Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,239 members, 7,818,812 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 05:15 AM

Aseje Awure - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Aseje Awure (3262 Views)

Awure Itaja (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Aseje Awure by Awogbengaapenao: 7:10am On Feb 17, 2021
ASEJE AWURE --
Ewe inabo, atajosin die, ao lopo, igbin nla Kan,ao bo, aogesi mesan , odidi eja aro tutu kan aonige rara, iru woro die, isasun tuntun,ao se ,ti obafe jinna, ao fo eyin ibile kan si, ao soka ori osuka ,ao fi iyerosun te Ifa ogundabede, leyin gbolohun re,ao dasi ao koje -- Ogundabede oleee /3x Owo niki olojikowa funmi o, owo nlanla nio, oju oloko ni inabo sesola, oju gbogbo omo araye ni kinsedi olowo, ki nmamo apadasi aburu laiye mo, gere aya ni igbin fifa, tokunrin tobinrim ki won maafa owo nlanla wafun emi lagbaja omo lagbaja loni ooo
FUN IBERE WhatsApp number 09010179226

(1) (Reply)

Do You Support Euthanasia? / My Wife Is A Possesed, Every Child Born By Her Dies Before Age 1 / The Most Powerful Brain Enhancer Drug In The World?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.