healing, diuretic, anti-inflammatory, and cough
suppressant. Leaf juice used to treat boils and skin
ulcers. Plant used for intestinal parasites, bronchitis,
pneumonia. (21)[/quot


A ko fi aye gba ede geesi lori abala yi, mo lero wipe e ka abala yi lati oju iwe kini?

2 Likes 2 Shares

(1) (2) (3) ... (16) (17) (18) (19) (20) (21) (22) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 59
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.