₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,008,991 members, 4,260,635 topics. Date: Saturday, 26 May 2018 at 06:55 AM

Post Yoruba Christian Hymns Here - Religion (3) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Post Yoruba Christian Hymns Here (170649 Views)

Post Your Favourite Christian Hymns / Share Your Best Hymns / Christian Hymns/songs And Copyrights (1) (2) (3) (4)

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply) (Go Down)

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by oluemmakay(m): 6:20pm On Feb 27, 2012
Ninu irin ajo mi
beni mo nkorin
mo ntoka si calvari
ni bi eje na
idanwo ninu lode
lota gbe dide
Jesu lo nto mi lo
isegun daju.

6 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Nobody: 8:39pm On Feb 27, 2012
abouqi:

This is interesting! So eyin omo kaa ro o jire po ni Nairaland bayi?

Ese gan o, l appreciate the Poster also.

So you guys still remember these Hymns like this?

E fe k'ori awon ko gbo nkan t'a n so ko maa swell ni yi o.

Well, let them post theirs.

Thank you all!

grin grin grin

Kilode to n waja ? grin grin grin
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Nobody: 8:49pm On Feb 27, 2012
Not sure if this one's a hymn but I heard it at an Anglican church once

Mor'ohun to j'ayo
Jesu mi j'ayo lo

Aso nla ko l'eniyan nla
Jesu mi j'ayo lo
Bata ese ko go ti giga o
Jesu mi j'ayo lo
Mi ri'le ola to da'horo ri
Jesu mi j'ayo lo

Emi ti r'ohun to j'ayo
Baba mi o j'ayo lo

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 8:51pm On Feb 27, 2012
Mo fe kin dabi Jesu

Ninu Iwa pele

Ko si eni to gbo roro binu

Lenu re lekan ri

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Ninilowo(m): 9:28pm On Feb 27, 2012
Oluwa mi mo njade lo
Lati se ise oojo mi
Iwo nikan lemii yoo mo
Loro lero ati nise

Ji okan mi ba oorun ji
Mura si ise oojo re
Mase ilora ji kutu
Ko san gbese ebo owuro

Ose ose rere iwo ojo sinmi
Oye ka fi ojo kan fun Olorun rere
B'ojo mi tile mekun wa
Iwo N'oju wa nu
Iwo ti n sojo ayo emi n ffe dide re.

E fun pe naa kikan
Ipe ihinre
Kodun jake jado
Leti gbogbo eda
Chrs:odu idasile ti de pada elese pa da aa
Odun idasile ti de pada elese pada.

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by suxes2006(m): 9:45pm On Feb 27, 2012
Join Yoruba heritage group here:

http://www.facebook.com/groups/260604827334729/

SHALOM
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ireke(m): 9:51pm On Feb 27, 2012
moremi2008:

Does anyone have the rest of the lyrics for:

Enikan be to feran wa, A o fe wa
Ife re ju ti ye kan lo, A o fe wa
Ore aye ko wa sile
Bi oni dun, ola le koro
Sugbon ore yi kii tan ni, A o fe wa


stanza 2:
Iye ni fun wa b'a ba mo
A! O fe wa
Ro b'a ti je n'igbese to
A! O fe wa
Eje re l'O si fi ra wa
Nin'aginju l'O wa wa ri
O simu wa wa s'agbo re
A! O fe wa

3:
Ore ododo ni jesu
A! O fe wa
Ofe lati ma bukun wa
A! O fe wa
Okan wa fe go ohun Re
Okan wa fe lati sunmo
On na ko si ni tan wa je
A! O fe wa

4:
L'oko Re l'a nri 'dariji
A! O fe wa
On o le ota wa sehin
A! O fe wa
On o pese 'bukun fun wa
Ire l'a o ma ri titi
On o fi mu wa lo s'ogo
A! O fe wa

1 Like 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ireke(m): 9:59pm On Feb 27, 2012
Bi Krist ti da  okan mi nde
Aye mi ti dabi orun
Larin 'banuje at' aro
Ayo ni lati mo jesu

Chorus:
Halleluya Ayo l'o je
Pe mo ti ri 'dariji gba
Ibikibi ti mo ba wa
Ko s'ewu Jesu wa nibe

Mo ti ro pe orun jinna
Sugbon nigba ti Jesu de
L'orun ti de 'nu okan mi
Nibe ni yo'o si wa titi

Nibo l'a ko le gbe l'aiye
L'or'oke tabi petele
L'ahere tabi agbala
Ko s'ewu Jesu wa nibe

===============
I have a special tie to this song because that was the song my mother used to send me forth when I was going away from home (18 years ago). I still remember all the words.

2 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by delpee(f): 10:12pm On Feb 27, 2012
Emi pelu won ni yo ko
Orin ayo lojo na (2ce)

Orin ayo t'oba ogo
Orin ayo t' irapada
Emi ati won ni yo ko
Orin ayo lojo na.

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Basics007: 6:07am On Feb 28, 2012
I'm getting goose pimples with all these nostalgic hymns. I need to go back to anglican church asap,i think i've had enough of being lost.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Basics007: 6:11am On Feb 28, 2012
Aigbagbo bila temi loluwa ohun yo si dide fun igbala mi.
Chorus
Kin sha ma gbadura ohun se iranwo
Bla bla bla etc(somebody rescue me pls)

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ydtaurus5: 7:19am On Feb 28, 2012
ajogun ati asegun ni aje,nipa eje jesu ani isegun,
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by spriteB(f): 7:54am On Feb 28, 2012
Asegun ati Ajogun ni aje
Nipa eje Kristi a ni isegun
b'oluwa je tiwa a ki yo subu
ko s'ohun to le bori agbara re,

Aaa segun niwa
Nipa eee eje Jesu
Baba fun wa ni'segun
Nipa eee eje Jesu
Eni ta pa f'elese
sibe o wa o n joba
awa ju asegun lo oooo
awa ju asegun lo,

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ireke(m): 7:54am On Feb 28, 2012
Basics007:

Aigbagbo bila temi loluwa ohun yo si dide fun igbala mi.
Chorus
Kin sha ma gbadura ohun se iranwo
Bla bla bla etc(somebody rescue me pls)

Aigbagbo bila temi l'Oluwa
Oun y'o si dide fun igbala mi
Ki nsa ma gbadura Oun o se 'ranwo
Gba Krist' wa l'odo mi ifoiya kosi
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Basics007: 8:53am On Feb 28, 2012
ireke:

Aigbagbo bila temi l'Oluwa
Oun y'o si dide fun igbala mi
Ki nsa ma gbadura Oun o se 'ranwo
Gba Krist' wa l'odo mi ifoiya kosi
God bless you real good. Thanks
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Basics007: 8:56am On Feb 28, 2012
spriteB:

Asegun ati Ajogun ni aje
Nipa eje Kristi a ni isegun
b'oluwa je tiwa a ki yo subu
ko s'ohun to le bori agbara re,

Aaa segun niwa
Nipa eee eje Jesu
Baba fun wa ni'segun
Nipa eee eje Jesu
Eni ta pa f'elese
sibe o wa o n joba
awa ju asegun lo oooo
awa ju asegun lo,
Yinka Ayelefe taught me this song
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Kunexy: 8:59am On Feb 28, 2012
Miss d Baptist church- Gba to bade/2x lati si ro'so re. Gbogbo oso re iyebiye, awon ti ofe. Bi irawo owuro won s'ade re l'oso. Ewa won o yo pupo ewa f'ade re. ANOTHER ONE: nigbati 'mole owuro ba nti ila orun tan wa. Ha! Orun ododo mimo ma sai fi anu ran simi. Tu isu dede ebi ka/2x So okunkun mi di imole nla/2x
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Olumogun: 9:12am On Feb 28, 2012
Emi mope Oludande mi nbe laiye
O nbe laiye (2ice)
Emi mope, Oludande mi nbe laiye,
O nbe laiye sibe.


Oluwa, Oluwa mi,
Olorun, Olorun mi,
Olowo ori mi E ma seun
Modupe ti e ko mi yo

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Horlarbissy: 10:53am On Feb 28, 2012
Okan mi yo ninu oluwa,tori oje iye fun mi.ohun re dun pupo lati gbo,adun ni lati ri oju re.
Cho: emi yo ninu re, emi yo ninu re.igba gbogbo lo fi ayo kun okan mi tori emi yo ninu re cheesy

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tunnytox(m): 8:35pm On Feb 28, 2012
Nice thread
Many of the hymns I want to post has already being posted, I'll print a copy of this thread for future reference.

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by armyofone(m): 3:39am On Feb 29, 2012
Arugbo ojo
lehin da, lawa da,
arugbo ojo

iwo lo oyin
kabo ma rora


2. Baba mo tun de o
iwo lo'ba to da mi
iwo ni mo gbekele

je ri se Baba Jehovah,
Alalafia la jaiye pe

amin


OP, repent for the kingdom of heaven is at hand. after you don collobo, ask for forgiveness.
Fada is in the sacristy.
omoge ti soro finish.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by spriteB(f): 6:14am On Feb 29, 2012
Aye si mbe, n'ile odo aguntan
ewa ogo re n pe o pe mabo
wole, wole, wole nisisinyi
ewa ogo re n pe o pe mabo.Ife re da wa si loni
la re a si dubule
ma so wa ni'dake oru
k'ota ma yo wa lenu
Jesu se olutoju wa
iwo lo dun gbekele
Jesu se olutoju wa
iwo lo dun gbekele
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by paradice: 8:07am On Mar 28, 2012
I love this tread. It remind me of how my grand pa would sing hymns for hours playing organ. My favourite though is this one:

;DKosuwa lati ma ko orin ti igbani ogo folorun alle-lu -u-ya
Ale fi igbagbo korin na so ke ki kan ogo folorun aleluya
Omo olorun ni e tolati ma busayo pe ona yi ye wa si okan wa sha fe ri re
Ni gbo se a o de afin oba wa ologo.
Ogo folorun ale-lu-u-ya grin
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Miroslavklose: 9:17pm On Mar 29, 2012
Na lie. so the op used to be one of us? Im so suprised to read this thread. Most of the songs posted here are the songs that make me feel good being a christian.

Smh. see what OAU turn my fellow munich fan into shocked


The song i love to listen is

Ire to fe wa la o ma sin titiBaba ire la o maa sin
Baba ire la o ma bo
Iwo to fe wa la o ma sin titi
Ninu ogo o la re
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 11:24pm On Mar 29, 2012
N go sunmo Olorun, N go sun mo o

Bo tile se iponju lo mu mi wa

Sibe orin mi je

Ngo sun mo olorun N go sun mo o.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 11:26pm On Mar 29, 2012
Mo j'alejo nihin

Ni ile ajeji

Ile mi jin rere, Lor'e bute wuraa

La ti je iranse, Iko oba orun

Eyi ni se mi f'oba mi


CHorus

Eyi nise, ti mo wa je

'Se ta won Angel nko lorinn,

A ba olorun laja ni oba orun wii

E ba Olorun yin la ja
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 11:27pm On Mar 29, 2012
Ki lo le we se mi nu

Kosi lehin eje Jesu

Ahhh Eje yebiye, to mu mi fun bi snow

Ko si sun miran mo

Kosi lehin eje Jesu

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Miroslavklose: 8:10pm On Mar 31, 2012
dayokanu: Ki lo le we se mi nu

Kosi lehin eje Jesu

Ahhh Eje yebiye, to mu mi fun bi snow

Ko si sun miran mo

Kosi lehin eje Jesu
This is a song i love the most when i was still at C&S before moving to Cele
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by worldgee: 9:48pm On Apr 16, 2012
U guys r just 3 much.

Pls somebody shld help me out wt dis song:
E yin Oba Ogo, Oun ni Olorun....

is it a full hymn. i used 2 know it been popularised by Mama Bola Are.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:19pm On Jun 13, 2012
why didnt calotti post here?
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Ayomivic(m): 3:32pm On Jun 14, 2012
I love this Tope Alabi song

A so mi a funfun, laulaulau,
Aisedede mi akuro, ma funfun lau,
Ese mi apare ma si funfun, ao wemi lawe moo bi egbon owu. *2

Eni towa ninu Jesu ti deda tuntun, oun atijo oti koja lo ,ati we wa kuro ninu ese wa ,aaso wa funfun un laulaulau

repeat chorus

karonu piwada kako ese sile kapara wa mo kase dede ni ,ki emi-mimo ko joba lokan wa ,Angeli nyo tori elese yipada.

Repeat chorus

Aalanu lo Lorun ,obe elese wo bi omo niii, kosi bese sele poto alaforiti ni, kikida ko jewo aye re agba isinmi.

Repeat chorus till it fade.

1 Like 2 Shares

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Enigma(m): 7:25pm On Jun 14, 2012
Fantastic thread!

Let me join in with gusto and start with this one first posted by the Allemania footballer.

Miroslav klose: . . . The song i love to listen is

Ire to fe wa la o ma sin titi

Baba ire la o maa sin
Baba ire la o ma bo
Iwo to fe wa la o ma sin titi
Ninu ogo o la re

I love it very much too and I've been able to get a version of the wording at the following site which has some 30 odd Yoruba hymns: http://belovedbrown.blogspot.co.uk/2010/04/yoruba-hymns.html


Iwo to fẹ wa la o ma sin

1. Iwọ to fẹ wa la o ma sin titi
Oluwa Olore wa
Iwọ to n ṣọ wa n’nu idanwo aye
Mimọ, logo ọla rẹ

Baba, iwọ l’a o ma sin
Baba, iwọ l’a o ma bọ
Iwọ to fẹ wa l’a o ma sin titi
Mimọ l’ogo ọla rẹ.

2. Iwọ to nsure s’ohun t’a gbin s’aye
T’aye fi nrohun jẹ o
Awọn to mura lati ma ṣ’otọ
Wọn tun nyọ n’nu iṣẹ rẹ.

Baba . . .

3. Iwọ to nf’agan lọmọ to npe ranṣẹ
Ninu ọla rẹ to ga
Eni t’o ti ṣ’alaileso si dupẹ
Fun ‘ṣẹ ogo ọla rẹ

Baba . . .

4. Eni t’ebi npa le ri ayọ ninu
Agbara nla rẹ to ga
Awọn to ti nwoju rẹ fun anu
Wọn tun n yọ n’nu iṣẹ rẹ.

Baba . . .

5. F’alafia rẹ fun ijọ rẹ l’aye
K’ore-ọfẹ rẹ ma ga;
k’awọn ẹni tirẹ ko ma yọ titi
ninu ogo iṣẹ rẹ.

Baba . . . Amin.

cool

1 Like 1 Share

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply)

Marine Spirits...what Are They?how To Identify Them And Defeat Them. / 42 Prayer Points To Tackle This Year 2015 By Dr D.k Olukoya / Jehovah's Witnesses: 17 Facts People Should Know About Them

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 110
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.