Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,951 members, 7,817,794 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 07:51 PM

Post Yoruba Christian Hymns Here - Religion (3) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Post Yoruba Christian Hymns Here (224549 Views)

Post Your Favourite Christian Hymns / Share Your Best Hymns / Christian Hymns/songs And Copyrights (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (Reply) (Go Down)

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tayotee(m): 11:29pm On Feb 26, 2012
Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya

Si O, ife eni t’Owa
Ninu Majemu Olorun
A nko, Aleluya

5 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:31pm On Feb 26, 2012
i know the songs in english and i have songs of praise even though i havent opened it in a while.

will get ancient and modern maybe when i go to nigeria.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tayotee(m): 11:31pm On Feb 26, 2012
Ija d’opin ogun si tan
Olugbala jagun molu
Orin ayo lao ma ko – Aleluya

Gbogbo ipa n’iku ti lo
Sugbon Kristi f’ogun re ka
Aye ! e ho iho ayo – Aleluya

Ojo meta na ti koja
O jinde kuro nin’oku
E f’ogo fun Oluwa wa – Aleluya

O d’ewon orun apadi
O silekun orun sile
Ekorin iyin ‘segun Re – Aleluya

Jesu, nipa iya t’O je
Gba wa lowo oro iku
K’a le ye ka si ma yin O – Aleluya. Amin.

7 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 11:33pm On Feb 26, 2012
tpia@:

i know the songs in english and i have songs of praise even though i havent opened it in a while.

will get ancient and modern maybe when i go to nigeria.

I actually had my mum buy me a Yoruba/English Bible when last I was home. It's good for practicing Yoruba! grin

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:36pm On Feb 26, 2012
hearing the bible read in yoruba is a very interesting/fascinating experience.


will get the audio version as soon as i find one.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Hibkay: 11:36pm On Feb 26, 2012
Igbagbo mi duro lori,eje ati ododo Jesu,nko je gbekele ohun kan,leyin oruko nla jesu. Chrs- Mo duro le kristi apata, ile miran iyanrin ni

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Nobody: 11:37pm On Feb 26, 2012
One from The Apostolic Church, attended a few times as a child and one of the hymns that stuck goes thus:

Igba aye wa aro gbede gbede (2X)

Kasa ti'beru Oluwa Oba ogo

Inu buruku, aso kamu kuro

Katoro fun suuru baba iwani

Igba aye wa aro gbede gbede

Kama se fi'wa ipa so ara d'egbin

Ejo elejo odi kamu kuro

Kayera fun rigimi, ipa osi ni

Igba aye wa aro gbede gbede

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 11:44pm On Feb 26, 2012
tpia@:

hearing the bible read in yoruba is a very interesting/fascinating experience.


will get the audio version as soon as i find one.

http://www.faithcomesbyhearing.com/ambassador/free-audio-bible-download

It might be dramatized though. grin
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:48pm On Feb 26, 2012
moremi2008:

http://www.faithcomesbyhearing.com/ambassador/free-audio-bible-download

It might be dramatized though. grin

hmm, thanks wink
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 2:59am On Feb 27, 2012
Okan mi yin Oba orun
Mu ore wa sodo Re.
Wo ta wosan ta'darin jin
tala ba a yin bi Re?
Chorus
Yin Oluwa
Yin Oluwa
Yin Oba ainipekun
Yin Oluwa
Yin Oluwa a
Yin Oba ainipekun.


Lai foya lapa Jesu
Lai foya lese Re
Labe ojiji 'fe e Re
lokan mi o sinmi.
Mo bo lowo banuje
Mo bo lowo eru
O ku idanwo die e
ti n fi're koja a.
Chorus
Lai foya lapa Jesu
Lai foya lese Re
Labe ojiji 'fe e Re
lokan mi o sinmi.

5 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:02am On Feb 27, 2012
Are mu o, Okan re si koro

So fun Jesu, So fun Jesu, Oun lore ti o mo

Ko tun sore , tabi Iyekan bi re So fun Jesu nikan

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:06am On Feb 27, 2012
E ma tesiwaju, Kristian ologun

Sa teju mo Jesu, ton be niwaju

Kristi Oluwa wa , Ni Balogun wa.

Wo basia re wa niwaju ogun,

Chorus

E ma tesiwaju, Kristian Ologun

Sa teju mo Jesu, to n be niwaju

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:29am On Feb 27, 2012
Mo fe kin dabi Jesu
ninu iwa pele.
Ko se ni to gbo'ro binu
lenu Re lekan ri.

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:38am On Feb 27, 2012
Adua didun, Adua didun
lo gbe mi lo kuro laye.
Lo waju ite Baba mi
kin so gbo edun mi fun.
Ni gba banje ataro
Adua labo fun okan mi.
Emi si bo lowo esu
gbati mo ba n gba adua didun.


Itan iyanu ti 'fe
so fun mi lekan.
Itan iyanu ti 'fe
e gbe orin kikan.
Awon angeli royin Re
Awon oluso si gbagbo
elese iwo ki yo gbo
Itan iyanu ti 'fe.
Chorus
Iyanu
Iyanu
Iyanu
Itan iyanu ti 'fe.

4 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:40am On Feb 27, 2012
En yin te fe Oluwa, E fi ayo yin han

E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun

Ke si yi te na ka, Ke si yi te na ka

An yan lo si Sion, Sion to dara Julo oo

An yan goke losi Sion, Ilu Olorun wa

(Englsih version We are matching to Zion)
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 5:20am On Feb 27, 2012
Does anyone have the rest of the lyrics for:

Enikan be to feran wa, A o fe wa
Ife re ju ti ye kan lo, A o fe wa
Ore aye ko wa sile
Bi oni dun, ola le koro
Sugbon ore yi kii tan ni, A o fe wa

Emi ni Jesu fe, ofe mi yeye
Emi ni Jesu feran ju enikeni lo
O ra mi pad lowo iku ekeji
Ayo igbala mi wa di pupo repete

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 6:40am On Feb 27, 2012
^^ Thats the full lyrics you posted
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 6:55am On Feb 27, 2012
dayokanu:

^^ Thats the full lyrics you posted

I want all the verses! I go hard, bros! grin
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 7:13am On Feb 27, 2012
Fun mi niwa pele Okan tutu
Ifarabale bi to luwa mi

Irele on suru ati opo iyonu

Ninu ohun gbogbo

Kin jo Jesu

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 7:18am On Feb 27, 2012
moremi2008:

I want all the verses! I go hard, bros! grin

Not sure I can help you though. Let me compose mine


Ore ododo ni Jesu ah o fe wa

O fe lati ma bukun wa A o fe wa

Okan wa fe gbo ohun re

Okan wa fe lati sun mo

Ohun na ko si ni tan wa je

A o fe wa

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by TonySpike: 8:20am On Feb 27, 2012
Let me add this catholic hymn:

Araiye e yoo, gbogbo agbaiye
pipe ni ise, owo Oluwa
Awa maa ri di ise re
Otito sha ni oro re
Iba Awimayehun


I can't remember much of the song again, lol
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Vickivicki(m): 9:26am On Feb 27, 2012
purpose100:

Adua didun, Adua didun
lo gbe mi lo kuro laye.
Lo waju ite Baba mi
kin so gbo edun mi fun.
Ni gba banje ataro
Adua labo fun okan mi.
Emi si bo lowo esu
gbati mo ba n gba adua didun.

Wakati adura didun
To gbe mi lo kuro laye
Lo'waju ite baba mi
Ki nso gbogbo edun mi fun
Nigba banuje at'aro
Adua l'abo fun okan mi
Emi si bo lowo esu
Gbat' mo gba adua didun
, ,

Another childern church hymnal here:
Ewe t'oba orun
Korin didun be ti n lo
Korin yin olugbala
Ologo ninu ise re
A nlo sodo Olorun lona t'awon baba rin,

This i can remember for now
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Pororo(f): 9:27am On Feb 27, 2012
@ Dayokanu
I've been looking for this hymn.

[i]Fun mi niwa pele , okan tutu uuu

Ifarabale bi, Toluwa mi

Irele ohun suru, ati opo iyonu

Ninu ohun gbogbo kin jo Jesu [i]

Thanks so much.
Do you happen to know the English version, please? undecided
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Chemmzy(f): 10:07am On Feb 27, 2012
Bi mo tiri, lai sa wawi
sugbon nitori eje re
bo si ti pe mi, pe kin wa
Olugbala, mo de, mo de.

Bi mo tiri, lai duro pe
mo fe kokan mi mo to to
so do re to le wemi mo
Olugbala, mo de mo de

WAKATI ADURA DIDUN.

Wakati adura didun
to gbe lo kuro laiye
lo waju ite Baba mi,
ki nso gbogbo edun mi fun
nigba banuje at'aro
adua la bo fun okan mi
emi si bo lowo ewu}
gbati mo ba gba dua didun}2ce.

Wakati adua didun
iye re yio gbe ebe mi
lo sod'eni to seleri
lati bukun okan adua
bo ti komi, kin woju re
ki ngbekele, ki nsi gbagbo
ngo ko gbogb'aniyan mi le}
ni akoko adua didun}2ce

DURO

Okan are ile kan nbe
lona jinjin saiye ise
ile tayi da, ko le de
tani ko fe sinmi ni be
chorus:
Duro, roju duro masekun}2ce
Duro, duro
sa roju duro mase kun.

Bi wahala ba bo o mole
bi ipin re laiye ba buru
woke sile ibukun na
sa roju duro mase kun
(repeat chorus).

Bi eegun ba wa lona re
ranti ori ta fe gun de
bi ibanuje bo okan re
o ti ri be folugbala
(repeat chorus).

Ma sise lo mase rope
a ko gbadura edun re
ojo isinmi nbo kokan
sa ro ju duro mase kun.
(repeat chorus)

5 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by oferefe(f): 1:12pm On Feb 27, 2012
Wa sa Adura owuro
kun le ka gba Adura!
Adura ni opa Kristien lati bOlorun rin

losan wo le labe
je kawi li emi pe
mosun sugbon okan mi ji
lati ba o sona.

Je kii gbo gbo Ile,


Men i like this song,dats our family altar song in those days
But personally,i like

Gba taboluwarin
n'u mole oro re
ona wa yio ti mole to,
Gbata ba nse fere
Onyo maba wa gbe
ati awon ti o gbeke le

chorus
Sa gbeke le ona miran kosi
Lati layo'nu jesu
jupe ka gbeke le

6 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bukkytroni: 1:17pm On Feb 27, 2012
Apata Ayeraye

Se ibi isadi mi

Jeki omi on eje

To san lati iha re

Se iwosan fe'se mi

Kosi so mi di mimo

5 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bencobenz(m): 2:26pm On Feb 27, 2012
Olugbala gbohun mi
Gbohun mi, gbohun mi,
Mo wa s'odo re gbami,
Nibi agbelebu
Chrs
Oluwa jo gbami,
Emi ki yio bi o ninu mo,
Alabukun gbami,
Ni bi agbelebu.

4 Likes 2 Shares

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bencobenz(m): 2:32pm On Feb 27, 2012
Aye si nbe nile odo aguntan,
Ewa ogo re npe o pe ma bo,
Wole wole, wole nisisiyi,
Ewa ogo re npe o pe ma bo.

Ki ile to su, ilekun na leti,
Gbana o ka bamo pe o se
Ose ose ko si aye mo ose
Ewa ogo re npe o pe ma bo

5 Likes 2 Shares

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 2:42pm On Feb 27, 2012
Chemmzy:


Okan are ile kan nbe
lona jinjin saiye ise
ile tayi da, ko le de
tani ko fe sinmi ni be
chorus:
Duro, roju duro masekun}2ce
Duro, duro
sa roju duro mase kun.


Bi wahala ba bo o mole
bi ipin re laiye ba buru
woke sile ibukun na
sa roju duro mase kun
(repeat chorus).

Bi eegun ba wa lona re
ranti ori ta fe gun de
bi ibanuje bo okan re
o ti ri be folugbala
(repeat chorus).

Ma sise lo mase rope
a ko gbadura edun re
ojo isinmi nbo kokan
sa ro ju duro mase kun.
(repeat chorus)

That was the song my grandma sang on her deathbed


In her memory let me dedicate this song

A o ha pade leti odo

Tese angeli tite

To mo gara bi Kristali

To n san leba ite na

A o pade leti odo, Odo didan, odo didan an na

Pelu awon mimo leba odo to n san leba ite na

3 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:26pm On Feb 27, 2012
Vickivicki:

Wakati adura didun
To gbe mi lo kuro laye
Lo'waju ite baba mi
Ki nso gbogbo edun mi fun
Nigba banuje at'aro
Adua l'abo fun okan mi
Emi si bo lowo esu
Gbat' mo gba adua didun
, ,


I think u posted either from CAC or Methodist hymnal. Because in Baptist hymnal we have it as 'Adua didun' not as 'Wakati Adura didun'. But they all mean the same thing sha.

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 4:31pm On Feb 27, 2012
Fun mi niwa pele

Okan tutu Ifarabale bi

Toluwa mi, Irele on suru ati opo iyonu

Ninu ohun gbogbo,

Kin jo Jesu
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by abouqi(f): 5:02pm On Feb 27, 2012
This is interesting! So eyin omo kaa ro o jire po ni Nairaland bayi?

Ese gan o, l appreciate the Poster also.

So you guys still remember these Hymns like this?

E fe k'ori awon ko gbo nkan t'a n so ko maa swell ni yi o.

Well, let them post theirs.

Thank you all!

grin grin grin

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (Reply)

Pastor Chris And T.b Joshua Are Satanic. (pst Chris Is A White Demon) / The First Britsh Slave Ship To Reach The Americas Was Called The Good Jesus! / Gospel Hymns And Songs — ♫Praise & Worship || Prevailing Prayers ♫

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 56
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.