Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,740 members, 7,817,042 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 12:27 AM

Igbeyawo Toyin Aimakhu Ti Bere Si Ni Yoro Bi Oori Ti Won Gbe Sinu Oorun Bayii - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Igbeyawo Toyin Aimakhu Ti Bere Si Ni Yoro Bi Oori Ti Won Gbe Sinu Oorun Bayii (1505 Views)

Ogun Ti Won Kii Fi Paro Mon Eniyan / Asiri Agbara Lati Mu Ona Ola Si Kia Kia / [Audio] "Bayii Ni E Se Le Se Awari Ebun Yin": Alaye Lati Enu Olayemi Oniroyin (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Igbeyawo Toyin Aimakhu Ti Bere Si Ni Yoro Bi Oori Ti Won Gbe Sinu Oorun Bayii by OlayemiOniroyin(m): 6:22pm On Aug 28, 2015
... /1KdnpYB

Laipe yii ni omobirin naa yo oruko oko re kuro ninu oruko re. Bakan naa ni awon eniyan tun kiyesi wi pe awon foto oko re to wa lori ikanni instagram re lo ti fe e gbonyo tan.


Adeniyi Johnson ti n be iyawo re bayii, o ni oun loun jebi ohun to n fa wahala laaarin awon mejeeji. E le ka alaye re nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881199908632560&set=gm.1037407549643887&type=1


Awon kan ni oko re se asemase kan ni, isele naa si bi Alakada ninu pupo ju.

Awon eniyan kan ti n be Toyin wi pe ko maa binu, nigba ti awon kan n naka abuko si oko re ati gbogbo okunrin gege bi olojukokoro, to je wi pe gbogbo ejo ni jije lodo won.

E tun le ka ohun ti awon ololufe Toyin n so nibi: http://www.facebook.com/photo.php?fbid=881200005299217&set=gm.1037407549643887&type=1

www.olayemioniroyin.com

(1) (Reply)

Community Where The People Move Around Naked And What Attracts Men Is Not Nudity / Please I Need English/ French Interpretation / New Pictures Of Emir Of Kano Fourth Wife, Sa'adatu

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.