Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,362 members, 7,957,969 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 06:10 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (176283 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (73) (Reply) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:51pm On Dec 23, 2009 |
@ everyone SE E GBORO IFELEKE SHA!,, ABI AWON EFCC TI GBEE NI, LOL |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 8:25pm On Dec 23, 2009 |
adolfe bad: Omo Hausa, lol, daadaa l'awa omo Yoruba wa o, Odun ti ndun sugbon ti awon ara wa ni ile ifowopamo ti ise nbo lowo won yii da bi nkan ooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dominique(f): 10:47pm On Dec 23, 2009 |
Remii: omase o! Olorun yo o pese ise gidi fun gbogbo won ni odun tun tun. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 5:16pm On Dec 25, 2009 |
Could some translate this to English for me? : Gambari nta nanma, eran nta eran. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 5:48pm On Dec 25, 2009 |
[size=18pt]~*~*EKU ODUN KERESIMESI~*~*[/size] |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 5:48pm On Dec 25, 2009 |
Orilee9ice: i WAS WONDERING ABOUT HIM too. Hope he's okay sha |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 6:08pm On Dec 25, 2009 |
Orilee9ice: E beere re lowo tubabie, a dabi eni wipe won mo ara won tayo NLand, lol |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dominique(f): 7:00pm On Dec 25, 2009 |
Remii: gambari nt mamma nko nse ede yoruba, hausa ni. means mola is selling meat ~~~EKU ODUN KERESIMESI GBOGBO OMO LEYIN KIRISTI NI NAIRALAND. . .ODUN A YABOOOOO!!! ~~~ |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 2:23am On Dec 26, 2009 |
Remii: Remii Tin ba translate oro re si ede oyinbo, ti enikan ba bu mi, ki o ya gbeja mi o. Gambari nta nanma, eran nta eran means 'Gambara is selling smoked meat, animal is selling animal' |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 9:03am On Jan 01, 2010 |
^^^^ @fayesik, mimi kan ko si. O see gan an, mo lero wipe maalu lonje nanma, I know better now, Thanks a lot. Happy New Year to all. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FBS: 11:54am On Jan 01, 2010 |
Gbogbo ile, eku odun titun yi o! Oluwa Olorun Oba A dawa si o! @Orile9ice, oremi ataata! Bawo ni le? awon temi nko? se gbogbo e n'dun? how was the New Year parriy? Iya mi ti de si ibi bayi, won de ti ri omo'mo won. Adupe ni owo Baba l'oke! E jowo eyin eniyan. . .Ifeleke nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by biina: 6:54pm On Jan 01, 2010 |
E ku odun, e ku iye'dun, odun titun yii a y'abo fun gbogbo wa. Iwo yi emi, a tun parapo wa yo ni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 6:57pm On Jan 01, 2010 |
happy new year, my lovely people |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 12:59am On Jan 02, 2010 |
Eyin eeyan mi , aku alaja odun, emi wa a se opo e lagbara Olorun. Eku igbadun, ekaabo si inu odun isimi yii |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 3:26am On Jan 02, 2010 |
Eku alaja odun o, eyin temi ni NL. 2010 a yabo fun gbogbo wao. Idunnu ati ayo ni a o fi lo odun na ja. ire ati aanu oluwa yo ma wa pelu gbogbo wa ati awon ara ile wa o (amin). Hmmmm! a si ku ti omo Nigeria ti o fe so wa loruko. Nigeria ko ni baje o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by geogentle: 11:40am On Jan 02, 2010 |
Eyin omo Oduduwa, mo ki gbogbo yin lookokan. Alale ile yoruba yio gbe gbogbo wa o. A si ku odun, a ku alaja odun. Emi wa a se pupo re. Lola Eleduwa gbogbo ire ti o to si wa ninu odun yii ko ni fo wa. Oba kabikabi ode orun a ka gbogbo ibi kuro ni ona wa gbogbo. ire ow, ire omo, alekun anfani ati alafia ti nse bale oro ni Eleduwa a fi te wa lorun ninu odun titun yi. Odun yi a se wa so'wo, a se wa s'mo. Alakoba o ni ko ba wa, gbaya gbaya ko ni gba aya wa, gbomo gbomo ko ni gbe wa lomo, gboko gboko ko ni ya lo de wa. Ire o, ire gbangba, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 11:54am On Jan 02, 2010 |
tubabie: tubabie, ni bo loo fi Ifeleke sii? or are you not your brother's keeper? FayeZik: Fun gba die naa ni, adun ni yoo gbeyin ewuro lagbara Olorun. Aa kuku yee. Nkan maa pada bo si po laipe. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 1:57pm On Jan 02, 2010 |
Remii: Ifeleke ke? Mo ni ro pe o n gbadun odun pelu awon ara ile e. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 2:56pm On Jan 02, 2010 |
awon ti won ma ntu brassiere ni NL ti fi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by ifyalways(f): 3:36pm On Jan 02, 2010 |
Eku odu gbogbo Omo Oduduwa. @FL gators ati Toyosi,wishing u a beautiful and stress-free 2010.Alafia front,back,right and left |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by skfa1: 3:37pm On Jan 02, 2010 |
Eyin temi ni abule, ki lon she le men |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 6:41am On Jan 03, 2010 |
ifyalways: I meela. Takia ma dear, the best for you this year |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 12:14pm On Jan 04, 2010 |
EYIN Ore mi GBOGBO, FBS, TUBABIE, CHOMATEX, OLUSENCHO, IFELEKE.A.B.B.L Happi new year oh! Mo korin fun gbogbo wa pe, (going down memory lane, The Good Women Choir led by Mrs Fashoyin in Ibadan ile) Odun yi a yabo ko ni le koko mo wa, odun yi a yabo ko ni le koko mo wa Ohun ti a dawo le, A YORI, Ohun ti a bere lo'luwa yo see, Odun yi a yabo ko ni le koko mo wa Olorun o seun to'dun to ko ja, (a.b.b.l) someone can complete this part 4me as i cant seem to remember this part of the Good women Choir song) Eni ko yi bi, e maa banu je, edumare ti segun a se danu Olowo a maa ri se, Onisegun a bo'de pade Ayun lo, a yun bo lo'wo ye nu, Amin! Odun a yabo fun wa. Amin, Odun a yabo fun wa ase!!, @FBS, Eku afojuba Mumsie o! se otutu o mu won ju sha? e maa Flenjor lo oh! 9ice one! THIS IS OUR YEAR TO SHINE IJN! AMEN! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 12:20pm On Jan 04, 2010 |
H mmmm! a si ku ti omo Nigeria ti o fe so wa loruko. Nigeria ko ni baje o.@fAYEZIK Hummmmmmmmm my sistha, abi o, o fe so waa lenu but olorun o ni fun see, waa woo bi won sen check wa in airport this last week, especially ti o ba ti ni pali abi oruko 9ja, Olorun ti segun sha! 9ja o ni baje o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 7:52pm On Jan 05, 2010 |
Emi ti nreti pe ti nba ma lo si 9ja laipe, ao ma se pap smear ni airport ni. Olorun sa ko wa yo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 7:40pm On Jan 09, 2010 |
[img]http://www.wired-and-inspired.ca/EDEL435/process/storytelling.jpg[/img] Ebe fon l'abata E yo obe, yo aake ti omi ni e ro pe omu ku ni ****************************************** Ogun logbon eniyan ni ko mo epile si owe yoruba nitori idi yi mi o si so ipinle owe yi ********************************************************** Ni odun gbere!! Akoni olode nkan nbe Oguniyi ni nje Ode aperin ni Oguniyi Osi ti di opolopo igun Ni irole ojokan ti Oguniyi dege gege bi asa re Oguniyi kan eranko nla kan - EFON Oguniyi luko Ohun ati Ibon owo re, ni nwa yo kele kele ti ofi sunmo efon na afi KEM!!!!!!!!!!!!!!!!!! ni o ba yin Ibon owo re Efon ke rora!!!!! ni dagbo ru, ni da gbogbo e ru afi fia fia fia, ni ma ja lo kia Oguniyi ti gba te le Ni to pa se e lo Nigbati efon de abata kan Afi gburu!!!!!!!!!! O wo lu le, osi gbe emi mi Awon ara abata yi Won ba ko ra jo Eni mu obe mu obe, eni mu aake mu aake Afi kia, won lo re bu efon Aipe re ni Oguniyi yo lehin wan ni oba wipe haaaaaaaaaaaaaaaaaaa! Ebe fon l'abata E yo obe, yo aake ti omi ni e ro pe omu ku ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by segoye2(m): 8:49pm On Jan 09, 2010 |
Dear All, You can now write for free on Media Lens Africa (www.medialensafrica.com) They currently look for writers/reporters/contributors/editors etc, send your articles to hotnews@medialensafrica.com our segoye4@gmail.com You stand a chance to secure an access as a contributor on the website after a long tested walking of sending in articles. Log on to the website and see how you can use it to read the entire world. Media Lens Africa gives all news without exception. Regards, Media Lens Africa website Administrator. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FayeZik(f): 3:48am On Jan 10, 2010 |
@ faakay Emi lero wipe 'e ba efon l'abata' ni won wi ni. Se 'abasa' ni tabi 'abata'? Ati wipe kinni nje bee? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 4:29am On Jan 10, 2010 |
FayeZik: thanks for the correction. mo ma make atunse |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by blandyne(f): 10:45pm On Jan 11, 2010 |
Sorry for derailing this thread but i really need someone to translate this for me : [b] MI O MO YEN[/b] I posted it in the translation thread, unfortunately no one reply to me. Thanks. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 11:05pm On Jan 11, 2010 |
MI O MO YEN = I don't know that |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IYANGBALI: 8:20pm On Jan 12, 2010 |
blandyne:it means come make we fok |
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (73) (Reply)
Yorubas, Please Help Me Translate These Words. / Most Frequently Used Insult In Nigeria / Funny But Wise African Proverbs.
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39 |