Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,157,922 members, 7,835,074 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 03:13 AM

.. - Culture (46) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831219 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (43) (44) (45) (46) (47) (48) (49) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Naturewonders: 6:52am On Dec 31, 2015
Shomar:
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.
.eku ise sir.ejo ogun eniti ounwa iyawo ati ogun ti owo ma fi duro lowo eniyan ni mon wa
Re: .. by Naturewonders: 9:08am On Dec 31, 2015
healthFirst:
115

EYONU FUN ENIKENI
Ileke itun,
Ileke ifa,
Irun abe obinrin,
Ewe eeyo
Ewe ata ijosi
Iiye agbe,
Iye aluko,
Iko Odide,
Egungun agbari ologbo die,
Awo ijimere

A o jo won papo, a o sun awo ewure ninu ina, a o ha edu ara re sinu ise ti ajo yen, a o wa lo gbogbo re papo, a o da sinu konjo kekere kan, a o fi ori, epo ati lofinda bintu tabi Miss paris sinu re pelu, a o fi iyerosun te ifa OgbeWonrin.

OFORE:
Siju womi, abifa gbuuru, siju womi la npe ifa, abifa gburu la npe esu odara, itun loni ki e fi enu rere tun mi se, ifa loni ki won fenu rere fami mora, ogbo loni ki won mu temi gbo,oro mi ka sai yo won ninu gerere, bi epo bafoju kan oorun ayo gerere, bi adi ba foju kan oorun ayo gerere , bi ori ba foju kan oorun ayo gerere bi awo ba fi oju kanna woranworan agun, bi oloko ba joko bi olobo ba debe a fi aye gba, Orisa sanu agbe o se aso re laro, orisa sanu aluko ose aso re losun, Ao se iwure fun ohun ti a fe.
ese pupo baba oruko wo latun le pe ewe eyo

1 Like

Re: .. by Ousmaf(m): 9:22am On Dec 31, 2015
Agoo nile, ejoo efun wa ni Ogun ti eni to sese pari eko re to nwa ise yio fi ri ise to lalubarika, eseun adua wa a man gba pelu ase Edumare.
Re: .. by omoalade144(m): 4:56pm On Dec 31, 2015
ejowo edakun kini oruko miran ti an pe ewe igbagbe.Ao ni sise o.Ase.
Re: .. by Oluokunoluwole: 11:39am On Jan 01, 2016
Shomar:
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.
ekaro ejowo mo nilo bibo asiri alaseje to gbona gidi ti koni eran ajiyo sugbon ti o nje bi idan,ekeji oogun ti awon customer fi ma ngbe ise fun ni ti onje gidi sugbon ti koni eran ajiyo.eseun gan ni
Re: .. by flame05: 2:54pm On Jan 01, 2016
Aboru boye nile awoo .ejowo mofe ogun (adodun)pelu ogun ki oyun male baje lara obirin
Re: .. by fbabs(m): 10:45pm On Jan 01, 2016
flame05:
Aboru boye nile awoo .ejowo mofe ogun (adodun)pelu ogun ki oyun male baje lara obirin

(1) lo eyo ataare kan pelu ase akeeke ki o fi sin gbere kan si ori oko
(2) lo eso inu abeere mo ori fifi pa oko BA iyawo sun
(3) PO eje adiye dudu PO mo oori fifi pa oko BA iyawo sun

1 Like

Re: .. by bwayomide: 10:35am On Jan 02, 2016
baba e jo kini oruko miran ti a le pe ewe eeyo,oodua agbewa ooo,ase

1 Like

Re: .. by Nobody: 9:33pm On Jan 02, 2016
bwayomide:
baba e jo kini oruko miran ti a le pe ewe eeyo,oodua agbewa ooo,ase
O wa lodo awon elewe omo
Re: .. by heritagesat: 8:42am On Jan 03, 2016
Bawo ni lilo eyonu yi ati wipe esalaye bi ase te ifa ogbewerin
Re: .. by Nobody: 1:28pm On Jan 03, 2016
heritagesat:
Bawo ni lilo eyonu yi ati wipe esalaye bi ase te ifa ogbewerin

Niwon igba ti e ti ri lofinda ninu re, o ye ke mo wipe ipara lo wa fun.

(6) OWONRIN MEJI
!! !!
!! !!
! !
! !

2 Likes

Re: .. by Nobody: 1:39pm On Jan 04, 2016
healthFirst:


Awon nkan ti mo le fi sita lofe ni awon to wa lori abala yi, lehin awon wonyi, eni to ba fe nkan miran gbudo se tan lati te owo bo apo. E ma binu.


....
Re: .. by boluwatife2313: 3:22pm On Jan 04, 2016
e jo kadunasouth nitori olohun e fun mi ni ogun owo(respect) to gbona gidi gan
Re: .. by boluwatife2313: 3:32pm On Jan 04, 2016
my pics

Re: .. by boluwatife2313: 3:34pm On Jan 04, 2016
tabi kefi ranse simi ni email mi kuddusadenusi2313
Re: .. by boluwatife2313: 7:51pm On Jan 04, 2016
e fi ranse si email yi kuddusadenusi2315@gmail.com
Re: .. by flame05: 6:50am On Jan 05, 2016
Eseun baba kini oku elena ninu OGUN MARAN
Re: .. by boluwatife2313: 9:49am On Jan 05, 2016
taloni ogun asegbe ejo
Re: .. by afoami(m): 11:47pm On Jan 05, 2016
AKU EWU ODUNTUNTUN MO KI GBOGBO ILE O. DIE NINU AWON OFIN TI AFINRI ISEMI IRORUN LO LAYE: 1. KAMO EWOO TI ELEDUMARE FUN GBOGBO AWON EDA ENIYAN TO DA PATAPATA 2. KAMO EWOO/ASIRI IRAWO WA {HOROLOGIAL\ASTRAL PROJECTION} 3. KAMO IKOSEJAYE WA 4. KAMO ISE TI AWA WA SE LAYE PATO.
IYOKU DI OJOMI OJORE. ESEUN
Re: .. by Nobody: 11:30am On Jan 06, 2016
Akeke so igi sa;
Awo ile alasake;
Difa fun alasake, abi iba oun ase l'enu;
Bi awo ba ni ma lowo, ma lowo;
Akeke so igi sa enu awo ni iba! ;
enu awo ase!;
Bi awo ba ni ma ni ire gbogbo ma n'ire gbogbo;
Enu awo n'iba, enu awo l'ase;

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:47am On Jan 06, 2016
x

1 Like 1 Share

Re: .. by boluwatife2313: 1:10pm On Jan 06, 2016
121 ogun ayeta ao po ojuolongbo to po ao po mose dudu a o ma fiwe ni ojo wednesday bi ojuolongbo base njabo ao jo pelu eyo atare meje fun okunrin mesan fun obinrin ao da sinu oti ao ma mu ni ojo wednesday

1 Like 1 Share

Re: .. by boluwatife2313: 1:15pm On Jan 06, 2016
ejo e fun mi ni ogun ijakadi nisin ejo nitori olorun
Re: .. by boluwatife2313: 1:58pm On Jan 06, 2016
e jo e post odu ifa
Re: .. by Nobody: 2:28pm On Jan 06, 2016
boluwatife2313:
ejo e fun mi ni ogun ijakadi nisin ejo nitori olorun

To ba irole, ma fun yin ni Oogun ijakadi sugbon e tori Edumare, e pa ise ayeta yen re kuro...ko pe rara, ati wipe bi eeyan ba je ojuologbo to ju eyo marun lo, o lewu.

Eni to ba ro wipe iro ni, ko gbiyanju lati je oju ologbo (iwerejeje) bi marun pere...ko fun wa labo lojo keji bo ba se ri.
Re: .. by Nobody: 2:30pm On Jan 06, 2016
boluwatife2313:
e jo e post odu ifa

A ti fi awon odu Ifa merindinlogun sita...e si oju iwe lo si eyin.
Re: .. by boluwatife2313: 2:49pm On Jan 06, 2016
[quote author=boluwatife2313 post=41711794]121 ogun okigbe ao lo ojuolongo meje pelu eyo atare meje ao fi singberen ejiogbe si ejika wa mejeji
Re: .. by boluwatife2313: 2:52pm On Jan 06, 2016
ayeta yen ko pe lo tan mo se mistake e ma binu e se pe e je kin mo olorun a pon yin le
Re: .. by boluwatife2313: 2:55pm On Jan 06, 2016
ejo mo ni fe obinrin kan mo fe ke fun mi logun to je wipe obinrin yen lo ma koko wa so pe ohun fe fe mi

(1) (2) (3) ... (43) (44) (45) (46) (47) (48) (49) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 22
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.