Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,303 members, 7,836,314 topics. Date: Wednesday, 22 May 2024 at 04:34 AM

Itọrẹ Anu – (onibu Ọrẹ) - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Itọrẹ Anu – (onibu Ọrẹ) (480 Views)

(2) (3) (4)

(1) (Reply)

Itọrẹ Anu – (onibu Ọrẹ) by Agod: 2:13pm On Mar 19, 2016
Itọrẹ Anu – (Onibu ọrẹ)

1. Oluwa ọrun on aiye,
'Wọ n' iyin at' ọpẹ yẹ fun;
Bawo l' a ba ti fẹ Ọ to,
Onibu ọrẹ.

Onibu ọrẹ,
Onibu ọrẹ;
Bawo l' a ba ti fẹ Ọ to,
Onibu ọrẹ.

2. Orun ti nran at' afẹfẹ,
Gbogbo eweko nsọfẹ Rẹ;
'Wọ l' o nmu irugbin dara,
Onibu ọrẹ.


3. Fun ara lile wa gbogbo,
Fun gbogbo ibukun aiye;
Awa yin Ọ a si dupẹ,
Onibu ọrẹ.

4. O ko du wa li Ọmọ Rẹ,
O fi fun aiye ẹsẹ wa;
O si f' ẹbun gbogbo pẹlu,
Onibu ọrẹ.

5. O fun wa l' Ẹmi Mimọ Rẹ,
Ẹmi iye at' agbara;
O rọ jo ẹkun 'bukun Rẹ,
Le wa lori.

Le wa lori,
Le wa lori;
O rọ jo ẹkun 'bukun Rẹ,
Le wa lori.

6. Fun idariji ẹsẹ wa,
Ati fun ireti ọrun;
Kil' ohun t'a ba fi fun Ọ?
Onibu ọrẹ.

7. Owo ti a npa ofo ni,
Sugbọn eyi t' a fi fun Ọ;
O je isura tit' aiye,
Onibu ọrẹ.

8. Ohun t' a bun Ọ, Oluwa,
'Wọ o san le pada fun wa;
L' ayọ l a o ta Ọ l' ọrẹ,
Onibu ọrẹ.

9. Ni ọdọ Rẹ l a ti san wa
Ọlorun Olodumare;
Jẹ k'a le ba Ọ gbe titi,
Onibu ọrẹ.

(1) (Reply)

How To Get Out Of Helplessness / The Chosen Daily Devotional 24th March, 2016 / Eternal Damnation

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.