Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,297 members, 7,811,887 topics. Date: Sunday, 28 April 2024 at 10:20 PM

Yara Iwosan Ibile Yoruba - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yara Iwosan Ibile Yoruba (5022 Views)

Oyinbo Ibile - Portuguese Boy Speaking Yoruba Fluently + American Lady Too / Ogun Ibile Awön Baba Wa / Asa Ibile (a Yoruba Drama) (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 9:58pm On May 04, 2018
Yara yi wa fun iwosan nikan, ogun iwosan lo je wa LOGUN ninu yara yi
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 10:00pm On May 04, 2018
A ku dede asiko yio gbogbo eniyan
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Obainoneandonly(m): 10:09pm On May 04, 2018
where is d venue
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 4:34pm On May 07, 2018
OOGUN INU RIRUN
Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O daju.
IDAKOLE(Amokole)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.
OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE
Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.
OORU INU(internal heat)
Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan leemeji lojumo.
OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo na.
Oogun iko to daju> Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!
ATOSI::: odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta. Odaju
AKOKORO:: Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju o.
EGBOGI GBOGBONISE............isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo arun.
EGBOGI JEDIJEDI (ogun jedijedi)
egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 4:36pm On May 07, 2018
*Emi woli Adejorin Michael a k a iyamah iyamah fi awon ise yi ki awon musulumi to wa larin wa pe a ku imunra sile awe tonbo lona yio bawa ninu alafia ati ifokanbale lase edumare.*

OOGUN INU RIRUN
Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE(Amokole)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE
Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.

OORU INU(internal heat)
Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan leemeji lojumo.

OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo na.

OOGUN IKO TO DAJU
Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

ATOSI:::
odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta. Odaju

AKOKORO::
Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju o.

EGBOGI GBOGBONISE............
isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo arun.

EGBOGI JEDIJEDI (ogun jedijedi)
egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.

✍� *WOLI ADEJORIN MICHAEL a k a iyamah iyamah*
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 4:46pm On May 07, 2018
*OGUN TI AFI WO AISAN WARAPA KAN RE,*
odidi omo aja kan ti ko ti laju,eru ti ko ba la enu,siri, iyere kan, obu otoyo,ao lo gbogbo re papo ao ge aja yen si mesan,adi eyan ni ao fi se obe yi,yio ma la eran yi ati omi obe na yio ma je eran na ni okokan ✍� *adejorin Michael a k a iyamah iyamah*
Re: Yara Iwosan Ibile Yoruba by Wam24(m): 3:56am On May 09, 2018
ASERO KI OYUN LE DURO (ANTI-MISCARRIAGE). ASEJE ASERO.
Ewe laali pelu omi agbon ni ao fise eja aro ... ni owuro ojo keji ti o pari nkan osu.

1 Like

(1) (Reply)

Itan Yoruba / Has Nigeria Ever Produced A True Genius In Any Field? / Igbo-ona, Ijebu-igbo, Igbomina: Are Yoruba's Historically Tied To Igbo's

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 23
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.